Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,808 members, 7,817,344 topics. Date: Saturday, 04 May 2024 at 10:40 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (12) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (197780 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (9) (10) (11) (12) (13) (14) (15) ... (100) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MrCrackles(m): 12:42am On Mar 13, 2009
Ta lo fe je koboko?

Ta lo gbadun koboko?

Morenike shey u like koboko
? cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 12:44am On Mar 13, 2009
ogbeni farotika. Se oro ni eyin ma n'so ti e ba wo yara lo ni tabi ere ife ni e n'se?  grin

Mo ti gbo oun ti e wi. Maa fi omo alaigboran eleke eebu ti n'pe ra re ni Ebony le yin lowo. Sugbon mo ma mu atorin mi dani. To ba tun ta felefele de egbe mi, mo ma naa bi won tin na ole nigboro.  tongue

farotika:

Je ki nso ooto oro fun o nipa goodaasi: Nigbati awon omoge elese teere yen ti bere si fi baba s'ako (nfi tage) ni o ti gba ile oloti lo ti o si fi ara re fun oti guda.

Ti o ba ri bobo yen nisinyi, aanu re maa se e. Oti ti yi ori e patapata cry cry
Koda oro ti e so yii ti bami ninu je. Se ore mi atata goodaasi to pa Jesu oyingbo je lo wa di asinwin ati were alaso kampala bi? Oti buru o! Emi rope star ati emu nikan ni o man ya yan ni were, sugbon etu ti ko mi pe guda naa le fa laburu fun omo luwabi.

Nje e mo ile iwosan kan kan to sunmo adugbo yii? Oye ki a wa oniwosan ki won ba le bawa da si oro goodassi o  sad

Se o ri ogbeni dayo yen, oro e ti sun mi patapata, nitooto, won ni kinni re tobi tobee ge ti ennyluv ko jale pe oun o ni le fi i sile. Ennyluv ti di mario si dayo lorun o, nibe lo maa ku si lipsrsealed
Emi naa sobe tele. Kusibe ni oro dayo ati ennyluv. Olorun eledumare nikan lo le ya won. Ennyluv gbadun nkan to dara, ko le fi dayo sile lai lai.  grin

Iwo elenu fife ti o n'je Ebony yii, mo tun kilo fun e o! To ba tun so oro to ju enu e yen lo, Ifoti ti mo ma gba e, waa ma gbabe mu omi ni.  tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 1:16am On Mar 13, 2009
chamotex:

Ori Ennyluv ni DK wa bayi, tori e ni ko se le respond cheesy
You want me to call TOYOSI on ya again? angry angry
I think not tongue

@MrCrackles
I'm a born again o, I dnt know what a koboko si.
Try the other girl wink

debosky:

ogbeni farotika. Se oro ni eyin ma n'so ti e ba wo yara lo ni tabi ere ife ni e n'se? grin

Mo ti gbo oun ti e wi. Maa fi omo alaigboran eleke eebu ti n'pe ra re ni Ebony le yin lowo. Sugbon mo ma mu atorin mi dani. To ba tun ta felefele de egbe mi, mo ma naa bi won tin na ole nigboro. tongue
Koda oro ti e so yii ti bami ninu je. Se ore mi atata goodaasi to pa Jesu oyingbo je lo wa di asinwin ati were alaso kampala bi? Oti buru o! Emi rope star ati emu nikan ni o man ya yan ni were, sugbon etu ti ko mi pe guda naa le fa laburu fun omo luwabi.

Nje e mo ile iwosan kan kan to sunmo adugbo yii? Oye ki a wa oniwosan ki won ba le bawa da si oro goodassi o sad
Emi naa sobe tele. Kusibe ni oro dayo ati ennyluv. Olorun eledumare nikan lo le ya won. Ennyluv gbadun nkan to dara, ko le fi dayo sile lai lai. grin

Iwo elenu fife ti o n'je Ebony yii, mo tun kilo fun e o! To ba tun so oro to ju enu e yen lo, Ifoti ti mo ma gba e, waa ma gbabe mu omi ni. tongue
na wa oooooooo, emi leti butan beye.
Bro BOLA grin grin se e moh pe I've been going ontopic ni tori yin for the past few hours. Sugbon rara o, o kan fe ma bu mi ni. kini mo se to beye? wait o, wetin gbeske mean sef? tongue Mo kan ma ngbo lenu awan naija to wa ni sukuri mi undecided

ewo lo kan pelu ere ti emi ati ololufe mi farotika mi n se? eh? ebi se e n jelose wa ni? grin grin

emi le fe fo leti? ee ti e le try e. ewo, tin ba fayin l'aso bayi, Oga Police of Aso Rock la wa laja wa. se eti gbo?
ebi o bayin rerin o, mii rerin rara.
E moh nkan ti awan yoruba nso. . . .dnt mess with our ekiti women, a moh igba ta ma sere, a de moh igba ti aale gba erekere lowo okunrin kan kan. grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 5:31am On Mar 13, 2009
Debosiki,

Ti o ba dide lori Ennyluv nisinyi, Ma kan eso mo ile fun e ni. ah ah!!!! Ewo ni ere yatayata ti e tin she lati ose meji tokoja?

Chamoteesi, She Simibrazil ti fi e sile ni?

Toyin, Ololufe mi Toyosi nko? Ma wa ri ni opin ose
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:22am On Mar 13, 2009
Si adumarandan mi,

Jowo ma binu si mi o. Emi o kan fe ki debo se e laburu kan kan ni embarassed
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:20am On Mar 13, 2009
MrCrackles:

Ta lo fe je koboko?

Ta lo gbadun koboko?

Morenike shey u like koboko
? cheesy

Ogbeni kirakusi abi kini won npe o Se iyawo mi ni o ntasi beyen Ti o ba sora, mo ma ge koboko e yen ni angry

Olodo nla.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:29am On Mar 13, 2009
Si debosiky,

Adura ni bobo ti won npe ni goodaasi yen nfe o. Boya 'ka gbe lo si ile baba onirugbon yeuke to a ma le ri iwosan fun undecided
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 10:37pm On Mar 13, 2009
farotika:

Si adumarandan mi,

Jowo ma binu si mi o. Emi o kan fe ki debo se e laburu kan kan ni embarassed
awwww, embarassed embarassed embarassed o seun, ololufe mi.

Oya, ma worry. broda ye ko le f'owo kan mi smiley wink

farotika:

Ogbeni kirakusi abi kini won npe o Se iyawo mi ni o ntasi beyen Ti o ba sora, mo ma ge koboko e yen ni angry

Olodo nla.
rotflmao cheesy cheesy cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 10:40pm On Mar 13, 2009
Bawo ni jor cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 11:06pm On Mar 13, 2009
Dayo, ma je kin binu si e o angry angry angry

@iBK
Kilo mean pe bawo ni? shocked shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 12:47am On Mar 14, 2009
Toyin,

Kini mo tun se o??
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 1:02am On Mar 14, 2009
dayokanu:

Toyin,

Kini mo tun se o??
angry angry angry angry angry angry angry Hiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 1:12am On Mar 14, 2009
So fun mi now
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 1:16am On Mar 14, 2009
dayokanu:

So fun mi now
ootie miss me, oobere mi cry cry cry
ngba ti mo tin miss yin. . . .but it's okay sha cry cry cry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 2:49am On Mar 14, 2009
Ma binu simi jare Ise arin ose yi ni o fe yin mi lorun.

TGIF
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 2:55am On Mar 14, 2009
dayokanu:

Ma binu simi jare Ise arin ose yi ni o fe yin mi lorun.

TGIF
fimisile jor angry angry angry hissssss

what's TGIF?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 3:16am On Mar 14, 2009
Thank God Its friday (TGIF)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 4:18am On Mar 14, 2009
dayokanu:

Thank God Its friday (TGIF)
Yea, I guess. . . .

got your message. And my answer, freeze, baby freeze!! angry angry angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TOYOSI20(f): 5:17am On Mar 14, 2009
Ebony-Silk:

Yea, I guess. . . .

got your message. And my answer, freeze, baby freeze!! angry angry angry

shocked shocked shocked shocked shocked lipsrsealed lipsrsealed lipsrsealed lipsrsealed

dayokanu:

Debosiki,

Ti o ba dide lori Ennyluv nisinyi, Ma kan eso mo ile fun e ni. ah ah!!!! Ewo ni ere yatayata ti e tin she lati ose meji tokoja?

Chamoteesi, She Simibrazil ti fi e sile ni?

Toyin, Ololufe mi Toyosi nko? Ma wa ri ni opin ose

Yeah rite!!! angry angry angry angry lipsrsealed lipsrsealed
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by PERVERT9: 8:04pm On Mar 14, 2009
TOYOSI20:

shocked shocked shocked shocked shocked lipsrsealed lipsrsealed lipsrsealed lipsrsealed

Yeah rite!!! angry angry angry angry lipsrsealed lipsrsealed
yes you are baby,how is you does wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 10:59am On Mar 16, 2009
PERVERT9:

yes you are baby,how is you does wink

Iwo omo yi pafaati gan an o. Shioooooooooooo wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 12:23pm On Mar 16, 2009
Farotika,
Kini o fun Adumaradan Toyin je o. O kan ronu nipa re ni . Je kin so asiri kan fun e , o ni ti ohun ba tin ronu nipa oruko re, ironu "EROTIKA" ni o ma n wa si ori ohun.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 1:12am On Mar 17, 2009
dayokanu:

Farotika,
Kini o fun Adumaradan Toyin je o. O kan ronu nipa re ni . Je kin so asiri kan fun e , o ni ti ohun ba tin ronu nipa oruko re, ironu "EROTIKA" ni o ma n wa si ori ohun.
shocked shocked shocked WDH?!! Homewrecker tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 1:07pm On Mar 18, 2009
dayokanu:

Farotika,
Kini o fun Adumaradan Toyin je o. O kan ronu nipa re ni . Je kin so asiri kan fun e , o ni ti ohun ba tin ronu nipa oruko re, ironu "EROTIKA" ni o ma n wa si ori ohun.

Oro yi o se ajeji si mi rara wink Ti o ba mo iru ise ti mo ma nse lori omo yen ti emi ati ohun ba wa ninu yara, o maa kan sara si mi cool

Mo maa n eroticala omo yen ni gbogbo igba ti o ba ti wa s'odo mi kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 3:16pm On Mar 18, 2009
Farotika/Erotika,

Sadankata ree oh. Mo ri ise takuntakun ti on se .

O wa je ki o han gbangba pe ogunna gbongbo ti on dato lenu igbin ni iwo je.

Ati wipe oga ni o je ni ile Ise "UNDER HONDA"
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 11:57pm On Mar 18, 2009
farotika:

Oro yi o se ajeji si mi rara wink Ti o ba mo iru ise ti mo ma nse lori omo yen ti emi ati ohun ba wa ninu yara, o maa kan sara si mi cool

Mo maa n eroticala omo yen ni gbogbo igba ti o ba ti wa s'odo mi kiss

dayokanu:

Farotika/Erotika,

Sadankata ree oh. Mo ri ise takuntakun ti on se .

O wa je ki o han gbangba pe ogunna gbongbo ti on dato lenu igbin ni iwo je.

Ati wipe oga ni o je ni ile Ise "UNDER HONDA"
angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry

Farerotic, oru ise wo lo se? You wey dey explode just by looking? cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Epi: 1:33am On Mar 19, 2009
Bawo ni n nkan? Orun n re lao sun
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:08am On Mar 19, 2009
Ebony-Silk:

angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry angry

Farerotic, oru ise wo lo se? You wey dey explode just by looking? cheesy

Eeeeemi shocked shocked shocked Iwo omo yi o o ni itelorun o; o o si moore pelu angry Pelu ise takun takun ti mo nse, o o ri ope du, nse ni o n fimi wole ninu tireedi yi embarassed O ma se o.

Je ki nwa wi fun o o, ti o ba fi orokun e mejeeji kunle fun mi, ki o si fi enu ara re so iru ise nla ti mo nse fun o ninu yara ibusun; mi o ni ba e sere ife mo lai tongue tongue tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by alimat2(f): 12:56pm On Mar 19, 2009
epi:

Bawo ni n nkan? Orun n re lao sun

soo ji re bi?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 1:22am On Mar 21, 2009
farotika:

Eeeeemi shocked shocked shocked Iwo omo yi o o ni itelorun o; o o si moore pelu angry Pelu ise takun takun ti mo nse, o o ri ope du, nse ni o n fimi wole ninu tireedi yi embarassed O ma se o.

Je ki nwa wi fun o o, ti o ba fi orokun e mejeeji kunle fun mi, ki o si fi enu ara re so iru ise nla ti mo nse fun o ninu yara ibusun; mi o ni ba e sere ife mo lai tongue tongue tongue
Ise takun takun wo? shocked shocked
se nitori pe o wa lori NL lo fin so ye? tongue
Oje so ooto fun wan.
Lanan, bi mo se wo inu yara, mo ba e lori bed, oti la e nu e so ke, o ti n snore. grin grin
nawa o. . . . mo suspect e sef. ko n se ekini e lele yi o, oti ju ere merin lo. se obirin imi wa ni? shocked shocked shocked

Eje so fun mi ooo. toripe dayokanu ti n fe owo mi, sugbon ni to ri ife ti mo ni si o ni mii fi da lo hun.
sugbon to ba je wipe o ti n se ashewo kakiri, so fun mi o sad sad
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Hauwa1: 4:18am On Mar 21, 2009
Silk ati erotica tabi farotica shocked grin. mo gbe oju si ile o cool

kare grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 10:21am On Mar 21, 2009
farotika:

Nipa ti ogbeni judaasi,  rara o ,  goodaasi, o dabi pe omo naa ti lo p'okunso o nitoripe o pe ti mo ti gbo nipa re gbeyin.

debosky:

ore mi atata farotikky mo n'jolifikeeti gidi gaani. Koda igbadun ti fe yi mi lorun!  grin
Oro buruku ma leyi o! Ejoo ki le ro pe ole fa ki goodaasi lo p'okunso? Se awon omoge o fun ni adun ti n'be laarin itan won ni tabi se o je gbese nla ti ko le san ni? Ara adugbo e dami lohun o! Ema dake je ki a ma ri ogbeni goodaasi o!

farotika:

Je ki nso ooto oro fun o nipa goodaasi: Nigbati awon omoge elese teere yen ti bere si fi baba s'ako (nfi tage) ni o ti gba ile oloti lo ti o si fi ara re fun oti guda.
Ti o ba ri bobo yen nisinyi, aanu re maa se e. Oti ti yi ori e patapata cry cry

debosky:

Koda oro ti e so yii ti bami ninu je. Se ore mi atata goodaasi to pa Jesu oyingbo je lo wa di asinwin ati were alaso kampala bi? Oti buru o! Emi rope star ati emu nikan ni o man ya yan ni were, sugbon etu ti ko mi pe guda naa le fa laburu fun omo luwabi.
Nje e mo ile iwosan kan kan to sunmo adugbo yii? Oye ki a wa oniwosan ki won ba le bawa da si oro goodassi o  sad

farotika:

Si debosiky,
Adura ni bobo ti won npe ni goodaasi yen nfe o. Boya 'ka gbe lo si ile baba onirugbon yeuke to a ma le ri iwosan fun undecided
singing. .

sibesibe ota nlu ilu ibaje
oba Oluwa ko ma nije o dun
toba lo dun nko?
omo awon ota ni yoo maa jo

aba ni'kan n da
ikan kan ko le d'okuta
ero ibi ti e ro
ire lo ja si fun wa
  tongue

debosky:

N'je eti ri ogbeni goodasi to pa jesu oyingbo je tabi babsongudus ni adugbo yii? Mo ni oro pataki ti mo fe ba won so o, eni keni to ba ri won ko ba mi so fun won o.
d[b]O[/b]bosky de-be de-be, mo n gbo ti e
maa wi, maa wi kii pa okorin
ki lo fe ri mi fun jare
and next tym ti o ba fe ri mi, iwo sha ti wa si Forum Games, maa get message e
babson wa ni 'kiloruko ti a npe obo?'

(1) (2) (3) ... (9) (10) (11) (12) (13) (14) (15) ... (100)

Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá / Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 55
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.