Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,150 members, 7,818,466 topics. Date: Sunday, 05 May 2024 at 04:23 PM

Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán - Culture (6) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán (2752 Views)

Àwọn Èso Ati Irúgbìn Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Awòrán / Transportation In Yoruba Land (àwọn Ọ̀nà Tí À Ń Gbà Rin Ìrìn Àjò) / Ònkà - The ABC Of Yorùbá Numerals (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (Reply) (Go Down)

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:24pm On Nov 14, 2023
Tọnátọná Alẹ́ — Firefly

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:30pm On Nov 14, 2023
Gúlúsọ/Kúlúsọ — antlion larva

Popular Song:

Gúlúsọ, Gulúso
Abiamọ Gúlúsọ
Gúlúsọ, Gúlúsọ
Abiamọ Gúlúsọ

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:37pm On Nov 14, 2023
Yínmiyínmi/Yígbẹ̀yigbẹ̀/Ogidi/Ogidimo/

Popular Proverb:

1. A kìí bá yínmiyínmi du'mi, A kìí bá Àtẹ̀lẹ̀sẹ́ du Ọ̀nà

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:44pm On Nov 14, 2023
Ayítalẹ́

Popular Saying:
1. Ikú ọmọ L'o un pa Ayítalẹ́

Does anyone have a picture of this animal? I can't seem to find it, And to be honest, I have never seen it before!

And what is the English name?
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:47pm On Nov 14, 2023
Àiná Ọlọrun

Popular song:

Àiná saré tete ogun un bọ̀
Àiná saré tete ogun ùn bọ̀

I can't find the picture for this too and the English name!
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:52pm On Nov 14, 2023
Àrígiṣẹ́gi — Woodcarrier

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:53pm On Nov 14, 2023
Tata — Grasshopper

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 2:17pm On Nov 14, 2023
Ìdin — Maggot

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 2:35pm On Nov 14, 2023
Dákódákó/Damọlóko — Mantis

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 2:39pm On Nov 14, 2023
Lámilámi — Dragonfly

Popular Saying:
1. Àlọ Lámilámi L'aa ri, Ẹnìkan kìí ri àbọ̀ rẹ̀

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 3:13pm On Nov 14, 2023
Ọká — Gaboon Viper

Popular Saying:
1. Ọmọ Inú ọká Ni ùn Ṣe ikú p'ọká

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 3:18pm On Nov 14, 2023
Paramọ́lẹ̀ — Puff adder/Night adder

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:38pm On Nov 14, 2023
Òjòlá/Òṣùmàrè — Python

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:44pm On Nov 14, 2023
Erè — Boa Constrictor

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:59pm On Nov 14, 2023
Olúfà — Anaconda

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:04pm On Nov 14, 2023
Ṣèbé — Spitting Cobra

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:17pm On Nov 14, 2023
Isán

A species of snake, But I can't find the picture on the internet and the English name too!
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:19pm On Nov 14, 2023
Nìnì


A specie of snake, I can't find a picture on the internet and, I don't know the English name!
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:21pm On Nov 14, 2023
Béwérẹ́/Abéwérẹ́ — Jameson's Mamba

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:35pm On Nov 14, 2023
Àgbàfúùfú/Gbàgbàfúùfú — Rattlesnake

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:36pm On Nov 14, 2023
Àgbadú — Black mamba

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:52pm On Nov 14, 2023
Ọ̀ṣa

A specie of snake, I can't find a picture on the internet, and I don't know he English name

Will be updated as soon as I get it
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 6:01pm On Nov 14, 2023
Mọ́námọ́ná — Ball python

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 7:42pm On Nov 14, 2023
Ọgbá/Gbaragogo

A specie of snake, I can't find a picture on the internet, and I don't know he English name

Will be updated as soon as I get it
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 7:51pm On Nov 14, 2023
Ọ̀ghọ́ta — Rhinoceros Viper/Bitis nasicornis
A specie of Viper

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:00pm On Nov 14, 2023
Abìrùṣoró — Boomslang

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:08pm On Nov 14, 2023
Ọ̀ọ́rú/Ọ̀wọ̀rú — Forest cobra

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:13pm On Nov 14, 2023
Ọ̀wùn — Black-necked Spitting Cobra

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:23pm On Nov 14, 2023
Komo — Boaedon

NB: I don't know how it's pronounced!

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:40pm On Nov 14, 2023
Ọ̀kùn — Millipede

1 Like 1 Share

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:52pm On Nov 14, 2023
Tanísankọ — Centipede

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 9:16pm On Nov 14, 2023
Ọ̀pọ̀lọ́ — Toad

1 Like

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (Reply)

ْ / Oso Owo Tabi Asiri Bibo / Where Do Yorubas Fit In The Middle East?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 18
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.