Keyguy59's Posts
Nairaland Forum › Keyguy59's Profile › Keyguy59's Posts
1 2 (of 2 pages)
Baba healthfirst se e ri.......awon ti won pe a wa ni copy and past.....afi suru........e mi o jin yan..sugbon eni ti won ma gba lo ma po ju.......emi......keyguy mi o je fi ogun mi si le fun enikeni.....aya fi ti ba ma....se copy and past......fun won.... |
MR...saliu elenugboro.....sorare.......ore mi ewe nje ben lo fi ise yi ran se si mi lori facebook.....mo si ri wipe o ma da fun a wa ojogbon ori site yi ni mo se ku fi si ta.............sugbon iwo lojo ye elenu gboro......sora re.........bi o ba ri ise ti o ba fe fi le fun awon ti o fe.......OGUN TI ENIYAN BA DAN WO TO BA SISE NI OGUN.....sorare...won ki se be soro si eniyan.... |
¤OOGUN OHUNMO¤ Ao wa odidin eiye kaaro kan, ori
olongbo kan, egungun eiye akala, eja ojiji kan, odindi
imo ope kan,odindi atare kan, ikodidere meta,ao jo
Gbogbo re po ao fi sin gbere kan si igba aya wa, ao fi
iyoku je Ogede omini pupa, kosi ohun kan ti o ma
sapamo siwa koda won a tunma kowa ni OGUN loju orun wa (Oju Ala) pelu.
BI OKO OKUNRIN BA NWALE NI IBAPADE OBINRIN Ao
wa egbo Ajara, ao ge keke sinu igo kan, ao fo eyin
adie ibile 7 si, ao da opolopo omi agbon si, lehin ojo
keta ao ma Mun. |
Awure anu,,,,,odidi eyele kan ao fi oga
sininu ao fi owo kan tele ape aogbe sinu
ape aofi padi atare kan si ao jo ao mafi
omi aye(oti) lo odaju |
ewe iyalode ni won tun pe ni botunje tabi ewe lapalapa sugbon ope orisi meji.... |
ogun todaju:ao wa owo eyo kan,ao fi pa
esinsin kan,ao lo po mon eyo atare meta,ao fi
singbere kan si waju ori,ikan si arin ori,ikan si ipako.ti
gbogbo nigeria ba yinyin lorun koni yin,odaju |
AWURE OWO KIAKIA ao wa omundun ewe ege mesan
fun okurin, meje fun obirin, aolopo ma ose iwe ekan
soso, aofi we ni aro, aose be fun ojo meta telerawon,
olohun ngbo ise ni iseyi, |
OSUKA ORERU AGBA,OLOGBON LO LE GBE NI ORO YI |
ITAN KEKERE KAN RE OO FUN GBOGBO OMO KARO OJIRE..... itan yi da lori bi otito ati bi otigba.....bi o tito kedere egbon bi otigba lo je...ni gbaye iwase......sugbon bi otito yi ti ku ojo ti pe......bi otigba yi ni aye tele ni asi ko yi.......awon baba wa laye johun ana....le fi ile,ona,ilu,iyawo,ore,ebi...sile ki won wo nu igbo lo tabi inu igi.....ni to ri won wa agbara....ati ogun lo........eyi tun mo si wipe bi otito ni awon baba wa tele ni aye johun ana........ti aye fi gunrege.........bi aye to daye olaju lawon baba wa ti mo wipe jesu bo,tele yinbo pe ni (jesus is coming)....sugbon ona ti won gba so ni ko ye awa omo laye ode oni toripe bi o ti gba lan tele........Awon baba wa laye jo wun ana,,,ohun ti won pe jesu ni IKU....to wipe jesu bo ti won so ki se wipe aye ma pare......sugbon awon baba wa so wipe eni ba ku ni ti re gbe....eni ba ku ni aye ti re pa re.....eni ba ku lo tan fun.......aye yi o pa re tori eni ba ku laye ti re pare......idi re ti awon baba wa fi so wipe ninu gbogbo ohun ta ba se ka ma ran ti iku........mo re ti ibere lori itan yi |
ASIRI ISOYE KAN RE OOO.........ori isu,owo eyo ti ko lu kan,odidi atare kan,a o wa jo papo.......lilore:a o ma ta sowo diedie..... ofore isu kin ta ko gbagbe ori,omode ki nsu ko gbagbe okan.......gbogb owun ti ba ko lo ni ki ma ranti......aro kutukutu ti aba lo si ilewe tabi enu ikose la o ma lo ise yi oooooooo..........:.....................iba baba healthfirst........irawe ki sun kun odo a o ni sun kun ara wa...... |
Bi oti le je wipe won ni ogun wa opee.......sugbon kaluku loni account ti re.....ati wipe account o le dogbo........... EBO AYE TODAJU* Eyin meje, Odidi Okete, Orogbo meje, Eyin Open meje, Oti ati epo, Awo sobi kan, Ao fi Ifa osa meji koru, Otan. |
AKOYA ABENU GONGO TOGBONA: ewe ailu, ewe kilofefimise, ewe mafowokan omo mi, ewe atikaparare, ewe gbegbe, ewe tete, awo ekun die, epo obo, odidin atare kan, ao lo wa ikaraun ibin to tobi ninu igbo, (ibi ti won ba ge imo ewe ope eyin si, ni eti le saba ri ikaraun ibin, tabi ki e so fun awon elewe o mo ki won ba yin wa, amo ko je ti korofo ikaraun ibin tinu igbo gan gan, ao ko gbogbo awon eroja yi sii ikaraun ibin na. Ao fi aso pupa bo ooo loju, a o fi owu dudu ati funfun di ni iko bere ti ara re ko ni han sita, (owu iranso lao lo) ao lo ri mole si orita meta ni oru (night) fun ojo meta, to ba ti di ojo keta, ao lo wu kuro nibe ni ale, ao jo lai tu, ao lo kunnaa, ao da si meta, afi idan kan: sin gbere yii abadi wa ka, ao wa sin bere ejiogbe si (center) lona meta si isale re. || || || Ao fi idakeji: ao ko lose dudu, ao ko sinu iba funfun, after 7days, lao fi we ni ago kan osan lekan soso. AO FI IDA KETA: ao da sinu awo funfun ao we ni tira pelu owu dudu ati pupa, ao fi aso pupa ran ni olounde ao wa fi owu ibile dudu ati funfun we round ti olounde yen ko ni han jade, ao ma wo si ibadi, after 7days ti aba ti fi ose yen we ni ao ma wo siidi. AKIYESI: ao ni je ki omi kan oju gbere yen fun ajo meje gbako, amo ele ma shin apa shin ese. Ao si ni ma fi olounde yen we, ao ma bo (remove) ti aba fe we. ISE OGUN YII: apota: se eyin gbo pe omi ti eyin wo igbin lenu re ni ? ti won ba sa ogun siwa lati fi pe ori wa ni bi, oso ni, aje ni, elebologun ni, tabi emere, walahi eninaa yio pa arare ni ooo. Maran: ogun yii deenaa kiko aisan ni pa ibasun tabi ti won ba le magun fun obinrin, ti aba ba ni ajosepo, tabi ti won ba fi ogun gbawa, ko si nkan ti yo se wa aforan: ojo ti ijanba ba fe sele si wa, o le je ija n ba MOTO, tabi OLE, or OGUN (war) ti nkan ba sele si gbo gbo won, ko si ikan ti yio o sele si wa, lai fi arapa. Etc Asegbe: ibi ti won ba niki gbegbe ma gbe ibe ni gbe, ibi ti won ba ni ki tete ma te ibe ni n te, ti aba wuwa ibaje ko si eni ti yio bi wa ooo |
e jo...eni to ba ni ogun ti omo yahoo fi gbowo lowo client e todaju....orisa oke agbe wa ooo |
baba....emo tan lo ma pa eniyan.......bi ba post ogun.....account ti yin oya to si titi emi......ise iriran yi....ki je ki eniyan ri ikan buruku...o wa fun awon babalawo,alfa,pastor......ni o wa fun......ise iriran pe orisirisi.........olorun aran yin lowo....odapo....... |
¤I HAPPILY GAVE ALL THESE TO PEOPLE WHO HAD BEEN COMMENTING REGULARLY ON MY UPADATES ONLY BECAUSE I PAGE WITHOUT COMMENTS IS A "GRAVE YARD"¤ (1) OGUN BASIRI FUN INAWO¤ Ewe abamoda, ata ijosi, ao ko sinu Isasun titun, ao fi oju Malu(eyes of a cow) mejeeji se laseje. O DAJU !!! (2) OGUN IRIRAN Ao be Gbaguda Oojo, ao gun ninu Odo, ao fun omi re. Ao fipo Efun ile, ao maa kan sinu oju wa mejeeji. O DAJU!!! (3) OGUN IDANWO Ojele ewe olosan ati glass, ao waa fi Ewe Olosan na pa GLASS na loju. ao maafi glass na wo oju nigba EXAM |
ASEJE AWURE TODAJU¤
Iru wooro(20), Iyere(20), eyo atare(20).
Igbin kan, ao lopo, ao fi se igbin yenje. |
Eje ka fi eleyi ki rawa ku osu tuntun................Ogun anu( ao ha tori tidi oko,ewe egun erupe ile oja,erupe ile ejo(court)erupe mosalasi(mosque)awo ere,ori Oka,ori aja,ori olongbo,Oga,ao Jo po,ao wa.po mo ose fun wiwe |
se ri gbogbo ile.....eni ti won ji owo re yi...ti won ba ni kin so....ko le ri owo re mo....awon babalawo ako ma gba owo lowo re ni.....tori oti koja ojo meje......ka ni ko ti koja ojo meje ni...ise kan wa ti mole se si ti oni towun yio gbe owo na wa fun ara re... Sugbon oti koja......ema fi si adura..... |
awo kin binu si awo.....baba hearthfirst.......emi ni mo bee re fun ogun kan lowo yen lo ri email...... |
olorun ni oda owun gbogbo.......iba oooo....:........,.aye yi alo ni ojo kan......aye bo wa wo ewu enaa....aye bo wa sa.........aye bo wa fa ya ke de re.........iwa ibi o pee laye.....reeree lo yee ka ma se.........itori ojo ti aba ku.......ini tori ojo ti a ba file saso bo ra....owun lo di fa fun baba lawo to lo sogun aiku....egbo baba hearthfirst inje eni kan wa ti o niku saa..........eje ka ma ran ti atunbotan...........baba hearthfirst.........ese mi oooooooo mo ti te ate ji se si yin......ese wun ooooooooo |
<OGUN KI OBINRIN MABI ABIKU MO>
Egbo sapo, egbo peregun, ako eyele, ose, igba
olomori, ao ha ara awon egbo yen, ao gun mo ose
dudu, ao la eyele yen laya, a ko ose yen sinu aya
eyele yen, ao wa gbe sinu igba olomori yen, obinrin
tabi omo tobi naa yio mafiwe. Ofore :- Ododun ni sapo nwu ewe, ososo ni peregun
nse ofo iyare, ako eyele kini isimi, gbogbo eni toba
nse oun buburu simi koma ni isimi. |
ASIRI NLA TI MO RI NINU IWE EGBGI AWON BABA MI.........NI AYE ATIJO BI OBINRIN LO ILE OKO....AWON BABA WA YIO FI MO BOYA IBALE RE YI WA NI BEE....KI OKUNRIN NA TO FE.......SUGBON BI OMO OBINRIN NA BA JEWO FUN BABA RE....OGBON AGBA WA TI WON YIO FI DAA IBALE NA PADA...............DANWO KI O FUN ILE LAABO RE BI OTI RI ...................Ogun ti ibale fin pada Sara obinrin( to regain virginity> Ewe ege were, owu Elena, lilopo, ao fipa ara eyin adie, ao fi owu Elena yi eyin adie na, ao fi aso osu ti obinrin na lo lowolowo we lawetan, ao mulo sinu okiti ogan, ti okiti ogan yi babo, ibale(virginity ) yio padabo Sibe. ...................ASIRI NLA NI EYI OOOO... |
ORO IKILO orunmila ni ko ko ifa,ki won le mo ifa da,,,won ko won ko ifa won o si mo ifa daa,,...won ni ko ko ewe ki won le ba mo ewe ja won ko won ko ewe mi mo,,,won o si mo ewe ja..won ni ko ko ohun jiju won ko won ko ko ohun jiju.....iba agbagba.........eyi so fun wape bi ologun ba se ni ke sa ni ke se sa oooooo.......iba healthfirst oo, |
Ori mi jowo ma je fi owo osi ju we ile baba to bi mi lomo......ta lo so wipe yoruba o ni science....ti gbogbo eniyan mo si ogun.......ti eyinbo ba soro ni pa science ti won pe ni imo ijile......ba kan na ni yoruba pe ti re ni ogun....ti definition je.......osuka oru eru agba....ologbon lo le gbe.....ki awon baba wa laye jowun ana to le pa ewe po wipe ise bayi ni o se....oye ke mo wipe owun na ni won pe ni imo ijinle..........iba olobinkin osanyin.......iba....iba orunmila baba agbonmirekun.....iba awon agbagba to gba ni waju ati ni eyin ti ko je ki oowo...iba ile aboko ye re.....iba agbede meji orun owun aye....mo se iba gunnugun ti jebo isalu aye......mo se ba akala ti je bo i sa lu orun.......bi omo ti tun ba de ileaye agbe ekun wa yin.....iba obo ti je ki ako,o ma da ti nu re sile..... Iba araba nilu remo.......iba ni mo se ema je ko pa mi lare oooo........OGUN WARAPA BO LONA TO DAJU |
"OGUN TI OKO OKUNRIN BAKERE TI YIO FI YO JADE TI YIO SI TOBI" ao wa igbin nkan toba bonu, ao ju sinu omi fun igba die, bi iseju mewa tabi marundogun,ao yo igbin naa pada, ao fi sile, tobati yo ori jade funrare, ao fi ada be ori re lekan, ao wa gun po mose dudu, ao mafi fo gbogbo ara oko wa. oko wa yojade ti yio si gun dada. |
e ma binu sir....emi ko mo wipe a ki fe number wa sori afefe ooooo........ |
ikun aboyun to ga ekan si mi........08133500074
|
odindin ologbo ni oooooo .....ko ba je gbigbe...ko sa ti je ologbo |
bawo bari awo,,,,awo asoro awo....bo gberi bari ogberi ,,,ogberi asoro ogberi......dide mode emi owa subu awo....dide mode emi o wa subu ogberi......to ri bi ado ba wo nu ado,,,ado mejeji arinu ara won......ogberi ko gbodo ri omije lo ju awo....e jo mo fe mo phone number healthfirst.....ewe a ma je ooo |
AFOSE ase oka ati odindi atare kan ao Jo papo ao fi sin gbenre kan si isale ete ao ma fi ahon kan Okigbe ida ogbe pada sodo eni sawa)ao wa agbon tobo sile funrare ao da lu lori ao lo efun ati osun po ao ro sinu agbon yen ao gbe sile di aro kutu ojo keji aoji po ao gbemu laiti soro si eni keni ao lo la agbon toku mole lorita laro yen otan MALU-opolo odidi kan ao fi okun di ese re ao wa ewe ina esinsin ewe airagba ewe oyin ewe sawerepepe pelu iyo ao lopo ao fi kun eyin opolo yen ao maki opolo yen pe "se ofe kuni? maiku, ori unfo e? Edo unrin e?, aragbigbona ni? Tio ba ti wa ku ao wa tu okun ese re ao jopo mon ijakariwo ati odidi atare kan ao fi se igbadi tabi tira ti won ba luwa mon ao sowipe "OJO TI OPOLO BATI KUN OSUN SAWEREPEPE OJO NA NI RORUN Amudo: imi ewure oriso,imi aguntan oriso,ewe rekureku. Eso agunmona ao gunpo aofi awo ojiji di mo ara aba irin ni owo mejeji aofi owu dudu ati funfun wepo o4 ibiti ewure abaso ewure si ni susi. Ibiti abaso aguntan si ni susi .rekureku kifo koja oju ona.agunmona kiraye gun igi re jake ao daruko obirin nasi ao kan mo ara igi abo odaju gan o ASEJE OWO NLA TODAJU- ewe tanapowo 50, iyere lopolopo, ao fi se akuku adie je, lepo niyo, ao ge ori ati ese adie naa ao ri mole ao se aseje naa, ao ri owo lopolopo OWO-ao te ifa ejiogbe sile ao pe ofo yi si lori-Oludari aye loruko ti anpe ifa,ina kaan loruko ti anpe etu,ojo ti obinrin bati di aya oba ojo naa ni won fi owo tire wo,ki tomode tagba ma fi owo wo emi lagbaja omo lagbaja loni,ao koju seyin fi ese osi ta yepe naa.(A le ra nkan ni owo eniyan ki won ma gba owo,eri daju pe efun won ni owo won)use it for your own protection AGBELEPOTA: Ori ako alangba1, ao fi osun pa, ao ko atare9 si lenu,ao jopo ao fi sin gbere mesan si arin ori. OGUN EYONU AIYE: Odidi ladaripon1, Ewe ewuro oojo, odidi atare1. aojopo, ao da sinu epo pupa ao ma la. TI AKIFI RANTI SA OGUN SENIYAN. Ewe igbagbe eyo atare 7 fun obinrin 9 fun okunrin ao lopo gbere 11 lori. ORUKA AYETA:ao ge igi atori mejo( nidogbandogba,oruka irin dudu mejo,awo{skin}o wawa,odindi atare kan,ao jopo ao ko gbogbore sinu igo kan ao fi etu die foko mu ao ki oruka kan bowo.Efi etu die si adie lenu kie ki oruka kan bo lese ki wa yibon si wo. ogun ki ole ma wole;ao ge ora ara ewure die ti aguntan die ati ti elede die sinu fitila kan,ao fi ewe ko ti won pe ni idariko tabi modesina si ao fi fitila miran de,ao we lowu dudu ati funfun a o gbeko enu ona OGUN ORUKA ANO SUBU. Bo wu ki enia ti tobi to tabi ki agbara re ju ti enikan ti a ba fi oruka yi na yio subu lese kan na. Ewe ina gbigbe ao lo pelu alahannahan ao pa bara kan ni oko [parsa] ao ko egbogi ti alo yi si ao wa ko oruka irin iye ti aba fe si ao wa osun ti won fi kun ibeji lara ao ko le oruka yi na ao de pa mo bara na ao lo ri si idi ogede wewe gba ijo meje ao lo ko oruka yi ni ijo keje ao to ju re. Lilo re:- ao fi ikan bowo fi na enia yio subu. OSOLE NLA TODAJU- odidi tagiri mejo a o ge wo si meji meji ti yo wa je 16, a o ko won sinu isasun pelu ori eiye akala, olongbo kan, iru woro ti ko ni iyo ko po die, ati ewe orijin a o jo gbogbo re a o si lo kuna daada a o ma bu ebu na die si owo osi wa a o si fi oyin gidi po a o fi lo ni eekan losu o ti di dsame date ta lo la o tun lo ni d following month, odaju baba mi kan lo fun mi. OTIDE OOOOOO, AMUDO AMUDO AMUDO, tested and OKAY AMUDO... Ewe ogbo meta, ewe apada meta, odidi oga kan, omi toromini, Áo jopo ao p month ose, ao ko sinu aso funfun, ao so ko si ibikan ninu ile (house) ti kogbodo kan ile, (ground). Tia abafe lo ao bu die ninu ose ye ao ho si owo, ao daruko obinrin ti a fe lo fun sinu re, ao fi we owo mejeji. OFO RE.... Ogbo loni kio gbo temi lonni, apada loni kio ma le pa oro mi da, aso alaso ni oga ngba, ekuin ekekun ni toromini nji sun, ekun mi ni ki lagbaja ma sun loni o . ODAJU Ogun Asma Ikarahun igbin ao lo dada yio kuna ao walo sugar oni koro eyo meta mon ti yio kuna dada ao mala yio gbadun pelu ogo oloun |
EJOWO GBOGBO OMO YORUBA EJE KI A SI WHATSAPP GROUP KI A LE MA SO ORO DA DA FUN GBOGBO ENI TI O FE WA NI GROUP YI E SEND MESSAGE SI MI LO RI WHATSAPP 08133500074 Olorun o ni da arin wa ru ooooooooo |
1 2 (of 2 pages)
ni