Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,151,772 members, 7,813,559 topics. Date: Tuesday, 30 April 2024 at 01:52 PM

.. - Culture (60) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1828157 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (57) (58) (59) (60) (61) (62) (63) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by toheeb1995: 11:48am On Mar 02, 2016
E jowo, mo fe ki e fi ogun ISOYE sita ....ewe a ma je o
Re: .. by kuddus: 12:01pm On Mar 02, 2016
ejo efun wa ni ayajo ti ama pe ti aba ti se eniyan ti won yo fi dariji wa ejo baba healthfirst ati kadunasouth
Re: .. by Ifankaleluya: 2:39pm On Mar 02, 2016
healthFirst:
Ogbeni Ifankaleluya ati OnileIfa, ki keke pa mo yin lenu, eyin obileje awo eke. ki le ri ninu obe te fi waro owo bayi? A gbe eto yi sita lati ran awon ti aye n fiya je lowo ati lati gba won sile lowo eyin Awo eke gbogbo. lehin gbogbo ikilo ta kin yin, e tun wa n paro orisirisi. Mo fe fi dayin loju, teo ba dawo ibi duro, eo gba Esu lalejo laipe. Egbinrin ote loro yin, ba se n pa kan nikan n ru jade. E ki owo omo yin sinu aso ni kiakia te ba fe ka fi Epe ranse si yin.

Ikilo leekan si fun gbogbo awon ti won fe se ogun kan tabi meji lori ikanni yi; yato si oogun ti mo fi sita ati awon eyi ti ogbeni kadunasouth fi sita, iro funfun ni gbogbo eyi to ku. E kiyesara o! Bi enikeni ba ko eti didi si awon ikilo wonyi, o ku si lowo ati Eleda re o. oogun eke ma n ba kadara eeyan je lehin igba ti won ba fi owo yin sofo. Ao ni ri ogun agbana lati owo awon Awo eke o!.

IWO ATI TANI KI KEKE PA MO LENU? O MA TI E G*(D*FT),NIBO LO TI RI BABALAWO GIDI KAN TI N TA IWE-OGUN? SE EMI WA NINU OLOOGUN TI E JO NSE OGUN EWE-OYO,ISU DAN-DAN ATI ATA IJOSI NI? SE BI MO TI E CHALLENGE E NI WHTSAPP PE KO KI(CITE) ESE IFA KAN PERE FUN MI SUGBON TI O KO RI ESI KANKAN FO? ABI OTI GBAGBE WIPE O JEWO(CONFESSED) FUN MI WIPE O KIN N SE BABALAWO? IWO ATI AWON WO NI YIO GBA ALEJO ESU? NJE O TI E MO N TI WON NPE NI ESU GAN? NJE O TI E NI EPE KAN TI N SISE LOWO NI? MO SE TAN LATI BA O GBE PEREGI IJA KA NA,TI N O SI FI EJO RE SUN IJO-ERIWO WIPE O N FI ORUKO AWON BABALAWO LU JIBITI LORI ERO AYE LUJARA. EMI TI TAYO ENI TI YIO SESE MA SA IFA LORI-ESU KIN TO BA ENIYAN JA, TI MO BA FI GBOLOHUN IFA LASAN RANSE SI OO,OO TO BE KO KA KI ORUN(N*CK) O MA WO EE.
SE PELE-PELE OO BABALAWO NI EMI,KIISE BABA-ALARIWO.
Re: .. by Ifankaleluya: 2:40pm On Mar 02, 2016
ONILEIFA:

Baba Ema binu ogbeni Ifankaleluya lo ni a mo ju lara... ologun eke ti on pe ra re ni aroni lati eni lo mi ko ni fi ise sita lai gba ase lowo yin

IWO ATI TANI KI KEKE PA MO LENU? O MA TI E G*(D*FT),NIBO LO TI RI BABALAWO GIDI KAN TI N TA IWE-OGUN? SE EMI WA NINU OLOOGUN TI E JO NSE OGUN EWE-OYO,ISU DAN-DAN ATI ATA IJOSI NI? SE BI MO TI E CHALLENGE E NI WHTSAPP PE KO KI(CITE) ESE IFA KAN PERE FUN MI SUGBON TI O KO RI ESI KANKAN FO? ABI OTI GBAGBE WIPE O JEWO(CONFESSED) FUN MI WIPE O KIN N SE BABALAWO? IWO ATI AWON WO NI YIO GBA ALEJO ESU? NJE O TI E MO N TI WON NPE NI ESU GAN? NJE O TI E NI EPE KAN TI N SISE LOWO NI? MO SE TAN LATI BA O GBE PEREGI IJA KA NA,TI N O SI FI EJO RE SUN IJO-ERIWO WIPE O N FI ORUKO AWON BABALAWO LU JIBITI LORI ERO AYE LUJARA. EMI TI TAYO ENI TI YIO SESE MA SA IFA LORI-ESU KIN TO BA ENIYAN JA, TI MO BA FI GBOLOHUN IFA LASAN RANSE SI OO,OO TO BE KO KA KI ORUN(N*CK) O MA WO EE.
SE PELE-PELE OO BABALAWO NI EMI,KIISE BABA-ALARIWO.

1 Like

Re: .. by Ifankaleluya: 2:42pm On Mar 02, 2016
healthFirst:

Ifa a gbe yin fun esi te fun mi. Mio kuku binu sugbon ko le da na mo gbiyanju. Ko si eni kan to le so wipe oun mon gbogbo inkan tan sugbon ta ba ri ayederu, o ye ki a mon wipe ayederu ni.

Eni tio ba ti fe ko ara re nijanu lori ikilo ti mo fi sita, ko lo da ikanni tire sile. ki won ma se ba ibi je fun mi ati fun gbogbo awon ti won se ogun lori ikanni yi.

E seun leekan si, ogbeni OnileIfa.

IWO ATI TANI KI KEKE PA MO LENU? O MA TI E G*(D*FT),NIBO LO TI RI BABALAWO GIDI KAN TI N TA IWE-OGUN? SE EMI WA NINU OLOOGUN TI E JO NSE OGUN EWE-OYO,ISU DAN-DAN ATI ATA IJOSI NI? SE BI MO TI E CHALLENGE E NI WHTSAPP PE KO KI(CITE) ESE IFA KAN PERE FUN MI SUGBON TI O KO RI ESI KANKAN FO? ABI OTI GBAGBE WIPE O JEWO(CONFESSED) FUN MI WIPE O KIN N SE BABALAWO? IWO ATI AWON WO NI YIO GBA ALEJO ESU? NJE O TI E MO N TI WON NPE NI ESU GAN? NJE O TI E NI EPE KAN TI N SISE LOWO NI? MO SE TAN LATI BA O GBE PEREGI IJA KA NA,TI N O SI FI EJO RE SUN IJO-ERIWO WIPE O N FI ORUKO AWON BABALAWO LU JIBITI LORI ERO AYE LUJARA. EMI TI TAYO ENI TI YIO SESE MA SA IFA LORI-ESU KIN TO BA ENIYAN JA, TI MO BA FI GBOLOHUN IFA LASAN RANSE SI OO,OO TO BE KO KA KI ORUN(N*CK) O MA WO EE.
SE PELE-PELE OO BABALAWO NI EMI,KIISE BABA-ALARIWO.

1 Like

Re: .. by Nobody: 2:45pm On Mar 02, 2016
Ifankaleluya:

ejowo e daunsi email timi fi ranse si yin sir?
Re: .. by Ifankaleluya: 2:48pm On Mar 02, 2016
ONILEIFA:
¤HAPPY NEW MONTH GREAT FANS¤
<OSA-OLOYAN>
! !!
! !
!! !
! !
Bi ara eni ba n laje, bao ba laje,
oju amaa yan ni.
Bi ara eni ba n kole, bao ba koo,
Oju amaa yan ni.
Bi ara eni ba n laya bao ba ni,
Oju amaa yan ni.
Bi ara eni ba sere gbogbo bao ba seekan, oju amaa yan ni.
Adiafun Osa oloyan,
Ekun ire gbogbo niisun.
Ebo niwon nio see,
O rubo tan, ire wole re wa.
Nje kini Oloyan gbewa fawo?
Jingbinjigbin ileke, ola nla loloyan gbewa fawo,
Jingbinjingbin ileke.
Kini Oloyan je lere o?
Jingbinjingbin Ileke, Ere nla loloyan je,
Jingbinjingbin ileke.
Gbogbo ohun to n dun awa FANS egbe yi lokan ni Olodumare aa see fun o(ase).
Aa je ere ninu osu tuntun yi o,
Gbogbo ire ti egbe awa FANS page yi nse lawa naa amaa bawon gbele aye se.
OLODUMARE KO NII SE AWA FANS PAGE YI LASINNIWAYE O(ASE).
Wishing you a joyful MONTH!!!.
O TUN TI BERE IWO OKUNRIN YI?
TA NI BABALAWO RE TO NI OSA-OLOYAN LO FI SILE YI?
ATI ODU ATI OFO IRO TO PA YEN,KOSI ELEYI TO CORRECT NIBE. KO BA DARA KO FE KAN LO RE KO IFA,TI ISE BABALAWO BA WU O LATI SE. ODU TI O FI SILE YEN NI A N PE NI '' OFUN-NA'GBE''.

SE PELE PELE OOO

ela-boru,ela-boye,ela-bosise.
Re: .. by Ifankaleluya: 2:52pm On Mar 02, 2016
Adupe lowo eledumare to mu ki oju wa ko ri osu titun,mo gbadura wipe emi wa ni yio reyin re...Ase!

Ifa ni modupe awo-oba,lo difa fun oba lalede oyo,ti a ba seni loore,ope laadu,ogunda-irosun ifa modupe.

Ela-boru, ela-boye, ela-bosise.

2 Likes

Re: .. by Ifankaleluya: 2:59pm On Mar 02, 2016
WiLdFLame:
ejowo e daunsi email timi fi ranse si yin sir?
kin ni e fe ki a se fun yin baba?
Re: .. by Nobody: 3:18pm On Mar 02, 2016
Ifankaleluya:

kin ni e fe ki a se fun yin baba?
MI ti send yin ni email beyen
Re: .. by Nobody: 3:23pm On Mar 02, 2016
Ifankaleluya:

kin ni e fe ki a se fun yin baba?

Mi ti ri edaun yin sir Eseun pupo baba!
Re: .. by Ifankaleluya: 6:50pm On Mar 02, 2016
Mo dupe pupo lowo gbogbo eyin ti e pe ati eyin ti e ba mi soro lori whatsapp to fi de odo eyin ti e lo e-mail. E seun mo dupe.

Emi ko dede ma ba enikeni ja,sugbon o semi ni aanu nigbati mo ri awon obayeje kan ti won n fi dudu pe fun-fun fun awon eniyan loje ki oro fe se bi ija nitori emi ko fe ibi ti ko ba si otito.
Nigbati a si bawon soro ni tutu,won ba bere si leri ogun,to je wipe won o ni ogun eyo-kan ti n sise lowo gan. Koda ti won ba tie ni gan,awa ti tayo eni ti enikeni le ma leri ogun si,notori wipe ifa ni kaka ki aye o ja ko pare,igbin ni a mu to,Ibi won ka sai sun siwon lorun,ibi won.

IFA NI KOKO IGI NI O BERE OJO,ADIFA FUN EJO N BE LORUN TI SE OMO-AWISUNKUN,IFA NI IRE LO BA MO SE. MA SE LOO,IKA LO BA MO SE, MA SE LO,AT'ORE AT'KA OKAN KAN KIIGBE.

Gbogbo eleyi to ba se ni wa je ere re...!

ela-boru, ela-boye, ela-bosise.
Re: .. by kuddus: 8:10pm On Mar 02, 2016
baba healthfirst eti dahun ibere mi ejo nitori olohun
Re: .. by Nudewhenu31(m): 11:42pm On Mar 02, 2016
Eku agba o, Baba health, e pe, e gbo, Ororun Oba ayeraye, Oba orun yio wa pelu yin, ejo eranmi lowo fun oruko mi ti yoruba npe ewe Urere, moti bere lowo awon elewe omo, sugbon wan ni awon ko mo ewe to n je be, mo fe fi se ise yin kan te fi si ta ni, eyi ti eni ama gun ewe Urere yen ati Abamoda papo, awa fun omi re sinu adin, fun arun oju ara obinrin. Eseun gan an ni
Re: .. by tayooluwole: 10:54am On Mar 03, 2016
healthFirst:
hello, this thread is for lovers of nature when it comes to health and other areas of our lives. This thread is also strictly for the Yorubas and those who can read and understand as the language here is going to be pure Yoruba and no translation will be allowed. Reason is that we are going to be revealing some Yoruba secret knowledge of the application of leaves and roots and we intend to preserve and guard these wisdom of our ancestors.

Please do not ask further question regarding my reason to keep this as a Yoruba affairs, it's my choice...but if you refused to respect this, I shall only dignify you with silence.

Aye wa fun o lati beere fun iru Oogun to ba fe sugbon ao ma ko awon orisirisi Oogun sita. Awon Oogun fun itoju aisan, akoya, ati awon Oogun fun isora/isori, awure, aworo, ati beebe lo. Sugbon kii se gbogbo Oogun ni a le fi sita lofe, awon eyi to ba ni agbara gan ni ao so wipe ki e kan siwa lori apo ifiwe ranse wa binaryteck@gmail.com fun ekun rere alaye.

E le dara po mo wa lori whatsapp pelu ero ibanisoro yi...08148398067...e fi gbogbo ibeere yin ranse, ao da yin lohun

Bi a ba ri inkan ti ko ye wa, e je ki a beere ibeere pelu alaye, ao si gbiyanju lati se alaye lekun rere.

Gbogbo Oogun ti a ba ko sita la ti dan wo, to de ni idaniloju wipe yio se ise ti a ba ran.

Iwe iwulo ewe, egbo ati eranko ti wa fun tita bayi pelu owo kekere. Die ninu awon oogun to wa ninu iwe na niwonyi: 1. Oogun arobi nla, 2. Agbelepota, ebe agba to daju, 3, eyonu nla, 4. Osole tutu, 5. Ayeta, 6. Okigbe ada, 5. Oki igo, 6. Ki ota ma le yin wa lorun, 7, isuju, 8. Bi omo ba dabu sinu alaboyun, 9. Ki alaboyun bimo pelu irorun lai se ise abe, 10. Bi inkan osu obinrin o ba se deede, 11. Afeeri to daju, 12. Oruka aluwo oni yepe, 13. Asubusere, 14. Oogun arun ito sugar, 15. Oogun arun ogbe inu, 17. Oogun arun ogun oru, 18. Olubasiri, 19 awure nla ti a n pe ni fayegbami, 19. Oogun apesin, 20. Oogun afaro nla, 21. Oogun fun awon omo yahoo. 22. Oogun ohunmo, 23. Oogun ariran, 24. Oogun isoye. 25, oogun jedojedo. 26. Oogun roparose, 27. Oogun ajidewe. 28. Oogun awoka/eje dudu, 29. Oogun obinrin ti o n yan ale, 30. Oogun afose, 31. Awise, 32. Agadagodo nla, 33. Aforan to lagbara, 34. Orikosungbo/egbe, 35 ipese awon agba 36. Oogun idakole, 37. Oogun fun ato okunrin ti ko le di omo, 38. Oogun afato ti kii fi tete re okunrin lori obinrin, 39. Oogun fun igbega lenu ise. 40. Oogun fun oju rere lati odo gbogbo eniyan .....ati beebelo...awon orisirisi oogun to wa ninu iwe na le ni 500. Gbogbo re si je ojulowo oogun. Bi e ba fe ipin ninu iwe yi, e kan si wa fun account number ti e ma san owo si. Iwe yio te yin lowo ni ojo keta te ba ti san owo. E seun o, isese a gbe wa o! Ase.

Iwe yi ti wa ni tita nile Eko bayi ni Iju_ishaga.

Too, mo seba awon agbalagba awo ile aye, mo seba awon awo ode orun, mo seba awon Iya mi abeni...e juba o se o.

Iba, iba, iba

Akoda iba

Aseda iba

Ile ogere a foko yeri

Alapo Iku

Olona ola, iba

Esu odara, iba

Irunmale olukotun

Igba imale olukosin

Iba gbogbo yin o

Ero osaju, ero eyin, iba

Adase ni ni wun omode

Iba ki wun ni o

Eyin to ni aye

E je sise mi o san mi

Emi lomo agba

E je owo a maa je fun mi o

Ada ki nmu, ki o ge eku idi e

Omo eni ki nburu,

Ki a gbe fun ekun pa je

E dari jimi, ki e fi owo mi wo mi

Emi lomo aie fepo we

Osoronga opiki elese osun

Ajefun jedo

Oriri aye

Ebo aye ni a ru o

Osoronga ni nba ni gbele aye

Aje ni npa eni

Osoronga gbigbe ni o gbe mi o

Aje ma pa mi lomo
Lomi ki o somo mi

Iya mi agba opiki elese osun

A woni maye

A woni loju re orun

Eje lepo ekuru won

Iya-mi aye elekuru pupa foo

O gberita jagun

O gbe origi ke kanran kanran

Fori jimi bi mo ba se

Fi owo re wo mi

Na ke kanran wonu ile mi

Iya-mogun alara

Bi igun jebo

Aje gbe ni nje

Bi akala jebo

Aje gbe ni nje

Gbogbo eyi a ba se

Asegben ni e je o je

Iya-agba alapo iku

Olokiki oru

Ki nfo o fara pa

Onile origi ki njebo

Ki ebo naa ma gun rege

A agba ki nfi abo bo eni

Ki Omo ara aye ma ri ami won Lara eni

A jefun jedo

Ki nje tire tan

Ki o ma fio na han eni

Iya mi toto aye

Fio na han mi

Bi o ba gbe ori igi ke

Ma ke ao mi

Bi o gbe orita ke

Ma ke pa mi

Kike ni ki o fi ike re ke mi

Omidan eleye oloju owiwi

A ri eni ko to pe eni

Omoran ologbon

Linmo riro ati w ri eda

Alapo iku olona ola

Iku ti nba nro nile mi

Re danu,Opiri eleye moran bi afefe

Arun ti nba nro nile mi

Ro danu

Iya-mi omoran eleye

A pani ma yoda

A mubo ti nbe laye mi

Re danu o

Eyin ti o ni aye

E fa mi mora

Aje eleye e fa mi mora o

Baba ejowo ilu wo le ti wa ?
Re: .. by Nobody: 11:40am On Mar 03, 2016
Nudewhenu31:
Eku agba o, Baba health, e pe, e gbo, Ororun Oba ayeraye, Oba orun yio wa pelu yin, ejo eranmi lowo fun oruko mi ti yoruba npe ewe Urere, moti bere lowo awon elewe omo, sugbon wan ni awon ko mo ewe to n je be, mo fe fi se ise yin kan te fi si ta ni, eyi ti eni ama gun ewe Urere yen ati Abamoda papo, awa fun omi re sinu adin, fun arun oju ara obinrin. Eseun gan an ni

Ewe urere wa kaakiri...e beere lowo awon agbalagba tabi awon to ti pe nidi iwosiwosi. Ti n ba ri, ma ba yin ya aworan re.
Re: .. by Ade231(m): 1:37pm On Mar 03, 2016
healthFirst:
IKEDE PATAKI:

Ao gbe eto yi lo sori whatsapp group nitori awon opuro ti won n fowo soya lori ayederu ogun lori ikanni yi ki o le seese fun wa lati ma yo won kuro bi a ba ti ri won. Ogun sise ati lilo kii se inkan ti o ye ki a ma pa iro fun awon eeyan. Bi oogun o ba pe tabi o je ayederu, o lewu pupo fun enikeni to ba je iru ogun be. Ao de fe ki awon epo to wa laarin alikama ba oruko wa je.

E dara po mon wa lori whatsapp number yi 08148398067, tabi ki e fi number yin sile nibi, ki a le add yin sinu group na. Iwulo Ewe Ati Egbo ni oruko group na. E dara po mon wa fun ojulowo oogun ati idaabobo lowo awon Oloogun eke.

Baba health ESE pupo polo yin koni daru o dara pupo big ese ni ki ada whatsapp group smile oda pupo koda semi gan nife so number mi niyi 08082819708 tabi 08032537603 ESE gan yio ma ju se fun wa o.
Re: .. by akingbemi(m): 4:12pm On Mar 03, 2016
kadunasouth:
ISOYE TA NFI RANTI GBOGBO NKAN
Akuko to batobi dada ao tu iye abiya re ti apa otun ao lomo eyo atare meta tapa osi eyo atare meta ao fi tapa otun sin gbere meta si abiya otun tapa osi si abiya osi ti aba gbagbe nkan kan ao fi apa lu apawa lemeta bi adie pelu ofore ao ranti nkan nan lese kese odaju
OFORE
Bi adie bafi apalu apa pipi iyere aso 3times kin ranti nkan bayi bayi opari.
Fun ibere kansimi lori email mi

ejo baba se gbogbo iye abiya akuku ni tabi melo ni? ati pe bawo ni eniyan tin fi apa lu apa re sir?
Re: .. by akingbemi(m): 6:24pm On Mar 03, 2016
[quote author=dominicson post=36820706]

Beeni![/quote ejo ebami se ayewo temi
Re: .. by kadunasouth(m): 6:49pm On Mar 03, 2016
akingbemi:

ejo baba se gbogbo iye abiya akuku ni tabi melo ni? ati pe bawo ni eniyan tin fi apa lu apa re sir?

Iye die die lema tu, gege bi adie mase fi apalu apare to bafeko tabi tobafe fo gege be leyin na mase niwaba, eo ka apa abiya yin soke eo tun da pada lemeta eo ranti nkanna lese kese

3 Likes 1 Share

Re: .. by Lero70: 2:32am On Mar 04, 2016
Ifankaleluya:

IWO ATI TANI KI KEKE PA MO LENU? O MA TI E G*(D*FT),NIBO LO TI RI BABALAWO GIDI KAN TI N TA IWE-OGUN? SE EMI WA NINU OLOOGUN TI E JO NSE OGUN EWE-OYO,ISU DAN-DAN ATI ATA IJOSI NI? SE BI MO TI E CHALLENGE E NI WHTSAPP PE KO KI(CITE) ESE IFA KAN PERE FUN MI SUGBON TI O KO RI ESI KANKAN FO? ABI OTI GBAGBE WIPE O JEWO(CONFESSED) FUN MI WIPE O KIN N SE BABALAWO? IWO ATI AWON WO NI YIO GBA ALEJO ESU? NJE O TI E MO N TI WON NPE NI ESU GAN? NJE O TI E NI EPE KAN TI N SISE LOWO NI? MO SE TAN LATI BA O GBE PEREGI IJA KA NA,TI N O SI FI EJO RE SUN IJO-ERIWO WIPE O N FI ORUKO AWON BABALAWO LU JIBITI LORI ERO AYE LUJARA. EMI TI TAYO ENI TI YIO SESE MA SA IFA LORI-ESU KIN TO BA ENIYAN JA, TI MO BA FI GBOLOHUN IFA LASAN RANSE SI OO,OO TO BE KO KA KI ORUN(N*CK) O MA WO EE.
SE PELE-PELE OO BABALAWO NI EMI,KIISE BABA-ALARIWO.
alagba Olaifa atipe baba healtfirst ebajebure awoolugbebe keefi suuru gboraayin lagboye keesimaaranti oro eyinagba teewipe awooniitojuogberi dafanu laelae atipe eteawo erin ogberi nio torinaa efi suuru yanju gbogbo ohuntoba jebii ede-aiyede laarin yino isese a gbewa o.
Re: .. by Nobody: 2:49am On Mar 04, 2016
IKA-IWORI

Ika fee,
Iwori fee,
Awo Oba lo difa fun Oba
Oba n sunkun, apa oun o kaye,
Ebo ni won ni ko wa se
O gbebo, O rubo
Apa Oba ni yio kaa
Adabi boruka o ba ka 'wo
Apa Oba ni yio kaaa.

1 Like

Re: .. by Lero70: 2:56am On Mar 04, 2016
[quote author=Ifankaleluya post=43423633]Mo dupe pupo lowo gbogbo eyin ti e pe ati eyin ti e ba mi soro lori whatsapp to fi de odo eyin ti e lo e-mail. E seun mo dupe.

Emi ko dede ma ba enikeni ja,sugbon o semi ni aanu nigbati mo ri awon obayeje kan ti won n fi dudu pe fun-fun fun awon eniyan loje ki oro fe se bi ija nitori emi ko fe ibi ti ko ba si otito.
Nigbati a si bawon soro ni tutu,won ba bere si leri ogun,to je wipe won o ni ogun eyo-kan ti n sise lowo gan. Koda ti won ba tie ni gan,awa ti tayo eni ti enikeni le ma leri ogun si,notori wipe ifa ni kaka ki aye o ja ko pare,igbin ni a mu to,Ibi won ka sai sun siwon lorun,ibi won.

IFA NI KOKO IGI NI O BERE OJO,ADIFA FUN EJO N BE LORUN TI SE OMO-AWISUNKUN,IFA NI IRE LO BA MO SE. MA SE LOO,IKA LO BA MO SE, MA SE LO,AT'ORE AT'KA OKAN KAN KIIGBE.

Gbogbo eleyi to ba se ni wa je ere re...!

ela-boru, ela-boye, ela-bosise.[/quote
alagba Olaifa eseun pupo esikuafomoniyan se yio maa ju yin se o ase. Modupe fun esi e-mail mi akoko ti efiranse, sugbon awon ibeere bii melo kanlesile timobeere ninu e-mail keji timofi ranse siiyin eedahun sii, looto momope owoyin ha, sugbon ejowo ewa aaye lati fesi si ibeere mi. Esee aseti konii bayi o.
Re: .. by Lero70: 3:33am On Mar 04, 2016
Ifankaleluya:
IFA-ISOYE

ODIDI OROGBO KAN, ODIDI ATAARE KAN, OBI-ABATA OLOJU MERIN KAN, EJA-ABORI KAN, EWE-ONIYEMIYE,EWE-EERAN ATI EWE ATORI. AO GUN PAPO TI YIO KUN NA DADA BI AGUNMU,AO WA TE NI ODU-IFA OLOGBON-MEJI,AO WA PE IFA RE SI

IFA RE: sabe lawo sade, asa lawo asagede,arara abori patoki awo ile orunmila, lodifa fun orunmila nigba ti baba nsawo ti ko ni iye ninu, ifa ni to ba bi ise tohun(to ba se bi ise temi lagbaja omo lagbaja ba ni. Ni e ma lo larin yen) ba ni, ifa ni iye-orogbo kiiku mo orogbo ninu ka je ko ma le koro,iye obi kiiku mo obi ninu ka so ko ma le yan,iye ataare kiiku mo ataare ninu ka je ko mo le ta ni lenu, eyi ti mo jaja gbagbe eja loni ko ja simi ninu,eeran loni kin ma ranti, atori loni ko to nikun mi worowo,ipanan merindinlogun ni ewe-oniyemiye ma n ni,gbogbo ara ni fi so. Ologbon-meji fun mi ni iye temi kin gbon sara-sara. AO MA FI MU EKO-TUN DIE-DIE.
NOTE
mo fi ifa yi sile fun iwulo awon eniyan ni. Ti iwo ti o n ta iwe ba ko sori iwe-re,lagbara lowo eledumare wa ri ija awon eleye. Mo fi odu-mererindinlogun bura.

FUN IMONRAN TABI OHUNKOHUN, E KAN SI WA LARI ifankaleluya@gmail.com
Ela boru, Ela boye, Ela bo sise.
alagba Olaifa ejowo se ewe iyeye naani wanton npe ni oniyemiye?
Atipe bawo ni ase ntefa ologbonmeji? Esee ifa o gbeyin o.
Re: .. by Zenlife: 10:31am On Mar 04, 2016
Ifankaleluya:

IWO ATI TANI KI KEKE PA MO LENU? O MA TI E G*(D*FT),NIBO LO TI RI BABALAWO GIDI KAN TI N TA IWE-OGUN? SE EMI WA NINU OLOOGUN TI E JO NSE OGUN EWE-OYO,ISU DAN-DAN ATI ATA IJOSI NI? SE BI MO TI E CHALLENGE E NI WHTSAPP PE KO KI(CITE) ESE IFA KAN PERE FUN MI SUGBON TI O KO RI ESI KANKAN FO? ABI OTI GBAGBE WIPE O JEWO(CONFESSED) FUN MI WIPE O KIN N SE BABALAWO? IWO ATI AWON WO NI YIO GBA ALEJO ESU? NJE O TI E MO N TI WON NPE NI ESU GAN? NJE O TI E NI EPE KAN TI N SISE LOWO NI? MO SE TAN LATI BA O GBE PEREGI IJA KA NA,TI N O SI FI EJO RE SUN IJO-ERIWO WIPE O N FI ORUKO AWON BABALAWO LU JIBITI LORI ERO AYE LUJARA. EMI TI TAYO ENI TI YIO SESE MA SA IFA LORI-ESU KIN TO BA ENIYAN JA, TI MO BA FI GBOLOHUN IFA LASAN RANSE SI OO,OO TO BE KO KA KI ORUN(N*CK) O MA WO EE.
SE PELE-PELE OO BABALAWO NI EMI,KIISE BABA-ALARIWO.

Healthfirst, is it true or a false accusation by Ogbeni Ifankaleluya that you confessed to him that you are not a babalawo? If it is true, you sure fooled us on this thread and is unfair, since most if not all perceived you as a babalawo because you presented yourself as such, moreso with the book sales, quotes, posts, etc.

Besides, you never debunked the accusations made by Ogbeni Ifankaleluya (''ABI OTI GBAGBE WIPE O JEWO(CONFESSED) FUN MI WIPE O KIN N SE BABALAWO?'').

Hmmmm... To each his own.

God is Supreme.
Re: .. by Ifankaleluya: 10:48am On Mar 04, 2016
Ifa ni; Adaseke jiyan won o lohun re lenu, adifafun Orunmila nijo ti asude suleke nbaye e je, ebo won ni ose,o gbebo nibe o si sebo,o gba akasu esu o si tu,asude suleke jowo ma ba aye yi je fun mi, asude suleke. Lagbara lowo Eledumare, aye gbogbo wa ko ni baje ooooo. Ase!

2 Likes

Re: .. by Ifankaleluya: 11:00am On Mar 04, 2016
Lero70:

alagba Olaifa ejowo se ewe iyeye naani wanton npe ni oniyemiye?
Atipe bawo ni ase ntefa ologbonmeji? Esee ifa o gbeyin o.

Rara oooo, ewe oniyemiye yato si ewe-iyeye ooo. Awon miran tun ma n pe ni ewe-oniyesoye. Inu-omi ni ewe yi saba ma n wa tabi ibi ti o ba tutu. Ti e ba kan ewe yi si meji e ma ri iho keke merindinlogun ninu ewe yen. E bere lowo awon elew-omo,ewe yen wa daadaa.

Odu ologbon-meji ni a n pe ni oturupon meji.
Bayi ni won se ma n te;
|| ||
|| ||
| |
|| ||

ela-boru, ela-boye, ela-bosise.

1 Like

Re: .. by Ifankaleluya: 11:03am On Mar 04, 2016
Lero70:

alagba Olaifa ejowo se ewe iyeye naani wanton npe ni oniyemiye?
Atipe bawo ni ase ntefa ologbonmeji? Esee ifa o gbeyin o.

Rara oooo, ewe oniyemiye yato si ewe-iyeye ooo. Awon miran tun ma n pe ni ewe-oniyesoye. Inu-omi ni ewe yi saba ma n wa tabi ibi ti o ba tutu. Ti e ba kan ewe yi si meji e ma ri iho keke merindinlogun ninu ewe yen. E bere lowo awon elew-omo,ewe yen wa daadaa.

Odu ologbon-meji ni a n pe ni oturupon meji.
Bayi ni won se ma n te;
|| ||
|| ||
| |
|| ||

ela-boru, ela-boye, ela-bosise.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 11:43am On Mar 04, 2016
Zenlife:

Healthfirst, is it true or a false accusation by Ogbeni Ifankaleluya that you confessed to him that you are not a babalawo? If it is true, you sure fooled us on this thread and is unfair, since most if not all perceived you as a babalawo because you presented yourself as such, moreso with the book sales, quotes, posts, etc.

Besides, you never debunked the accusations made by Ogbeni Ifankaleluya (''ABI OTI GBAGBE WIPE O JEWO(CONFESSED) FUN MI WIPE O KIN N SE BABALAWO?'').

Hmmmm... To each his own.

God is Supreme.

I would have loved if IFANKALELUYAH can produce the details of his whatsapp chat with baba Healthfirst here and now. Very simple, he should just copy and paste here. Sometimes, people quote you when you never said anything. ADAKE MA SORO, KIN LE MO TI O LE SE?
Re: .. by Zenlife: 12:16pm On Mar 04, 2016
Titiloye247:

I would have loved if IFANKALELUYAH can produce the details of his whatsapp chat with baba Healthfirst here and now. Very simple, he should just copy and paste here. Sometimes, people quote you when you never said anything. ADAKE MA SORO, KIN LE MO TI O LE SE?

True, and i agree with your premise that... ''IFANKALELUYAH can produce the details of his whatsapp chat with baba Healthfirst here and now. Very simple, he should just copy and paste here.'' That will surely shed light to the truth, and if he is worth his salt as professed, it is the honorable thing to do.

It is important the air is cleared between them two and the 'whatsapp chat' excerpt will clear it. At least since Ifa doesn't lie, the true disciples shouldn't either.

In addition i believe patrons of this thread and its 'sacred' culture shouldn't be deceived and exploited emotionally, physically, spiritually and financially or be put in a situation to question or be weary.

For the sake of our heritage and culture and the sacred Ifa, if the thread cannot function without deceit in any form, including the posting of false, incomplete medicinal recipes or formulas, which could be injurious or harm its users, i move the motion that the Moderators should close the thread permanently.

IFA SHOULD NOT BE ABUSED BY NOBODY!!!
Re: .. by Ifankaleluya: 1:20pm On Mar 04, 2016

I've vowed not 2 write on this issue again cos some pple av spoke 2 m 2 let it go. But, anytime i observed unbalanced on this issue my emotion always moved.

I do not av any personal issue with him(healthfirst) so far i w nt ask 4 a share 4rm d money he is collecting 4rm pple. All my accusation 2 him was 4 d benefit of users of this thread. Though,he owns d thread,but,nt dt he can collect money from users of this thread under d false pretence dt he is an ifa-priest nd he w help dem consult ifa.

I'm very sure he did not known dt am d one dt challenged him on d social network called whatspp until I respond 2 his comment concerning I nd one Onile-iro called himself Onile-ifa. It was after I challenged him nd found dt he was not an ifa-priest i registered nd began 2 post on this thread. This is our last conversation''I WAS BORN INTO IT BUT SINCE AV NT ENTERED GBODU THAT IS WHY I CAN NOT CALLED MYSELF BABALAWO'' then I respond ''YOU WAS NOT BORN INTO IT COS D EXCUSED THAT YOU AV NOT ENTERED IGBODU DOES NOT RESTRAIN YOU 2 CITE A VERSE ND CONVINCED M THAT U'A REAL BABALAWO. i said gentleman go away..! He does'nt even know how 2 respond when an ifa-priest is greeting! I'm not here 2 spoil his business,but,he shld b more truthful.
Re: .. by Ifankaleluya: 1:36pm On Mar 04, 2016
Some pple av tried 2 confirm if truly am an ifa-priest....but,so far I am one,I easily convinced them, if not they would av come 2 post on this thread to accused me.
Even lately yst9t....som1 asked m what Okanran-odi says nd when I respond,I asked him if am lying or not,nd he said I was not lying that was wht araba-oluawo of osogbo told him. Abt 2 days ago,someone asked m abt Obara-bogbe,nd so many things like that. If u ask m wht I kno,,,I'l tell u,nd If I dnt kno it,i'l tell d truth.
Ifa kii-puro,Opele kii-seke babalawo ni o ya ni gbo ohun ti ifa n so. Iranse lo si gbo-ifa ju,ohun to ba ru ni loju,a ma n fi iranse bere ni.

Ela-boru, ela-boye, ela-bosise.

1 Like 1 Share

(1) (2) (3) ... (57) (58) (59) (60) (61) (62) (63) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 116
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.