Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,195,024 members, 7,956,793 topics. Date: Monday, 23 September 2024 at 07:06 PM

E Ba Oloye Olusegun Aremu Obasanjo Soro.o To Geeee. - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / E Ba Oloye Olusegun Aremu Obasanjo Soro.o To Geeee. (2591 Views)

Ni Ipinle Oyo, Owo Awon Olopa Ti Ba Awon Afurasi L'ebo-l'oogun Merin / The Ooni Of Ife And Tradition By Olusegun Adeniyi / Ejo Talo Le Ba Mi Translate Orin Sunny Ade Kan (2) (3) (4)

(1) (Reply)

E Ba Oloye Olusegun Aremu Obasanjo Soro.o To Geeee. by olutomiwa(m): 8:41pm On Jul 11, 2007
Awa omo odua rere ti nbe lode ile yi,mo ki yin o,ajose wa koni baje.
E jowo mofe fe ki gbogbo wa panu po ka pe oloye OLUSEGUN OBASANJO,pe ki won fi aare UMAR YAR,ADUA sile ko se ijoba re lai ma pase fun,ipo agba la nba agba ki baba Obasanjo fi oro orile ede nigeria sile ki won lo simi lota,afterall ko seni to pa ase fun won nigba ti won wa lori alefa.
Ti a ba wi fun won ti won o ba gbo tabi jawo ETE NI WON O GBA O.E dakun e bawa ba won soro o,o to ge,enough is enough.
Re: E Ba Oloye Olusegun Aremu Obasanjo Soro.o To Geeee. by jagunlabi(m): 6:39pm On Aug 10, 2007
Shebi ogagun sa ti kuro lori aleefa.E wo wa tun ni gbogbo ariwo yi o?
Re: E Ba Oloye Olusegun Aremu Obasanjo Soro.o To Geeee. by MP007(m): 8:36am On Aug 21, 2007
se bi oti kuro lori ijoba

(1) (Reply)

Oh My Africa / Abram Is Also The Person Called Orunmila. / East Africa's Top Special Force

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.