Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,416 members, 7,815,936 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 09:26 PM

.. - Culture (11) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1828556 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (8) (9) (10) (11) (12) (13) (14) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by fardolly: 5:48pm On Jun 22, 2015
Baba ooooo
Iba agba
Re: .. by Nobody: 5:58pm On Jun 22, 2015
pappykay0428:

E jowo bawo ni a sele bo Ori wa toriwipe awon agba ma n so pe ori ni a ba bo a ko ba fi orisa sile.
Won si tun so wipe Bibo Ori eni se pataki

Gege bi awon agbalagba se ko wa, bi eniyan ba fe bo Ori, eni na yio to Awo lo nitoripe, eeyan funrare ko le boo Ori ara re funrare
Re: .. by Nobody: 6:24pm On Jun 22, 2015
pappykay0428:

E jowo se e ni oruka aluwo to daju abi agbaseje
tabi agbawo abi agbefuye ti o daju...aboru boye
nile awo.

pappi kay osha

Awa o ki se Awo Ika... ki lo de to fi je wipe awon oogun ija le n wa? Kini e fe fi won se?

2 Likes

Re: .. by Nobody: 6:28pm On Jun 22, 2015
sammyjay76:

EJOWO MO FE PE AKIYESI YIN SI NKANKAN LORI OGUN SCKLE CELL TI E SO NAA, ESO RERE. WADI MI FI HAN PE EWE RERE PE MEJI AKO WA ABO SII WA PELU. NJE EYI TI O SO BI EWA NI NJUWE RE NI ABI BAWO NI ESO NA TI RI? EJOWO TAN IMOLE SI DARADAR.
IDI NIIWIPE, AWON EWE NA NI ORUKO ORISIRSI ATI BI WON TI NPE WON KAKLIRI ILE KARO O JIRE.
ILE ANAGO TI BENIN REPUBLIC NI EMI WA SUGBON OMO BIBI ILE EGBA, ABEOKUTA, NIGERIA NI MO JE.
PELUPELU, EJOWO FI OGUN SC MIRAN SITA FUN WA FUN IRANLOWO DIDEKUN AISAN NA
ESEUN PUPO.

Eso Ako Rere ni mo n so.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 6:30pm On Jun 22, 2015
bosrote:


EJO SIR, IGBIN YEN SE AMA SE PELU IKARAHUN NI ABI BA WO ATI PE SE ISE YI NI IMULE? TO BA NI E LA HAN WA SIR THANKS

Haha!...E fe je igbin je ikarahun pelu re! Eewo Orisa!
Re: .. by Nobody: 6:30pm On Jun 22, 2015
kadunasouth:

Ogun stroke
Egun jeki alubosa ayu ati odidi atare ao jo ao fi sin gbere yipo idiwa ati owo ati esewa mejeji,

Elekeji. Ese aja mererin ao jo pelu odidi atare kan ao fi sin gbere lati etiwa mejeji de ika arin ati lati ibadiwa de esswa mejeji


Oogun yi dara pupo. kare o Awo.

2 Likes

Re: .. by kadunasouth(m): 5:42am On Jun 23, 2015
ASEJE ARISIKI todaju
Ewe areyinkosun, ewe orijin, ewe sawerepepe ao lo yio kuna dada ao fi din eyin ororo meta je lepo niyo

NB wase bi emeta lerawon toba fe ko daun dada

2 Likes

Re: .. by dominicson: 8:30am On Jun 23, 2015
healthFirst:
BELEJE
E teti beleje o, ke gbohun tawo o gbodo se, Awo kii paro o. Awo kii dale awo. Awo kii san bante awo egbe re o. Egbe re laake o. Eegbe re looko o. Egbe re lola. Tofi dele owa orangun olomo. Oogboye o!.

Eeeeeee pa 'mole!
Agbo ato e! Ogbo edan Ogbo ...

2 Likes

Re: .. by dominicson: 8:41am On Jun 23, 2015
healthFirst:
KAHINKAHIN EMINA Kahinkahin emina ni mo da o. Kahinkahin emina ni mo da. Akii fi imi fogba, Akii fi ito fawo o. Emi ti dewe ki leo fimise o? Kahinkahin emina ni mo daa. Kahinkahin emina ni mo da laake o, ni mo da looko o, ni mo da lola. Tofi dele owa orangun olomo, Oogboye o.

Ni ibo ni osu tie ti le o?

1 Like

Re: .. by Nobody: 9:56am On Jun 23, 2015
dominicson:



Eeeeeee pa 'mole!

Agbo ato e!
Ogbo edan
Ogbo ...

Ogbo Akokoniko o Awo.

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 10:27am On Jun 23, 2015

.
Re: .. by Hardetutu01(m): 10:36am On Jun 23, 2015
kadunasouth:
ASEJE ARISIKI todaju
Ewe areyinkosun, ewe orijin, ewe sawerepepe ao lo yio kuna dada ao fi din eyin ororo meta je lepo niyo

NB wase bi emeta lerawon toba fe ko daun dada
mi o understand lepo niyo sir...ejowo e laa ye mi daadaa sir
Re: .. by Hardetutu01(m): 10:49am On Jun 23, 2015
kadunasouth:
Ewe areyinkosun, ewe orijin, ewe sawerepepe ao lo yio kuna dada ao fi din eyin ororo meta je Opari
"lepo niyo" means "pelu epo ati iyo abi"?
Re: .. by gawab: 10:51am On Jun 23, 2015
E jowo e fun wa ni ogun gege ofun to daju.

1 Like

Re: .. by gawab: 10:54am On Jun 23, 2015
kadunasouth:
ASEJE ARISIKI todaju
Ewe areyinkosun, ewe orijin, ewe sawerepepe ao lo yio kuna dada ao fi din eyin ororo meta je lepo niyo

NB wase bi emeta lerawon toba fe ko daun dada
E jowo egbogi wo ni a le lo si gege ofun.
Re: .. by Richie016: 4:21pm On Jun 23, 2015
iba awon ti o koko ja ewe o. E jowo baba, nje oogun ti won fi le gba eeyan si ibi ise pada leyin ti won ti le onitoun kuro nibe wa bi? E seun. Ewe a maa je o
Re: .. by kadunasouth(m): 9:01pm On Jun 23, 2015
.
Re: .. by leckxy(m): 9:39pm On Jun 23, 2015
kadunasouth:


ATUDE TODAJU
Ewe tude egbo tude iyere ao lo ti yio kuna dada ao ra isasun tuntun ao fi se odidi igbin kan je lepo niyo lodidi ni ao se igbin yi o akoni ge ti obajina ao so kale ao je ko tutu ao wa bo gbogbo aso orun wa ati oruka ao wa ni ihoho omoluabi ao wa da aseje na si ilele ao kunle ti ao wa ka owo wa mejeji seyin wa ao wa se adua itusile ao wa fi enu gbeje lodindi iseyi daju danwo kori botiri
Ike oloun ola oloun komaba alayelorun
NB ori ilele cement or tiles lamada aseje yi si leyin ti ati nunu dada ao dasi ao waje

Iba akoda iba aseda iba agba merindinlogun lotu ife iba baba iba mama iba omode iba agbalagba iba okunrin iba obinrin efi oju rere womin o! Ase edumare
Contact me 08028358926a@gmail.com
Ejo baba kini anpe ni iyere?
Re: .. by gawab: 6:58am On Jun 24, 2015
kadunasouth:
ASEJE ARISIKI todaju
Ewe areyinkosun, ewe orijin, ewe sawerepepe ao lo yio kuna dada ao fi din eyin ororo meta je lepo niyo
NB wase bi emeta lerawon toba fe ko daun dada

Ogun wo ni enia le lo ti gege orun/ofun yio fi lo patapata.
Re: .. by kadunasouth(m): 9:08am On Jun 25, 2015
Hardetutu01:
mi o understand lepo niyo sir...ejowo e laa ye mi daadaa sir
Leyin teti lo aWon ewe wonyi eo fo awon eyin na sinu abo ebu ewe die si eo fi iyo die si eo wa ro papo dada eo wa gbe epo kana eo wa fi din to ba tutu eo koje ebu tobaku elo mi na lelo

2 Likes

Re: .. by kadunasouth(m): 9:12am On Jun 25, 2015
leckxy:
Ejo baba kini anpe ni iyere?
Elosi odo awon elewe omo ebere wan ota funyin bi oni muri kan tito niwan ba die leo fisi bi eyo 16

2 Likes 1 Share

Re: .. by Nobody: 12:54pm On Jun 25, 2015
x

1 Like

Re: .. by Nobody: 12:55pm On Jun 25, 2015
x

1 Like

Re: .. by Nobody: 12:57pm On Jun 25, 2015
ORISIRISI OOGUN
Oogun funfun
Oogun dudu
Oogun pupa
Kiyesi oogun toba romo eleda re.

1 Like

Re: .. by Nobody: 12:58pm On Jun 25, 2015
Ifunra loogun agba, agba loogun ifunra.

E kiye sara.

1 Like

Re: .. by Nobody: 1:00pm On Jun 25, 2015
x

1 Like 2 Shares

Re: .. by Nobody: 1:06pm On Jun 25, 2015
x
Re: .. by idrisalomagold(m): 4:00pm On Jun 25, 2015
Mo gbadun yin gan ni o. Ejowo, ohun ti mo n fe ni ogun ti o ma n mu nnkan omokunrin tobi gidi gan.
Re: .. by Nobody: 4:52pm On Jun 25, 2015
x

1 Like

Re: .. by Nobody: 4:53pm On Jun 25, 2015
idrisalomagold:
Mo gbadun yin gan ni o. Ejowo, ohun ti mo n fe ni ogun ti o ma n mu nnkan omokunrin tobi gidi gan.

Mo n bo.
Re: .. by bolorunfem(f): 10:56am On Jun 26, 2015
E jowo, oogun ibile wo ni a le lo fun omo ti pneumonia nyo lenu. A dupe pupo.
Re: .. by sammyjay76(m): 1:57pm On Jun 26, 2015
[quote author=healthFirst post=35136583]ORISIRISI OOGUN
Oogun funfun
Oogun dudu
Oogun pupa
Kiyesi oogun toba romo eleda re.[/quote
[color=#006600][/color]
Ejowo se alaye dada nipa awon oogun ti e daruko naa, ki olukuluku le mo bo ti ye ka se si.
Leekan si edakun efi oogun Sickle Cell miran ranse si bi fun anfaani awon to ni awon eniyan bee lowo to si gbagbo ninu ewe ati egbo, awa naa ni ona ewe ati egbo ti a n lo sugbon karin ka po yiyeni ye ni oooo.
olorun a ma fun yin se o.

(1) (2) (3) ... (8) (9) (10) (11) (12) (13) (14) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 26
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.