Culture › Re: .. by zenith329: 10:53am On Apr 25, 2016 |
zenith329: Eka aro gbogbo ile, ejo kilo je egun monu? |
Culture › Re: .. by zenith329: 10:52am On Apr 25, 2016 |
Eka aro gbogbo ile, ejo kilo egun monu? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 8:31am On Apr 25, 2016 |
Good morning sir, ejo kilo je onlo adire? |
Culture › Re: .. by zenith329: 8:21am On Apr 25, 2016 |
Ifatoki16: Baba mi Agbalagba oye.mo ti bere fun imule awon aje titi,sugbon o dabi e ko fe fun mi.mo kan sori mail yin,mo fi nomba ipe mi sile,sibe e ko tie wo ibiti mo wa.E joo mo fi orunmila beyin.ti mo ba seyin kie dara jimi.baba omo ni gbomo,irukere......09053297971 llcatz@yahoo.com Good morning sir, mo ni lo ifa imule aje, email mi re : johnmike329@yahoo.com |
Culture › Re: .. by zenith329: 9:12am On Apr 24, 2016 |
Ifankaleluya: IFA ASINA OLOGUNDA-MEJI
Onlo adire, a gun mo sawerepepe ati ose, a te iyere-osun ni ogunda-meji lori Ada, ori Ada yi ni ose yi yio ma gbe
ifa re ; Ona si Ona la
Ona kii di mo oloko
Ona kii di mo alada
Ona kii di mo onlo adie lataro dale
Atole(do do mi), Atole ni ki ire gbogbo o mo towa domi lodeleyi
Atole, Atole ni Adire tomo oka
Atole, Atole ni adire tomo agbado
Ada loni ki ire gbogbo o mo da wa
Ogunda-meji loni kire gbogbo o ma dagiri-giri wa do mi
Sawerepepe ni e fi pe ire ti n be lode ile yi fun mi wa. Ao ma di ose yi we nigbakugba to ba wu wa.
Ti a ba ti pe ifa yi sori iyere-osun yen tan,ao wa po mo ose ti a ti gun yen lori Ada, Ose yen yio si ma gbe ori-Ada yen ti ao fi we tan Aboru, Aboye, Abosise! Ejo sir, ki lo je onlo adire? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 7:08am On Apr 08, 2016 |
kadunasouth: Olulana Arisiki Todaju Koro isin egusi inure, koro palabe(Agbaluma) egusi inure ao lo papo ao gun ma ose dudu ao ma fiwe Gbolohunre Olulana lana ire ko emi Lagbaja omo Lagbaja tori bi isin baso omo araye alana debe, bi osan baso omo araye alana debe ki gbogbo omo araye lana ore nla nla kanmi kiwan fi ire owo wan wami ri NB tan bati bu ose yiwe lao ma pe gboloun ayajo yisi odaju Good morning sir, e jo kini oruko imi ti koro isin tun je? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 11:37am On Apr 06, 2016 |
kadunasouth: Aseje Atude Ao ra eyin agiriki meta ao bo yio jina dada to batutu ao bo epo eyin yi ao wa koko isasaun kekere kan ao lo ewe tude die ati egbo tude die ati iyere 16 ao lo ao da sinu koko isasun ao to omi oronbo die si akonifi epo si ati iyo ao gbe kana ao wa da eyin yi si ao se to ba tutu ao ra agban kan ao lu agban yi lona meta ao fi omiyi sin owo wa katoje aseje yi taba jetan ao fi owowa mejeji nu ara agbanna alefise sara tabi kalore jusi ori atan ide arawa yio tu patapata sugbon aseje yi osoro latije ama odaju NB taba jetan gbogbo arawa ni yio weak sugban leyin wakati die tabi ojo alafia yio de ona yio si si funwa ibare olodumare ati awan agbagba Ekaaro sir, e jo kiloje omi oronbo? Se omi agbon yen a maa fi san (wash) owo wa ni? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 4:13am On Apr 04, 2016 |
kadunasouth: Atude/Asina/Bibo Asiri Ori ako alangba tapa lojo epo obo die ao gun papo dada ao ra igba olomori kekere ao gun ma ose niwanba ao fi eyin ojo po ose yi ao ko sinu igba kekere yi idire kogbodo kanle month tobati denu igba toba we oseyi ibikibi tobadurosi ore owo yio wa owa sibe lojona odaju Ejo sir,se a le lo eyin agric Oojo? |
Culture › Re: .. by zenith329: 10:10pm On Apr 01, 2016 |
Ejo, kilo je koro isin? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 1:47pm On Mar 29, 2016 |
kadunasouth: Olulana Arisiki Todaju Koro isin egusi inure, koro palabe(Agbaluma) egusi inure ao lo papo ao gun ma ose dudu ao ma fiwe Gbolohunre Olulana lana ire ko emi Lagbaja omo Lagbaja tori bi isin baso omo araye alana debe, bi osan baso omo araye alana debe ki gbogbo omo araye lana ore nla nla kanmi kiwan fi ire owo wan wami ri NB tan bati bu ose yiwe lao ma pe gboloun ayajo yisi odaju Ejo sir, ki lo je koro isin? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 1:46pm On Mar 29, 2016 |
kadunasouth: Ebe/imule awon Agba todaju Alubosa elewe tutu kopo die ao gun dada ao popo ma ose dudu ao wa eyin adie Oojo ao do gbon fo lori die ti korofo eyin yi konibaje ao jo omin eyin yi sinu ose yi ao tun gun dada ao wa igba olomori ao ko ose yi si ninu ao wa fi korofo eyin yi gun ose yi lori logan gan ibi ti ati fo eyin na ni yio koju sinu ose, ao ti koko dogban fowo jin ibibe kato fi eyin na gun ki korofo eyin na maba fo. Ao ma buwe nigba toba wuwa. Iseyi daju ijo taba bere wiwe re ojona ni yio bere ise Ejo sir, se a le lo eyin adie agric Oojo taba ri ti eyin ibile Oojo? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 3:51pm On Mar 28, 2016 |
kadunasouth: Onma Arina Ewe tete abalaye ao tu tegbo tegbo ao jo ma odidi atare kan ninu koko tuntun ao dasi ona meta ao lo fun ojo meta ojo alakoko epo pupa elekeji ori eleketa adi, Gboloun yi lao ma filo Ise arina onma ti moloyi mio fe ko sise osan o, ise oru ni mofe komase funmi gbogbo nkan toba fe sele ni kin mama NB ki ise yi le daun dada ese imule ati ebe ati iyonu awan agba dada iba fun awan agba Ejo sir, se lila ni abi a maa fi para ? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 2:25pm On Mar 28, 2016 |
kadunasouth: Ebe/imule awon Agba todaju Alubosa elewe tutu kopo die ao gun dada ao popo ma ose dudu ao wa eyin adie Oojo ao do gbon fo lori die ti korofo eyin yi konibaje ao jo omin eyin yi sinu ose yi ao tun gun dada ao wa igba olomori ao ko ose yi si ninu ao wa fi korofo eyin yi gun ose yi lori logan gan ibi ti ati fo eyin na ni yio koju sinu ose, ao ti koko dogban fowo jin ibibe kato fi eyin na gun ki korofo eyin na maba fo. Ao ma buwe nigba toba wuwa. Iseyi daju ijo taba bere wiwe re ojona ni yio bere ise Good afternoon sir, se eyin agric Oojo ni tabi eyin ororo Oojo, ta bi ri eyin Oojo, se a le lo eyin to kin se to Oojo? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 8:48pm On Mar 26, 2016 |
kadunasouth: Olulana Arisiki Todaju Koro isin egusi inure, koro palabe(Agbaluma) egusi inure ao lo papo ao gun ma ose dudu ao ma fiwe Gbolohunre Olulana lana ire ko emi Lagbaja omo Lagbaja tori bi isin baso omo araye alana debe, bi osan baso omo araye alana debe ki gbogbo omo araye lana ore nla nla kanmi kiwan fi ire owo wan wami ri NB tan bati bu ose yiwe lao ma pe gboloun ayajo yisi odaju Ekale sir, ki lo je koro isin tabi oruko imiran wo loje? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 8:32am On Mar 24, 2016 |
Ejo sir, kin ni won pe ni ogunna? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 7:04am On Mar 24, 2016 |
[quote author=kadunasouth post=44027171]Olulana Arisiki Todaju Koro isin egusi inure, koro palabe(Agbaluma) egusi inure ao lo papo ao gun ma ose dudu ao ma fiwe Gbolohunre Olulana lana ire ko emi Lagbaja omo Lagbaja tori bi isin baso omo araye alana debe, bi osan baso omo araye alana debe ki gbogbo omo araye lana ore nla nla kanmi kiwan fi ire owo wan wami ri NB tan bati bu ose yiwe lao ma pe gboloun ayajo yisi oda
Good morning sir, ejo kini oruko imi ti koro isin tun je tabi kilo je koro isin? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 12:01pm On Mar 21, 2016 |
Good morning sir,
Ejo, kini itumo ogunna? |
Culture › Re: .. by zenith329: 10:05pm On Mar 19, 2016 |
[quote author=dominicson post=43910265]I intended posting ten confirmed Imule, but now I'm afraid the next eight could make the female ones among us 'fly'.
So helpless I am to help those I know they really need these imule here!
Ejo sir, mo need awon imule yii, pls, kindly send it to my e mail : johnmike329@yahoo.com |
Culture › Re: .. by zenith329: 11:34am On Mar 16, 2016 |
Ifankaleluya: FUN ENITI KO BA SE ASEYORI LORI GBOGBO IDAWOLE RE TABI TI AWON AGBALAGBA KO JE KO RI ONA ABAYO.
IFA NI AWA NI TI A LE FUN YIN,KO KIN NSE OGUN LASAN.
IFA YI JE AKO ATI ABO.
AKOKO NI IWE(BATH) ASEYORI TI GBOGBO OGUN ATI OHUN TI O BA DAWOLE YIO FI MA SESE EKEJI NI IMULE AJE TI WON FI MA N YOJU SI ENIYAN LOJU ORUN TI WON YIO SI FI ASIRI OGUN AYE RE HAN E. IFA ELEKEJI YI, TI O BA SE BI WON TI MA N SE,OKUNRIN YIO LO FUN OJO MESAN,OBINRIN YIO LO FUN OJO MEJE. LEYIN TI O BA LO IFA YI TAN,TI ENIYAN BA LO YA X-RAY NI HOSPITAL,WON A RI IGBA NI AYA WA,IGBA(CALABASH) YEN NI AMI TI AWON AJE YIO FI SI WA LARA TO TUMO SI WIPE AWON AJE KO GBODO FI OWO KAN WA MO.
SUGBON NKO NI NI ANFANI LATI FI IFA KEJI YEN SILE LORI IKANNI YI,NITORI AWON KAN TO JE WIPE IWE OGUN NI WON N TA. AWA SI MO ASIRI WON.TORI AWON IWE KAN NI WON N DAKO FUN YIN,WON KIISE BABALAWO. IRO LASAN NI WON N PA FUN YIN.
1. IWE ASEYORI.
EWE-IYALODE TI KO JA TI KO LU 201, AKO-OKUTA MESAN, ATI EPO-OBO NI AO FI SE AGBO YEN. OMUNU EWE-IYALODE MESAN ATI EPO-OBO DIE NI AO GUN PAPO,TI AO PO MO OSE DUDU DIE TI AO FI SE OSE RE.AO KO AKO-OKUTA YEN TELE IKOKO,AO FI EPO-OBO YEN LE LORI,AO WA KO GBOGBO EWE YEN LE LORI. AO BU OMI TO PO DADA SI,AO GBEKA INA NI DEDE AGOGO-MEFA IROLE. TI AGBO YEN BA TI JINNA,A KO GBODO FI IDI RE KAN ILE OO. A LE WA AKO-OKUTA TI O TOBI DADA KI A GBELE LORI. AO WA KO GBOGBO EWE YEN KURO,AO LO DA SI ORI-AKIITAN. SUGBON,A KO NI KO AKO-OKUTA YEN KURO. FUN ENITI KO BA NI AGBARA LATI PA ODIDI ERAN,AO TI RA(BUY) ORI ORUKO ATI ESE RE MERERIN SILE,AO KO SINU AWO ABOKADELE DUDU,AO BU EPO PUPA SI LORI. TI O BA DI NI AGOGO-MOKANLA ALE,AO SE ADURA SI,AO LO GBE SI ORITA-META,A KO GBODO WEYIN TI A BA TI GBE KA LE OO. AO NI SUUURU KI O FI DI AGO-KAN ORU,TI AGO-KAN ORU BA TI LU NI AO FI AGBO YEN WE PELU KENKEHIN TITUN. TI A BA TI WE TAN,AO RI KENKENHIN YEN MOLE,AO KO AKO-OKUTA YEN LO DA SI ORITA-META LORU YEN,A KO SI GBODO WO EYIN TI AO FI WOLE PADA.
GBERE IFA YEN; ESO-LOWEREJENJE MESAN ATI OMO-IRULA MESAN NI AO LO PAPO TI AO FI SIN GBERE MERIN NI AYA APA-OTUN,META NI EYIN APA-OTUN ATI GBERE META NI AYA APA-OSI,MERIN NI EYIN APA OSI. LO BA TAN.
IKILO RE OOO OBINRIN KO GBODO WE IWE YEN OOO. TI OBINRIN BA WE,AWON IYAMI MA FUN NI EIYE NI OOO.
2 IMULE AWON AJE TO DAJU ABO ADIE TO DUDU TIKO NI AMI KANKAN, IKODE KAN,OBI-IFIN,OBI-IPA,TEWE-TEGBO AJEOBALE,IGBA OLOMORI ATI ........., AO LO WA EGBO AJEOBALE YEN NI ARO KUTU-KUTU,AO WA FI EGBO YEN WON IKA-ARIN WA,AO GE SI META,AO YA AWE-KAN NIBI OBI-IPA,AO GE SI MARUN,AO YA AWE KAN NIBI OBI-IFIN AO GE SI MERIN. AO KO EGBO TI A GE SI META YEN TELE IGBA,AO DA AWON OBI TI A GE YEN SI,AO FI IKODE YEN ATI EWE........,AO WA KO GBOGBO IFUN ADIE YEN TI A YO LATI IDI,TORI A KO GBODO PA ADIE YEN LORI,LATI IDI(OBO) NI AO TI GE,TI AO SI TIKO GBOGBO IFUN RE JADE. TI A BA TI KO TAN. AO KO SINU IGBA(CALABASH) YEN,AO WA KO EWE AJE-OBALE TO PO DADA SI LORI. AO WA DE IGBE YEN PA. AO GBE SINU IKOKO,AO GBE KA INA. AO DE KOKO YEN,A KO GBO RO PAPO TI YIO FI JO TAN. TI O BAJO TAN TI ATI LO,AO WA TE NI ODU-IFA OSA-MEJI. AO WA PE IFA RE SI. SUGBON N KO NI FI IFA YI SILE TAN TORI AWON TI WON N TA IWE-OGUN.
NOTE;; TI O BA NILO GBOGBO IFA YI TAN,FI NUMBER RE SILE LABE KIN NI YI. PELU OGO OLORUN,MA SI FI SILE FUN OOO.
ABORU,ABOYE,ABO-SISE. |
Culture › Re: .. by zenith329: 11:24am On Mar 16, 2016 |
Ifankaleluya: Ifa ni: Aridigi ni ti eegun,ako-tagiri ni ti ejo, ojo ti owu alahun-takun ba ja, agbaagba meta won kii roju so, adifa fun orunmila nijo ti baba n lo soju-ogun to le,won ni ki orunmila o ma lo,orunmila ni nitori kin ni,won ni awon to n yin ni nibon,awon to n sa ni lada,awon to na eni loogun ati awon to n se ni ni ajogun gbogbo wa nibe, orunmila ni ohun o lo,orunmila ni ti won ti fi oju kan ohun gbogbo ohun buruku ti n be ninu won yio si ma ra si won ninu, iwo won ka sai sun si won lapo iwo won.
NOTE ifa ti o wa loke yi ni kiije ki ogun ti won ba fi na eeyan ati ibon,ati ohun buruku ti won ba fe se si wa ko sise. Aso eegun,owu-alahuntakun,ori-ejo,ewe aruso oko ati be-be-be loooo. Aso-eegun yen ni ao fi di ni ikobere.
Ela-boru, ela-boye, ela-bosise. Ejo sir, e fun mi ni ise pe nitori mo fe se........08034833675 tabi johnmike329@yahoo.com |
Culture › Re: .. by zenith329: 10:08am On Mar 16, 2016 |
Ifankaleluya: OBARA-OGUNDA NI A N PE NI OBARA-EGUN TAN.
IFA NI;
Obara-egun tan
oni(today) la o pa egun run
adifa fun orunmila nijo ti omo-araye ni awon o fi eegun,epe ba aye baba je
ifa ni iro ni won n pa
egun kii mu ila
egun kii mu ikan
ati egun ati epe kii mu ata
obara-egun tan
ifa ba mi pa gbogbo egun aye mi.
IFA YI NI A MA N FI, ata,ikan,ila ati etu-ibon se. Ti a ba pari re, enu ona ni ao ti te ifa re,ti a ba pe ifa tan. Ao wa fi etu ibon yen si ni aarin,ao wa sa ina si. Ti ina yen ba gbi, ise yen ti dahun niyen.
Ela-boru, ela-boye, elo-bosise. Ejo sir, se a maa jo ata, ikan, ila yen tabi a maa lo ni, bawo ni a maa se pari re ? |
Culture › Re: .. by zenith329: 9:33am On Mar 16, 2016 |
[quote author=Ifankaleluya post=43528328]Boya ki e tun lo bere lowo awon agbalagba, OMI-AGBON NI WON N PE NI OMI - APEGUNRUN. EWE-PEREGUN SI DA WA LOTO.
Bayi ni won se ma n lo omi agbon lati fi pa egun, epe, ati ise run.
A o lo wa omi-agbon to po daadaa, ao wa mu oguna to ti pon daadaa ninu ina,ao sare ju si inu omi(owo(hand) ni ao fi mu ogunna yen ninu aro),ao ju si ori-olo,ao lo,ao po mo ose dudu,omi-agbon yen ni ao fi po ose yen. Kanrinkan titun ni ao fi we ose yen ni odo to n san. Ejo sir, kin ni oruko miran ti oguna je tabi ki lo je oguna? |
Culture › Re: .. by zenith329: 8:47am On Mar 16, 2016 |
[quote author=Ifankaleluya post=43794051]Fun awon ti won bere asiri-bibo lori e-mail.
E lo re wa isu~etiponola, ewe papasan,awom miran n pe ni dedenkude, eyin adire ororo meta,ati ori.
E o lo awon ewe yen papo ni,eo jo eyin yen sibi kan,eo da ewe yen si ti e ba ti lo tan,eo po papo daada.
Eo ju ori yen sinu agbada,ti o ba ti yo,ori yen ni eo fi din eyin yen.
Ejo sir, se isu etiponola tabi ewe etiponola? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 9:45pm On Mar 15, 2016 |
kadunasouth: Eyonu Ebe Awon Agba Igi Asorin(igi nla)) epo obo iye igun akopa eyokan ao lo gbogbore ti yio kuna ao wa dasinu adi eyan ao ma fi para odaju sugbon oni eewo eyokan ijo kijo tabati lo ise yi akogbodo lo turare yala fi para abi fi saso odaju Ejowo baba kadunasouth, mo ti bere akopa lowo awon elewe omo sugbon woni awon ko mo ohun ti o jebe, ejowo sir, kini oruko miran ti akopa je? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 12:28pm On Mar 15, 2016 |
kadunasouth: Gbere Ebe Awon Agba Igo ngori ewe Agogo igun ao ja 99 odidid atare kan ao jo papo ao fi sin gbere si igbaya otun gbere meta, eyin meta, igbaya osi meta eyin igbaya osi na meta opari odaju Ejo sir, ki lo je igo ngori, e salaye? |
Health › Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 11:39am On Mar 15, 2016 |
Ejo sir, kini oruko miran ti akopa jen? |