₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,329,307 members, 8,439,832 topics. Date: Monday, 06 July 2026 at 06:07 AM

Toggle theme

Cancioamor's Posts

Nairaland ForumCancioamor's ProfileCancioamor's Posts

1 (of 1 pages)

CultureRe: .. by cancioamor: 4:58pm On Jul 31, 2016
emtar:
[color=#990000][/color] Iba Eyin agba. E ku ise. Baba ejowo kini won npe ni "IGI NLA"
Ti eba de odo elewe omo, e o ri ra.
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by cancioamor: 7:04pm On May 01, 2016
Esuen mo wa dupe lowo yin oe mo lo ise yi o si ribe esun . olohun agba adura yin ami[quote author=aguns1980 post=45125901][/quote]
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by cancioamor: 6:48pm On May 01, 2016
Esuen mo wa dupe lowo yin oe mo lo ise yi o si ribe esun . olohun agba adura yin ami
[quote author=aguns1980 post=45125901][/quote]
CultureRe: .. by cancioamor: 10:50pm On Mar 30, 2016
she nkan etoyin lefe fi gba. tio ba ti je nkan eto yin, eyi ti mofe fun yin koni sise ooo?
Rokeeb75:
[color=#990000]EJOWO MOFE MAYEHUN EYI TI A LE FI GBA NKAN NI OWO ENIYAN LATI ORI PHONE.... EJOWO MA DUPE DUPE TI EBA SE MI LORE YI..
CultureRe: .. by cancioamor:
Thank you baba ifankaleluya and healthfirst
Ifankaleluya:
MO FE RO(urge) WA. E JE KA MU ORO(do do) KURO LORI ORO YEN.

SE EMO WIPE ORO-SISO OBEY HOOKE'S LAW, BI A BA TI N SO,BEE NI YIO MA GUN(do) SI, UNTIL IT EXCEEDS THE ELASTIC LIMIT.

SUGBON TA LO MO IGBA TI YIO EXCEED ELASTIC LIMIT? NO-ONE.

SO,LETS STOP POSTING ABOUT IT. KOSI ENIKENI TO N BA ARA WON JA LORI FANRAN YI.

LETS CONCENTRATE ON THE SALIENT OF THE THREAD.

THANK YOU ALL FOR THE SPOKEN & UNSPOKEN WORDS. I WISH YOU ALL, ALL THE BEST.
CultureRe: .. by cancioamor: 1:01pm On Mar 19, 2016
thank you. please dont forget me as well . cancioamor@gmail.com. ese pupo
dominicson:
I intended posting ten confirmed Imule, but now I'm afraid the next eight could make the female ones among us 'fly'.

So helpless I am to help those I know they really need these imule here!
CultureRe: .. by cancioamor: 12:54pm On Mar 19, 2016
Beni emi o ri nkan tiko da rara ninu tita iwe ogun, ofe ko ni won print e sita fun anfani awa omo yoruba amo ere ajeju nio da rara, Ki awon agba mejiji yi dakun kiwon jebure bi awon agba tin wi, epari ija ti owa larin ara yin, alagba ifankaleluya mo mo wipe agba awo ni yin. kin ma paro fun yin ona po pupo ti ele fi ran ikanni yii lowo. ema se binu. siso oro, gbigbo oro, titumo oro.. oun to lagbara ni. emase binu rara. baba healthfirst mo fi olohun oba be eyin na emase binu mo. We need you both. i have been following this thread long ago. alufa, pastor ati onisegun po pupo ti won follow thread yii. ibi ti n ba ti siso efi ori ese mi jin mi.
Titiloye247:
Awon ologbon ati oloye eniyan po lori ikanni yii daadaa, bee naa ni awon awo ati ogberi ko lonka. Ko si ohun to ye ko mu ede aiyede wa lori ikanni yii rara. Emi juo, iwo jumi, Olorun lo ju gbogbo wa lo. Bi a paro ewe ati egbo funra wa, ti o ba sise, o wu Olorun oba oke lo fase si. Ologbon kan ko ri omi ta ni koko, amoran kan ko le so iye erupe ile, alarinka kan to le mo ibi ti ile pekun si.

Alagba Oluwole Oluokun a.k.a Ifankaleluya, emi ko ri ibi ti enikeni ti bayin soro ajulo nibi. Ohunkohun ti eyin ati baba Healthfirst ba dijo so, laarin ara yin ni, ko kanwa lori ikanni yii rara. Bi e ba so wipe ki won ki ese ifa kan fun yin, ti won si ko, tabi e kiwon ni kiki awo, ti won ko ba dahun daadaa, iyen ko ni nnkan se pelu awa nibi. Emi ko ri nnkan to buru ninu iwe tita. Emi naa te iwe jade, ibi gbogbo si ni won ti nta iwe orisirisi, ati iwe oogun- eleyi ko je tuntun; eni ti o ba wu lo maa raa. Baba wa, Yemi Eleburuibon ni ipinle Osun, babalawo to mo ifa gidi gan-an,se iwe lorisirisi, okan ninu re ''THE HEALING POWER OF SACRIFICE'' .Tita ni won ntaa, kii se ofe. Nitori naa, e ma ri iwe tita bi ese.

Bi Olorun ba funyin loore ofe lati maa se iranlowo iyere ifa, ifa fun orisirisi ona abayo, aseyori, ibori ota, isoye, afare, arobi, owo, eyonu etc ati oogun lorisiri, e funwa bi Orunmila ba se dari yin.
CultureRe: .. by cancioamor: 9:17am On Mar 19, 2016
Bawo ni lilo ises yi? esheun
dominicson:
Imule 2: Osa Eleye

Igbin apinnu meji, otutu opon, sefunsefun, aluki, ajeobale, iyere.



Psalm:

Alagada nla l'oruko ti a n pe ifa. Araba-tasi l'oruko ti a n pe ile. Ti a ba fi efun fun aye, ara aye a ya gaga. Ti a ba s'epe (curse) so Ogun, ara ogun a le koko. Ogun aseje, awo won lootu Ife, oun l'obi Atepe, Atepe l'obi ile. Nje okunrin l'o ba ni kin ma t'ele yi pe, ki o ku bi aja se n ku ti oun ti ogboro. Agbalagba l'o ba ni ki n ma tele yii pe, ki o ku bi aguntan se ku ti oun ti bolobolo enu re. Ti o ba se pe eyin aje gan ni e wipe ki n ma t'ele yi pe, ki eku bi adire opipi se n ku ti oun ti agada ese re mejeji. Enikeni ti o ba so wipe ki n ma te ile yi pe, ona odi, ona odi ni ki won ma gba lo s'orun. Eye s'eye, o fi apa se eye. Eye s'eye, o fi ese se eye. Eye fo omo owu alagbede pomu. Eye wo(enter) ile Alara, o pa omo Alara. Eye wo ile Ajero, o pa omo Ajero. Eye wo ile Orangun ile Ila, o pa omo Orangun ile Ila. Won ni nibo ni ile awon babalawo to gbo'ju kun si? Won wa k'ori (face) si ile olori Ajangbo-wewe tii se awo ile Alara, eye pa! Bobo-l'aguntan-wo ti se awo ile Ajero, eye pa! Won wa k'ori si ile Aforikori-oke tii se awo Orangun ile Ila, o yan kete, eye pa! Won wa f'abo si ile Orunmila, won ni awon wa wo(pull down) ile re, awon wa pa omo re, awon wa pa aya re, awon wa pa molebi re. Orunmila ni eewo! Orunmila ni oun yoo so oruko yin fun yin nisisiyi. Won ni iro ni, won ni ko si eniti o mo oruko awon laye mo. Orunmila ni sebi Atidisoro l'oruko iya(mother) yin je. Sebi Atedojokan l'oruko ti baba yin je. Sebi Owale-karakara l'oruko ti eyin gan paapa n je. Won ni o di oro imule, won ni ki Orunmila o ke si Otutu-opon, ko kesi Sefunsefun, ki o wa pe Osa meji dani. Won ni ki Orunmila fise Igbin meji yii je. Won ni gbogbo eniti o ba je obe yi ti di eni owo. Won ni ti erin(elephant) ba je oko titi, a fi ewe aluki si le. Bi efon naa ba je oko titi, i fi aluki s'oto ni. Aje kan kii gboju-gboju ko ba sori igi ajeobale, gbogbo ara ni sefunsefun fi sefun aje, ki ile mi o kun fun aje(wealth), ki awon eleye fi owo t'emi wo mi. Oun kohun ti mo ba ti pe ni ko ma je mi.
CultureRe: .. by cancioamor: 8:01pm On Mar 18, 2016
Eyin agba mejeji mofi ojo ti awaye beyin , motun fi ojo ti aoni simo beyin . epari ija arin arayin nitori Olohun, nje emo wipe awon agba agba wa lori ikan yii, gbogbo oro ti e fin exchange si ara yin la nri ooo. Ti awo ko ba gbawo nigbowo nko? Epari e nitori nkan eyokan ti koni pe meji lailai. IBA AWON EKAN AGBA-AGBA TIO PAMO, MOJUBA OOO
CultureRe: .. by cancioamor: 6:22pm On Mar 06, 2016
Ifankaleluya:
OBARA-OGUNDA NI A N PE NI OBARA-EGUN TAN.

IFA NI;

Obara-egun tan

oni(today) la o pa egun run

adifa fun orunmila nijo ti omo-araye ni awon o fi eegun,epe ba aye baba je

ifa ni iro ni won n pa

egun kii mu ila

egun kii mu ikan

ati egun ati epe kii mu ata

obara-egun tan

ifa ba mi pa gbogbo egun aye mi.

IFA YI NI A MA N FI, ata,ikan,ila ati etu-ibon se. Ti a ba pari re, enu ona ni ao ti te ifa re,ti a ba pe ifa tan. Ao wa fi etu ibon yen si ni aarin,ao wa sa ina si. Ti ina yen ba gbi, ise yen ti dahun niyen.

Ela-boru, ela-boye, elo-bosise.
Can You please send me your email to cancioamor@gmail.com sir. ejo sir efun mi ise yi. olohun aduro ti yin ati gbogbo agbagba lori ikan yii,
CultureRe: .. by cancioamor: 8:44pm On Feb 27, 2016
@ Ifankaleluya ejowo efunmi ni ifa yen ni pipe 09032601045
CultureRe: .. by cancioamor:
number mi re ooo. 008079869007 .. mo juba agba

1 (of 1 pages)