Remii's Posts
Nairaland Forum › Remii's Profile › Remii's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 ... 119 120 121 122 123 124 125 126 127 (of 164 pages)
I seeeeeeeeee! @topic,: |
tubabie:Tu ati Ilorin, o de loo kin se mesu jamba, se "UI" of Ilorin loo lo ni. |
^^^^ FBS, O ya tun ibeere re beere, maa gbiyan ati dahun ti o ba moo. Emi naa feran Abefe jengbetiele, mo de ni almost gbogbo CD re lati ori PHD beatle, iboosi NEPA ati beebeelo. |
IFELEKE:Aworawo e wo loo tun ri in the making? |
Countries, States and the rest are created on administrative conveniences not on tribes or languages, that is why Awolowo regarded Nigeria as a geographical expression and not a Nation. Imesi Ile is in Osun, Oke Imesi is Ekiti, Yorubas are in Benin Republic and they have close ties with people around Ilaro and Idi Iroko, Nigeria. Naturally Offa people of Kwara would love to be in Osun State since they have closer cultural ties than to Ilorin. Northern Nigeria and Southern Niger are inhabited by Hausa/Fulani and they attend each others cultural ceremonies, etc etc |
platinumnk used to have (f) on her profile now (m), lol |
pass, she/he is transsexual, was a girl two months ago, |
tubabie:Yoruba mi mehe ko ni yen? O ya, dayokanu soro ponbele ka mo n too wi. |
dayokanu:Ngbo tubabie, woo se fun dayokanu oo, rflamao. |
Sisi Ologe eeeeeeeeeeeeeee, Iyangbalife kii ise obinrin o, shine your eyes, mo wi temi oo. Ki oro e ma dabi eniti ode lowo ale to so wipe oun je abibu, lol. |
@tu, kilo npa e lerin @topsy25, ai dupe ara eni, @Ife, oungbe ni yen jare, adupe emi ti nrehin osu bo diedie, ki Olorun gba adura gbogbo wa Amin. |
[quote author=rita@NL link=topic=308045.msg4329278#msg4329278 date=1249924581]Nt evry guy dat smokes or weed or drink are bad,as a matter of fact most of them are shy and down-to-earth. so dey can find nt only a lady but a good lady.[/quote]are you talking from experience? |
You are welcome, thanks for your understanding too. |
Ni ile Yoruba, oun to yee ka fi se oge tabi ako laa fi se oge tabi ako, aso ewon ko ye eni, ibaa je lace ni won fi ran. oun to yeni lo yeni, okun orun ko ye adie. |
Gbogbo ile see wa, @tu, do you think that your poster is funny, I beg to differ, oun ye faga laa fii se faga, i jus think oooo!!!!!!!!!!! ![]() |
mikeansy:Atomic energy release is called radiation which can cause cancer if one is exposed to it enough. that is the main reason for non usage of nuclear weapons. atomic energy agencies regulates use and operation of radiation generating equipment and activities all over the world, these includes medical X ray, chemoteraphy, etc. It is possible that as part of control and mitigation of effect of emission the agency have fund for cancer management so her visit maybe relevant. |
jeki mba dayokanu pari, Beni kan gba mi l'eti ma do'bale fun aso ija mi yaa, mi ti ya, mi ti ya, mi ti ya, aso ija mi ti gbo. (e ma confirm e o) |
Ma worry o si maa ye e se kadankada. |
To je wipe o ma gravity nka to get ara e involve ni, tufikwa loo ba pariwo, shikena. |
The children said he left that instruction, it is largely wrong they should have disobeyed the order if they themselves have strong understanding of Islamic rules on burial. Even right now on AIT the burial is going on live, with coffin and in cemented pit covered with slabs. But only Allah has the final decision on variance from rules and consequences |
@IFELEKE, o ba mi lara mu lati se alarina fun toposimeedogbon, sugbon, o so wipe oun ko fe iranlowo, imu elede ti wo ogba. ka ma wo ibi idan orita nlo, @arjent, ewo lewo? |
topsy25:Mo gbo ooo, Ko i tii mu eru o ti nta fun Ado, |
topsy25:Eniyan tan ara e bi iya Jimoh, o de Mosalasi oja oni oun de ile omo oun. |
dayokanu: Krayola2:I think "pdu" is a typo, he intended to write "odu" refering to full fledge grasscutter, oya (pronunced - or yer). in the bold is "Telling lies to get public recognision would lead to disgrace eventually. This is a Yoruba trend I do not think any level of Yoruba displayed here can be said to be "bloody" showoff. |
tubabie:O se jare, tubabie, ma gbadun ara e, je ki a pe oruko e, Olorun ko ni fie pamo. Eniyan gbogbo eku gbengbele, lati Qatar nibi titi to fi de Ilu Obama, US ti A, ilu iya Charles, London titi Niaja ti wa ntiwa. |
IFELEKE:Tubabie, Ooooori mi wu ooooooo!!!!! |
@ife, mo mo wipe okan re si wa lara tu, so, hope si wa laaye. die die imu elede yoo wo ogba, se mo jana? |
topsy25:Iwo fi won sile, ifeleke nlo theory "ko je n'gbadun l'obinrin gb'ore e fun ni, |
E kaaro o gbogbo ile, ore wa toposiimeedogbon, boo ni nkan, opin ose eyi ni odun ipari awe ramadan fun awa musulumi, a o se odun ayo ooo. |
chamotex:iru modewetor wo leyi, ina njo on la gutter, wow! |
@gator, my post could be summarized, no need to fight imaginary war over internet, we are here to have fun. |
Tu, pweety, toyin et al, e simi gbogbo eyi, ko si ntaa gba ninu ija ori afefe. Ere lo ye ka se nibi, a o ba tija wao. As KSA once sang: Kini kita kita lara kekete taa gun tio sare, agun fese wole atannifogun eranko. |
1 2 3 4 5 6 7 8 ... 119 120 121 122 123 124 125 126 127 (of 164 pages)




Bee, oro ti ani ki baba ma gbo, baba ni o pari e