Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,151 members, 7,818,467 topics. Date: Sunday, 05 May 2024 at 04:27 PM

.. - Culture (22) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1828986 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (19) (20) (21) (22) (23) (24) (25) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Ade231(m): 12:39pm On Sep 08, 2015
sammyjay76:

@healthfirst, ejowo gege bi omo yoruba to mo nipa ewe ati egbo, kini e ri si iwosan nipa lilo ito ara wa?
Urine.

nje o n sise bi? ti o ba nise, iru awon nkan wo la le li fun ati bi a se le lo?
Ejowo gbogbo eyin ojogbon inu ile yi e bawa da si o.
Eseun.
ese pupo baba e ma pe fun wa lola eledua ase,gege bi omo yoruba ito ara wa dara fun iwosan ara,fun apere ale lo fun ti jankariwo ba n ko eyan ni oju ona ti aba fe ji to loru ao fi owo gbe ito wa ao fi boju lemeta ao si iyoku danu ese iba eyin agbalagba o.
Re: .. by sammyjay76(m): 8:22am On Sep 09, 2015
Ejowo gbogbo ile e fun wa ni ogun ti a fi n wo egungun .... Eniti ko ti ju bi omo okandinlogoji 39 ti ko si ni aisan egungun tele, sugbon ti nkan na bere si se bayi, lehin ise die ki gbogbo egungun orikerike ara ma dun ni pe iwora egungun. ejowo eba ni so si.
Re: .. by tundebadmus(m): 1:17pm On Sep 09, 2015
kadunasouth:


ATUDE TODAJU
Ewe tude egbo tude iyere ao lo ti yio kuna dada ao ra isasun tuntun ao fi se odidi igbin kan je lepo niyo lodidi ni ao se igbin yi o akoni ge ti obajina ao so kale ao je ko tutu ao wa bo gbogbo aso orun wa ati oruka ao wa ni ihoho omoluabi ao wa da aseje na si ilele ao kunle ti ao wa ka owo wa mejeji seyin wa ao wa se adua itusile ao wa fi enu gbeje lodindi iseyi daju danwo kori botiri
Ike oloun ola oloun komaba alayelorun
NB ori ilele cement or tiles lamada aseje yi si leyin ti ati nunu dada ao dasi ao waje

Iba akoda iba aseda iba agba merindinlogun lotu ife iba baba iba mama iba omode iba agbalagba iba okunrin iba obinrin efi oju rere womin o! Ase edumare
Contact me 08028358926a@gmail.com
ejowo baba monilo ogun yi ejowo se ele fun tan mio fise ika rara oo ejowo eyo dare fun mi tan ma kan siyin lori email yin ejowo ki e fun mi ni esi o aboru boye

1 Like

Re: .. by enigstil(m): 2:51pm On Sep 09, 2015
Ejowo gbogbo Ile, iba won agba gba to wa lori ikanni yi, ejowo kini oruko ti wonn pe eiye kowe ni geesi
Re: .. by oscartee: 11:36pm On Sep 09, 2015
aboru aboye sir,
e ku agbaale gbogbo eniyan lowo arun gbogbo. e si ku itoni sona nipa sise afihan opolopo ogun lori eto yi. ibeere mi ni wipe bawo ni ao se lo ogun yi ? se lila ni tabi ao po mo ose fun wiwe tabi gbere?................OGUN TI OWU ALANTAKUN BA N KO ENIYAN LARA
Oku opolo kan ao ki igi bo lati enu ti yoo wole dada ti yoo ha mon ninu dada ao wa mun ao ma fi ko gbogbo jankariwo inu ile titi afi ni leri ara opolo yen mo ti aba ti se bayen tan ao gbodo fi owo kan mon, ao fi ada ge igi yen mo ao wa fi igi gbe sinu agbada ao jo pelu odidi atare kan sugbon ako gbodo fi owo kan ti oba ti jo tan na... ao wa lo epo obo ti yio kuna daada bi atike, ao wa da mo igba yen ni a to le fowo kan.

2 Likes

Re: .. by kadunasouth(m): 12:27pm On Sep 10, 2015
tundebadmus:
ejowo baba monilo ogun yi ejowo se ele fun tan mio fise ika rara oo ejowo eyo dare fun mi tan ma kan siyin lori email yin ejowo ki e fun mi ni esi o aboru boye

Ogun wo lenso koyemi molerepo moti dayin lohun ni
Re: .. by kadunasouth(m): 1:00pm On Sep 10, 2015
Ebe ati Asina awon Agba
Eye alapandede ao gun po ma ewe lapalapa funfun ao wa popo ma ose dudu ao wa igba olomori ao wa fi igbin kan si ao wa ko ose yi lelori ao ma buwe pelu kehin kehin tun tun odaju

4 Likes 3 Shares

Re: .. by tundebadmus(m): 3:14pm On Sep 10, 2015
healthFirst:
38 IFUNPA MOLU, ENIKENI BA LU WA, O KERAN.

Eso bomubomu kan, ati......
ao jopo, ao wa da sinu aso funfun, ao fi abere ta diedie, ao wa lo pa
lawo funfun, ao maa de mo apa, ti won ba lu ise yii mowa lara, eyin e
kan rora bo ifunpa yi jusi inu omi ninu ikoko kan, eni naa ma wu titi
yoo fi ku nii, eyin e shaa ma lu eni naa pada, ekan rora so fun pe
osheee.
ERO-RE: E mu ifunpa yi kuro ninu omi ki e sa ko gbe, eni naa ma
fa pada.

Awon Oogun bi eleyi ko se fi sita tan ni gbangba sugbon bi a ba ri eni ti kii se oni janduku, ao fun tan.

binaryteck@gmail.com
baba ejowo emabi un simi ogun yin gangan ni mofe je kefun mi tan olohun ni mofi beyin tori eyin na tise adeun fun wa pe eni ti obafe ogun yin wipe efun tan alale ni mofe beyin ejowo efun mi tan.moti kan siyin lori email yin eda milo un.ejowo ebami fisi ori email mi (tundebadmus38@yahoo.com)or(tundebadmus82@gmail.com) ma mo reti yio ese gan oluwa aduro ti o

2 Likes

Re: .. by tundebadmus(m): 3:22pm On Sep 10, 2015
kadunasouth:
Ebe ati Asina awon Agba
Eye alapandede ao gun po ma ewe lapalapa funfun ao wa popo ma ose dudu ao wa igba olomori ao wa fi igbin kan si ao wa ko ose yi lelori ao ma buwe pelu kehin kehin tun tun odaju
baba moju bayin o mi ori agba fi o ejowo koda bi ese sewa mobere fun kan lowo yin lori email yin esi dami loun motun send mesg si yin etun dami milo un ejowo baba efun mi nikan ti mobere fun lowo yin ejowo
Re: .. by Ayomidegbenga1(m): 4:59pm On Sep 10, 2015
E jowo baba,ti eeyan ba lo nkan aajo si ara ni aaro(morning), ti o ba wa ba iyawo re ni nkan ajosepo ni osan(afternoon),kini ewu ti o wa nibe.
Re: .. by Nobody: 9:26am On Sep 12, 2015
omoaribaba1:


pelu (OLUGBOHUN) sugbon akin ngbe eleyi sile ooo afi yara idalejo lohun nikan nia le gbesi.

E jawo ninu ika sise. Ko sunwon e yiwa pada. Ogun ti a se omo araye lanfani ni ki e mu ni pataki. Imoran ni, e se.
Re: .. by tiphareth1: 12:32pm On Sep 12, 2015
Mo ki yin ninu yara yi o Awon awo so wipe ebo ya osi lagbara ju ogun lo. A nfi towotowo peyin ki e ba wa da si Yara Ebo ya ju ogun lo lori facebook lo wa o. Awon ojogbon awo ti wa nikale lati to wa sona. A tun pe eyin awo na lati wa polowo oja yin nipa titowa sona lori ebo at ipese. Gbogbo eni ti o ba je awo lo ni anfani latipolowo oja to ba wu ati lati fi numba won si ori gbogbo ebo ati ipese ti e ba post. Eyin awo e dakun e ran wa lowo o. orunmila yio ran gbogbo wa lowo o. Ase

1 Like

Re: .. by Ousmaf(m): 3:57pm On Sep 13, 2015
Aboru boye o ise a ma je o e jowo kini ma fa to fi je wipe ti mba sise fun eyan a ma je ama ti mba se fun ara mi mi kii ri ami e joo e fun mi lesi re oluwa yio pelu wa ase
Re: .. by Isholex1love: 12:44pm On Sep 14, 2015
healthFirst:
IFA IBASIRI TI ENIYAN BA FE SE INAWO TI FI YE ENIYAN Ao da iyerosun sinu aso funfun ao wa teni OTUAMEJI. OFO RE:Amilara, amiloro, iyi ni seru akora baba yin, orunmila o to gege, kowa fun emi lagbaja omo lagbaja niyi temi nibi n kan ti mo fe se yi, ka siri mi o bo, asiri aso funfun ki tuu, ifa moje kasiri temi lagbaja omo lagbaja o tu o, otuameji moje kasiri temi lagbaja omo lagbaja o tu o, kin gba iyi kin gbeye, aso funfun kisi loju oloosa.
e jo sir, bawo ni asema lo ogun tio wa ninu aso funfun

1 Like

Re: .. by Davidifa(m): 11:44pm On Sep 15, 2015
E jo iyawo mi ti fi mi sile lo mo fe ko pada wa ba mi,ejo efun mi ni ogun ti mo lese si. A ma dun yise oooo
Re: .. by Lionhearted: 10:29am On Sep 16, 2015
Davidifa:
E jo iyawo mi ti fi mi sile lo mo fe ko pada wa ba mi,ejo efun mi ni ogun ti mo lese si. A ma dun yise oooo

Emu ra si ise yin ki esi wa ojurere Olorun fun aseyori ati oro.

Fun rara e ni yio pada wa.
Re: .. by Davidifa(m): 12:48pm On Sep 16, 2015
Mo ti na owo mi fun ju, efum mi ni ogun ta fi pada
Re: .. by scholes0(m): 1:18pm On Sep 16, 2015
walexy30:


E jawo ninu ika sise. Ko sunwon e yiwa pada. Ogun ti a se omo araye lanfani ni ki e mu ni pataki. Imoran ni, e se.

grin grin grin
Re: .. by kadunasouth(m): 1:23pm On Sep 16, 2015
Ogun ta nfi pe obirin/okunrin to salo pada
Adan 1 eye onbe 1 akeke 1 atare 1 ao jo papo pomo ose dudu kosinu igba olomori gbesi nu apo aso fun fun odi wiwe kia kia ni yio de
Ofore adan kilori ade obe kilorun atokunbo akeke kinidi aga lagbaja omo lagbaja koma nidi aga komalesun komalewo koma sare pada bowa sodomi

NB ise yi wafun obinrin tosalo tabi okunrin tosalo fun iyawo tabi okore tia ko ba jebire yio de larin ojo meje ti kobade ye arare wo iwo koloto odaju

3 Likes 3 Shares

Re: .. by Davidifa(m): 7:07pm On Sep 16, 2015
E se pupo oooo
Re: .. by Davidifa(m): 7:10pm On Sep 16, 2015
E jo ta loni afose ti ale lo fi ba maga soro ko fun mi

1 Like

Re: .. by Mediji: 10:09pm On Sep 16, 2015
Eku Dede akoko yio.Ejowo gbogbo eyin agba'gba omo yoruba kini Ogun staphlococcus.
Re: .. by Davidifa(m): 8:31pm On Sep 17, 2015
Ejo kilo je isu dandan ati kolobo kekere
Re: .. by Nobody: 2:31am On Sep 19, 2015
Peki ni mo ko, Yaba ni mo ya, D'Ifa fun Agboniregun nijo ti baba nlo si ode Awo Olodumerindinlogun, Orita meta Oja-Ejigbomekun ni Baba ti gbe pade Arugbobinrin t'oun takisa lorun; Sebi ore Orunmila se Eleye ana lo so Barapetu di Olola ayeraye... Ifa dakun mo di mi loju pe Olore mi l'abinrun O, Ase.
Re: .. by KEHINDE633(m): 10:57am On Sep 19, 2015
MAYEHUN TODAJU
awon okete meje. irudi okete meje. ewe ogbo. ewe ogba. ewe abamoda. atare odidi kan jijopo fisin gbere meta isale enu wa
OFORE=

2 Likes

Re: .. by kadunasouth(m): 12:20pm On Sep 19, 2015
Ogun iwe ikorira
iyere osun, osun pupa, ao gun mose dudu, ao pin sona meta wekan laro losan lale. Ankatif funfun meta lama fise kehin kehin ao lo dasi ori akitan tabati we meteta

2 Likes

Re: .. by tundebadmus(m): 1:17pm On Sep 19, 2015
KEHINDE633:
MAYEHUN TODAJU
awon okete meje. irudi okete meje. ewe ogbo. ewe ogba. ewe abamoda. atare odidi kan jijopo fisin gbere meta isale enu wa
OFORE=
ofore da eje kamo alale ni mofi beyin
Re: .. by kadunasouth(m): 1:26pm On Sep 19, 2015
ẸYỌNU AWỌN AGBA
Ifunni ekete kan, egbo akerejupon , ati ewe ajẹọbale, ao jo papọ̀, ao po ma ọṣẹ dudu ao ko sinu igba olomori ao ma fiwẹ leralera.

1 Like

Re: .. by Nobody: 7:03pm On Sep 19, 2015
x

2 Likes

Re: .. by Nobody: 7:07pm On Sep 19, 2015
x

1 Like

Re: .. by Nobody: 7:25pm On Sep 19, 2015
x

2 Likes 1 Share

(1) (2) (3) ... (19) (20) (21) (22) (23) (24) (25) ... (99) (Reply)

Viewing this topic: 1 guest(s)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 35
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.