Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,166,994 members, 7,866,737 topics. Date: Friday, 21 June 2024 at 01:46 AM

Alhajialhaji's Posts

Nairaland Forum / Alhajialhaji's Profile / Alhajialhaji's Posts

(1) (of 1 pages)

Politics / Re: Ten Niger-Delta Avengers Members Arrested By The Army (Photo) by alhajialhaji(m): 3:00pm On May 30, 2016
sage50:
Fuk the Nigerian police. They are always fond of parading wrong suspects. Ikorodu robbery dat was lead by a female. According to eye witnesses. When dey paraded suspects na just males dem parade. These are not avengera biko

Yes.. u got it right jare. They are truly not avengera as u said...They are avengers.
Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 3:03am On Feb 28, 2016
Ifankaleluya:
FUN ENITI KO BA SE ASEYORI LORI GBOGBO IDAWOLE RE TABI TI AWON AGBALAGBA KO JE KO RI ONA ABAYO.

IFA NI AWA NI TI A LE FUN YIN,KO KIN NSE OGUN LASAN.

IFA YI JE AKO ATI ABO.

AKOKO NI IWE(BATH) ASEYORI TI GBOGBO OGUN ATI OHUN TI O BA DAWOLE YIO FI MA SESE
EKEJI NI IMULE AJE TI WON FI MA N YOJU SI ENIYAN LOJU ORUN TI WON YIO SI FI ASIRI OGUN AYE RE HAN E.
IFA ELEKEJI YI, TI O BA SE BI WON TI MA N SE,OKUNRIN YIO LO FUN OJO MESAN,OBINRIN YIO LO FUN OJO MEJE. LEYIN TI O BA LO IFA YI TAN,TI ENIYAN BA LO YA X-RAY NI HOSPITAL,WON A RI IGBA NI AYA WA,IGBA(CALABASH) YEN NI AMI TI AWON AJE YIO FI SI WA LARA TO TUMO SI WIPE AWON AJE KO GBODO FI OWO KAN WA MO.

SUGBON NKO NI NI ANFANI LATI FI IFA KEJI YEN SILE LORI IKANNI YI,NITORI AWON KAN TO JE WIPE IWE OGUN NI WON N TA. AWA SI MO ASIRI WON.TORI AWON IWE KAN NI WON N DAKO FUN YIN,WON KIISE BABALAWO. IRO LASAN NI WON N PA FUN YIN.

1.
IWE ASEYORI.

EWE-IYALODE TI KO JA TI KO LU 201, AKO-OKUTA MESAN, ATI EPO-OBO NI AO FI SE AGBO YEN. OMUNU EWE-IYALODE MESAN ATI EPO-OBO DIE NI AO GUN PAPO,TI AO PO MO OSE DUDU DIE TI AO FI SE OSE RE.AO KO AKO-OKUTA YEN TELE IKOKO,AO FI EPO-OBO YEN LE LORI,AO WA KO GBOGBO EWE YEN LE LORI. AO BU OMI TO PO DADA SI,AO GBEKA INA NI DEDE AGOGO-MEFA IROLE. TI AGBO YEN BA TI JINNA,A KO GBODO FI IDI RE KAN ILE OO. A LE WA AKO-OKUTA TI O TOBI DADA KI A GBELE LORI. AO WA KO GBOGBO EWE YEN KURO,AO LO DA SI ORI-AKIITAN. SUGBON,A KO NI KO AKO-OKUTA YEN KURO.
FUN ENITI KO BA NI AGBARA LATI PA ODIDI ERAN,AO TI RA(BUY) ORI ORUKO ATI ESE RE MERERIN SILE,AO KO SINU AWO ABOKADELE DUDU,AO BU EPO PUPA SI LORI. TI O BA DI NI AGOGO-MOKANLA ALE,AO SE ADURA SI,AO LO GBE SI ORITA-META,A KO GBODO WEYIN TI A BA TI GBE KA LE OO.
AO NI SUUURU KI O FI DI AGO-KAN ORU,TI AGO-KAN ORU BA TI LU NI AO FI AGBO YEN WE PELU KENKEHIN TITUN. TI A BA TI WE TAN,AO RI KENKENHIN YEN MOLE,AO KO AKO-OKUTA YEN LO DA SI ORITA-META LORU YEN,A KO SI GBODO WO EYIN TI AO FI WOLE PADA.

GBERE IFA YEN; ESO-LOWEREJENJE MESAN ATI OMO-IRULA MESAN NI AO LO PAPO TI AO FI SIN GBERE MERIN NI AYA APA-OTUN,META NI EYIN APA-OTUN ATI GBERE META NI AYA APA-OSI,MERIN NI EYIN APA OSI. LO BA TAN.

IKILO RE OOO
OBINRIN KO GBODO WE IWE YEN OOO. TI OBINRIN BA WE,AWON IYAMI MA FUN NI EIYE NI OOO.

2
IMULE AWON AJE TO DAJU
ABO ADIE TO DUDU TIKO NI AMI KANKAN, IKODE KAN,OBI-IFIN,OBI-IPA,TEWE-TEGBO AJEOBALE,IGBA OLOMORI ATI ........., AO LO WA EGBO AJEOBALE YEN NI ARO KUTU-KUTU,AO WA FI EGBO YEN WON IKA-ARIN WA,AO GE SI META,AO YA AWE-KAN NIBI OBI-IPA,AO GE SI MARUN,AO YA AWE KAN NIBI OBI-IFIN AO GE SI MERIN. AO KO EGBO TI A GE SI META YEN TELE IGBA,AO DA AWON OBI TI A GE YEN SI,AO FI IKODE YEN ATI EWE........,AO WA KO GBOGBO IFUN ADIE YEN TI A YO LATI IDI,TORI A KO GBODO PA ADIE YEN LORI,LATI IDI(OBO) NI AO TI GE,TI AO SI TIKO GBOGBO IFUN RE JADE. TI A BA TI KO TAN. AO KO SINU IGBA(CALABASH) YEN,AO WA KO EWE AJE-OBALE TO PO DADA SI LORI. AO WA DE IGBE YEN PA. AO GBE SINU IKOKO,AO GBE KA INA. AO DE KOKO YEN,A KO GBO RO PAPO TI YIO FI JO TAN. TI O BAJO TAN TI ATI LO,AO WA TE NI ODU-IFA OSA-MEJI. AO WA PE IFA RE SI. SUGBON N KO NI FI IFA YI SILE TAN TORI AWON TI WON N TA IWE-OGUN.

NOTE;;
TI O BA NILO GBOGBO IFA YI TAN,FI NUMBER RE SILE LABE KIN NI YI. PELU OGO OLORUN,MA SI FI SILE FUN OOO.

ABORU,ABOYE,ABO-SISE.
Ifankaleluya, E jo e fun mi ni ise yi pe ooooo... 070529055775...Alhaji [img][/img]Taofeeq.
Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 8:28am On Feb 14, 2016
healthFirst:
IKEDE PATAKI:
Ao gbe eto yi lo sori whatsapp group nitori awon opuro ti won n fowo soya lori ayederu ogun lori ikanni yi ki o le seese fun wa lati ma yo won kuro bi a ba ti ri won. Ogun sise ati lilo kii se inkan ti o ye ki a ma pa iro fun awon eeyan. Bi oogun o ba pe tabi o je ayederu, o lewu pupo fun enikeni to ba je iru ogun be. Ao de fe ki awon epo to wa laarin alikama ba oruko wa je.
E dara po mon wa lori whatsapp number yi 08148398067, tabi ki e fi number yin sile nibi, ki a le add yin sinu group na. Iwulo Ewe Ati Egbo ni oruko group na. E dara po mon wa fun ojulowo oogun ati idaabobo lowo awon Oloogun eke.

07052905575....e add mi sori whatsapp group yin sir..
Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 1:57pm On Nov 17, 2015
kadunasouth:

Agbaarin pelebe egusi inure ao lo pelu ori aparo yio kuna dada ao wa popo ma ose dudu ao fi oyin die de ose yi obirin na yio ma fi tanba toba tise kolegbadu obirin mi bi todore sugbon don't misbehave ki ogun na mabaje tori odaju gbogbo nto bafe niyio mase fune
Odaju

E jo e Funmi ni e-mail yin sir...
Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 1:15pm On Nov 16, 2015
kadunasouth:
Ogun ti akofini je nkan loju orun
Ao wa ajesi adie ao jo pelu odidi atare kan ao lo ti yio kuna dada ao fi foko mun lekanna opari

Se a maa da awon nkann to wa ninu ajesi Adie nu ni, abi ao jo gbogbo e lodidi bee?

1 Like

Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 10:34am On Nov 16, 2015
kadunasouth:
Ogbe-fun

Emi alhaji Taofeeq ti e fun ni Ajegun orissi merin ni ooooo...

E se mo dupe pupo lowo yin ooooooooo..
Olohun a maa tun bo wa pelu yin...
Eo pe ju bi mope tinpe lo..

Ma fun yin ni esi bi o ba se ri.... E jo! mo fe onmo to gbona gidi,ounmo ti a fin wo iyepe, ati onmo kamo oun ti oni jalabi ba babawa.

Efu mi ni phone number yin ati email address yin pelu.....email mi ni yi. taofeeqyeqeen@yahoo.com...
Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 10:33am On Nov 16, 2015
Harjibode:

Pls I Need Your Email Asap.. Thanks

Emi alhaji Taofeeq ti e fun ni Ajegun orissi merin ni ooooo...

E se mo dupe pupo lowo yin ooooooooo..
Olohun a maa tun bo wa pelu yin...
Eo pe ju bi mope tinpe lo..

Ma fun yin ni esi bi o ba se ri.... E jo! mo fe onmo to gbona gidi,ounmo ti a fin wo iyepe, ati onmo kamo oun ti oni jalabi ba babawa.

Efu mi ni phone number yin ati email address yin pelu.....email mi ni yi. taofeeqyeqeen@yahoo.com...
Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 10:16am On Nov 16, 2015
rsk14rsk:
ke mi yin ogun baba! Ejo kini won pe ni eyin agiriki?

Emi Alhaji Taofeeq Oladapo ti e fun ni Ajegun ni sir...

E se mo dupe pupo lowo yin ooooooooo..
Olohun a maa tun bo wa pelu yin...
Eo pe ju bi mope tinpe lo..

Ma fun yin ni esi bi o ba se ri.... E jo! mo fe onmo to gbona gidi,ounmo ti a fin wo iyepe, ati onmo kamo oun ti oni jalabi ba babawa. Efu mi ni phone number yin...email mi ni yi. taofeeqyeqeen@yahoo.com. Ejo e Funmi ni email yiin.....
Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 10:12am On Nov 16, 2015
[quote author=alhajialhaji post=40073071][/quote]

E se mo dupe pupo lowo yin ooooooooo..
Olohun a maa tun bo wa pelu yin...
Eo pe ju bi mope tinpe lo..

Ma fun yin ni esi bi o ba se ri.... E jo! mo fe onmo to gbona gidi,ounmo ti a fin wo iyepe, ati onmo kamo oun ti oni jalabi ba babawa. Efu mi ni phone number yin...email mi ni yi. taofeeqyeqeen@yahoo.com.
Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 10:11am On Nov 16, 2015
kadunasouth:
Ogun fun eni ti aye ban dalamu
ewe lapalapa pupa pelu ewe agogogun, ebo obo ao gun mo ose dudu ao ko sinu igba olomori ao eedu eyokan ao kibo ose na larin ao ma fiwe.
Wan atuwo lorore
.

E se mo dupe pupo lowo yin ooooooooo..
Olohun a maa tun bo wa pelu yin...
Eo pe ju bi mope tinpe lo..

Ma fun yin ni esi bi o ba se ri.... E jo! mo fe onmo to gbona gidi,ounmo ti a fin wo iyepe, ati onmo kamo oun ti oni jalabi ba babawa. Efu mi ni phone number yin...email mi ni yi. taofeeqyeqeen@yahoo.com.
Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 10:08am On Nov 16, 2015
alhajialhaji:
E se mo dupe pupo lowo yin ooooooooo..
Olohun a maa tun bo wa pelu yin...
Eo pe ju bi mope tinpe lo..

Ma fun yin ni esi bi o ba se ri.... E jo! mo fe onmo ti a fin wo iyepe, ati onmo kamo oun ti oni jalabi ba babawa. Efu mi ni phone number yin...email mi ni yi...Taofeeqyeqeen@yahoo.com.

Baba wa Kadunasouth ati Baba waa Healthfirst, e se mo dupe pupo oooooooo...

wonyi kia ni ayipada rere yio de
1. Ajegun ebe awon Agba
Ogede omini eyokan odidi atare kan elelo atare gidi tabi atare aja eo wa bo epo atare yi eo yo gbogbo idoti arare kuro lai ni jeki okankan kojabo ninure eo fe dada eo wa dasinu tanganran funfun eo wa juba fun awon ti oloun ko aye lelowo dada eo waso bayi

Ona merindinlogun lalake tiso gbo gbo igi ti elegbeje ba fowo ba didun nidun lati onilo tin ba jawe komaje tin bawa egbo komaje ti basogun komaje funmin, gbogbo aburu omo araye ati isakusa to walarami ti koje ki ogun ti mobase kojemo kotudanu lati onilo month palase nio ao wa fi ogede yi ba atare ao maje tafijetan
Ewo nio okogbodo mumin fun bi wakati kan, gbogbo ori eni toba je yio gbona wa yio ma lagun wa fi owo gba eledare mun pelu iWure aje fun yin o

Elekeji
Egbo lapalapa ati odidi atare ao jopo ao mafi epo la lalale

Eleketa egbo akese ati afoma lapalapa ati odidi atare kan ao jo idi ogun yi kogbodo kanle taba ti jotan koko na ao so si bikan ni akogbodo so kale ao mato si awon ogun tabase diedie

Elekerin
Ewe ata ewe alupaida 3 eyo atare meje ase oga ao gun papo gbere yipo owo wa mejeji ati gbere mesan si ika arin fun eni to nte yepe (isabi) tebase gbogbo eleyi ayipada rere deeeeeee
Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 9:44am On Nov 16, 2015
E se mo dupe pupo lowo yin ooooooooo..
Olohun a maa tun bo wa pelu yin...
Eo pe ju bi mope tinpe lo..

wonyi kia ni ayipada rere yio de
1. Ajegun ebe awon Agba
Ogede omini eyokan odidi atare kan elelo atare gidi tabi atare aja eo wa bo epo atare yi eo yo gbogbo idoti arare kuro lai ni jeki okankan kojabo ninure eo fe dada eo wa dasinu tanganran funfun eo wa juba fun awon ti oloun ko aye lelowo dada eo waso bayi

Ona merindinlogun lalake tiso gbo gbo igi ti elegbeje ba fowo ba didun nidun lati onilo tin ba jawe komaje tin bawa egbo komaje ti basogun komaje funmin, gbogbo aburu omo araye ati isakusa to walarami ti koje ki ogun ti mobase kojemo kotudanu lati onilo month palase nio ao wa fi ogede yi ba atare ao maje tafijetan
Ewo nio okogbodo mumin fun bi wakati kan, gbogbo ori eni toba je yio gbona wa yio ma lagun wa fi owo gba eledare mun pelu iWure aje fun yin o

Elekeji
Egbo lapalapa ati odidi atare ao jopo ao mafi epo la lalale

Eleketa egbo akese ati afoma lapalapa ati odidi atare kan ao jo idi ogun yi kogbodo kanle taba ti jotan koko na ao so si bikan ni akogbodo so kale ao mato si awon ogun tabase diedie

Elekerin
Ewe ata ewe alupaida 3 eyo atare meje ase oga ao gun papo gbere yipo owo wa mejeji ati gbere mesan si ika arin fun eni to nte yepe (isabi) tebase gbogbo eleyi ayipada rere deeeeeee[/quote]

1 Like

Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 2:28pm On Nov 12, 2015
Aburo Aboye Nile Ifa oooo.. Mo nilo iranlowo eyin baba wa ni ooo... emi omo yin Alhaji Taofeeq ni ooo..Baba Healthfirst ati Baba wa Kadunsouth.. e dakun e sanu omo Awo oooo...

Gbogbo Ise Aajo ti a nse fun awo eyan ko je mo ni ooo... mio ma oun to fa ooo...e sanu mi ooo...... mio mo bi mo se le kan si yin Lori e-mail yin ni ooooo.

1 Like

Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 2:23pm On Nov 12, 2015
kadunasouth:
Fun gbogbo omo ilewe lati pass Exam (secondary/university)
Eso werenjeje eyo meta eyo atare Meta ewe alupaida meta ewe atare die ao lo papo ao fi sin gbere meta si orun owo wa mejeji odaju
NB ti exam bati ku ose kan lati sin, lasiko tasin owo yio ma hunwa sugban mumara oti bere ise niye

Aburo Aboye Nile Ifa oooo.. Mo nilo iranlowo eyin baba wa ni ooo... emi omo yin Alhaji Taofeeq ni ooo..Baba Healthfirst ati Baba wa Kadunsouth.. e dakun e sanu omo Awo oooo...

Gbogbo Ise Aajo ti a nse fun awo eyan ko je mo ni ooo... mio ma oun to fa ooo...e sanu mi ooo...... mio mo bi mo se le kan si yin Lori e-mail yin ni ooooo.
Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 2:16pm On Nov 12, 2015
healthFirst:
hello, this thread is for lovers of nature when it comes to health and other areas of our lives. This thread is also strictly for the Yorubas and those who can read and understand as the language here is going to be pure Yoruba and no translation will be allowed. Reason is that we are going to be revealing some Yoruba secret knowledge of the application of leaves and roots and we intend to preserve and guard these wisdom of our ancestors.

Please do not ask further question regarding my reason to keep this as a Yoruba affairs, it's my choice...but if you refused to respect this, I shall only dignify you with silence.

Aye wa fun o lati beere fun iru Oogun to ba fe sugbon ao ma ko awon orisirisi Oogun sita. Awon Oogun fun itoju aisan, akoya, ati awon Oogun fun isora/isori, awure, aworo, ati beebe lo. Sugbon kii se gbogbo Oogun ni a le fi sita lofe, awon eyi to ba ni agbara gan ni ao so wipe ki e kan siwa lori apo ifiwe ranse wa binaryteck@gmail.com fun ekun rere alaye.

E le dara po mo wa lori whatsapp pelu ero ibanisoro yi...08148398067...e fi gbogbo ibeere yin ranse, ao da yin lohun

Bi a ba ri inkan ti ko ye wa, e je ki a beere ibeere pelu alaye, ao si gbiyanju lati se alaye lekun rere.

Gbogbo Oogun ti a ba ko sita la ti dan wo, to de ni idaniloju wipe yio se ise ti a ba ran.

Too, mo seba awon agbalagba awo ile aye, mo seba awon awo ode orun, mo seba awon Iya mi abeni...e juba o se o.

Iba, iba, iba

Akoda iba

Aseda iba

Ile ogere a foko yeri

Alapo Iku

Olona ola, iba

Esu odara, iba

Irunmale olukotun

Igba imale olukosin

Iba gbogbo yin o

Ero osaju, ero eyin, iba

Adase ni ni wun omode

Iba ki wun ni o

Eyin to ni aye

E je sise mi o san mi

Emi lomo agba

E je owo a maa je fun mi o

Ada ki nmu, ki o ge eku idi e

Omo eni ki nburu,

Ki a gbe fun ekun pa je

E dari jimi, ki e fi owo mi wo mi

Emi lomo aie fepo we

Osoronga opiki elese osun

Ajefun jedo

Oriri aye

Ebo aye ni a ru o

Osoronga ni nba ni gbele aye

Aje ni npa eni

Osoronga gbigbe ni o gbe mi o

Aje ma pa mi lomo
Lomi ki o somo mi

Iya mi agba opiki elese osun

A woni maye

A woni loju re orun

Eje lepo ekuru won

Iya-mi aye elekuru pupa foo

O gberita jagun

O gbe origi ke kanran kanran

Fori jimi bi mo ba se

Fi owo re wo mi

Na ke kanran wonu ile mi

Iya-mogun alara

Bi igun jebo

Aje gbe ni nje

Bi akala jebo

Aje gbe ni nje

Gbogbo eyi a ba se

Asegben ni e je o je

Iya-agba alapo iku

Olokiki oru

Ki nfo o fara pa

Onile origi ki njebo

Ki ebo naa ma gun rege

A agba ki nfi abo bo eni

Ki Omo ara aye ma ri ami won Lara eni

A jefun jedo

Ki nje tire tan

Ki o ma fio na han eni

Iya mi toto aye

Fio na han mi

Bi o ba gbe ori igi ke

Ma ke ao mi

Bi o gbe orita ke

Ma ke pa mi

Kike ni ki o fi ike re ke mi

Omidan eleye oloju owiwi

A ri eni ko to pe eni

Omoran ologbon

Linmo riro ati w ri eda

Alapo iku olona ola

Iku ti nba nro nile mi

Re danu,Opiri eleye moran bi afefe

Arun ti nba nro nile mi

Ro danu

Iya-mi omoran eleye

A pani ma yoda

A mubo ti nbe laye mi

Re danu o

Eyin ti o ni aye

E fa mi mora

Aje eleye e fa mi mora o

Aburo Aboye Nile Ifa oooo.. Mo nilo iranlowo eyin baba wa ni ooo... emi omo yin Alhaji Taofeeq ni ooo..Baba Healthfirst ati Baba wa Kadunsouth.. e dakun e sanu omo Awo oooo...

Gbogbo Ise Aajo ti a nse fun awo eyan ko je mo ni ooo... mio ma oun to fa ooo...e sanu mi ooo...
Culture / Re: .. by alhajialhaji(m): 2:07pm On Nov 12, 2015
Aburo Aboye Nile Ifa oooo.. Mo nilo iranlowo eyin baba wa ni ooo... emi omo yin Alhaji Taofeeq ni ooo..Baba Healthfirst ati Baba wa Kadunsouth.. e dakun e sanu omo Awo oooo...

Gbogbo Ise Aajo ti a nse fun awo eyan ko je mo ni ooo... mio ma oun to fa ooo...e sanu mi ooo...

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 63
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.