Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,069 members, 7,814,697 topics. Date: Wednesday, 01 May 2024 at 05:37 PM

Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko (9413 Views)

Join This Group Today: Lilo Ewe Ati Egbo Ati Eranko (herbs; The Magic Healer) / Ogun Awon Bàba Wa / Awon Koko Inu Iwe Iroyin To Jade Loni (2) (3) (4)

(1) (2) (Reply) (Go Down)

Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by kadunasouth(m): 5:48am On Jun 28, 2015
ÒKÉTÉ
Okete je ọkan ninu eranko abami to lagbara pupọ.
Amọn gbe ninu iho.
ELEDUMARE fun ni asẹ pupọ.
Okete kii fi ọwọ tabi ẹsẹ gbẹ iho,
iru ni okete ma'nfi gbẹ iho,idi eyi ẹo le ri erupẹ lẹnu isa okete,
bi eniyan ba gbẹ iho okete igbamiran ama se isa mon e'yan lọwọ.
Ti aba gbẹ isa kan okete ti o ba fi ahọn Kan ilẹ gende kan ko faa jade,
okete ni asẹ kan ni ipari Iru rẹ, bi eniyan ba'nle okete lọ toba fi asẹ Iru rẹ nan ilẹ,kosi bi eni nan tile lagbara to yo subu lulẹ,awọn idi eyi lobi owe ''ORO TOKETE BA BALẸ SỌ NI ILẸ GBỌ'' ti eniyan ba pa okete ti eni na ba ge asẹ iru rẹ sinu isa rẹ okete na yo tun da pada wo inu isa na lẹyin ọdun kan eyi lobi owe ''MIO LE FI ILE BABA MI SILẸ LOUN SEKU POKETE LỌDỌỌDUN'' ti okete baa ti bimọ yo yọ yara fun awọn ọmọ rẹ ninu Isa kanan wọn yo yọ palọ sibẹ eyi ni anpe ni agburu okete ibẹ ni gbogbo wọn tiun jẹun, ti okete bati darugbo daadaa ti ẹnu rẹ ko ran onjẹ mọ awọn ọmọ rẹ abo ni wọn o ma fun lọyan mu, eyi lobi owe ''BI OKETE BA DAGBA ỌMUN ỌMỌ RẸ NI MUN'' okete fẹran ekurọ pupọ ẹkurọ ti a ba ri ninu isa okete a kii pe ni ekurọ eese lama npe eyi lobi owe ''KAKA KI OKETE MAJE EESE A FI SAWADANU NI''
okete a ma dide rin bi eniyan lọganjọ oru yo si ko ounjẹ lọwọ tabi ko gberu,ọdẹ tabi ẹnikẹni ko gbọdọ pa okete toba wa ni ipo na.
Orukọ miran fun okete ni ewú,okete Kii jade ni ọsan eyi lobi owe''AKI RI EWU LỌSAN'' ti eniyan ba gbẹ Isa kan okete toba gbe awọn lelẹ ao gbọdọ faa Ju ki iru rẹ ma ba bo,ti okete ba boru mo eniyan lọwọ amunbọ loun fa.
ti eniyan ba pa okete toun sun lọwọ to bu eeru si oju ọnan yo ri oju ẹsẹ okete toti jade pada eyi lomu awọn agba ma pe ni AKUDAAYA' ti aba tu ifun okete ama ri mọlẹ nitori aja,bi aja ba jẹ ifun okete aja na yo ya digbolugi/were.
bi eniyan ba fẹran lati ma jẹ okete ju,o rọrun fun awọn agba lati ma wo ifun ẹni nan.
Eemọ ati iyanu pọ lori ọrọ okete sugbọn kosi aaye. Ao ma tẹ siwaju laipe..
09090305775

2 Likes 1 Share

Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by xreal: 5:59am On Jun 28, 2015
Àshírí nlá.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Lionhearted: 6:25am On Jun 28, 2015
Okete!!!

Itakun yi mu kin ran ti igbati mo wa lomode.

Ninu ogba wa okete po pupo. Ni owuro ojo kan mo ri okete kan to n je buredi ti ada so aitan. Mofe mu igi ki n le. Ni moba ri ti okete na fi buredi na sile to si dide lori ese(leg) re toun fi owo(hand) re mejeeji ra ra bi igba ti eniyan ba n be be. Mosi fi sile. Kayefi lo je si mi titi di oni.

2 Likes

Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Zenlife: 10:53pm On Jan 14, 2016
Baba e kale o, e jowo bawo ni mo se le bo Ogun? Bawo ni won se set up shrine Ogun si ile eni? E se pupo sir, ebun oluwa a po si fun yin o. Ase.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by tpiah2: 11:05pm On Jan 14, 2016
Zenlife:
Baba e kale o, e jowo bawo ni mo se le bo Ogun? Bawo ni won se set up shrine Ogun si ile eni? E se pupo sir, ebun oluwa a po si fun yin o. Ase.

Bo Jesu.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by tpiah2: 11:09pm On Jan 14, 2016
.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Zenlife: 10:26am On Jan 15, 2016
Bo jesu!
tpiah2:

Bo Jesu.
i gladly dont do myths esp slow or non-acting foreign gods. Besides, i havent exhausted those within my geo-location. Eat from your own fig tree. Keep it simple. sogbo?
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Zenlife: 10:33am On Jan 15, 2016
tpiah2:


Bo Jesu.
i gladly dont do myths.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Zenlife: 10:39am On Jan 15, 2016
tpiah2:

Bo Jesu.
i gladly dont do myths and slow or non-acting foreign gods. Besides, i havent exhausted those within my geo-boundary. Eat from your own fig tree. Keep it simple. sogbo?
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Zenlife: 11:00am On Jan 15, 2016
Baba, mo ki yin o, ejo kini enia le se ti awon aye ba lo rubo fun Ogun lati fi di eni lowo lati ba ti eni je?
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by tpiah2: 3:32pm On Jan 15, 2016
Zenlife:
Bo jesu! i gladly dont do myths esp slow or non-acting foreign gods. Besides, i havent exhausted those within my geo-location.I Eat from my own fig tree. Keep it simple. sogbo?


like I said, Ogun does not accept you, turn to Christ.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Zenlife: 5:56pm On Jan 15, 2016
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by tpiah2: 6:08pm On Jan 15, 2016
Zenlife:
congratulations for being accepted and enslaved to a myth. To each his own. I rily dont have or give a shit about my time. I will go and kiss a black or white a*s. I am a TATAFO!!!

throwing insults says a lot about you.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Zenlife: 6:18pm On Jan 15, 2016
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by tpiah2: 6:19pm On Jan 15, 2016
Zenlife:
same as I am a Tatafo. Gee dont I get it dude? I should busy my sorry self elsewhere
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Zenlife: 6:35pm On Jan 15, 2016
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by tpiah2: 6:58pm On Jan 15, 2016
Zenlife:
Zenlife (christ lover) cant even be original, meanwhile I take lotta tissue or water with me;I enjoy flushing myself down the out-house niga. I am a Tatafo copycat!
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Zenlife: 8:56pm On Jan 15, 2016
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by tpiah2: 9:04pm On Jan 15, 2016
Zenlife:
I be original suegbe kanpe. Zenlife my Christ dey teach me 4 me 4 church at all? I sm a 4kin moda4ka a*shole 4ka, bomboclaud. Hehehe Zenlife ko tgoro2 ni. Atuwa mi soponsopon ni e alakori adofuro.I am a Copybum niga. Oya copy dis I am a sicko.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Zenlife: 9:40pm On Jan 15, 2016
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by tpiar: 11:30pm On Jan 15, 2016
Zenlife:
I am a douche bag moda4ka. Damn is zenlife . i am an Olodo and i will keep my darn church. Once again i am a mumu, zenlife dont do all church and Christo. I play a Nice game of draft. Damn I njoy flyin me likka kite or spinnin me like koto. I am Ode, robot, parrot, my move.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Zenlife: 6:45am On Jan 16, 2016
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by eposho: 9:59am On Jan 16, 2016
Tpia y don't u let ppl be. Please. OK.
I was enjoying this thread till I scrolled down and u derailed the damn thing.
There is a clown missing in your village. OK.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by tpiah2: 10:46am On Jan 16, 2016
Zenlife:
Zenlife emi omo shalanga! Zenlife ni Ayekoto olodo!
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by tpiah2: 10:46am On Jan 16, 2016
eposho:
y don't I let ppl be. Please. OK.
I was enjoying this thread till I scrolled down and I derailed the damn thing.
There is a clown missing in my village. OK.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Zenlife: 11:04am On Jan 16, 2016
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by Zenlife: 11:08am On Jan 16, 2016
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by tpiah2: 11:16am On Jan 16, 2016
Zenlife:
thanks bro. Good advise for me.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by eposho: 11:34am On Jan 16, 2016
Otapiapia or whatever u r called don't let me start with u this morning, mofo lyk u.
Emi o ri ibiti oro okete ti Debi Jesu afi igbati Iwo olo run tpia wa da orikan yi ru oloshi ayirada eyan.
Lo si Jerusalemu ki olo MA juba fun awom baba e nibe. Ki o fi wa sile nibi. Omo oduua ni Emi .
Woord to your moda.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by tpiah2: 12:07pm On Jan 16, 2016
eposho:
eposho oshi or whatever I am called don't let me start with me this morning, mofo lyk me.
Emi ti ri ibiti oro okete ti Debi Jesu afi igbati emi olo run eposho wa da orikan yi ru oloshi ayirada eyan ni mi.
Emi Lo si Jerusalemu ki nle MA juba fun awom baba mi nibe. Ki n fi wa sile nibi. Omo oduua ko ni Emi .
Woord to my s.tupid moda and fada.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by eposho: 12:20pm On Jan 16, 2016
@ tpia, typical of religious bigot preaching one none existing Jesus.
Regurgitating mofo.
Re: Okete Abami Loje Ninu Awon Eranko by tpiah2: 12:25pm On Jan 16, 2016
eposho:
@I am a typical irreligious bigot and I am a regurgitating mofo.

turn to Jesus, you are empty hence your situation.

(1) (2) (Reply)

For Racism Against Blacks To Reduce Drastically, The Black Race Needs To Be Rich / . / Le Cercle Francais De Nairaland!

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 37
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.