₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,330,950 members, 8,447,897 topics. Date: Sunday, 19 July 2026 at 09:19 AM

Toggle theme

Zenith329's Posts

Nairaland ForumZenith329's ProfileZenith329's Posts

1 2 (of 2 pages)

CultureRe: .. by zenith329: 12:20pm On Nov 19, 2016
Ifankaleluya:
ONMO

Eiye-opere to ye eyin-meji sori ite re

ati eyin, ati ite yen ni ao ko

atare kan

Kowe dudu kan

Esuru funfun ati Pupa

koriko inu-yaya

ao jo awon nkan yen papo ni, ao ma fi mu eko-tutu ninu igba-funfun ni ago-kan oru.

Aboru, Aboye, Abosise.
Ekasan sir, e jor sir, oruko miran wo ni yaya je?
CultureRe: .. by zenith329: 11:46am On Nov 19, 2016
dominicson:
Asegbe Odi-meji

Ogun-Lakaye nii se ibi, ti je ibi, tii sanra yo bamubamu. Esu odara nii se odi, nii je odi, ti sanra yo borokoto. Orumila baba Agbonmeregun nii s'oju eleru k'eru, ni eleru tun ki pe baba e seun ana, ti tun ba won gbe ile aye, ti won ko si ri fi se nkankan. Ologbo-finni, Ologbo-finni, Ologbo-finni sa to Eledumare lo. O ni oun ki Ogun-Lakaye, Ogun ko da oun l'ohun. Oun ki Esu-odara, Esu gbo ko dahun. Oun Ki Orunmila baba Agbonmeregun, Orunmila naa ko, ko da oun l'ohun. Eledumare ni ki o lo ba Ogun, ki o bi Ogun leere wipe bawo ni se n se ibi, ti nje ibi, ti n sanra yo bamubamu ti won ko si fi bi. Ki o lo bi Esu-odara naa leere wipe bawo ni se n se odi, ti n je odi, ti n sanra yo borokoto, bee ti omo araye ko ri fi se nkankan. Ki o tun bi Orunmila baba Agbonmeregun bi o se n se, ti o fi n ko eru l'oju eleru, ti eleru tun nki pe o seun ana, ti tun ba won gbe ile aye, sibe, won ko ri fi se nkankan. Emi Lagbaja omo Lagbaja naa sa to Eledumare wa loni o, mo ti se ibi, mo ti je ibi, mo ti yo bamubamu, Eledumare ma je ki omo araye fi ibi bi mi o. Mo ti se odi, mo ti je odi, mo ti yo borokoto, Eledumare, ma je ki omo araye fi odi ti mo je bi mi o. Mo ti ko eru eleru ni isoju eleru, eleru si ti dami mo, sugbon ma je ki won fi bi mi o, kaka ti won i ba fi bimi, ki won tun ma kimi ni mesan-mewa ni o, ki n ma ba won gbe ile aye yi ki won ma le fi ibi kankan se mi. Odi-meji, Odi-meji, Odi-meji wa lo bami di gbogbo awon ota mi lenu o. Ota mi okunrin, ota mi obinrin, oso, aje, emere, ajinnilese, abbl.
Ekaro sir, e jor sir, kini a fi te odu odi meji, se iyerosun ?
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by zenith329: 4:49am On Oct 30, 2016
ayokomi1010:
Osole:olongbo dudu,eyele dudu, eye kowe kan,obi abata oloju merin,ao ge obi na si 200,ewe igi ose 200,kaka iru 200,igba ademo nla kan,ao ko Gbogbo nkan yi sinu igba na,ao gbe sinu agbada ,ao jo ao ro sinu sere,ao mafi oti lo,tabi ka ma fi fo eko mu,odaju wa mari owo nla gba Lori isere.
Ejor sir, se odidi olongbo abi ori olongbo?
CultureRe: .. by zenith329: 2:57pm On Sep 29, 2016
If you have it in abundant, kindly give him, he will surely appreciate it and be grateful to you, remember, this world is a small world
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 5:22am On Sep 04, 2016
Ekaro sir, please help me interpret this dream, I had a dream that I was coming from a woman shop and on my way, I met three secondary boys, we were talking and we gets to a place and I sits down on a bench and place my bag beside me and suddenly two of the boys started searching my bag and taking the money they found inside the bag and as I was walking toward them to stop them from stealing the money in my bag, the third guy grasped me from behind and hold my two hands and urged the remaining guys to hurry up and escape with the money and which they did and fortunately I manage to grasp the guy that hold me from behinds and started beating the hell out of him and demanded my money from him which his colleague took from my bag, I didn't stop beating him until I wakes from my dream.
Please sir,kindly interpret this dream for me
HealthRe: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by zenith329: 9:05pm On Aug 10, 2016
Good evening sir, I had a dream that I was romancing someone that look like a princess and later saw two big houses in the same dream. Kindly,interpret the dream
CultureRe: .. by zenith329: 8:17pm On Aug 06, 2016
Eka ale, gbogbo ile. E jo oruko miran wo ni ewe kasan je?
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 4:34pm On Aug 06, 2016
Good afternoon sir, e jo orunko miran wo ni ewe kasan tun je?
CultureRe: .. by zenith329: 10:01am On Aug 04, 2016
E ka aro gbogbo ile. E jo, e ba wa te odu owonrinmiki sita.
CultureRe: .. by zenith329: 8:24am On Aug 02, 2016
Ifankaleluya:
Ifa isegun ota o ni Obara-ika to daju.

Ao lo wa epo igi-iroko, ao lo kunna daadaa, ao sa gbe, ao fi te Obara-ika sinu awo-amo dudu. Ao pa obi-meji fun, ao je die ninu obi na ni ao fi pe ifa re

Ogun ni be mo lori omo-okege

Iroko alu ji ni deru ba agba

Opelope obara-ika

Ngba tomo araiye yo ida

Ti won ni awon o pa mi

se bi akaniku,Orunmila lekun

Aja ki ja mo lehin ekun paje

Oso ile to ba nperi mi nibi

Obara-ika o,ka oluwa re sorun

Aje-ile, okunrin, obinrin ti ba n

peri mi nibi, Obara-ika, ko ka

Oluwa re sorun.

Ao da obi yen fun, ti obi yen ba ti yan, ao bu epo pupa si, ao la ti a ba fe sun lale.

Aboru, Aboye.
E jo sir, e ba wa te odu obara ika si ta
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 9:36pm On Jul 24, 2016
[quote author=kadunasouth post=47730835]Awure OWO larin ojo meta
Ewe sawerepepe tutu taja lojo ata ijosi eyo meta ao lo yio kuna ao jo eyin agiriki meji sinu santana leda ao to iyo die si ao di bi iga ti afese olele ao gbe omi kana ao wa se jina toba tutu ao se adua owo si larin ojo meta ao koje larin ojo meta toba sise funo ogbodo ri owo dada, ti ojo meta bati koja isere ti tan





E jo sir, kilo je santana leda?
CultureRe: .. by zenith329: 7:31am On Jul 14, 2016
Good morning sir, this is my number: 08034833675. Kindly add me to isese lagba whatapp group
CultureRe: .. by zenith329: 11:04am On Jun 19, 2016
E jo sir, ki lo je koro isin?
CultureRe: .. by zenith329: 9:45am On Jun 19, 2016
Ifankaleluya:
IFA TI A MA FI N SI IPA BURUKU KURO LARA ENIYAN ONI IRETE-META




Ao lo efun loto, osun loto ati edu loto.

Ao wa te ni irete-meta loju opan-kan na

Ao wa ro itan-ifa re si

Ao wa po mo ose. O di wiwe lale-lale

Ifa re; Aku-mo-nisepe loruko ta pe ina

Agbi-mo-letu loruko tape omi

Ara-mo-sindin loruko ta pe ori eni

Nijo ti eyin meteta n tode orun bo wa ile-aye

E ni, eniti ori re ba buru

Tori re ko sunwon

Ti ko ni aje

Ti ko ni ire gbogbo

E ni e o ma ba bi gbogbo e danu

O wa to gege, ke wa bi gbogbo ibi ara lagbaja omo lagbaja danu lati oni lo

Efun ni biwa osun je

Osun ni biwa efun je

Atefun-atosun, edu ni biwa won je

E wa ba gbogbo ogun buruku ti n be lara lagbaja omo lagbaja je lati oni lo

Irete-meta ni e fi ba te gbogbo olubi ara re mole lati oni lo

Ela-boru, Ela-boye, Ela-bosise!
E jo sir, e ba wa te irete meta si ta
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 10:14am On Jun 18, 2016
E ka aro sir, e jo mo ni lo agadagodo todaju.
CultureRe: .. by zenith329: 9:18am On Jun 18, 2016
Eka aro gbogbo ile, e jo, mo ni lo agadagodo todaju. Baba ifakehaleluya, dominicson, marv 006 etc e jo, e fun mi ni ise pe.
CultureRe: .. by zenith329: 5:46am On Jun 18, 2016
[quote author=Ifankaleluya post=44438123]Aworo Itaja

Era aladi

Awo-eta

Ao fi owo(re mi) fon ina si

Ose

Ao gun papo ati ose yen,ao wa pe gbolohun re si, ao ma fi we.

Gbolohun re; Afi atewo fon ina kii duro, ina loni ki e fi owo(re mi) owo(hand) yin ba mi na, era loni ki e fi owo owo(re mi) yin ba mi ra, eta ni koko ta ki omo-eranko miran to ta.
E jo sir, e ma binu si mi, ba w
o ni ao fi owo(re mi) fon ina si?
CultureRe: .. by zenith329: 6:45am On May 29, 2016
Ejo sir, se ori ako alangba loje ori langba abi won yato?
CultureRe: .. by zenith329: 10:47am On May 17, 2016
Ekaro gbogbo ile, e jo, ki lo je ekiri eran, oronro malu ati onlo adie?
HealthRe: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by zenith329: 10:43am On May 17, 2016
E jo sir, ki lo je ekiri eran ati oronro malu?
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 5:50am On May 15, 2016
E jo sir, kilo je oju oro tabi oruko miran wo lo je?
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 5:37am On May 15, 2016
kadunasouth:
ASINA ATUDE
Ewe ewuro ojo, epo obo, eru alamo ao gun papo oronro malu lama fi po ose yi omin kogbodo kan ao ko sinu roba fun fun ao wa so ori niwan ba si ao gbe sinu orun toba yo ao tun po papo ma ose yi taba tipo tan idire ko gbodo kanle mon ao ma fiwe ni ojo merin larin ose sunday monday tuesday thusday ti aba lo ose yi yato si awan ojo wonyi koni sise mon, taba si fe se ose yi arin ojo mererin yi lalese tabase yato si ojo mererin yi koni sise odaju
Good morning sir, ki lo je oronro malu?
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 11:37am On May 14, 2016
kadunasouth:
ASINA ATUDE
Ewe ewuro ojo, epo obo, eru alamo ao gun papo oronro malu lama fi po ose yi omin kogbodo kan ao ko sinu roba fun fun ao wa so ori niwan ba si ao gbe sinu orun toba yo ao tun po papo ma ose yi taba tipo tan idire ko gbodo kanle mon ao ma fiwe ni ojo merin larin ose sunday monday tuesday thusday ti aba lo ose yi yato si awan ojo wonyi koni sise mon, taba si fe se ose yi arin ojo mererin yi lalese tabase yato si ojo mererin yi koni sise odaju
Good morning sir, ejo ki lo je oronro malu?
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 10:14pm On May 13, 2016
kadunasouth:
ASINA ATUDE
Ewe ewuro ojo, epo obo, eru alamo ao gun papo oronro malu lama fi po ose yi omin kogbodo kan ao ko sinu roba fun fun ao wa so ori niwan ba si ao gbe sinu orun toba yo ao tun po papo ma ose yi taba tipo tan idire ko gbodo kanle mon ao ma fiwe ni ojo merin larin ose sunday monday tuesday thusday ti aba lo ose yi yato si awan ojo wonyi koni sise mon, taba si fe se ose yi arin ojo mererin yi lalese tabase yato si ojo mererin yi koni sise odaju
Ejo sir, ki lo je oronro malu?
CultureRe: .. by zenith329: 8:04am On May 08, 2016
[quote author=Ifankaleluya post=45414089]OGUN KI A MA BA LU MAGUN

Panumo, ewe seyo, ao lo papo mo oko-atare kan, ao fi sin gbere yika isale ikun wa.
Baba ifankehaleluya, e ma binu, se ewe sayo le fe ko?
HealthRe: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by zenith329: 11:52am On May 06, 2016
Good morning sir, please help me out with this dream interpretation. Few days ago, I dreamt of picking cat fishes (eja aro) in a mud land and throwing it to a friend of mine, that stay in a dry land and a woman came to me and informs me that a woman was calling me and on getting there, the woman that came to informed me that I was been called wanted to grab me but I escape from her and I wakes up.
Sir, what is the meaning of this dream?
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 7:15am On May 02, 2016
Eka aro sir, ejo ki lo je tangaran funfun?
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 6:54am On May 02, 2016
Eka aro baba kaduna south ati gbogbo ile, Ejo kilo je tangaran funfun tabi oruko miran to je?
CultureRe: .. by zenith329: 6:50am On May 02, 2016
Eka aro, gbo gbo ile, e jo kilo je tangaran funfun tabi oruko miran wo loje?
CultureRe: .. by zenith329: 5:56am On Apr 29, 2016
Ifankaleluya:
E 4ward e-mail yin si e-mail yi baba ''ifankaleluya@gmail.com''...i'l 4ward mi number 2 u.
Baba ifankaleluya, this is my email I'd : johnmike329@yahoo.com
CultureRe: .. by zenith329: 2:48pm On Apr 28, 2016
Ifankaleluya:
I have some documents sent 2 m by a users of ds thread that confirmed his dirty game in whatsapp group he formed here. But..i'l nt drop it, I hope some pple w do so.
Baba ifankaleluya, please can I have your phone number?
CultureRe: .. by zenith329: 10:30am On Apr 27, 2016
Ifankaleluya:
nkan ti e bere yen lagbara baba...emi ko mo oun ti e fe fi se. Sugbon emi fi be nife si iru-ogun ba yen. Egun-Oku(do mi) ni won n pe be.
Thanks you sir, eniyan mi nkan lo ju we ise kan fun, oni a fi egun monu haa lenu.
Kini idi ti e fi be nife si iru ogun be yen?

1 2 (of 2 pages)