Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,151,721 members, 7,813,381 topics. Date: Tuesday, 30 April 2024 at 11:35 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1828137 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (56) (57) (58) (59) (60) (61) (62) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Ifankaleluya: 6:13pm On Feb 28, 2016 |
ONILEIFA: Nibo lo ti ri gbogbo awon odu-ifa iro re yi okunrin yi? Haaaaaaa.....erin re pa mi. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 6:17pm On Feb 28, 2016 |
healthFirst: Baba healthfirst eejo wo mo nidi alaye ranpe die si lori ise yi : Ki la ma fi iyere yen se ?, elekeji se a ma yo ikarahun igbin ka to ge si 16 ? 2 Likes |
Re: .. by ONILEIFA: 7:03pm On Feb 28, 2016 |
[quote author=Ifankaleluya post=43334982][/quote] Eyi owun e wi mi o ni lo lati ba yin jiyan rara to ri wipe eyin ni aroni lale odo |
Re: .. by ONILEIFA: 7:05pm On Feb 28, 2016 |
Ìbà o, Obatala, Oba taasa, Oba patapata lode Iranje, Ìbà Iranje’le Iba Iranje oko, Ìbà Ifon-Osun, Ìbà Igbin, Iba Igbin-Oosa, Ìbà Alágemo-téérekangé, Je a gbo Je a to; Ìbà Abamoda omo Oosa-Agbowujin, Mo daba ire aje, ire aya/oko, ire omo, ire gbogbo, Aba ti Alagemo bada lOosa-Oke n gba, Ìbà Gunyan gunyan ile Ido, Ìbà rokaroka obinrin Ibadan, Ìbà Aje tii n somo Olu-Ibini, Ìbà Okun tii n somo Ode-Irada, Ìbà Orò, òròpòtò pómùpómù, Tobi ‘mo léweléwe ti kan kan o sofun, Ìbà Osanyin –mògbòráyè, To gba opa lowo olókùnrùn sanu. Aye mo juba é jé ki o ju mi sé 2 Likes |
Re: .. by ONILEIFA: 7:34pm On Feb 28, 2016 |
Ifankaleluya: [quote author=Ifankaleluya post=43334982][/quote] BABA IFAKALELUYA EJO WO KI NI MO RA NI IGBA YIN ONIKON KO JABELE KALUKU N SE TI RE O DAMI LOJU GBAN GBA PE ODU IFA YEN NI OGBE IRETE TI AN PE NI OGBE ATE TI KO BA RI BE E FI TI YIN SI TA KA RI EDA TO NWO SE OKUNKUN KO MA SE DO SUPA LORO.
|
Re: .. by keyguy59(m): 8:07pm On Feb 28, 2016 |
Baba healthfirst se e ri.......awon ti won pe a wa ni copy and past.....afi suru........e mi o jin yan..sugbon eni ti won ma gba lo ma po ju.......emi......keyguy mi o je fi ogun mi si le fun enikeni.....aya fi ti ba ma....se copy and past......fun won.... |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:55pm On Feb 28, 2016 |
ONILEIFA: arunkunrin o le bami jiyan tori onijibiti ni ooooo. Nibo loti ri gbogbo odu-ifa iro re yen? Dakun nje o ti e mo odu to bi o gan? Pelepele re ooo...ko ye ki e mo fi oruko babalawo gba awon eniyan,ti o ba wu o lo ona miran. |
Re: .. by Ifankaleluya: 11:08pm On Feb 28, 2016 |
ONILEIFA: Ogbeni..ko wu mi lati da o lohun oro re tori mo ti se ipinnu lati ma so oro lori thread yi mo,sugbon mi o ni la oju mi sile ki o ma fi ifa paro fun awon eniyan. Emi o kin n se baba-alariwo, babalawo ni emi,fun idi eyi mo ni lati fo esi si oro re. LO BA BABALAWO RE PE IFA IRE-N-TEGBE LOPE FUN O NI OGBE-ATE. ONIJIBITI NI OOO,INU-IWE ALAWIYE LO TI WO,O KIN NSE BABALAWO. ifa ni ogbe wa te ki ara o ro won,eni wa iwakuwa,a ri irikuri lodifa fun apon to sai laya nile to n toro omo lowo-orisa. Arakunrin se pele-pele,mo ri ibinu awon awo. Ma wa iwakuwa loruko awon babalawo! Dakun ki ese ifa kan ninu ogbe-ate to so yen gan? |
Re: .. by Ifankaleluya: 11:13pm On Feb 28, 2016 |
ONILEIFA:Dake enu re joorr...Iba iro re wo? Ifon-osun ko....Ifon-oyo ni. Onijibiti..! |
Re: .. by Ifankaleluya: 11:23pm On Feb 28, 2016 |
ONILEIFA: gbe enu re dake joorr...iwo mo ohun ti won npe ni aye?igi-abo re wo lo fi n nu idi? Din-dinrin,dakun bawo lo se fi ifa osa-meji ko ebo ru jare? ONIJIBITI! |
Re: .. by Naturewonders: 11:31pm On Feb 28, 2016 |
Hymn...Oludasile ku agba,won de ku opolopo suruu.emi kii se awo,sugbon ni gba ti mo ri ohun ti awon ti won pe ara won ni babalawo post nse ni erin kan pami ni.Se efe ba ti awon eyan je ni.mo ro awon ogberi ,ogun ti healthfirst oba fi owo si ,ko ma se dawole ti won ba nife arawon.iro se wa dun lenu eyin oni jibiti bi oyin bai.oro baba sese nye mi ni.baba edakun ema wo ran tori oruko yin.won ti fe ba eto yi jeo.esun pupo |
Re: .. by Nobody: 6:01am On Feb 29, 2016 |
. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 6:14am On Feb 29, 2016 |
keyguy59: Ejabure...mr keyguy59. ejowo e fun mi ni email yin? |
Re: .. by ONILEIFA: 9:00am On Feb 29, 2016 |
Ifankaleluya: Ara lon ta ee onijibiti agba. |
Re: .. by Nobody: 9:40am On Feb 29, 2016 |
Ogbeni Ifankaleluya ati OnileIfa, ki keke pa mo yin lenu, eyin obileje awo eke. ki le ri ninu obe te fi waro owo bayi? A gbe eto yi sita lati ran awon ti aye n fiya je lowo ati lati gba won sile lowo eyin Awo eke gbogbo. lehin gbogbo ikilo ta kin yin, e tun wa n paro orisirisi. Mo fe fi dayin loju, teo ba dawo ibi duro, eo gba Esu lalejo laipe. Egbinrin ote loro yin, ba se n pa kan nikan n ru jade. E ki owo omo yin sinu aso ni kiakia te ba fe ka fi Epe ranse si yin. Ikilo leekan si fun gbogbo awon ti won fe se ogun kan tabi meji lori ikanni yi; yato si oogun ti mo fi sita ati awon eyi ti ogbeni kadunasouth fi sita, iro funfun ni gbogbo eyi to ku. E kiyesara o! Bi enikeni ba ko eti didi si awon ikilo wonyi, o ku si lowo ati Eleda re o. oogun eke ma n ba kadara eeyan je lehin igba ti won ba fi owo yin sofo. Ao ni ri ogun agbana lati owo awon Awo eke o!. 3 Likes |
Re: .. by Oluokunoluwole: 11:20am On Feb 29, 2016 |
Ifankaleluya:eku ise opolo eledua a ran yin lowo,ti eba ni orisi isoye miran ebawa fi sita |
Re: .. by ONILEIFA: 12:21pm On Feb 29, 2016 |
healthFirst: Baba Ema binu ogbeni Ifankaleluya lo ni a mo ju lara... ologun eke ti on pe ra re ni aroni lati eni lo mi ko ni fi ise sita lai gba ase lowo yin 1 Like |
Re: .. by Nobody: 3:19pm On Feb 29, 2016 |
ONILEIFA: Ifa a gbe yin fun esi te fun mi. Mio kuku binu sugbon ko le da na mo gbiyanju. Ko si eni kan to le so wipe oun mon gbogbo inkan tan sugbon ta ba ri ayederu, o ye ki a mon wipe ayederu ni. Eni tio ba ti fe ko ara re nijanu lori ikilo ti mo fi sita, ko lo da ikanni tire sile. ki won ma se ba ibi je fun mi ati fun gbogbo awon ti won se ogun lori ikanni yi. E seun leekan si, ogbeni OnileIfa. |
Re: .. by akingbemi(m): 3:36pm On Feb 29, 2016 |
healthFirst:ejo kini oko sango |
Re: .. by akingbemi(m): 3:42pm On Feb 29, 2016 |
[quote author=Jadonjack post=32751371] Ejoor, seh eleyi ni agbara re kopo abi fun igba wo ni eleyi lee siseh di?[/quote ejo kin I itumo eleyi to ko lu rara |
Re: .. by Nobody: 5:23pm On Feb 29, 2016 |
akingbemi: Edun Aara/Sango 2 Likes |
Re: .. by tundeologo: 6:18pm On Feb 29, 2016 |
Suuru baba iwa Suuru loba awure Eni toba ni suuru-ohun gbogbo loni. Emi koi tii Dan ise kan wo ri toje ti ori ikanni yii Sugbon igba kugba ni mo man ko eko gidi lori ikanni naa Nipa eto ilana iwosan Yoruba ni ka soni Abi ti ona iyanu ti yoruba n GBA toju emi(spiritual.....) Moti fi igbakan je alatako si ijinle agbara ti olohun fun Yoruba ri Sugbon Lehin opolopo experience pelu research Mori otito dimu sinsin lai pa esin mi Lara Eko ni mo maan ko ni ojoojumo lori ikanni yi Mo si mo wi pe opolopo naa wa bee Mo tun ti wa ko eko tuntun lat'ara baba healthfirst Baba, oluwa atubo je ki e le maa se suuru Bi eniyan yio ba te, bi eda yio ba kan abuku, Suuru ni yio koko sonu lowo oluwa re Baba,e o ni te o, eo ni kan abuku ati gbogbo wa naa Gbogbo wa na ao ni te, ao sini subu , ao ni so ire owo wa nu E je ki gbogbo wa naa maa ni suuru daada Kasi mo tori Ohun ti aoje, ba ti eni eleni je, Ka ma ko idamu ba omolakeji Ka ma da wahala si won l'agbada Ranti wipe, "bi iwo ko bale pa eniyan lerin, Ko ni eto ki o paa lekun o" Bi ogun ba jelo, ogbon a jebo A tubo maa dara fun wani o(ase edumare) 2 Likes 1 Share |
Re: .. by Nobody: 9:55pm On Feb 29, 2016 |
Ifa A gbe Yin O! tundeologo: 1 Like |
Re: .. by akingbemi(m): 10:48pm On Feb 29, 2016 |
healthFirst:ejo mio no bi won tin Jo Ogun sir |
Re: .. by akingbemi(m): 6:37am On Mar 01, 2016 |
Ousmaf:ejo Baba mio more big won Tin Jo Ogun esaye e fun mi sir |
Re: .. by akingbemi(m): 6:38am On Mar 01, 2016 |
Ousmaf:ejo Baba mio mo bi won Tin Jo Ogun esaye e fun mi sir |
Re: .. by scholes0(m): 6:58am On Mar 01, 2016 |
healthFirst: Se oun ni awon elede geesi ma n pe ni "fulgurite"? Okuta ti o maa n wa ni ibi ti monamona bá ti ba ilè? |
Re: .. by Zalam5: 3:35pm On Mar 01, 2016 |
healthFirst:Subgon number Te fisita wipe kadarapo moyin Lori what's app yen o ti wa active Lori what's appeal Ko is number yen ni what's app now Why ? |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:54pm On Mar 01, 2016 |
hmm! okan wa dunmi fun awon ogberi ni thread yii sha, nitori awo ni awo amaje, sugbo ogberi loma nri nkan ti koto nkan ti afelatimo ju oni nkan, ode tun dun mi fun gan eni ti oni abalayi, nitori kosi bi ase fese ebolo ti koni run igbe, tori awon eyan toje alapa leti si nbo wa, ki Olorun fun wa lagbara lati kapa won atanni ni suuru'o. Ojogbon wa H.F. Olorun amakoyi'o. Tori awon towa nile ti won'o soro safefe, won po ju eyin ti ewa lori ategun lo, sugbon onikaluku lonsa fun oruko, tori oruko rere san ju wura ohun fadaka lo. AJUWASE'O |
Re: .. by ONILEIFA: 9:58pm On Mar 01, 2016 |
¤HAPPY NEW MONTH GREAT FANS¤ <OSA-OLOYAN> ! !! ! ! !! ! ! ! Bi ara eni ba n laje, bao ba laje, oju amaa yan ni. Bi ara eni ba n kole, bao ba koo, Oju amaa yan ni. Bi ara eni ba n laya bao ba ni, Oju amaa yan ni. Bi ara eni ba sere gbogbo bao ba seekan, oju amaa yan ni. Adiafun Osa oloyan, Ekun ire gbogbo niisun. Ebo niwon nio see, O rubo tan, ire wole re wa. Nje kini Oloyan gbewa fawo? Jingbinjigbin ileke, ola nla loloyan gbewa fawo, Jingbinjingbin ileke. Kini Oloyan je lere o? Jingbinjingbin Ileke, Ere nla loloyan je, Jingbinjingbin ileke. Gbogbo ohun to n dun awa FANS egbe yi lokan ni Olodumare aa see fun o(ase). Aa je ere ninu osu tuntun yi o, Gbogbo ire ti egbe awa FANS page yi nse lawa naa amaa bawon gbele aye se. OLODUMARE KO NII SE AWA FANS PAGE YI LASINNIWAYE O(ASE). Wishing you a joyful MONTH!!!. |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:08pm On Mar 01, 2016 |
AGO'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye, opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati kansi awon ojogbon ni abalayi tabi ki ofi ojo ibi re ranse. ajuwase'o |
(1) (2) (3) ... (56) (57) (58) (59) (60) (61) (62) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 88 |