₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,331,083 members, 8,448,569 topics. Date: Monday, 20 July 2026 at 02:27 PM

Toggle theme

Desorlah's Posts

Nairaland ForumDesorlah's ProfileDesorlah's Posts

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 (of 17 pages)

Forum GamesRe: One-word Association by desorlah(f): 6:47pm On Jun 18, 2007
War
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 6:36pm On Jun 18, 2007
Gbogbo omo yoruba ile naira, se alafia ni mo ba yin o!

Mo sare lo si oja lati lo ra awon nkan kan fun eeto iwuye ni eo se ri mi lati aaro, se ko si iyonu?
Baale, e ku ile o
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 1:53pm On Jun 18, 2007
Eku ile o, se daada ni mo ba gbogbo yin.
Gege bi oko mi se ti so fun yin, mo sare lo si Nigeria ni lati lo fi oro ayeye iwuye to awon eniyan wa leti ni, se daada mi mo ba gbogbo yin?

Baale, Kara oo le o, se alafia ni e wa, e si ku oro ilu wa yii, ko ni tori yin baje o!!!, awon olori na nko, se daada ni won wa.

Segoye2, oko mi, olowo ori mi, se alafia ni o wa, mo sese de bayi na ni, mo ri wipe oo si ni ile, se ko si problem rara?

Ore mi Nana, se daada lowa, awon family nko, se ko si iyonu?

Everybody, e take care.
EducationRe: What Is Happening To Nigerian Polytechnics! by desorlah(op): 1:46pm On Jun 18, 2007
Just got a gist from a friend that Yar Adua wants the re-structuring to hold on for some time, that polytechnics should continue with their HND for the mean-time, How true is that?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 8:35pm On Jun 15, 2007
O da bii eni pe mo ti fe maa lo ile, nitori mo ni lati gbo ounje aale. lol grin

Baale ati gbogbo omo ilu naira, aa tun ma rira later.
E jowo e ba mi sofun segoye ti o ba tii de wipe mo ti lo gbo ounje o.

Ese pupo
Forum GamesRe: Be The Last Person To Post Here: by desorlah(f): 8:33pm On Jun 15, 2007
I dey kampe
RomanceRe: How To Know When A Man Loves You by desorlah(f): 8:25pm On Jun 15, 2007
debosky:
na these kain girls I dey find when i was in the world,
where are you now? grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 8:02pm On Jun 15, 2007
Baale, e ku oro mi o, e mase da debosky lohun o, o da mi loju pe oro ilu wa yi ati oro iwuye ni segoye ba lo, mo si mo wipe ko ni pe ki o to de.
EducationRe: What Is Happening To Nigerian Polytechnics! by desorlah(op): 7:53pm On Jun 15, 2007
Thanks Terry
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 7:32pm On Jun 15, 2007
debosky:
Desorlah, oko re segeoye ti gba ile emu lo oh, sebi o mo pe eni gege bii ojo eti (friday) oun ati awon ore re maa n lo mu emu ati pepper soup ni ile emu iya sikira, ibe ni segeoye maa n'gba lo tio o ba fe sinmi lehin ise lantu lantu to se laarin ose.
Sebi e dijo man lo ni, kilode ti iwo oi tii lo?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 7:26pm On Jun 15, 2007
richylaw:
Iro o, ko si ni aafin o, wo abe kobodu ati kapeti boya o ti sun lo si be ni grin
Aafin lo da gbere nigba ti o jade laaro, mo si lero wipe eyin le ran nise ni.

richylaw:
wo abe kobodu ati kapeti boya o ti sun lo si be ni grin
shocked shocked shocked shockednot expecting this from baale
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 7:21pm On Jun 15, 2007
Eyin omo oodua ni ile naira, se daada ni mo ba gbogbo yin,

Ejowo talo ba mi ri Segoye o, lati aaro lo ti jade mi o de i tii gburo e,
Baale, abi se laafin lo wa ni?
Nairaland GeneralRe: New Pictures Of My Children Tom And Aicha by desorlah(f): 5:31pm On Jun 15, 2007
@ Nferyn, Wonderful kids u've got there.

Would you allow me marry Tom? (dont worry, i'll wait till he's grown up) grin grin
Forum GamesRe: Answer A Question With A Question. by desorlah(f): 5:04pm On Jun 15, 2007
do i have to tell you the question you'll ask?
Forum GamesRe: Be The Last Person To Post Here: by desorlah(f): 4:58pm On Jun 15, 2007
How una dey?
Jokes EtcRe: Scrabble by desorlah(f): 4:49pm On Jun 15, 2007
olawunmi05:
mail
huhhuhhuhhuhhuh

bail
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 4:35pm On Jun 15, 2007
n korin E de le o fesu labule. . . . . . . .

richylaw:
koda o ri ro daadaa o. ha ha , baba olowo.
Ninu gbogbo ile ise ti o n be ti eniyan lee da sile , eyi ti won yi o ti maa se oti lile ni o wa wu o lokan lati da si ilu wa.
uhn, oro sunnukun! Emi nikan ko ni mo ni oro yi o, gbogbo ilu ni yi o da si.
GBOGBO EYIN ARA ILU E BA WA DA SI ORO YI O, SE KI A GBA LAAYE A BI KI A KO EHIN ETI SI ORO ILE ISE OTI LILE NI ILU WA?
Baale, Se ara le o, Emi ko ni fe ki a gba ogbeni yi laaye lati maa ta oti lile ni ilu wa yi o, nitori Apere esu niyen o, ao de fe esu ni ilu wa yi o.

Si Ogbeni Tafari, Oti lile ko, oti riro ni, se e de fe joye ni ilu wa yi na. . . .  ooda na o, oju wa laase.

Si Segoye, se alafia ni o wa?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 12:57pm On Jun 15, 2007
tafari:
Baale, oko ilu, se daada ni ede wa. gege bi mo se so fun yin, eniyan pataki ni mi ni awujo. mo ni owo, okiki ati ogun.awon ibere ti e nbere yii ko to si mi. e je ki nfun yin ni owo (egberun lona millionu naira) lati ra oye naa.
Mo se ileri wipe ma ko aafin miran fun yin. ma si ra moto ayokele meta pelu.
baale oko ilu, e gba mi towo tese.
ilu wa yii a toro bi omi ati owuro pon o.
e se pupo.
shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked
Forum GamesRe: Be The Last Person To Post Here: by desorlah(f): 12:50pm On Jun 15, 2007
grin grin grin grin grin This is funny though, why do u keep coming to this thread grin grin grin grin
Forum GamesRe: Answer A Question With A Question. by desorlah(f): 12:34pm On Jun 15, 2007
are u asking me?
Dating And Meet-up ZoneRe: Who's Dating Who On Nairaland? by desorlah(f): 12:32pm On Jun 15, 2007
kitaun:
@desorlah

Orobos are not welcome here tongue grin
I dont have your time *hissing*
Jokes EtcRe: Scrabble by desorlah(f): 12:27pm On Jun 15, 2007
fade
Forum GamesRe: One-word Association by desorlah(f): 12:25pm On Jun 15, 2007
Theatre
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 11:58am On Jun 15, 2007
E kaaro o, e jowo e ma binu wipe o pe mi die ni aaro yi, Oro ayeye iwuye yen na ni mo ba lo. Aso Elegbejoda ni mo sare lo wo ni oja ni aaro yi, ma wa fun yin ni sample later.

Se daada ni mo ba gbogbo yin o.

Baale, E kaaro o, Se ara le?

@ Segoye, Olowo ori mi, bawo ni, se daada ni o wa, jo ma binu si mi wipe mo pe die, aso yen na ni mo lo wo ni oja.
Se o ti jeun sha?
Nairaland GeneralRe: A Survey For Everyone! by desorlah(f): 7:00pm On Jun 14, 2007
First name: Hardeysorlah
Gender: Female
Favorite food(s): Noodles and Salad
Favorite color(s):   Lilac, pink and sky blue
Future child's names:  Akorede
Sign or b-day:  25th January (Aquarius)
Favorite number: 1
Biggest fear:None
Favorite quote:  Do unto others as you wish them do unto you
Obsession(S):  My look
Addiction(s):  None
Biggest turn off:  Pretence
Biggest turn on:  Facing Challenges
First thing you notice in the opposite sex:  Physique
Last book you read:  Night Shift

Preferences,

Chocolate or vanilla: Vanilla
Hot or cold:  Cold
Coke or Pepsi:  Coke
Truth or Dare:  Truth
Rightie or Leftie:  Rightie
20/20 vision or glasses: 20/20
Big or small:  Medium


Do you,

Speak another language: Yes
Own your room or share with sibling: Share with a sister
Have a sibling(s): Yes
Think that God should be male or female: Female
Think that God should be white or black: Black
Like your handwriting: Very well
Type fast or slow: Very very fast
Think you're beautiful/cute: much more beautiful
Sleep with a stuffed animal("teddy bears"  and the likes in case you don't know): sometimes did, not anymore

Misc,
What is/are the thing(s) you miss the most: Not taking the most advantage of my childhood
Are you straight/gay/bi: Very straight
Piercings: Yes
How tall are you:5'2"
How tall do you wish you were: 5'7''
What would you change about yourself: My height
What wouldn't you change:
My look
Forum GamesRe: Answer A Question With A Question. by desorlah(f): 6:40pm On Jun 14, 2007
Do i care about what you think of?
EventsRe: Please Announce Your Birthday Here: by desorlah(f): 6:17pm On Jun 14, 2007
January 25th
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 6:07pm On Jun 14, 2007
Adupe o. . . . . . . . E de ku ipale mo ayeye ijoye na o
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 5:53pm On Jun 14, 2007
Ika, kaabo o
Forum GamesRe: Reply Signatures. by desorlah(f): 5:35pm On Jun 14, 2007
huhhuhhuhhuhhuh??
Forum GamesRe: Be The Last Person To Post Here: by desorlah(f): 5:19pm On Jun 14, 2007
Dont know why i keep coming here

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 (of 17 pages)