Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,719 members, 7,820,504 topics. Date: Tuesday, 07 May 2024 at 04:04 PM

Agoetomorewo's Posts

Nairaland Forum / Agoetomorewo's Profile / Agoetomorewo's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by Agoetomorewo: 8:47am On Jan 09, 2022
Agoetomorewo:
Ebo afin baba wa, ewe aje egbo aje, ejo ibere mi wipe se;
* Ewe lali tutu ni tabi gbigbe?
* Eyin yen, tepotepo ni tabi bawo ni gigun po e?
* Ao tu bintu kan to ku si arin hiho Yi, tabi ao tu si yika

Culture / Re: .. by Agoetomorewo: 4:53am On Jun 13, 2021
Baba, ebo afin, mo ti wa yin ni ikani Facebook, sugbon orisirisi ojumi mo ri Abe oruko yii ifankaleluya, mo need lati contact yin number mi ni Yi, 08034256987, ejo sir.
Aboruboye oo ...
Culture / Re: .. by Agoetomorewo: 8:26pm On Apr 02, 2021
Ebo afin baba wa, ewe aje egbo aje, ejo ibere mi wipe se;
* Ewe lali tutu ni tabi gbigbe?
* Eyin yen, tepotepo ni tabi bawo ni gigun po e?
* Ao tu bintu kan to ku si arin hiho Yi, tabi ao tu si yika

Ifankaleluya:

OSO KEKE KAN TO GBONA NIYI
Ewe-laali
Eyin adire ororo(do do do) merin
Oga aaye kan
Owo-titun (#500 or 1000)
Igba-olomori
Ose
Oyin
Lofinda bintu meji.

Ao gun ewe-lali yen daadaa, ao gun awon eyin yen mo, ao gun ose yen papo mo, ao fi oyin po ose yen, leyin na ao tun po pelu lofinda bintu kan, ao fi owo(money) yen tele(mi do) igba, ao fi Oga yen le owo yen lori ki o gba awo(do do) owo yen, ao gbe ose yen le lori, ao wa lu ose yen laarin ti yio fi kan Oga yen lara, ao wa tun bintu kan to ku yen si. ao de igba yen pa fun ojo-merindinlogun(16days) ki a to ma we ose na.

Pelu Ogo-Olohun yio si ri be.

NOTE; Akii fi omi si oso yen ti a ba n se lowo oo.

Aboru, Aboye!

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 8
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.