Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,596 members, 7,809,166 topics. Date: Friday, 26 April 2024 at 02:21 AM

.. - Culture (23) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1827266 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (20) (21) (22) (23) (24) (25) (26) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Lionhearted: 8:25pm On Sep 19, 2015
healthFirst:
56

OOGUN ADEESU
Ewe akerejupon ao gun mose ao fi oyin po ao wa fi oga aye kan ti owo ti a ba fe bi 1000 tabi 5000, ao wa je ki o gba awo owo yen, ao wa mu owo yen kuro ao le ose yen mo ori oga na tiko n ifi ku ti yio ni aye ti ko fi ni ku ao wa fi owo na le lori pada ao ma sope ajo temi niyi o, ao ma mu ni ojojumo, elomiran ko gbodo fi oju ri ise yio.

IKILO PATAKI: Oogun yi daju sugbon oni eewo o...O lewu fun ogberi lati se, nitori awon omo eni naa yio ma ku to ba pe to ti n na owo yi...sugbon omo awo to ba mon owo we yio ba agba jeun.

Edakun awa ogberi lo po ni ori itakun yi. Oogun ti ko ba ye kase ema fi sita. Eseun.

1 Like

Re: .. by Nobody: 9:28pm On Sep 19, 2015
Lionhearted:


Edakun awa ogberi lo po ni ori itakun yi. Oogun ti ko ba ye kase ema fi sita. Eseun.

beeni looto sugbon bi awon ogberi ti po to bee na ni awon omo awo wa ti o le nife si. Eyi to ba je ti yin ni ke mu. Eyi ti a ba ti so wipe ko ye fun ogberi, ki ogberi mase de idi re.

2 Likes

Re: .. by Lionhearted: 9:34pm On Sep 19, 2015
healthFirst:


beeni looto sugbon bi awon ogberi ti po to bee na ni awon omo awo wa ti o le nife si. Eyi to ba je ti yin ni ke mu. Eyi ti a ba ti so wipe ko ye fun ogberi, ki ogberi mase de idi re.

O daa. Igbagbo mi ni wipe omo awo a mon awon ogun wonyi tele.

Eku ise takun takun.
Re: .. by Trustworthy1234: 12:53am On Sep 20, 2015
Eku ojumo re oooo. Osa Oke asee alatilehin fun gbogbo wa ooo

Ejowo... Alaa (dream) Kan ni Mola tio ba mi leru gidigan.

Bayi ni mose laa...
Mo la Ala wipe, awon Kan koba debi wipe oran na de iwaju olori agba ibikan nimu Ala na. Won si ni ki won fi iya jemi dada.

Sugbon, kini Kan lo wa yami lenu, Arabinrin tio je pe oun gangan lo se okunfa akoba na ko da simi rara.

Arabinrin ti mon soro re ninu alayi, ore mini ni Ile iwe Eko iwe giga... ore Timo timo..

Nigba to ya mo ko enu ife si, nio eyi toje pe ko gba rara.


Ejowo talo le tunmo alayi Funmi tabi bami se iwadi nipa re.



Ese ooooooo. Ewe ATI Egbo ama je fun wa O
Re: .. by KEHINDE633(m): 6:27am On Sep 20, 2015
ifura logun agba
Re: .. by KEHINDE633(m): 6:31am On Sep 20, 2015
OFORE. MAYEHUN YEN NIYI
ogbo loni kiogbo mi. ogba loni kiogba. abamoda kan onida tie kio mase. ase ti okete baba ile so nigba ..iwo LXL oya se nukan bayi

2 Likes

Re: .. by omoaribaba1(m): 11:19am On Sep 20, 2015
shoyemiayodeji:
E Jo mo fe mo oruko ewe yi ni Ede yoruba ati Ede gesin ( English). Ese pupo
ewe abamoda loruko ti anpe ewe yi
Re: .. by omoaribaba1(m): 11:55am On Sep 20, 2015
IWOSAN FUN EGBO ADAJINA: Alubosa elewe, aidan, Fofo okun,( Oku Okun) ayu 'kanafuru' eru awonka, imi ojo die, ao gun po, ao sa yio gbe daada, ao tun gun, ao ku ni ajo yio kuna daada, ao ma bu sibi kankan sinu eko gbigbona, ao tun bu adin eyan die si eko na, ao po papo, ao maa mun laro. Olorun loni wibe jebe

1 Like

Re: .. by omoaribaba1(m): 11:58am On Sep 20, 2015
EYONU AYE!
Ewe rerinkomi, eyin ope ibile kan, padi atare kan, ao jo papo, ao mafi oyin lo, tabi kia daa sinu oyin ao maa la larolaro. ODAJU!
Re: .. by tundebadmus(m): 6:02pm On Sep 20, 2015
healthFirst:
56

OOGUN ADEESU
Ewe akerejupon ao gun mose ao fi oyin po ao wa fi oga aye kan ti owo ti a ba fe bi 1000 tabi 5000, ao wa je ki o gba awo owo yen, ao wa mu owo yen kuro ao le ose yen mo ori oga na tiko n ifi ku ti yio ni aye ti ko fi ni ku ao wa fi owo na le lori pada ao ma sope ajo temi niyi o, ao ma mu ni ojojumo, elomiran ko gbodo fi oju ri ise yio.

IKILO PATAKI: Oogun yi daju sugbon oni eewo o...O lewu fun ogberi lati se, nitori awon omo eni naa yio ma ku to ba pe to ti n na owo yi...sugbon omo awo to ba mon owo we yio ba agba jeun.
ejowo baba olohun yio jeki epe fun wa nipa ogun (adeesun)se awa ti ojewipe aki se ogun fun eyan akan mase fun afa ni arawa ni ati fun awon eyan wa ti oje wipe afi ogun sise jeun ti irun awaba hi base ogun yin fun ara wa se laburu koni sele siwa.esi monpe ogun sorose seti eyan base fun arare se omo eyan koni ku atiwipe seowo yen yio mapada sibi ori oga ni.ejowo baba efun mini esi o,
Re: .. by kadunasouth(m): 6:15pm On Sep 20, 2015
OGUN YI DARA FUN ENI AWON ELEYE NBA YOLENU


Imi esu, epo-ọbọ, ewe ajẹobale gbigbẹ. Ao gun pọ. Ao fi adin si, ao fi ọṣẹ dudu ko ao popo, ao ko sinu igba olomori ao ma wẹ nigba gbogbo.
NB toba pe ojo meta totin lo ise yi wa fi akara elepo se sara fun obinrin yio je fun yin o!
Iba oloun iba agbagba

3 Likes

Re: .. by Davidifa(m): 9:16pm On Sep 20, 2015
Obinrin kan gba owo lowo mi ti ba sope kaba ara wa sun a ni ero oo,oo tu pe mi ni maga. Ejo ogun ni mo le fi ba sun todaju ki owo mi ma lo la san
Re: .. by Isholex1love: 5:57pm On Sep 21, 2015
mo juba eyin agbagba nibi e jo sir se ogun basiri kia toni isu dandan ati igbin ma dayan lamu ni tori igba ti mo je o worry inu mi
Re: .. by Nobody: 9:47pm On Sep 21, 2015
Ìlú tó bá yi
Won ò l’árúgbó
Arúgbbó tó bá yi
Won ò l’óbe ìje’su n’ílé
Won ò l’óbe ìje’su l’óko
D’ífá fún Àrànsà
Ti nse erú Òsemàwé
Àrànsà, ìwo lo te apá ní Ifá
Ara ro apá
Ìwo lo te ìrókò ní Ifá
Ara ro ìrókò
Ìwo lo te ooro ní Ifá
Ara ro ooro
Súré wá, kí o wá te ikin tèmi fún mi
Ìwo Àrànsà
Súré wá, kí o wá te ikin tèmi fún mi.
Re: .. by kadunasouth(m): 10:31pm On Sep 21, 2015
Isholex1love:
mo juba eyin agbagba nibi e jo sir se ogun basiri kia toni isu dandan ati igbin ma dayan lamu ni tori igba ti mo je o worry inu mi

Ema ri aridaju wipe era eronja oju lowo nkan teba fese ti eko bamo ewa awan tiwan ma nipa ewe ati egbo ki wan bayin wowo boya ojulowo ni kietose elekeji tie kobase ajo ri funrayin ekojade fun awan ti wan ma nipare wan ma biwan ase bayin se odiwan re apoju gbo gbo kan lefa ipalara bi apejuwe aseje ti iyere ba pojo nibe amafa ki eyan ma yagbe
Idi eleyi kosi ipalara nibe

3 Likes

Re: .. by enigstil(m): 12:53am On Sep 22, 2015
Davidifa, oje ki ifa to wa nibi oruko re ki o r o o, onifa okin she ka.Omo obirin yi omu o ni tipa tikuku lati ma na owo fun o hun.Iwo lo wu lemi.Nkan ti o fe she yi, ika ni won pe.File je ki o ma bati re lo, dan dan ko ni gbogbo obinrin ti eniyan ba na owo fun ki eeyan ba won sun.Imoran temi siyin niyen o.Alafia.
Davidifa:
Obinrin kan gba owo lowo mi ti ba sope kaba ara wa sun a ni ero oo,oo tu pe mi ni maga. Ejo ogun ni mo le fi ba sun todaju ki owo mi ma lo la san

1 Like

Re: .. by enigstil(m): 12:57am On Sep 22, 2015
Baba edakun, imi esu yi, she eyi ti oti gbe ni, tabi tutu, abi mejeji ati tutu ati gbigbe lo she ise po.
kadunasouth:
OGUN YI DARA FUN ENI AWON ELEYE NBA YOLENU


Imi esu, epo-ọbọ, ewe ajẹobale gbigbẹ. Ao gun pọ. Ao fi adin si, ao fi ọṣẹ dudu ko ao popo, ao ko sinu igba olomori ao ma wẹ nigba gbogbo.
NB toba pe ojo meta totin lo ise yi wa fi akara elepo se sara fun obinrin yio je fun yin o!
Iba oloun iba agbagba

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 8:47am On Sep 22, 2015
enigstil:
Baba edakun, imi esu yi, she eyi ti oti gbe ni, tabi tutu, abi mejeji ati tutu ati gbigbe lo she ise po.
Ale lo tutu asilelo gbigbe eyi keyi tabarini kosaburu nibe

1 Like

Re: .. by enigstil(m): 8:54am On Sep 22, 2015
Eshe pupo modupe sir.
kadunasouth:

Ale lo tutu asilelo gbigbe eyi keyi tabarini kosaburu nibe
Re: .. by dosht(f): 11:18am On Sep 22, 2015
healthFirst:
54 E KU ILE O GBOGBO ENIYAN LATI IHA ILA ORUN ATI IWO ORUN IFA N KI YIN OOOO!!! FUN ANFANNI ARAWA

OOGUN TA FIN BA ELEDA WA SORO
Ogbe ori akuko adie 1, ewe ela 1, eyo atare 1,A o l o po ao fi sin gbere eyo kan si ori wa to oba di ojo keta ao bo sita gbangba ni ago kan oru 1:00) a o fi owo gba ori wa leme ta,
OFO- Eleda mio 3*emi L omo L ewe ela loni kinla sowo, kinla somo, kin laa salafia, kin la si ohun rere ni ile aye mi, ni tori pe bi akuko orun ba ko , ni se ni egba ayen gba , ki okiki Emi L omo L kan si rere ni ile aye miooooo (Adura)
Se aajo yi ko lewu fun ogberi??

1 Like

Re: .. by Davidifa(m): 2:50pm On Sep 22, 2015
Efun mi ni ogun ti mo beere. Ifa agbe wa
Re: .. by Ousmaf(m): 6:37pm On Sep 22, 2015
healthFirst:
55
Ose Awure Todaju
Irun Ori Were, Ewe Isaju, Ewe Ajeobale, Akuko Adiye Kan, Eiyele Kan, Akuko Adiye Ati Eiyele Yen, Ao Fi Ese{leg} Wa Ja Ori Re, Ao Wa Jo Po, Ao Po Mo Ose, Ao Ko Si Inu Ikoko Ajere, Ao Fi Aso Funfun Te Isale Ikoko Naa, Ao Wa Gbe Ko Enu Ona Aba Wole, Ao Wa Bu Ose Na We. IBA OLODUMARE!!!
ejoo baba se enu ona kato wole tabi taba wole loke ni ao fi ose na ko si? ati wipe se awon ori (akuko adie ati eiyele) na nikan lao jo po fi po ose na? eseun Olohun a tunbo man ran yin lowo si.

1 Like

Re: .. by Nobody: 7:10pm On Sep 22, 2015
Ousmaf:

ejoo baba se enu ona kato wole tabi taba wole loke ni ao fi ose na ko si? ati wipe se awon ori (akuko adie ati eiyele) na nikan lao jo po fi po ose na? eseun Olohun a tunbo man ran yin lowo si.

E lo tun ka daada...mo se alaye lekun rere
Re: .. by Nobody: 7:13pm On Sep 22, 2015
Isholex1love:
mo juba eyin agbagba nibi e jo sir se ogun basiri kia toni isu dandan ati igbin ma dayan lamu ni tori igba ti mo je o worry inu mi

Ewu nbe loko Alonge, Alonge funrare, ewu ni...E sora nipa jije Oogun ti e ko mon idi re...E kan si eni to ko Oogun sita fun itosona ki e to ma beere si je inkan te mo idi re. Gbogbo inkan lo ni iwontuwonsi

1 Like

Re: .. by sammyjay76(m): 4:19pm On Sep 23, 2015
healthFirst:


Ewu nbe loko Alonge, Alonge funrare, ewu ni...E sora nipa jije Oogun ti e ko mon idi re...E kan si eni to ko Oogun sita fun itosona ki e to ma beere si je inkan te mo idi re. Gbogbo inkan lo ni iwontuwonsi
ejowo funmi ni ogun ti mo le fi gba owo lowo egbon to ko lati ran ni lowo grgebi daodu ile to si owo yi lowo daada.
Re: .. by Nobody: 5:38pm On Sep 23, 2015
OBATALA OBA TOOSA

Oba tapa tapa tí n gbóde Ìrànjé
Aníre níwà
Aníwà níre
Oko abuké
Oko aro
Oko Aràrá borí pèté
Òrò oko Àfin
Afí ojó gbogbo tóbi
Ó tóbi kò se é gbé
Bàntàbanta nínú àlà
Oba àlà funfun gbò ò
Ó sùn nínú àlà
Ó ji nínú àlà
Ó tinú àlà dide
Babanlá oko Yemòó
Olá-se-é-wò
Arúgbó ilé Ifón
A-fún-Níní-gbà-fún-Àìní
Ò-so-enìkàn-digba-eni
Alágbède òrun
Morímorí tó n morí omo tuntún
Òrìsà tó n se ojú tó n se imú
Òrìsà-nlá alámò rere
Òrìsànlá Alámò ìwà
Òrìsànlá Alámò amòpín
Alábàáláse
Òrìsà gbìngbin nìkìn.
Ase Ti Eledunmare
Edunmare Ase

2 Likes

Re: .. by jades5050(m): 9:36am On Sep 24, 2015
E joo oogun ti won ba fun yin ni abala yii a ko ni ki e ma fi se ika , abala yii wa fun a wa omo YORUBA ka kiri ile kotu o ji mi , awon AWO ti o n fun yin ni oogun won ko ni ki e ma fi se ika. a fi ngbe asa ile YORUBA ga ni , ati wi pe Abala yii wa fun ITUNSILE ni orisirisi ona. Ati ironi ni Agbara, Abala yi is tun kun fun awon Awo ati Ogberi , awon Awo ti o wa ni Abala yii ti ko orisirisi oogun si eyin , won o is tun ma fun yin si , si waju ati si waju nitorina. E jo mo ro yin awon oogun won yii ema fi se Ika , oogun ti o ba si ye yin, e bere lowo eni ti o ko si ita fun yin ko le se alaye e fun yin dada, bi e ba se nsa yio ma je o Ase ni ti EDUMARE
Re: .. by greatolusegun: 8:58am On Sep 25, 2015
e Ku owuro o eyin omo odua,mo gbadu itaku yi gan ni o,gbogbo ohun to a ba nse a ma je fun wa o.iwadi fi han wipe ti a back ni Ogun si ara,ti a ba obirin ni asepo o se se ko gba lara fi idi eyi,e jo eni to ni Ogun ti obirin o fi ni left gba Ogun Lara wa tabi eyi ti a fi left gba pada ko ju sita.
AJEEGUN TO DAJU
OWO INAKI,EWE AJEOBALE MESAN PELU ODIDI ATARE KAN AO JO PO AO FI SIGBERE YI ORUN OWO WA MEJEEJI KA.GBOGBO IGI TI ELEGBEDE BA TI LU LODE AYE LO NDU.
Re: .. by kadunasouth(m): 1:31pm On Sep 25, 2015
kiss
Re: .. by keyguy59(m): 8:14pm On Sep 25, 2015
ogun owo (respect)
orogbo kan,a o wa da orogbo yi lu ni ori,a o ko atare mesan 9 si nu re ati oju ologbo mesan si nu re....a o wa we ni owu dudu ati funfun...a o ma fi ko orun wa tabi ki a ma fi si apo......odaju.......
Re: .. by keyguy59(m): 8:25pm On Sep 25, 2015
iba olodumare to fi ogbo si awon agbagba lori,,,olojo o ni mo wa juba,,,
Iba olukogun ti gbe agbede origun mererin agbaye,,,,,
iba awon iyami soromoniga,,,,,,,eje ki ewe ki oma je,,,,,
Iba omode ilu
Iba agba ilu
Iba ako
Iba abo......
Ema je ki ewe sun oko ooooo................iba ni moju tori ti lekeleke ba juba efun oda efun oni da.......iba o iba..........iba awon agbagba ti gbe lorogun ila......e ma je ki ewe ko sun oko ooooo............
Re: .. by keyguy59(m): 8:35pm On Sep 25, 2015
IFERAN OBIRIN
a o ma so ibi ti omo obirin ti a feran na ba to si,a o wa lopa laabalaba,a o lopo pelu atare eyokan mo ibi ti o to si gugu,a o fi sin gberin kan si okan aya wa...
Ofo re::tinu teyin ni laabalaba fi won ilele gbogbo owun to be ninu l omo l ko fi mo won emi l omo l lati oni lo.....:.........

1 Like 1 Share

(1) (2) (3) ... (20) (21) (22) (23) (24) (25) (26) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 54
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.