Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,839 members, 7,851,841 topics. Date: Thursday, 06 June 2024 at 09:01 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (34) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (198752 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (31) (32) (33) (34) (35) (36) (37) ... (100) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Sauron1: 11:51pm On Jun 18, 2009
chamotex:

Bleep it . . . . . . I give up man. grin grin grin That sounded more like Somali Pirates

Nor vex Chamotex. . . . . . .I just wanted to disturb you a bit. grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dyabman(m): 12:00am On Jun 19, 2009
ok oooo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 12:01am On Jun 19, 2009
~Sauron~:

Nor vex Chamotex. . . . . . .I just wanted to disturb you a bit. grin

But they did a good job though . . . . . just remembering the script was impressive enough.
It's like asking Sauron to freestyle in Japanese.  grin grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 12:05am On Jun 19, 2009
chamotex:

Did anyone see that guy wearing BANTE? cheesy grin
grin grin

o da bi ti AGBAKO!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 12:07am On Jun 19, 2009
faakay:

grin grin

o da bi ti AGBAKO!

LMAO grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TOPE20001(f): 12:07am On Jun 19, 2009
faakay:

grin   grin   

o da bi ti AGBAKO!

death grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 12:14am On Jun 19, 2009
chamotex:

LMAO grin grin grin

TOPE2000!:

death grin grin grin

OLorun oni je ka koLu AGBAKO ooo grin

Awon AJE wani NairaLand yi! grin

Aro meta!!! Tani oranti AYA MATANGA?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 12:42am On Jun 19, 2009
faakay:

OLorun oni je ka koLu AGBAKO ooo grin

Amin ooooooooooo cheesy grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 6:58am On Jun 19, 2009
Eyin olote tun ti de ibiyi. Topsy/Farerotica ati Adobosiki Iroyin buruku ni e ngbe kiri.

Kaka ko remi Ma mu ire re odo. Emi okunrin meta Ojabo kofo Omo na stud.

Debo, ToH tin wa e kakiri Omo yen nife re pupoju sugbon mo so fun pe Ennyluv lo wa loju opon re bayi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dyabman(m): 7:04am On Jun 19, 2009
iwo nkan , se iwo kin se olote ni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:41am On Jun 19, 2009
dayokanu:

Eyin olote tun ti de ibiyi. Topsy/Farerotica ati Adobosiki Iroyin buruku ni e ngbe kiri.

Kaka ko remi Ma mu ire re odo. Emi okunrin meta Ojabo kofo Omo na stud.

Debo, ToH tin wa e kakiri Omo yen nife re pupoju sugbon mo so fun pe Ennyluv lo wa loju opon re bayi

Dayo, se iro ni mo pa mo e ni wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:34pm On Jun 19, 2009
KAMOTEESI K'AGBAKO LODO ASEWO[center][/center]

Awon yooba bo won ni: "afogbon ologbon sogbon o ni te boro". Owo awon agba yi ni mo ranti ti mo se pinu ati so itan kekere kan ti o sele si ogagun obinrin KAMOTEESI.

Isele yi ni yio fi idi ti kamoteesi se feran obinrin mule.

Ojo buruku esu gbomimu ni ojo ketala, osu kefa egberun meji odun o le marun-un lehin iku oluwa wa. Ni Irole ojo ti a nwi yi ni Kamoteesi ri omobinrin kan ni oju popo. Omobinrin yi dara, o pon, o singbonle o si lewa bii koro isin. Omo yi wo booda Kamoteesi loju to be gee ti won ni lati paaki oko ayokele won. Won se owo si omobinrin naa pe ko wa; ohun naa ti tele won wo oko lai beere ibi ti won nlo.

Ni kete ti won te oko leti ni uncle Kamo ti beere oruko obinrin yi, o si dahun pe Blialu ni oruko ohun. Won fi oro jomitoro oro ki won to de ile booda wa Kamo.

Bi won se wole, Kamo beere nkan ti Bilialu ma je tabi mu; sugbon omo naa ko oni ohun o je tabi mu. O ni ki Kamo wa se nkan ti o ba fe se (booda Kamo o fe se  nkankan tele o, o kan fe mo omobinrin naa ni nitoripe isekuse o si ninu eje won). Sugbon yooba bo won ni: nkan ti o ba ma se eeyan ko gbo. Bi Kamo se gbo oro Bilialu ni kinni e gberaso, l'oba ki omo naa mole ti o si gbe wo iyewu lo.

Won se ere ife fun bii wakati meta. Nigba ti o ya ni booda Kamo toro aye lati lo si ile iwe. Omo naa gba ni aye. Booda we tan, o si wo yara ibusun pada; sugbon Bilialu ti kuro ninu yara. O wo gbogbo ayika, o pe oruko re sugbon ko ri enikeni daa lohun. Eru baa o si pada si iyewu. Bo se de ori ibusun ti won se ti se ere ife, Iwe pelebe kan ni o ba ni ori ibusun naa.

Bi o se mu iwe yi ti o si woo; ni o di letter ti Bilialu ko sii; ni ori re ba wu gboooooooo. O sinmi fun iseju kan ki o to ka letter naa. Ninu letter yi ni Bilialu ti so pe oku ni ohun, o tun soo siwaju sii pe Kamo o gbodo fi owo kan obinrin miran titi di ojo iku re pe ijo ti o ba ti dan an wo, gbogbo igba ni yio maa wu pe ki o ba obinrin sun, ti o ba ya, a maa ba eranko sun, bi o ba si pe die si, yio maa ba igi inu igbo sun.

Booda Kamo duro fun odindi osu mefa ni alai ba obinrin sun. Igba ti won o le fi mo ara mo ni won ba lo si ile alasewo. Gbara ti won dide lori asewo yii ni o yira pada ti o si di Bilialu pelu erin muye lenu.

Lati igba naa ni booda Kamo ti da bi won se da yi o cool cool cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 7:45pm On Jun 19, 2009
OMG!! TOPSY MI, THAT'S TOO DEEP FOR ME TO UNDERSTAND O.

topsy25:

Yooba bo won ni: "agba o si mo, ilu bage; baale ile ku, ile d'ahoro". Se toripe mo fun ara mi ni aye ojo die ni toyin se fe ko oju mi si oorun ale Paga!!! o ma se ooooooo. "ologinni r'ajo, ile wa dile ekute" angry Se tori ise kekeeke ti omo ti won npe ni ifeleke yen so wipe ohun ko lo si ile egbon e (kii se ile daddy e o) ni o se wa nso wipe ohun ni o maa fe

Emi o le maa ba ifeleke du iyawo o. Ti o ba fe se temi o mo bi o se maa ri mi cool cool angry angry
LOL, sebi iwo nan moh wipe emi ni ti e tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 7:46pm On Jun 19, 2009
IFELEKE,

bawo ni na? oti tojo meta ti mo ti ba e s'ere soro.
se ke si? in an nu'le si ko? (ekiti yoruba)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 1:31pm On Jun 21, 2009
Toyin Tomato,
Ojo kan pelu joo(ise lo gbomimu lenu ojo meta yi), bawo ni? se alaafia lo wa?
@Gbogbo Ile
In Okun oo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 12:25am On Jun 22, 2009
IFELEKE:

Toyin Tomato,
Ojo kan pelu joo(ise lo gbomimu lenu ojo meta yi), bawo ni? se alaafia lo wa?
@Gbogbo Ile
In Okun oo
eyah, mo moh wipe o responsible. ku ise jare.
Mo kuku wa pa, sukuru ti fe bere, mo kan get ready ni.
Jor, bawo ni YME? se ke si?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 6:45am On Jun 22, 2009
FL Gators:

OMG!! TOPSY MI, THAT'S TOO DEEP FOR ME TO UNDERSTAND O.
LOL, sebi iwo nan moh wipe emi ni ti e tongue

We yoo p'aja lobo komi awe wink. Ko ba tia se temi, gbon ifeleke re. Me yoo b'omode kekere ni a du aya (ekiti kete)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 10:09am On Jun 22, 2009
FL Gators:

eyah, mo moh wipe o responsible. ku ise jare.
Mo kuku wa pa, sukuru ti fe bere, mo kan get ready ni.
Jor, bawo ni YME? se ke si?

y me wa ninu isinmi olojo gbogboro(long holiday).
Ku imura ile iwe.

topsy25:

We yoo p'aja lobo komi awe wink. Ko ba tia se temi, gbon ifeleke re. Me yoo b'omode kekere ni a du aya (ekiti kete)
ogbeni Ijare yi so ra re o!
Ere melo lu o fe kimi wi si o kuo gbon aya mi re?
Mo wi si o kuo wa aya titun lo su'jare.
Gbon toyin re!. . .(Ekiti Kete grin)
@dayo,ajenti,toyin,tubabie,tope,kamoteesi ati Gbogbo Ile
Ojumo Ire oo
Aba rin A gbe In o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 6:44am On Jun 23, 2009
eeyah, mo hope pe o wah alright sha.
Wishing her a safe holiday.

@Topsy
I no want you o, make you carry go to your Ijebu wife lipsrsealed tongue

Ifeleke, nice Ekiti there. Keep it up, am learning from you kiss kiss
Jo bami wi si awe topsy ye wipe mi ke se moh. mi ke ni gba oko'loko o. tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayoorr: 7:55am On Jun 23, 2009
FL Gators:

eeyah, mo hope pe o wah alright sha.
Wishing her a safe holiday.

@Topsy
I no want you o, make you carry go to your Ijebu wife lipsrsealed tongue

Ifeleke, nice Ekiti there. Keep it up, am learning from you kiss kiss
Jo bami wi si awe topsy ye wipe mi ke se moh. mi ke ni gba oko'loko o. tongue

Ye se wi si o fo mo ti l'oya Gbogbo awawi e yen o sise o, mo nife e, mo si fe fi e s'aya. Ti o ba feran mi bi mo se feran e, so fun mi maa si se bo se to wink kiss kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 9:34am On Jun 23, 2009
FL Gators:

Ifeleke, nice Ekiti there. Keep it up, am learning from you kiss kiss
Jo bami wi si awe topsy ye wipe mi ke se moh. mi ke ni gba oko'loko o. tongue
Ogbeni tope, gbon re! toyin lo shu ba(ekiti)
@gbogbo Ile
In ku ojumo oo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:13am On Jun 23, 2009
FL Gators:

eeyah, mo hope pe o wah alright sha.
Wishing her a safe holiday.

@Topsy
I no want you o, make you carry go to your Ijebu wife lipsrsealed tongue

Ifeleke, nice Ekiti there. Keep it up, am learning from you kiss kiss
Jo bami wi si awe topsy ye wipe mi ke se moh. mi ke ni gba oko'loko o. tongue

Ye se wi si o fo mo ti l'oya Gbogbo awawi e yen o sise o, mo nife e, mo si fe fi e s'aya. Ti o ba feran mi bi mo se feran e, so fun mi maa si se bo se to wink kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 2:30am On Jun 24, 2009
Topsy, se wan ban e ni? tani ayoor?

topsy25:

[/b]

Ye se wi si o fo mo ti l'oya Gbogbo awawi e yen o sise o, mo nife e, mo si fe fi e s'aya. Ti o ba feran mi bi mo se feran e, so fun mi maa si se bo se to wink kiss
mo fe ran e sugbon on'iyawo. o dun mi o cry cry cry
grin

@IFE
bawo ni, ololufe mi smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 2:39pm On Jun 24, 2009
FL Gators:

Topsy, se wan ban e ni? tani ayoor?
mo fe ran e sugbon on'iyawo. o dun mi o cry cry cry
grin

Rara o cool Won ban mi o. Mi o mo bi ayoor se yo lori ise mi o undecided

Gbagbe nipa ifeleke ki o si f'ara mo mi. Ifeleke kan nparo fun o ni, o ti ni iyawo meji sile pelu omo meje tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by UNLEASHED(m): 3:46pm On Jun 24, 2009
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 5:24pm On Jun 24, 2009
topsy25:

Gbagbe nipa ifeleke ki o si f'ara mo mi. Ifeleke kan nparo fun o ni, o ti ni iyawo meji sile pelu omo meje tongue
Ahhh awe, we e pa yeye ninu iro.Ta lo so fun e pe mo ni iyawo meji?
toyin mi(adumaradan)mo mi daada so,ko le gba e gbo in fact e yo'o gba o gbo tete w'aya re lo s'ujare. tongue

FL Gators:

@IFE
bawo ni, ololufe mi smiley
orekelewa temi nikan(ti awon kan wa ona lati gba) alaafia ni mo wa joo.
bawo ni? se o n palemo fun ibere ile-iwe e?

@unleashed
kini awon efon yen n se ni agbari e?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by PERVERT9: 7:19pm On Jun 24, 2009
e jowo eyin enia mi nibo ni moti le ri ORUKA AMUDO ATI ORUKA ALUWO mo fe setu ara mi pelu awon enia kan ninu ilu wa yi tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 7:39pm On Jun 24, 2009
PERVERT9:

e jowo eyin enia mi nibo ni moti le ri ORUKA AMUDO ATI ORUKA ALUWO mo fe setu ara mi pelu awon enia kan ninu ilu wa yi tongue
grin
Oruka Amudo ati aluwo ke? ta lo fe fi do?
awon wo lo fe luwo?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 10:40pm On Jun 24, 2009
topsy25:

Rara o cool Won ban mi o. Mi o mo bi ayoor se yo lori ise mi o undecided

Gbagbe nipa ifeleke ki o si f'ara mo mi. Ifeleke kan nparo fun o ni, o ti ni iyawo meji sile pelu omo meje tongue
Mii le gbagbe IFE na. Omo ye ti fine ju. lol
Sugbon o moh wipe mo feran e ju lo.
Ti okurun ba le fe obirin meji, then emi nan e fe okurin meji grin grin

IFELEKE:

Ahhh awe, we e pa yeye ninu iro.Ta lo so fun e pe mo ni iyawo meji?
toyin mi(adumaradan)mo mi daada so,ko le gba e gbo in fact e yo'o gba o gbo tete w'aya re lo s'ujare. tongue
orekelewa temi nikan(ti awon kan wa ona lati gba) alaafia ni mo wa joo.
bawo ni? se o n palemo fun ibere ile-iwe e?

in kasan o, se dada nu le? (I tried tongue)
My dear, mo ti wa ni nu suite mi jare, mo kan duro di next week ki sukuru bere smiley
Inu mi dun lati gbo alafia e. Se awan boys aka robber ye ko disturb e man embarassed embarassed

IFELEKE:

@unleashed
kini awon efon yen n se ni agbari e?
rotflmao. oh dear.
So you're nughty like this cheesy cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 10:50pm On Jun 24, 2009
Eyin eeyan mi kilonsele, Eku dede iwo yii?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 10:55pm On Jun 24, 2009
O kun o. in seun, dede la a. in siko? smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 11:02pm On Jun 24, 2009
Seun Keye, emorokun kabi seri? I can speak my dialect too cheesy

(1) (2) (3) ... (31) (32) (33) (34) (35) (36) (37) ... (100)

Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá / Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 53
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.