Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,386 members, 7,958,082 topics. Date: Wednesday, 25 September 2024 at 08:33 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1842276 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (60) (61) (62) (63) (64) (65) (66) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Nobody: 10:38pm On Mar 08, 2016 |
| Se Ogbe-Ogunda ni yen sa ? | 1 Like
|
Re: .. by Nobody: 10:39pm On Mar 08, 2016 |
c |
Re: .. by wale259(m): 6:31am On Mar 09, 2016 |
Baba e jo se ewedu na ni Ewe-ooyo ati wipe se a le fi agbon yen se sara fun onibara tabi awon agbalagba ta ba ri awon omo kekere ni aye lewu baba.wiwe ose yi nigbagbo? Ifankaleluya: |
Re: .. by wale259(m): 6:38am On Mar 09, 2016 |
Eku ise lopolopo,sugbon mofe alaye lori ise yi baba,se iwonba ose ta le lo tan ni a ma fi po omi agbon yi ni a bi ale se ose na sile pupo ati wipe se inu omi agbon ni a ma so oguna na si ka to lo lori olo abi omi lasan.ma dupe te ba dami loun awon ibere wonyi. Ifankaleluya: |
Re: .. by wale259(m): 8:42am On Mar 09, 2016 |
Baba e jowo e fun mi ni ifa isoye,e fi sanu fun mi....email me re waleadewale2002@yahoo.com Ifankaleluya: |
Re: .. by wale259(m): 8:46am On Mar 09, 2016 |
Baba e ma fun wa ni awon ise tan ki awa na le ma sa wo ko le ri bo se ye kori fun wa ni ti dada. Ifankaleluya: 1 Like |
Re: .. by wale259(m): 9:13am On Mar 09, 2016 |
Baba ifankaleluya,e ma se be...nitori ta ba ni ka diju keni buruku koja eni rere akoja pelu ati wipe agba o kogbon...emi nife si mo si ti fi email ranse si yin lori e Ifankaleluya: |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:29am On Mar 09, 2016 |
skypeme: BEE NI, O KARE OKUNRIN YI. OGBE'YONU NIYEN. E LE FIAGBON YEN SE SARA FUN ENIKENI. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:32am On Mar 09, 2016 |
wale259: E LE PO KO PO DADA. SUGBON KIISE OHUN TI AO MA WE NIGBA GBOGBO OO. BI EEKAN LOSU-META NI. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:54am On Mar 09, 2016 |
wale259: IFA-ISOYE TI O MA N JE GBOGBO OHUN TA BA KA KO DURO SIKUN WA LOKOKAN. E LO RE WA IGBA-AHUN, ATI IKARA-HUN IGBIN. AO JO MEJEEJI PAPO, AO LO KO NI ATAARE NINU OO AO WA TE NI IFA OFUN-SE (OFUN LOWO-OTUN ATI OSE LOWO-OSI) NI A N PE BAYEN AO WA PE IFA RE SI BAYI MO DE IBI WON TI N MUMI OGBON(WISDOM) MO BA WON MU MO DE IBI WON TI N GBAMON-RAN IMO MO BA WON GBA ADIFA FUN ORUNMILA NIJO TI N LORE KO MO-IFA, TI N LORE KO OGUN MO-OGUN WON NI BAWO NI O SE NI GBAGBE IFA NI EEWO-ORISA IGBIN KII-FA KO GBAGBE IKARA-HUN BEENI AHUN KIIFA KO GBAGBE IGBA-EYIN RE WON NI TI O BA GBAGBE BAWO NI O SE NI WO'NU ARA WON ORUNMILA NI EEWO ORISA IGBIN KII-FA KO WO'NU AHUN BEENI AHUN KIIFA KO WO'NU IGBIN OFUN-SE FUN MI NIYE TEMI KI N MU SAWO. AO MA FI MU EKO-TUTU. BI WON TI MA N SE NIYEN, E LE TUN BERE LOWO BABALAWO MIRAN TI O BA MO IFA YEN. ELA-BORU, ELA-BOYE, ELA-BOSISE. 3 Likes 1 Share |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:56am On Mar 09, 2016 |
wale259: BEE NI. |
Re: .. by ALIUDAVID: 11:17am On Mar 09, 2016 |
akingbemi: Ele lo ki ori sa ti dan nii, sugbo abe lodaju |
Re: .. by Nobody: 12:18pm On Mar 09, 2016 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 12:55pm On Mar 09, 2016 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 12:59pm On Mar 09, 2016 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 1:30pm On Mar 09, 2016 |
x 1 Like |
Re: .. by wale259(m): 11:04pm On Mar 09, 2016 |
E se baba,Eledumare oni fi yin sile nigba kankan...se mo le lo fun omo mi na bi omo odun meta Ifankaleluya: |
Re: .. by skamo74: 6:38am On Mar 10, 2016 |
Baba kini Ogun ISETO ( Diabetes) |
Re: .. by Ayomidegbenga1(m): 7:24am On Mar 10, 2016 |
Ifankaleluya: Baba ewe a maa je fun yin, ise Tailor ni mo nse e jowo mo need ogun ti maa fi ni awon omo ise(apprentice) E see pupo 1 Like |
Re: .. by Ayokunumi24(f): 8:21am On Mar 10, 2016 |
Ayokunumi24:ejowo e dami loun ibere mi olorun a se ninu ise tiyin na. |
Re: .. by wale259(m): 11:48am On Mar 10, 2016 |
Baba ifankaleluya,ta ba te ni ifa yen tan,se. Ko ni gbolohun kankan,se o ti di wiwe ni yen,nigba gbogbo abi? wale259: |
Re: .. by Oluokunoluwole: 2:40pm On Mar 10, 2016 |
Ifankaleluya:baba kilode ti mo email yin ti e o funmi lesi ohun ti mo bere fun,mobeyin e damilohun awon nkan ti mo bere fun ifa agbeyin oo |
Re: .. by Oluokunoluwole: 3:16pm On Mar 10, 2016 |
Ifankaleluya: 1 Like |
Re: .. by Oluokunoluwole: 4:46pm On Mar 10, 2016 |
Ifankaleluya: |
Re: .. by Oluokunoluwole: 4:50pm On Mar 10, 2016 |
Ifankaleluya: |
Re: .. by Ifankaleluya: 6:25pm On Mar 10, 2016 |
wale259: BEE NI. |
Re: .. by Ifankaleluya: 6:26pm On Mar 10, 2016 |
wale259: OMO YEN SI KERE OO. |
Re: .. by Ifankaleluya: 6:28pm On Mar 10, 2016 |
Oluokunoluwole: E MA BINU MESSAGE PO LORI E-MAIL WA NI. |
Re: .. by Ifankaleluya: 6:39pm On Mar 10, 2016 |
Ifa ni, Ọtọtọtọ, ọrọrọrọ, ọtọtọ laa jẹpa. Ọtọtọ nla jẹ imumi. Ohun tori tori, ohun tore tore nlaa fọba makin nile Iranje, ko ba le fi ohun to ri to re ta ni lọrẹ a dia fun Ogotẹẹrẹ ẹyi ti n gbogun lọ Ẹhinwọran. Ogotẹẹrẹ lorukọ a n poko. Ẹhinwọran lorukọ a n pobo. Eewọ oriṣa oko ii jagun ilobo ko sanwọ-o. Lagbara lowo Eledumare ao ni sanwo(lack) ohun rere. eewo-orisa ni, oko kii jagun ilobo ko sanwọ. Ela-boru, Ela-boye, Ela-bosise. 2 Likes |
Re: .. by kuddus: 7:56pm On Mar 10, 2016 |
ejo e fun wa ni ero abilu healthFirst:ejo e fun wa ni ero abilu 1 Like |
Re: .. by kuddus: 7:57pm On Mar 10, 2016 |
ejo nitori olohun |
Re: .. by Ifankaleluya: 9:42pm On Mar 10, 2016 |
kuddus: ERO-ABILU PE ORISI-RISI.....ADURA MI NI WIPE KI OLORUN MA JE KI E BO SI OWO(HAND) BABALAWO TI O NI EKO(KNOWLEDGE) DAADA. TORI KIN-NI KAN WA TI A N PE NI AKOFA(NEUTRALISES OF CHARMS OR MEDICINE IN SOMEONE's BODY), KINNI YI NI BABALAWO TO BA LEKO DAADA MA N KOKO SE LATI FI BA OGUN TO WA LARA ENIYAN JE TO BA FE BA ENIYAN JA. AASAN(gbolohun) RE WA, WON SI MA N SA OMIRAN LORI ESU PELU AWON EWE-IFA KAN. SUGBON JU GBOGBO E LO, TI E BA TI RI OMO-OWU KI E KAN SI MI. KIISE OGUN TI MO LE FI SILE LORI FANRAN YI. 2 Likes |
(1) (2) (3) ... (60) (61) (62) (63) (64) (65) (66) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 51 |