Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,647 members, 7,816,659 topics. Date: Friday, 03 May 2024 at 02:39 PM

Ousmaf's Posts

Nairaland Forum / Ousmaf's Profile / Ousmaf's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by Ousmaf(m): 2:29pm On Aug 04, 2016
Ifankaleluya:
ATOSI

Imi-orun, etu-ibon, a lo po, ao da sinu oyin igan, ao ma fi mu eko gbigbona
eku ise takuntakun baba Ifankaleluya, keepe fun wa lase Edumare, ejoo baba eba wa te odu Ologbon meji sita, ko ni tan nibi te ti mu ooo pelu ase Edumare

2 Likes

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ousmaf(m): 12:36pm On Mar 13, 2016
kadunasouth:
Asiri Ola (ki ona owo le lakanwa)
Ako ati Abo eye ega owo eyo mesan ewe ola ati ewe sawerepepe odidi atare kan ao ko gbogbore sinu fitila oloju merindinlogun inure lao tijo ao lo ao mafi miliki lo lararo iseyi daju fun owo ati okiki and connection

Ejo baba Agba yin a dale e o sini ri ogun akoba, oruko miran wo latule pe 'ewe ola', ese Olohun Oba to ga julo aman ran yin se, ameen.
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ousmaf(m): 7:20pm On Jan 23, 2016
kadunasouth:
Ogun Awure Ayigba pada sirere
Imi malu(igbe malu) ao sa yio gbe ao lopo month epo obo ao po ma ose dudu ao ma fiwe pelu gbolohun re
Imi nla nla ni malu su owo nlala ni kiwan oma gbewa funmi ki ona si ki ona ola fun mi, imi nlanla ni malu su, obo loni ki tomode tagba to lowo lowo wama fi owo owoyin bomi kie wa mabe mi ni ise nlanla tabi gbe ise nlala funmi bi contract etc
Ao wa ma fiwe odaju
ejo baba se dandan ni kalo ose dudu abi ale lo ose miran, eseun.

1 Like

Culture / Re: ? by Ousmaf(m): 9:55am On Jan 22, 2016
Eku ojumo baba, ejoo efunwa ni number 168: gbetugbetu, Olohun Oba Edumare a ma fun yin se.
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ousmaf(m): 9:42am On Dec 31, 2015
Agoo nile, ejoo efun wa ni Ogun ti eni to sese pari eko re to nwa ise yio fi ri ise to lalubarika, eseun adua wa a man gba pelu ase Edumare.

1 Like

Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by Ousmaf(m): 9:24am On Dec 31, 2015
Agoo nile, ejoo efun wa ni Ogun ti eni to sese pari eko re to nwa ise yio fi ri ise to lalubarika, eseun adua wa a man gba pelu ase Edumare.
Culture / Re: .. by Ousmaf(m): 9:22am On Dec 31, 2015
Agoo nile, ejoo efun wa ni Ogun ti eni to sese pari eko re to nwa ise yio fi ri ise to lalubarika, eseun adua wa a man gba pelu ase Edumare.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by Ousmaf(m): 9:17am On Dec 27, 2015
Agoo nile yi o, iba oo iba, mo se ba gbogbo eyin awo lori ikani yi, mo se ba eyin ogberi pelu, iba okunrin iba obinrin lori ikani yio, idunnu mi loje lati darapo moyin tori ki isese ma se baje tabi dohun igbagbe, Edumare Oba nla atobi julo aman fun wa se ooo! Ase ni tEdumare.

Ogun Awure owo, Aya rere ati omo ati ohun rere gbogbo
- Ewe alukerese
- Ewe ejinrin wewe
- Ewe olojongbodu
- omo atare 201
- esebi funfun 201
- esebi pupa 201
lo gbogbo re po, di mo oju igbin ao fi iyerosun tefa owonrinturupon si ao wa fi aso funfun di patapata
Ofo re niyi bi aba fe lo: toto nro ko ki le tan oko, o koju re si oloko, o kohin re si Orisa, o da fun ologun iro omo anikan te ile do, ifa emi ko le nikan dase, emi ko le nikan sin o, bi mo ba gbe igba obi omo mi a gbe gba ata, ati erebe de erebe ni ti alukerese, ibo to nbole lo nbo igi oko, tigbo tiju ni ejo nfa si, igbin kii kole re ko ma kun, omi kii tan lara olojongbodu, omo yoyo ni ti akosan, omo kii tan nidi ogede, omo kii tan nidi porogun, ojo ti okin doja leiye oko aba na. Ao fi sile nile ao ma sure nidi re.

1 Like 1 Share

Culture / Re: .. by Ousmaf(m): 8:43pm On Dec 22, 2015
healthFirst:
Eyi ni lati kede si gbogbo Omo Oodua nile loko, lona Oja fun atejade Iwe 'Iwulo Ewe Ati Egbo' ti yio jade laipe. A gbe igbese yi lati ri wipe awon imon ijinle Baba wa ko parun, Yoruba bo, won ni A kii Juba Agboogun lo Orun' Gbogbo Omo Oodua to ba nife si Iwe yi ki o kan si wa lori e-mail tabi whatsapp eyi ti ero ibanisoro re wa loju iwe kini ikani yi.

Iwe na yio je atejade nipa awon Oogun Iwosan fun orisirisi arun ti o wa ninu ago ara wa ati eyi ti o n ja wa logun nipa ti emi. Iwe na yio ni awon oogun Akoya lorisirisi ati awon Oogun tii so omokunrin di ojulowo okunrin. Iwe aabo lowo ewu kewu. Mo gba yin niyanju ki e ni ipin ninu iwe Iwulo Ewe Ati Egbo fun itusile, igbega ati ohun amu sagbara gegebi omo Oodua.
Ejoo Baba Cotonou ni emi wa ni Benin republic bawo mo se le ri iwe na ra tioba jade, eseun.
Culture / Re: .. by Ousmaf(m): 12:29pm On Dec 17, 2015
healthFirst:
116

BI AYE BA DE EEYAN MOLE
Odindi Aaye Okete kan, ao gun ninu Odo pelu Ata Ijosi die ati Eepo Obo die pelu Ose dudu. Ao maa we ninu Apere ajadi fun ojo meje pelu omi to lo wooro.

ejoo baba kini nje apere ajadi, Oodua a man ranyin lowo.

3 Likes

Culture / Re: .. by Ousmaf(m): 5:58pm On Nov 02, 2015
keyguy59:
AFOSE ase oka ati odindi atare kan ao Jo papo ao fi sin
gbenre kan si isale ete ao ma fi ahon kan
Okigbe ida ogbe pada sodo eni sawa)ao wa agbon
tobo sile funrare ao da lu lori ao lo efun ati osun po ao
ro sinu agbon yen ao gbe sile di aro kutu ojo keji aoji
po ao gbemu laiti soro si eni keni ao lo la agbon toku
mole lorita laro yen otan
MALU-opolo odidi kan ao fi okun di ese re ao wa ewe
ina esinsin ewe airagba ewe oyin ewe sawerepepe
pelu iyo ao lopo ao fi kun eyin opolo yen ao maki
opolo yen pe "se ofe kuni? maiku, ori unfo e? Edo unrin
e?, aragbigbona ni? Tio ba ti wa ku ao wa tu okun ese
re ao jopo mon ijakariwo ati odidi atare kan ao fi se igbadi tabi tira ti won ba luwa mon ao sowipe "OJO TI
OPOLO BATI KUN OSUN SAWEREPEPE OJO NA NI RORUN
Amudo: imi ewure oriso,imi aguntan oriso,ewe
rekureku. Eso agunmona ao gunpo aofi awo ojiji di mo
ara aba irin ni owo mejeji aofi owu dudu ati funfun
wepo o4 ibiti ewure abaso ewure si ni susi. Ibiti abaso
aguntan si ni susi .rekureku kifo koja oju
ona.agunmona kiraye gun igi re jake ao daruko obirin nasi ao kan mo ara igi abo odaju gan o
ASEJE OWO NLA TODAJU- ewe tanapowo 50, iyere
lopolopo, ao fi se akuku adie je, lepo niyo, ao ge ori ati
ese adie naa ao ri mole ao se aseje naa, ao ri owo
lopolopo
OWO-ao te ifa ejiogbe sile ao pe ofo yi si lori-Oludari
aye loruko ti anpe ifa,ina kaan loruko ti anpe etu,ojo ti
obinrin bati di aya oba ojo naa ni won fi owo tire wo,ki
tomode tagba ma fi owo wo emi lagbaja omo lagbaja
loni,ao koju seyin fi ese osi ta yepe naa.(A le ra nkan
ni owo eniyan ki won ma gba owo,eri daju pe efun won ni owo won)use it for your own protection
AGBELEPOTA: Ori ako alangba1, ao fi osun pa, ao ko
atare9 si lenu,ao jopo ao fi sin gbere mesan si arin ori.
OGUN EYONU AIYE: Odidi ladaripon1, Ewe ewuro oojo,
odidi atare1. aojopo, ao da sinu epo pupa ao ma la.
TI AKIFI RANTI SA OGUN SENIYAN.
Ewe igbagbe eyo atare 7 fun obinrin 9 fun okunrin ao
lopo gbere 11 lori.
ORUKA AYETA:ao ge igi atori mejo(coolni
dogbandogba,oruka irin dudu mejo,awo{skin}o
wawa,odindi atare kan,ao jopo ao ko gbogbore sinu
igo kan ao fi etu die foko mu ao ki oruka kan bowo.Efi
etu die si adie lenu kie ki oruka kan bo lese ki wa
yibon si wo.
ogun ki ole ma wole;ao ge ora ara ewure die ti
aguntan die ati ti elede die sinu fitila kan,ao fi ewe ko
ti won pe ni idariko tabi modesina si ao fi fitila miran
de,ao we lowu dudu ati funfun a o gbeko enu ona
OGUN ORUKA ANO SUBU.
Bo wu ki enia ti tobi to tabi ki agbara re ju ti enikan ti a
ba fi oruka yi na yio subu lese kan na.
Ewe ina gbigbe ao lo pelu alahannahan ao pa bara
kan ni oko [parsa] ao ko egbogi ti alo yi si ao wa ko
oruka irin iye ti aba fe si ao wa osun ti won fi kun ibeji lara ao ko le oruka yi na ao de pa mo bara na ao lo ri
si idi ogede wewe gba ijo meje ao lo ko oruka yi ni ijo
keje ao to ju re.
Lilo re:- ao fi ikan bowo fi na enia yio subu.
OSOLE NLA TODAJU- odidi tagiri mejo a o ge wo si meji
meji ti yo wa je 16, a o ko won sinu isasun pelu ori
eiye akala, olongbo kan, iru woro ti ko ni iyo ko po die,
ati ewe orijin a o jo gbogbo re a o si lo kuna daada a o
ma bu ebu na die si owo osi wa a o si fi oyin gidi po a
o fi lo ni eekan losu o ti di dsame date ta lo la o tun lo ni d following month, odaju baba mi kan lo fun mi.
OTIDE OOOOOO, AMUDO AMUDO AMUDO, tested and
OKAY AMUDO... Ewe ogbo meta, ewe apada meta, odidi oga kan, omi
toromini, Áo jopo ao p month ose, ao ko sinu aso
funfun, ao so ko si ibikan ninu ile (house) ti kogbodo
kan ile, (ground). Tia abafe lo ao bu die ninu ose ye ao
ho si owo, ao daruko obinrin ti a fe lo fun sinu re, ao fi
we owo mejeji. OFO RE.... Ogbo loni kio gbo temi lonni, apada loni kio ma le pa oro mi da, aso alaso ni oga
ngba, ekuin ekekun ni toromini nji sun, ekun mi ni ki
lagbaja ma sun loni o . ODAJU
Ogun Asma
Ikarahun igbin ao lo dada yio kuna ao walo sugar
oni koro eyo meta mon ti yio kuna dada ao mala yio
gbadun pelu ogo oloun
ejoo sir se odindi OLONGBO abi ori re lao lo fun osole nla yen abi bao?

3 Likes 3 Shares

Culture / Re: .. by Ousmaf(m): 10:15am On Oct 22, 2015
Ejoo baba mo nilo ogun ti afi ngba owo lowo eni tojeni lowo tio fe san, edaakun e fun mi, owo mi poo ni gboro ti won o fe san fun mi, Edumare a ma ran yin se.

1 Like 1 Share

Religion / Re: Asiri Gbigba Adua by Ousmaf(m): 6:24pm On Oct 11, 2015
kadunasouth:
Atunse Fun Eniti Ayare Nja tikoma nkan to nja laya
Ki iru enibeye lore ra omin samsam tabi omi ojo ofurufu tikobari nkan kan ninu omi wonyi kolo swan water koka Ayatul Kursiyu 66 fatia 1 sinu omin komun pelu ogo oloun ayare koni jama
Otun sise fun eni to nla alakala.
Aduaa wa yio gba Alubarika Anabi (s.a.w)
Ejo Ustaz, mo nilo adua ti eyan le fi se ISTIHARA fun ara eni tio fi mon ohun ti nsele si igbesi aye re, eseun Olohun o lora emi yin fun wa ola Anabi wa Muhamad (SAW)
Culture / Re: .. by Ousmaf(m): 6:37pm On Sep 22, 2015
healthFirst:
55
Ose Awure Todaju
Irun Ori Were, Ewe Isaju, Ewe Ajeobale, Akuko Adiye Kan, Eiyele Kan, Akuko Adiye Ati Eiyele Yen, Ao Fi Ese{leg} Wa Ja Ori Re, Ao Wa Jo Po, Ao Po Mo Ose, Ao Ko Si Inu Ikoko Ajere, Ao Fi Aso Funfun Te Isale Ikoko Naa, Ao Wa Gbe Ko Enu Ona Aba Wole, Ao Wa Bu Ose Na We. IBA OLODUMARE!!!
ejoo baba se enu ona kato wole tabi taba wole loke ni ao fi ose na ko si? ati wipe se awon ori (akuko adie ati eiyele) na nikan lao jo po fi po ose na? eseun Olohun a tunbo man ran yin lowo si.

1 Like

Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Ousmaf(m): 7:45am On Sep 14, 2015
Ekaaro nile yi o se dada laji?
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Ousmaf(m): 7:43am On Sep 14, 2015
Eku ojumo nle se alafia laji bii?
Culture / Re: .. by Ousmaf(m): 3:57pm On Sep 13, 2015
Aboru boye o ise a ma je o e jowo kini ma fa to fi je wipe ti mba sise fun eyan a ma je ama ti mba se fun ara mi mi kii ri ami e joo e fun mi lesi re oluwa yio pelu wa ase

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 50
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.