Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,155,832 members, 7,828,037 topics. Date: Tuesday, 14 May 2024 at 10:28 PM

Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán - Culture (5) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán (2786 Views)

Àwọn Èso Ati Irúgbìn Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Awòrán / Transportation In Yoruba Land (àwọn Ọ̀nà Tí À Ń Gbà Rin Ìrìn Àjò) / Ònkà - The ABC Of Yorùbá Numerals (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (Reply) (Go Down)

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 9:57pm On Nov 09, 2023
Adìyẹ Odò — Kiwi

2 Likes 1 Share

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 10:04pm On Nov 09, 2023
Agánrán — Senegal parrot, Green parrot

Popular Proverb :
1. Agánrán tó bímọ sílẹ̀ tí kò ní ìkà, ọmọ tirẹ̀ kọ́, ọmọ ẹlòmíràn ni.

3 Likes

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 10:18pm On Nov 09, 2023
Ìkóódẹ — African Grey parrot

2 Likes

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 7:46am On Nov 10, 2023
Ọ̀pẹ́ẹ̀rẹ̀ — Bulbul

Popular saying:
1. O ùn sọ òyìnbó bi Ti Ọ̀pẹ́ẹ̀rẹ̀

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:25am On Nov 10, 2023
Ẹiyẹ Omi — Flamingo

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:25am On Nov 10, 2023
Reserved
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:29am On Nov 10, 2023
Still reserved
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:30am On Nov 10, 2023
Reserved for birds
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:37am On Nov 10, 2023
Reserved-
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:42am On Nov 10, 2023
Reserved
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:06pm On Nov 10, 2023
Ìrẹ̀ — Cricket

3 Likes 1 Share

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:23pm On Nov 10, 2023
Ẹ̀fọn/Yànmù-yánmú — Mosquito

2 Likes

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:24pm On Nov 10, 2023
Ẹ̀ka/Àkányín — Black Ant

2 Likes

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:25pm On Nov 10, 2023
Ìjàlọ — Soldier Ant

1 Like 1 Share

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:37pm On Nov 10, 2023
Èèrà

2 Likes

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:44pm On Nov 10, 2023
Kòkòrò Sugar

Well I don't know the precise name for this in Yoruba, I'm trying to make some research if it has a name in Yoruba, and If it doesn't, I'll give it a name!

But for now, Let's call it "Kòkòrò Sugar"

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:03pm On Nov 10, 2023
Ìdun — Bedbugs

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:05pm On Nov 10, 2023
Èkùọ́ — Beans weavil

Popular Saying:
1. Èkùọ́ L'alábàkú Ẹ̀wà

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 11:48am On Nov 13, 2023
Ikán — Termite.
Òkìtì Ọ̀gán — Termite Mound


I don't know why my post keep getting removed by the Bots, I haven't done anything wrong, Lalasticlala, Myndd44 Seun pleas do something!

1 Like 1 Share

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by caye(m): 9:05am On Nov 14, 2023
Raydos:
Ikún — Ground squirrel


Ikun n j'ọgẹdẹ, / ikun is eating a banana
Ikun n re'di, / Ikun shakes her behind joyfully
Ikun o mọ wípé / ikun doesn't know that
oun to dun/ what sweetens one
nii n pa ni
/ could end up killing oneself
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by dominique(f): 11:25am On Nov 14, 2023
Your hidden posts are now visible, stop spamming front-page topics please

2 Likes

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 12:32pm On Nov 14, 2023
Iná-Orí — Lice

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 12:48pm On Nov 14, 2023
Esunsun/Ilé Esun — Flying termite

1 Like 1 Share

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 12:49pm On Nov 14, 2023
Eṣinṣin — Housefly

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Zimri(m): 1:06pm On Nov 14, 2023
Raydos:
Iná-Orí — Lice


WTF grin
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:09pm On Nov 14, 2023
Agbọ́n — Wasp

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:10pm On Nov 14, 2023
Oyin — Bee

2 Likes

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:12pm On Nov 14, 2023
Alábọ̀nbọ̀n/Lábọ̀nbọ̀n — Bumblebee

2 Likes

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:21pm On Nov 14, 2023
Aáyán — Cockroach

1 Like

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:22pm On Nov 14, 2023
Labalábá — Butterfly

1 Like

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (Reply)

Igbo Speaking Tribe Discovered In Equatorial Guinea / Black Power / Colonial Lies About Igbos: Killing Of Twins.

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 13
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.