Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,162,736 members, 7,851,532 topics. Date: Wednesday, 05 June 2024 at 09:40 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (198741 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (33) (34) (35) (36) (37) (38) (39) ... (100) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by No2Atheism(m): 8:52pm On Jun 27, 2009 |
men i am hopeless at reading and writing yoruba, its a like advance mathematics whenever i want to read or write it. speak - very good at it listening - also very good at it write - poor at it read - poor at it @topic Odabi enipe awadakerikeri ni awon eniyan kan se ni ibibayi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 3:35pm On Jun 28, 2009 |
No2Atheism, oruko e yi le yo eeyan leyin oo. Ede yoruba dun lati so ati lati ko sile. . .it only needs practise. @gbogbo ile Eku Isinmi oo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 5:42pm On Jun 28, 2009 |
N2A, Yoruba is not that hard to write na. Just write it down as you say it. @IFELEKE and topsy25 and eyin ara thread How you dey. moti miss gbogbo yin eku isimin eni o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by No2Atheism(m): 6:50pm On Jun 28, 2009 |
FL Gators: yes u are correct but the problem is that: I can't separate the words properly hence i become slow to write it. for example: nigbawo or igba wo or nigba wo is a typical confusion that i face regularly. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kaypumpin2(m): 7:49pm On Jun 28, 2009 |
Ibi yi ni awon omo k'aro o'jire fi idi kale si. Eku atoto nu. Oodua a gbe wa oo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:13am On Jun 29, 2009 |
No2Atheism: Igbakeji atenisiimu (aka. No2atheism) Emi gege bi enikan ni igbagbo pe o le ko yooba daadaa. Iwo saa ti ni igbagbo ninu ara re, o maa ya e lenu iru imo ijinle ti o ni ninu ede yooba |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by benlay(m): 9:18am On Jun 29, 2009 |
eba mi pari oye tabi ijinle oro wonyi e wo iyawo asesefe to nse bi enipe ko le pe oko loruko, beeni , , iyawo pastor to nkiri buredi lojo sonde, , , |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:28am On Jun 29, 2009 |
FL Gators: Bawo ni iyawo temi nikan Se daadaa lo wa gege bi mo se wa Se sukuru e nlo deedee Pele o, mo ti nsaferi e gan an ni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 1:04pm On Jun 29, 2009 |
topsy25:tope oore mii, Awe mo wi si o kuo gbon'ya mi re abi iru ore wo luore? gbon toyin re,woya lo su'jare benlay:be n le owo ija o ti ba iyawo asesefe ni, ti ise ba dun lara e, aadadanmo. iyawo alufa to n kiri bureedi lojo sonde,oni bara e n bole bo ni yen. topsy25:Ooto oro lo so ore. No2atheism There is no proffesor of yoruba on this thread(my thought) all of us are rookies joined together by the love of our mother tongue.We speak it anyhow but the message is always properly passed across. So,gbiyanju lati darapo mo tireedi yi,o ma se e l'anfani to po. kay_pumpin:kayode,oodua a gbe gbogbo ya. . .bawo ni? FL Gators:aayo mi, aayun re so mi lopo lopo(Ve missed you seriously) se alaafia lo wa? mo yoju si baba ati iyami re lo pin ose to koja yi won si se mi lalejo daada. Joo bami dupe lowo won fun iyan,eran okuru and emu funfun ti won fi se mi lalejo, mo gbadun e gan ni. Bawo ni ile-iwe? se on gbaradi?. Ma se gbo oro si awon abelejayan lenu(bi oree mii tope) won kan n se lasan ni. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 1:32pm On Jun 29, 2009 |
topsy25: Ogbeni topsy aayan ogbufo oruko ogbeni yen ko da maran. Itumo No2atheism ni ainife atenisiimu/ akofe atenisiimu/ ko saye atenisiimu. Awon omobirin ti won kun ori tireedi yi nko? Ati ma ba omokunrin soro ti su mi o! Argenti aya mi owon - nibo lo wa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 3:40am On Jun 30, 2009 |
atenisimu abi alatenuje ni e n pe. Eyin omoge asiko e ma bo nibiyi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 2:55pm On Jun 30, 2009 |
tireedi yi se wa da(dry) bayi? @gbogbo Ile, se ko si o? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 5:38pm On Jun 30, 2009 |
IFELEKE: Kosi o, gbogbo wa wa bi oyin. Sugbon kini iwo niro pe ale se lati mu tireedi yii dun sii ju eleyii lo? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:03am On Jul 01, 2009 |
debosky: Debo, oro e ti sun mi. Olorun o ni je ki abeyinto lasan lasan pa e o. Amin |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:09am On Jul 01, 2009 |
tubabie: Emi leero pe o ye ki a le maa fi awon ajasa kan kan si inu tireedi yi. Nkan ti mo ro ni eyi ti mo fi nko awon itan nkan ti o ti sele si awon oloju bi-o-mu-o-lo bi ti debo ati kamoteesi. Sugbon ko si eni ti o ri oro so si awon itan alarinrin ti mo so. Bi enikeni ba ni awon nkan alarinrin ti o le fun wa ninu tireedi yi, ki iru eni be soo ki a si gbe l'ese. Ko je bo se je. Si Ifeleke, iyawo olele re nkan, se o nfun e se daadaa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 12:44pm On Jul 01, 2009 |
Gbogbo ile se dada l'ewa? debosky: mo ti miss e gan, ibo ni o wa lati ojo yi? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 1:13pm On Jul 01, 2009 |
tubabie:tubabie, emi gan n gbiyanju lati ronu si awon nkan ti o le mu tireedi wa yi larinrin(dun). iwo naa darapo pelu mi ati awon to ku lati gbe tireedi wa yi laruge. topsy25:tope ooto lo so, ma a tesiwaju pelu awon ajasa to n ju si inu tireedi yi, emi gan ma fun e ni full support pelu contributory ajasas ti te mi. iyawo olele mi(adunmaradan temi nikan) wa, o n gbe fun mi ni 24/7. Gbogbo ile, se alaafia ni? gbogbo eyin orekelewa wa ninu tireedi yi, tireedi o gbodo dry mo oo, ojuse yin ni lati gbe laruge pelu presence yin all the time. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 1:35pm On Jul 01, 2009 |
argent: Ise ni mo nse aya mi. Mo ti fe ra rolls royce ikeji fun e fun ipariose (weekend) to nbo. topsy25:Oro gidi ni o so ogbeni farotopzi. Ise ti mo nse ni o je kin raye ko esi si itan alarinrin ti o ko nipa kamoteesi omo onisekuse yen. Dajudaju a nilo ori oro titun lori tireedi yii, mo fara mo oro ti o so, emi naa si ma wa ajasa lati ma ju sori eto yii. PERVERT9: Emi mo onisegun kan ti o le ran e lowo lati ra ogun moko le - oruko e ni goodaasi (to pa jesu oyingbo je nitori obo). Ogbeni yen si ni ore kan ti o nje babsongudus - awon mejeji le ran e lowo. Sugbon teti si ikilo mi: Awon kan bii dayokunu ti padanu lehin ti won lo ogun moko le yii o! Mo gbo pe nse ni opa dayokunnu di kekere bii ika omode. Awon aya dayo ko si feran re mo nitoripe ko le te won lorun mo lori idubule. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 4:01pm On Jul 01, 2009 |
debosky:doboski dobo-lawin shey o fe ki n ban e ni? ma ma ba mi loruko je o, oruko rere ko see fowo ra. omo jeje ni mi, jeje lomo eko nlo. awon iyawo e nko? so fun [b]Pafati [/b]ki o lo si Pen Cinema ni Agege, ki o bere Opa Ehin ati Ajase PokiPoki epa ijebu. ti o ba ti lo mejeji po pelu burutanshi awon mallam, kia ni oko e to wa ni recession maa soji sharp sharp. sugbon o gbodo ready lati fun gbogbo omoge ni kini yen o nitori pe won maa maa bee ni nigba ti won ba ri eru to wa labe e to ranju tantan e ku ojo mewa, eyin eeyan. osu tuntun yi a san wa sowo, somo, si alaafia baba oro. A dara fun wa oooo!!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 5:29pm On Jul 01, 2009 |
IFELEKE:awwww, now that sweet. Thanks love mo hope wipe awan ile mi tan ju e dada Ile-iwe n se dada. but e no easy topsy25:kini awan question mark ye wa fun? se o n question ife e simi ni? dayokanu:SMH. No be you? topsy25: |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by PERVERT9: 7:31pm On Jul 01, 2009 |
IFELEKE:apayan niwo okunrin ifeleke yi o fe pami so dat wa le ma domi niywo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 10:22am On Jul 02, 2009 |
goodass:goodaasi, se pe iwo naa ma n na pen cinema? se baba iyabo oni shot shi wa nibe? FL Gators:Awon wo niyen? iwo naa mo wipe iwo nikan ni now, iwo lo ma lo mi gbo mo de ma make sure mo mo lo e gbo naa Pele, nothing good comes easy you know so, mura si ile iwe e daada. PERVERT9:apayan ke? iwo ko lo bere nipa nkan to ma mu e le? mo de prescribe fun e ko lo. Mi o ready lati pa e oo sugbon mo le ma render free services in kind fun awon iyawo incase. . . @gbogbo Ile,(tope,toyin,pafati.debo,dayo,ajenti,tubabie. . .et al) eku ojumo oo, se alaafia ni? Ojumo Ire fun gbogbo wa oo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 11:30am On Jul 02, 2009 |
Gbogbo awon aroni pin? awon da? Ni bo le wa, Ni ori field of play mo da bi Roger Miller, Ti o ba ko lu mi mo da bi Caterpilla haaaaaaaaaaaaaaaaaaaaa!!! Ma te anybody mo le |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 12:22pm On Jul 02, 2009 |
Dobolawin abi Adobosiki, Se Mokole ti o n lo fun ennyluv niyen ti o fi fe ku nitori re? Ma ba oruko rere mi je. Se o mo pe awon omoge asiko wa nibiyi ni? Ogun Mokole to dara ju niyi: Po simenti and Milo die. Gbe mu ni aaro kutukutu Ajebiidan ni Bi concrete se man le be ni oko re yi o se le titi ipadabo Oluwa wa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:02pm On Jul 02, 2009 |
FL Gators: Laise aini aini, mo mo pe nkan kan wa laarin iwo ati ifeleke. Ifeleke si ree, aburo mi ni Mo ti parowa fun o titi ki o se temi nikan sugbon o dabi eni pe o si fe maa gbe ija kiri Ti o ba je pe o ni ife mi ni tooto ni, iwo iba ti so fun omo ifeleke yen ki o jawo ninu apon ti o yo ki o lo gb'omi ila ka ina. Si Ifeleke, awe o, gbon aya mi re o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:03pm On Jul 02, 2009 |
faakay: Awon wo ni o nro e pin. Abi iwo ni o nro ara e pin |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:06pm On Jul 02, 2009 |
PERVERT9: Sebi iwo ni o nwa amokole ati ameponro |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:11pm On Jul 02, 2009 |
Eyin temi ninu tireedi yi, mo mo pe opolopo wa ni o ti ka iwe alawiye yooba ni kekere; eni ti o ba ranti awon eko inu iwe yii, ki o gbee si wa leti. Fun Apeere: Obe baba bo, o ba obo oba A o ba baba be oba A o baa bee |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 5:47pm On Jul 02, 2009 |
topsy25: olobe ni boboyi sha? se mo ba e wi ni? e wo ni ti yin? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 6:15pm On Jul 02, 2009 |
dayokanu:pafati she o n gbo be yen? ogun ti mo ni ko lo ni dayo tun soro nipa e yii. gbiyanju ko lo, wa a ri wipe ajebiidan ni. topsy25:ogbeni tope, awe ke e se o ran? se me ji o han kuo gbon'ya mi re? we wa pupon oju mi oo! mo je mi ba o ja o, suo mo fo ore laaare. topsy25: topsy25:O mu mi ranti igba ewe(childhood) Awon bi: Gbade De Ade Oba A o ba a deee . . .tope,se I.J london loti ko gbogbo iyen? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 10:00am On Jul 03, 2009 |
topsy25: Ha mo ranti dada, a o ba bade be oba A o ba bee. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 10:45am On Jul 03, 2009 |
IFELEKE: Iwo wii Ode ta ofa Ofa foo, o ba ife oba A o ba ode be oba A o baa bee |
(1) (2) (3) ... (33) (34) (35) (36) (37) (38) (39) ... (100)
Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá / Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 75 |