Culture › Re: .. by Frayo93: 11:08pm On Sep 01, 2015 |
omoaribaba1: , emi ni afose tio nje bi idan oooooo, sugbon afose yi gbona debi wipe eni ti akobafe ki aye re nitumo mo ni ale loo fun oo, ko ni ero. (MAYEHUN) na tun wa ooooo, tie ba fe ni ise yi lowo ero alatagba mi ree (omoaribaba1@gmail.com) . . eeju sitaa |
Culture › Re: .. by Frayo93: 9:04pm On Aug 30, 2015 |
¤OGUN IFERAN¤ . . Awo ekun, igbe eyele, odidi atare kan, ao jo gbogbore, ao wa po mo ose, fifiwe. |
Culture › Re: .. by Frayo93: 7:40am On Aug 16, 2015 |
kadunasouth: Aseje Owo togbona Ewe imi esu eyokan tojo, ao loma iyere 3 ao fi din eyin ororo kanje pelu epo ati iyo die ninu koko Aseje ao wa ogorun nera ao fikale ao se adua iye ti anbafe si owo yi ao wa so aseje sori ibikan tobati jina ao nije ki idi isasun na kanle toba tutu die ao gbeka ori ogorun nera yi ao wa je aseje na ao wa lo fi owo na se sara fun oni bara odaju . ewe imi esu eyokan tojo, (tojo) yii ko ye mi. e joo kini o tunmo sii |