Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ifadamilola30: 3:14pm On Jan 24, 2016 |
kadunasouth: Ogun Awure owo Odidi eye ega kan ikode meta ao ki ikode kan bo lenu ao fi ikan si apa otun ikan ni apa osi ao jo pelu odidi atare kan ao lo ao pin si ona meje ao wa mafi foko mu lararo fun ojo meje opari Baba mi, e dakun se a ma fi ikode kookan to ku ha apa eye yi kookan ni?? Abi bawo ni sir?? 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 9:10pm On Dec 12, 2015 |
healthFirst: 109
IMULE FUN EYONU AYE Okete OOoye kan, ao ge ori re ati iru re, ao ko ifun re jade, ao jo pelu odindi atare kan. Ao sun iyoku ara re, ao ge si 16, ao wa bo lori ina, ti o ba jina die, ohun ni ao fi gbe ipese ni aago kan oru. Ao fi ebu ti a jo yen die si, eyi to ku yen, ao fi schinap lo lekan na ti a ba ti gbe ipese yen ti a ti wole ni ao to lo. Agba yin a dale baba, e dakun se a ma fi iyo se eran yen?? 2 Likes 1 Share |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 2:50pm On Dec 08, 2015 |
healthFirst:
Ewe laa yato si lapalapa...ti n ri picture re, ma post re later. E seun lopolopo baba!! Ewe a ma je!! |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 9:25am On Dec 05, 2015 |
Mo ki gbogbo ile, e dakun iru ewe wo ni won npe ni "Ewe La"?? E dakun se Ewe Lapalapa ni abi iru ewe wo ni Eyin awo E dakun e tomi sona!! Awon onile yio gbeyin!! Ewe a ma je!! |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 9:27am On Dec 02, 2015 |
burticious:
E jowo ,repercussion wo lo wa leyin ise yii , se ko ni pa awon omo mi lara COPY AND PASTE NI ISE YIOO!!! |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 6:05pm On Dec 01, 2015 |
omoaribaba1: OGUN ARUN KARUN
EWE AWOGBA-ARUN, EGBO AWOGBA-ARUN, EGUN-EIYE KANAKANA EGUN-AKALA EWE TABA GIDI IDARO ALAGBEDE KANHUN-BILALA ODIDI ATARE KAN EGBO EWE OWO EWE ARUNYANYAN ERU ALAMON AIDAN ATA-IJOSIN A O JO PO A O MA FI OTI LO LOBATAN ARUN KO NI SEWA: ti koba yeo; mail mi ni:omoaribaba1@gmail.com Baba, e dakun kini oruko min ti Egbo ewe Owo yii nje?? |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 10:07am On Dec 01, 2015 |
keyguy59: AFOSE ase oka ati odindi atare kan ao Jo papo ao fi sin gbenre kan si isale ete ao ma fi ahon kan Okigbe ida ogbe pada sodo eni sawa)ao wa agbon tobo sile funrare ao da lu lori ao lo efun ati osun po ao ro sinu agbon yen ao gbe sile di aro kutu ojo keji aoji po ao gbemu laiti soro si eni keni ao lo la agbon toku mole lorita laro yen otan MALU-opolo odidi kan ao fi okun di ese re ao wa ewe ina esinsin ewe airagba ewe oyin ewe sawerepepe pelu iyo ao lopo ao fi kun eyin opolo yen ao maki opolo yen pe "se ofe kuni? maiku, ori unfo e? Edo unrin e?, aragbigbona ni? Tio ba ti wa ku ao wa tu okun ese re ao jopo mon ijakariwo ati odidi atare kan ao fi se igbadi tabi tira ti won ba luwa mon ao sowipe "OJO TI OPOLO BATI KUN OSUN SAWEREPEPE OJO NA NI RORUN Amudo: imi ewure oriso,imi aguntan oriso,ewe rekureku. Eso agunmona ao gunpo aofi awo ojiji di mo ara aba irin ni owo mejeji aofi owu dudu ati funfun wepo o4 ibiti ewure abaso ewure si ni susi. Ibiti abaso aguntan si ni susi .rekureku kifo koja oju ona.agunmona kiraye gun igi re jake ao daruko obirin nasi ao kan mo ara igi abo odaju gan o ASEJE OWO NLA TODAJU- ewe tanapowo 50, iyere lopolopo, ao fi se akuku adie je, lepo niyo, ao ge ori ati ese adie naa ao ri mole ao se aseje naa, ao ri owo lopolopo OWO-ao te ifa ejiogbe sile ao pe ofo yi si lori-Oludari aye loruko ti anpe ifa,ina kaan loruko ti anpe etu,ojo ti obinrin bati di aya oba ojo naa ni won fi owo tire wo,ki tomode tagba ma fi owo wo emi lagbaja omo lagbaja loni,ao koju seyin fi ese osi ta yepe naa.(A le ra nkan ni owo eniyan ki won ma gba owo,eri daju pe efun won ni owo won)use it for your own protection AGBELEPOTA: Ori ako alangba1, ao fi osun pa, ao ko atare9 si lenu,ao jopo ao fi sin gbere mesan si arin ori. OGUN EYONU AIYE: Odidi ladaripon1, Ewe ewuro oojo, odidi atare1. aojopo, ao da sinu epo pupa ao ma la. TI AKIFI RANTI SA OGUN SENIYAN. Ewe igbagbe eyo atare 7 fun obinrin 9 fun okunrin ao lopo gbere 11 lori. ORUKA AYETA:ao ge igi atori mejo(ni dogbandogba,oruka irin dudu mejo,awo{skin}o wawa,odindi atare kan,ao jopo ao ko gbogbore sinu igo kan ao fi etu die foko mu ao ki oruka kan bowo.Efi etu die si adie lenu kie ki oruka kan bo lese ki wa yibon si wo. ogun ki ole ma wole;ao ge ora ara ewure die ti aguntan die ati ti elede die sinu fitila kan,ao fi ewe ko ti won pe ni idariko tabi modesina si ao fi fitila miran de,ao we lowu dudu ati funfun a o gbeko enu ona OGUN ORUKA ANO SUBU. Bo wu ki enia ti tobi to tabi ki agbara re ju ti enikan ti a ba fi oruka yi na yio subu lese kan na. Ewe ina gbigbe ao lo pelu alahannahan ao pa bara kan ni oko [parsa] ao ko egbogi ti alo yi si ao wa ko oruka irin iye ti aba fe si ao wa osun ti won fi kun ibeji lara ao ko le oruka yi na ao de pa mo bara na ao lo ri si idi ogede wewe gba ijo meje ao lo ko oruka yi ni ijo keje ao to ju re. Lilo re:- ao fi ikan bowo fi na enia yio subu. OSOLE NLA TODAJU- odidi tagiri mejo a o ge wo si meji meji ti yo wa je 16, a o ko won sinu isasun pelu ori eiye akala, olongbo kan, iru woro ti ko ni iyo ko po die, ati ewe orijin a o jo gbogbo re a o si lo kuna daada a o ma bu ebu na die si owo osi wa a o si fi oyin gidi po a o fi lo ni eekan losu o ti di dsame date ta lo la o tun lo ni d following month, odaju baba mi kan lo fun mi. OTIDE OOOOOO, AMUDO AMUDO AMUDO, tested and OKAY AMUDO... Ewe ogbo meta, ewe apada meta, odidi oga kan, omi toromini, Áo jopo ao p month ose, ao ko sinu aso funfun, ao so ko si ibikan ninu ile (house) ti kogbodo kan ile, (ground). Tia abafe lo ao bu die ninu ose ye ao ho si owo, ao daruko obinrin ti a fe lo fun sinu re, ao fi we owo mejeji. OFO RE.... Ogbo loni kio gbo temi lonni, apada loni kio ma le pa oro mi da, aso alaso ni oga ngba, ekuin ekekun ni toromini nji sun, ekun mi ni ki lagbaja ma sun loni o . ODAJU Ogun Asma Ikarahun igbin ao lo dada yio kuna ao walo sugar oni koro eyo meta mon ti yio kuna dada ao mala yio gbadun pelu ogo oloun MALU-opolo odidi kan ao fi okun di ese re ao wa ***ewe ina esinsin**** Mo ki yin lopolopo baba keyguy59, e dakun se Ewe Ina ati Ewe Esinsin ni e fe type sibe yen abi Ewe Esinsin?? Oodua yio gbeyin!! |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 10:03am On Dec 01, 2015 |
|
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 8:42am On Dec 01, 2015 |
kadunasouth:
Awan Apere Arun iba lopo leleyi bi atosi, ogun atosi lemalo Egbiyanju eleyi
OGUN ATOSI:- Bara, baaka, egbo jebo, kanhun bilala, ao la bara si meji, ao ko gbogbo egusi inu re kuro, ao wa ge si wewe, ao ko sinu ikoko agbo, ao se gbogbo re lagbo pelu kanhun bilala na ti oba ti jina daadaa, eni na yio ma mu ilaji gaasi cup stainless laro ati laale
Modupe lowo yin baba mi kadunasouth ati baba Healthfirst!!. Maa gbiyanju ee wo, ma funyin labo!! Eo ni foju sunkun omo lola OLODUMARE, lola awon iyami abeni aboju merindinlogun, lola orunmila ati lola laaroye!! Ejowo baba, teba le funmi nise ti mio fini ko aarun lara obinrin mon, e dakun e funmi, inu mi yio dun!! Ewe ati Egbo yio ma je funyin!! |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 8:04am On Nov 30, 2015 |
healthFirst: 104 EYONU OWO NLA KAN LARIN OJO 9 Ao wa ori oka toni ase lenu, iyere 41 ao lo po dada tio kunna ao fi se eja aro tutu kan je, ao ge si meta, ao ni ge ja o, ao je pelu adua. E dan wo ke fun mi labo. IBA!! Baba Healthfirst, baba Kadunasouth, ati eyin Awo, e dakun e gbami!! ti mo ba ti nto, inu inkan omo kunrin mi ma n tami, a si tun ma gbona. E dakun e gbami. O se pe Osekan ti eyi bere!! E gbami, eo ni foju sunkun ikankan ninu awon omo yin!! |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 10:12pm On Nov 29, 2015 |
healthFirst: 104 EYONU OWO NLA KAN LARIN OJO 9 Ao wa ori oka toni ase lenu, iyere 41 ao lo po dada tio kunna ao fi se eja aro tutu kan je, ao ge si meta, ao ni ge ja o, ao je pelu adua. E dan wo ke fun mi labo. Mo ki yin lopolopo, baba Healthfirst, e dakun se ao se aseje yi Lepo Niyo?? 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 11:28pm On Nov 26, 2015 |
scholes0:
Se Aiyan ni tabi Aayan? Inkankan na ni!! |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 11:22pm On Nov 26, 2015 |
healthFirst: 102 ALA WIPE OKUNRIN NI IBALOPO LOJU OORUN( Ifasehin ni Awon Aye ma n fi eyi se fun eniyan) E lo wa osun abalaye ki e loo ni ileele pelu eyo ataare meta ki e fi sin oke inkan omokunrin yin si oke ki o je meta pere, eo ji laaro kutu ja ewe ewuro ki oorun to yo yoo je 201, ao gbo 200 sinu omi ao gbe si oorun laaro ao da eyo ataare 7 si ao fi owo meta daa bi agbelebu, ao fi sibe, ao gun eyokan ti o ku mose ti e le fi we leekannaaa ao se(sieve) omi yen n ao gbe omi yen ao lo fi we ose yen ni ale ki a to lo sun. Pelu ase Olohun gbogbo ona ti won ba di mon wa yo si patapata
Adura yin a gba, baba!! Edumare koni fiyin sile! E jowo iru osun wo ni osun abalaye?? 1 Like |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 11:18am On Nov 26, 2015 |
Ayomidegbenga1:
ejoo sir,kini won n pe ni adodun ati wipe kini itumo aiyan. Adodun!! Ni kukuru, ti obinrin ba nfi Ogun adodun pa oju ara, oko re yio gbadun re ju nkan miran lo. Bee gege fun okunrin to ba nfi ise yi pa nkan omokunrin re, obinrin to ba lo fun yio fe ko tun ma ba oun lopo si ni!! Aiyan ni awon oloyinbo npe ni Cockroach!! 2 Likes |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 11:06am On Nov 26, 2015 |
E seun lopolopo, ajagunmale a duro tiyin!! |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 7:32am On Nov 26, 2015 |
ayokomi1010: Ogun Adodun Nla.ao toju aiyan kan ao lo ni enu ona wa ao wa fi ori po,ao ma fi wo nkan omokunrin wa ti a ba ti fe ba Obinrin ni ajosepo,be na ni Obinrin na le lo fun OKUNRIN ki o Sa ti fi pa oju ara re saju ki OKUNRIN to ba ni ajosepo,Adodun yi ni agbara pupo,Iba eyin agba oooooo,ewe ama je o. Ewe a ma je oo!! E dakun se a ma gbe olo ti a o fi lo ise na si Enu Ona wa ni?? Abi ao lo ni ilele enu Ona wa ni?? |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 7:31am On Nov 26, 2015 |
|
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 7:01pm On Nov 25, 2015 |
Baba Healthfirst, baba Kanosouth ati eyin Awo te wa nibi, e dakun awon aafani wo lowa ninu ki enia KO-FA, (Ki enia wo igbodu, ko si ni ifa ti a ma bo ninu ile Re) IFA KIKO! .. Awon aafani wo lo ro mon... |
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 6:34pm On Nov 25, 2015 |
|
Culture / Re: .. by Ifadamilola30: 6:31pm On Nov 25, 2015 |
MOJUBA OLODUMARE!!! IBA Osanyin!! Orunmila, IBA!! Esu odara, IBA!! Eyin Iyami Eleye, IBA!! IBA agba, IBA Omode!! Moki gbogbo ile oo!! IBA gbogbo Eyin Awo oo!! Moki awon Ogberi pelu.!! IBA baba Healthfirst, baba Kanosouth, keyguy59, ati gbogbo eyin Awo ire/Onisegun ti e finnu-findo ti e si fowosowopo lati ko Ise lorisirisi sita lori thread yii..!! E ku ise takuntakun!! Orunmila a gbewa ooo. Gbogbo eni to ba fi tie sile to ngbo teni eleni, Odaju wipe OLODUMARE yio gbo tiwon na!! 1 Like |