₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,325,765 members, 8,423,640 topics. Date: Wednesday, 10 June 2026 at 04:47 AM

Toggle theme

Yoruba Commonwealth and Politics - Politics (75) - Nairaland

Nairaland ForumNairaland GeneralPoliticsYoruba Commonwealth and Politics (802221 Views)

1 2 3 ... 72 73 74 75 76 77 78 ... 384 Reply (Go Down)

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:25pm On Oct 28, 2015
Rilwayne001:
Mo nife si awon ofin yi oo cheesy
grin grin cheesy Mo mo wipe oma soro fun opolopo lati so Yoruba la lai fii geesi si
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by tunde1200(m): 9:25pm On Oct 28, 2015
Omo ilu Igbaja legbe ilorin ni mii.

Aareonakakanfo:
Ko n se wipe oni nkankan pataki ti a ni lati so ju wipe kako fi Yoruba so oro fun wakati kan.To ba de ni nkan pataki te ni la ti so ko si waala sugbon mo ni ibeere kan.Omo ilorin ni yin abi
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:27pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:
Hahaha boya ka fi "erin" fi ropo gbolohun akoko yen.ooto le so
'Erin'

bawo le se ri si?

LOL Erin

cheesy
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:28pm On Oct 28, 2015
tunde1200:
Omo ilu Igbaja legbe ilorin ni mii.
Bawo lo se sunmo ilorin to.Idi ti mo fi n bere ni wipe alaimo kan nimi ni pa oro Ilorin.mo fe mo ni pa awon Yoruba to wa n be
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by laudate: 9:29pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:
Anti mi tabi Egbon mi. mo moomo pe yin wa si bi yi ke yin naa wa wo bi ede yoruba se rewa
Ehn.... the only word I recognise in this whole phrase is 'Egbon.' cheesy Now, please tell me, what is the meaning of the rest of the words you wrote up here?? Please....abeg, just kindly translate. I hope it means you are going to send me some money?? grin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:30pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:
Erin grin cheesy Ni iwoyi ana gbogbo won so oro bi eni wipe wan ma san owo fun won.Asiko ati so yoruba de ni sin.aa ri won mo
awon eni eleni, oro do'ju e, wa yi ese pada.

Alagba Shym3x nko, a ma kofiri wan?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:30pm On Oct 28, 2015
laudate:
Ehn.... the only word I recognise in this whole phrase is 'Egbon.' cheesy Now, please tell me, what is the meaning of the rest of the words you wrote up here?? Please....abeg, just kindly translate. I hope it means you are going to send me some money?? grin
Eewo le leyi oo. ema so geesi ni wakati yi.To ba to asiko, maa so itumo gbogbo nkan ti mo wi fun yin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by SUBWAY101(m): 9:31pm On Oct 28, 2015
Rilwayne001:
Mo nife si awon ofin yi oo cheesy
Oga mi, Mo gbo wipe omo Ilu Kwara le yin. Shey lo to o nii?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by SUBWAY101(m): 9:32pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:
Eewo le leyi oo. ema so geesi ni wakati yi.To ba to asiko, maa so itumo gbogbo nkan ti mo wi fun yin
Ara Kurin yen Ki she Omo Ile Yooba, O ko feran wa nii.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:32pm On Oct 28, 2015
Se woni omo ale omo ni kii mo itan ile baba re. Ti oridi eyi, mo pe gbogbo eyin omo kaaro ojire lati tiraka ka iwe itan yoruba yii. Mo sheshe daunlooodu re lori ero ayelukara mi ni. Iwe naa poo sugbon laipe laijina maa gbiyanju lati kaa tan.

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:33pm On Oct 28, 2015
9jacrip:
awon eni eleni, oro do'ju e, wa yi ese pada.

Alagba Shym3x nko, a ma kofiri wan?
grin grin cheesy Alagba shymm3x ti so fun mi wipe awon o ni so nkankan ni wakati yi ki awon eyan ma fi se yeye.egbon lobinrin ilekehd nko? aba won naa ti salo ni grin cheesy
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:34pm On Oct 28, 2015
SUBWAY101:
Ara Kurin yen Ki she Omo Ile Yooba, O ko feran wa nii.
Mo moomo pe wa sibi yii.emi naa mo wipe ki n se Yooba
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:35pm On Oct 28, 2015
Rilwayne001:
Se woni omo ale omo ni kii mo itan ile baba re. Ti oridi eyi, mo pe gbogbo eyin omo kaaro ojire lati tiraka ka iwe itan yoruba yii. Mo sheshe daunlooodu re lori ero ayelukara mi ni. Iwe naa poo sugbon laipe laijina maa gbiyanju lati kaa tan.
Mo ni iwe yi sile sugbon mi o tii ka
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:35pm On Oct 28, 2015
SUBWAY101:
Oga mi, Mo gbo wipe omo Ilu Kwara le yin. Shey lo to o nii?
Beeni omo iya.. Omo Ilorin ni baba to bimi lomo, omo Ède si ni Iya mi, sugbon Ibadan ni wo bimi si. Omo ilu pupo lemi see, sugbon mo feran Ilorin gidigan ni. smiley
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by SUBWAY101(m): 9:37pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:
Mo moomo pe wa sibi yii.emi naa mo wipe ki n se Yooba
O da be nigba yen.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:38pm On Oct 28, 2015
Ogbeni nisai.mo ri yin te n wo tiredi yi.Oya ewa so ede abinibi yin oo
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by tunde1200(m): 9:38pm On Oct 28, 2015
kojina sii Ilorin pupo bii maili ogoji lomafii jina.

Aareonakakanfo:
Bawo lo se sunmo ilorin to.Idi ti mo fi n bere ni wipe alaimo kan nimi ni pa oro Ilorin.mo fe mo ni pa awon Yoruba to wa n be
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by PrincessJaneDoe: 9:40pm On Oct 28, 2015
Aare, Yoruba mi ku die ka to, amon mon gbiyanju. Mi o gbo ede mi o sad Yoruba Eko nikan ni mo le so.

Kini oruko awon mods section yi? (eforiji Yoruba-English mi cheesy)

alcatraz001, alcatraz002
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:41pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:
grin grin cheesy Mo mo wipe oma soro fun opolopo lati so Yoruba la lai fii geesi si
Beeni omo iya, ko rorun. sheri ti gbogbo won kan lugbe grin grin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Musiwa419: 9:42pm On Oct 28, 2015
Kilo'n sele ni ibi bayi ni ale yi o
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:43pm On Oct 28, 2015
Rilwayne001:
Beeni omo iya, ko rorun. sheri ti gbogbo won kan lugbe grin grin
grin grin cheesy Emi naa ti mo wipe gbogbo wan ma sa lo.O dami loju wi pe awon kan wa ni awon tiredi biafra yen ton ro ejo lowo lede geesi grin grin cheesy
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:43pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:
grin grin cheesy Alagba shymm3x ti so fun mi wipe awon o ni so nkankan ni wakati yi ki awon eyan ma fi se yeye.egbon lobinrin ilekehd nko? aba won naa ti salo ni grin cheesy
Alagba Shymm3x le ma ko ede na die die, ko je ko soro lo titi nitoripe eje yoruba wa lara wan.

Egbon Ilekehd le so Yoruba, ati jo so yoruba die ni ana.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by totit: 9:44pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:
Hahaha opolopo eyan beru lati wa soro nibi yii.Kilode ti eru se n ba gbogbo yin
Eru ti wa je?
Bii temi ko o. Ra ra o
Moo kunle repetè, kooada pupoo gan

Omo egba la wa se oo

Baá wa oo grin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by SUBWAY101(m): 9:44pm On Oct 28, 2015
Rilwayne001:
Beeni omo iya.. Omo Ilorin ni baba to bimi lomo, omo Ède si ni Iya mi, sugbon Ibadan ni wo bimi si. Omo ilu pupo lemi see, sugbon mo feran Ilorin gidigan ni. smiley
O da bee. Emi no nii awon ore to je omo Omupo, won de ma nfi ye mi pe, omo odua tokan tokan la won. Odua agbe wa ooo.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:45pm On Oct 28, 2015
PrincessJaneDoe:
Aare, Yoruba mi ku die ka to, amon mon gbiyanju. Mi o gbo ede mi o sad Yoruba Eko nikan ni mo le so.

Kini oruko awon mods section yi? (eforiji Yoruba-English mi cheesy)

alcatraz001, alcatraz002
Yooba eleyi ti e so ni bi yii koo ku die ka to o.Yooba gidi ni ele yi ti e so yii oo.O ka mi lara wipe mii pero ogbeni alcatraz001.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:47pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:
grin grin cheesy Emi naa ti mo wipe gbogbo wan ma sa lo.O dami loju wi pe awon kan wa ni awon tiredi biafra yen ton ro ejo lowo lede geesi grin grin cheesy
grin grin Tiredi awon omo olori pelebe (biafra) ma ndun bii kaasi nkan. Erin le mi ma nfi won rin.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:48pm On Oct 28, 2015
9jacrip:
Alagba Shymm3x le ma ko ede na die die, ko je ko soro lo titi nitoripe eje yoruba wa lara wan.

Egbon Ilekehd le so Yoruba, ati jo so yoruba die ni ana.
Boya ka fun alagba shymm3x la ye lati so Yooba pelu geesi papo.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by laudate: 9:50pm On Oct 28, 2015
Uh...this is so unfair! Am going to report all of you to my maternal grandmother's sister! cry cry
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:50pm On Oct 28, 2015
totit:
Eru ti wa je?
Bii temi ko o. Ra ra o
Moo kunle repetè, kooada pupoo gan

Omo egba la wa se oo

Baá wa oo grin
E kaa bo oo

Rilwayne001:
grin grin Tiredi awon omo olori pelebe (biafra) ma ndun bii kaasi nkan. Erin le mi ma nfi won rin.
Kilode ti awon yooba se wa feran tiredi awon olori pelebe ba yii.mii ti e ka won kun.alawada lawon olori pelebe yen
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by superstar1(m): 9:50pm On Oct 28, 2015
ibo ni IlekeHD wa ni ale yii.

a ko si eri ina ikoni nijanu/bureki re ni ale yii. grin grin grin grin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:51pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:
Bawo lo se sunmo ilorin to.Idi ti mo fi n bere ni wipe alaimo kan nimi ni pa oro Ilorin.mo fe mo ni pa awon Yoruba to wa n be
Ilorin o se bee yato si Ogbomoso rara. Kini awon nkan ti efe mo nipa Ilu Ilorin ?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:51pm On Oct 28, 2015
SUBWAY101:
O da bee. Emi no nii awon ore to je omo Omupo, won de ma nfi ye mi pe, omo odua tokan tokan la won. Odua agbe wa ooo.
Asee oo smiley
1 2 3 ... 72 73 74 75 76 77 78 ... 384 Reply

OPC - Faseun & Adams Unite For Security Of Yoruba CommonwealthSEUN - Re: Yoruba-commonwealth-politicsGoodluck Jonathan Returns From Commonwealth Assignment (photo)234

Anambra light of the nation, eastern economy power house.Kenyans Are Far Behind Nigerians In Every Aspect – Fani-KayodeEnugu, The Pride Of The East.