Tevez83839's Posts
Nairaland Forum › Tevez83839's Profile › Tevez83839's Posts
1 (of 1 pages)
Hello baba Ifankaleluyah |
Edakun eranmilowo awure togbona |
Edakun odara efunmi ni awure togbona ,todaju tojepe maa fi maa ri owo titi mafi se iyen .ki e si funmi ni number yin pelu adress yi |
Edakun eranmilowo baba Ifakanlelluyah tabi healthfirst tabi kadunasouth....artist nimi pelu paintersugbon ise daagun funmi .kosise,kosowo eramilowo ,mo fe ma gba contract nlla nla .ise kekeere owo nla,ki emi naa je eyan lawujo ati olowo laarin egbe painter ati ore ilu mi.toori Oorun ni mo ma n sunkale ni shop mi .edakun e seeto awure tabi osole tutu koda kii ba se eyi ti maa rimole ni shop mi .kin sati lowo lowo ,kin jeeyan laipe edakun08162736520 |
Hello |
Se osise ti ti ewe onikutukutu nio (ewe ata) |
Koda bo se eyi tii maa rimole ninu shop pls help |
Ejowo eranmilowo edakun ...mo fe ako awure aje bii idan ni kiakia |
Healthfirst or KadunaSouth Am An Artist,house painter and signwritter but i have had a shop 4 a while back .so since i have got shop i often sleep ni because it's shopping complex no work no money ,so am fed of of this even am timid 4 being sleeping while i suppose to be doing work. So 4 this above reasons i want you to help me ....so i can't prescribe any particular charm 4 u to tell me But in the situation as this U know the charm that will relevant and serve as remedy 4 my problem.... So i want many customer to b grant me Big Big contract and pay good money 4 me so dat within a few days i may hav had large amounts of money Even is because of my parents helps me in feeding ..pls sir perhaps you will tell me to do soap or put something under ground inside my shop or whatever my situation deserves or Big Awure Because i want become big Famous amongst painter in my town and including D towns surrounded .pls. ................Baba edakun esanu mi emi naa fee di olowo nipa ise mi .edakun ako awure ti ko ni ni repercussion rara koda lojo iwaju gan.......mo fee je eeyan gbese po bukata si poju edakun.......e text pada ni yooba ki n ke ba clear dada . |
Kola belieive pls.flash me i wnt discuss wd u |
Baba Ejo o |
Edakun eyin babawa monife arabinrin kan ni mosi fee fe sile sugbon oni ohun ko le femi edakun mo mo oruko re ati ti baba re .ko ki se omo timo le fun ni afunje .,sugbon iru ise wo nimole sasi |
Respect.............baba kadunasouth....gbogbo ohun tieso ni mo gbo...edakun mo fe oso aworo ti maa se si shop mi ki customer lee maa yawa bi omi....atipe mo ti n gbiyanju lati add yin suggbon ko lo ejowo mofi Orunmila beyin e add me adebayoyusuff41@gmail.com...,,,, leyinaa ,,eyi agbalagba sope die omokunrin ko toooooo .... Lotito owo lanwa sugbon awon firanfiran wa .tori na .efunwa ni oruka .okigbe fun idabobo.lasan tori ija le besile tojepe eeyan gan ko dasi tiwon a maa kanra mo gbogbo eniyan sugbon ti aba fi oruka okigbe ada yi sowo ..... A ko fi ni fi ori ko oro taomowo mese...edakun ...a o kin se onijangbon oooo.. Sugbon fun idaboobo |
Edakun nipa oso aworo ...shop mi fee dada .e salaye funmi .nipa oso aworo |
Edakun nipa oso aworo ...shop mi fee dada .e salaye funmi |
Etundakun...mo notice pe ogun kii sise lara mi .eyi ti won ba sefunmi ati eyi ti mo ba se.toripe ise kadunasouth meji ni motise .ti mio ri iyato.....oni eyin adie oojo.ati ori ako alangba.......2 pelu koro isin,koro agbalumo.......ko sise edakun iru ajeegun wo ni mo le se ti ara mi yoo fi ma pick ise |
E se babawa kaduna south .agba yin yoo dale.eku agbaale wa .edakun .moti n sise lati bi osu meji seyin ni shop ti mo sese gba tori inu osu kokanla odun tokoja ni mo se freedom Artist =ayaworan. Sugbon kaka ki n maata oorun ni emi ati awon omo-ise mi n fi gbgbo igba sun ni complex ti mo gba...edakun .edakun aajo wo/ ogun wo ni mo le rimole tabi fiko oke shop ni enu ona ti awon customer yoo fi maa yaa odo mi tiwon yoo si ma gbe contract nlanla ati ise miran .ti odo mi yoo ma kun fofo fun customer ..edakun efumi ni ise yen.tabi ise miran ti erope molese ti owo yoo fi de laarin bi osu kan ...tori owo ti mo fi gba shop yen gan mo ya ni .mio deti dapada ,won den damilamu ...so emi naa fee di olowo laarin osukan .nidi ise mi.kin popular....,..,,.emi tun wope tobaje bii turari gbogbo awa ti awa ni complex laamaa ma je anfaani re ....sugbon ti eminikan yoo ma ta witiwiti pelu customer pelu owo nlanla edakun ...loje kin sope boya ririmole tabi fifiko.......soke...sugbon Olorun funyin ni imo gan-an .emi kan so temini ..eyi teebamope molese .eso funmi maase .ise yi ti poju ...mo fe joro edakun................... Babawa kadunasouth:............ 08162736520 |
Edakun baba ema gbagbe agbo yen |
Ejo babawa kadunasouth.agbo tee sope oma fo idoti oko jade ti yoo fi pada saaye re ti koni sunki mo.edakun .mofi Olorun beyin |
Edakun babawa kadunasouth .Agbo tee sope ema bami fi sita lori oko mi to n sunki teeni gbogbo idoti yen akuro ti oko mi yoo si pada si aaye re .edakun awon ore mi n fimi se yeye pe oko mi kere sitawon |
Baba edakun e add mi ni whatxapp 08162736520..eko dami lohun ni.. Atipe ti oko okunrin ba kere baba health first soro lorire won ni ogun re todaju awon koni fe post e pe eyi to daju wa torii ayederu poni ita 08162736520.edakun titi ise shop yen eranmilowo nipae |
Edakun baba oluyaworan nimi .lati igba timo ti si shop kosi oja edakun mofe maa ta gba ise nlanla .i tomode tagba ma gbe ise wa funmi ,ki ero ma da lodomi..boya eyi ti mo le se si shop ti maa rimole tabi gbeko tabi eyikeyi edakun .moje gbese mofee sanwo .monilo iranlowo yin ooo.kadunasouth ibao |
Ibaoooooo Dis is my number 08162736520 whatsapp me pls....kaadunasouth or healthfirst adebayoyusuff41@gmail.com |
Dis is my number |
Healthfirst/kadunasouth . Edakun oogun wo ni mo le ri mo inu shop ki customer le maa wa .miota ..oorun la n sun..emi ati awon omo ise mi..mo fe ki shop mi dabi oja . |
[color=#770077][/color .ejowo e add me ni whatsapp .ejowo..ki ale baa maa soro daada 08162736520 |
Edakun shop yen fee die .e koo fun mi boya mo le see. Tabi ejowo e add me 08162736520.EDAKUN OJA KO WA |
Baba edakun.ise ayaworan ni mo yan-an laayo. Sugbon ni shop mi oja ko yaa daada oorun ni mo n sun edakun kini ogun ti mo le ri mo inu shop bi aworo todaju ti customer fi maa wa pupo...boya eyi ti eyan ma gbe ile fun Atipe se ise yi daju ( ao gbe ile sinu shop ,ao da iyo sibe ,aote ni eji ogbe ao wa fi pandoro si inu ile yii .ao da iyo lee lori to maa bo pandoro yii ,ao wa da aso funfun boo lori ao wa ro iyepe lee lori ) se odaju tabi afikun .tabi ki e fun mi ni ominra aje biidan .edakun |
Number mi niyi baba healthfirst .pls add me to whatsapp group 08162736520 |
Aboruboyeooo Baba Edakun omo gidi nimi. Won n yan mi je lori tori mio le jaa .ejowo mo nilo oruka agbefuye/ anasare todaju kiwon le mo pe mo ni baba nigbejo.Ibaoooo |
1 (of 1 pages)