Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,297 members, 7,836,297 topics. Date: Wednesday, 22 May 2024 at 03:37 AM

Auggswell's Posts

Nairaland Forum / Auggswell's Profile / Auggswell's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by auggswell: 12:08am On May 12, 2016
[quote author=Legendbaba1 post=44872377]BABA KEPE EJO WO TI ENIYAN BANI AYISAN Staphylococcus KINI ENIYAN LELO FUN ARUN YI MAY U LIVE LONG AMIN [



aarun buruku ni staph, oogun wa ti e ma lo amo yi o gba yin ni time, at leas OSU meta, o wa le kuro Lara yin laarin OSU kan oo amo OSU meta ni ki e ma fi okan le. toripe e le lo se test ki won ni won o ri nlankan ti o de si wa nibe. aasi ma fa aisan orisirisi si yin lara. torina Bi e ba se n lo oogun ni e o ma se ayewo leekan tabi emeji losu
Culture / Re: .. by auggswell: 3:44am On Mar 05, 2016
Ifankaleluya:



mo ti fi esi ranse si e-mail yin. Bi e ba ti se, be ni o ri tori tokan-tokan ni mo fi yonda ifa yen fun yin.



baba ifankaleluya ejowo e fun emi naa ni ise yen pari, mo ti kan so yin Lori email amo mi o gbo nkankan lati odoyin. email mi ni auggswell@yahoo.com. ejowo sir mo n reti lati gbo lati odoyin e seun sir
Culture / Re: .. by auggswell: 1:54pm On Feb 28, 2016
[quote author=Ifankaleluya ejowo sir mo need number yin sir oni awon nkan ti mofe bayin so sir.
Culture / Re: .. by auggswell: 1:06pm On Feb 28, 2016
hello sir baba ifankaleluya number mi Niyi oo 09038958544, email address mi si ni auggswell@yahoo.com] ejowo sir need IFA IMULE AJE YEN NI PIPE SIR eseun sir
Culture / Re: .. by auggswell: 11:04pm On Feb 19, 2016
healthFirst:
135
OGUN OYUN IJU
Isu alubosa were
Kanhun bilala
Odindi atare 3
Iru
Aidan
Ewe omisinmisin
Bakaa
Aogun papo yiokunna, aodasi inu omi orombo were, yomaamu Ni GAASI kookan Ni aaro ki otojeun, leyin21days ki o lo ya scan, pelu ogo oloun yio ti poora.




e SEUN gidigan baba health first fun ise takuntakun yin , please sir, se aidan toro ni tabi Aidan onigun

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 8
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.