Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,156,367 members, 7,829,941 topics. Date: Thursday, 16 May 2024 at 01:58 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (37) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (198201 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (34) (35) (36) (37) (38) (39) (40) ... (100) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 10:48am On Jul 03, 2009
Lati inu iwe alawiye ti ewe kaarun:

Eranko nla ni efon, o si fi ara jo maalu pupo. O ni iwo meji ni ori re. O si ni patako tabi bata ni ese re , undecided
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by PERVERT9: 7:54pm On Jul 04, 2009
igba wo ni a to ma bere si ni gbe nkan si nkan ninu ile yi abi ejo nikan la ma ma barawa ro ni,e ranti pe oro pupo ko kun agbon o.
Its time for action e je ka bere sini gbe nkan sikan
E PANA
E PANA O
KO LU KALUKU KO WA MU TI E

mo ti fi magun si lady ti mo like ninu ile yi lara,anybody to ba de be ma takikti bi obo ni,so e ma try ibe rara o
iku lero e tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 1:14am On Jul 05, 2009
Hi guys smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by vikiviko(m): 10:18am On Jul 05, 2009
Eyin ara eko ati gbogbo nigeria mo ki yin.

Olorun ko sowa .

nigeria o ni baje

se mo try pelu ede yoruba mi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 2:37pm On Jul 05, 2009
PERVERT9:

igba wo ni a to ma bere si ni gbe nkan si nkan ninu ile yi abi ejo nikan la ma ma barawa ro ni,e ranti pe oro pupo ko kun agbon o.
Its time for action e je ka bere sini gbe nkan sikan
E PANA
E PANA O
KO LU KALUKU KO WA MU TI E

mo ti fi magun si lady ti mo like ninu ile yi lara,anybody to ba de be ma takikti bi obo ni,so e ma try ibe rara o
iku lero e tongue
pafati!
olorun o ni je ki o gbe nkan sinu panpe/takute.
nipa ti magun, se iwo o mo wipe awa kan ni awosoke ni? mo ma wo magun e soke titi ti iwo gan ma wa fi takiti obo.

vikiviko:

Eyin ara eko ati gbogbo nigeria mo ki yin.

Olorun ko sowa .

nigeria o ni baje

se mo try pelu ede yoruba mi
fikifiko ogbiyanju joo sugbon oruko e yi lagbara oo fiki-fiko!

FL Gators:

Hi guys smiley
aayo temi nikan, se alaafia ni?

@gbogbo ile
E n le oo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:01am On Jul 06, 2009
PERVERT9:

igba wo ni a to ma bere si ni gbe nkan si nkan ninu ile yi abi ejo nikan la ma ma barawa ro ni,e ranti pe oro pupo ko kun agbon o.
Its time for action e je ka bere sini gbe nkan sikan
E PANA
E PANA O
KO LU KALUKU KO WA MU TI E

mo ti fi magun si lady ti mo like ninu ile yi lara,anybody to ba de be ma takikti bi obo ni,so e ma try ibe rara o
iku lero e tongue

Pafaati, mo fe ki o mo pe bi a se nbara wa ro ejo ni a nse nkan miran leyin ti oju ba ti pa firin grin cheesy

Ti o ba fe wada ooto ti o wa ninu oro mi, beere lowo Ifeleke a si so fun o pe mo tu fun toyin loyun. Nitooto, oyun naa ti nlo si bi osu meta nisinsinyi wink

E seun o, ki e si ma jolifikeeti
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ronkeenuf(f): 11:26am On Jul 06, 2009
E ku ile eyin omo kaaro ojiire, mo ni ki n ki yin ni. Mo sese mo pe iru thread bayii wa ni, inu mi si dun si i. Omo yooba gidi mi, ko si ti mi loju lati soo. ee tu ma gbo lati odo mi l'agbara Olorun. Ire oo wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrTomgirl(f): 3:42pm On Jul 06, 2009
Eyin omo kaaro ojiire, e kaabo si osu Agemo!!!!!!!!!!!!!!!!!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 6:11pm On Jul 06, 2009
IFE,
Mo wa pa. thanks for asking.
You nko? smiley
I hope those robbers did not come to disturb you again eh? angry

topsy25:

Ti o ba fe wada ooto ti o wa ninu oro mi, beere lowo Ifeleke a si so fun o pe mo tu fun toyin loyun. Nitooto, oyun naa ti nlo si bi osu meta nisinsinyi wink

E seun o, ki e si ma jolifikeeti
shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked But. . . . but. . . . .I. . . .ehrrrrm. . . shocked shocked shocked shocked

IFELEKE shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 6:25pm On Jul 06, 2009
Toyin ba wo ni?
Mo gbo pe o ti l'oyun tongue
Se baby n kick?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 6:32pm On Jul 06, 2009
argent:

Toyin ba wo ni?
Mo gbo pe o ti l'oyun tongue
Se baby n kick?
((((((((((((hugssss)))))))))))))) Long time oh.
Woah, what's that that just bumped me, so debosky did his job already? shocked tongue
No wonder you've been missing. Awww, twins or triplets? grin

Anywaz, I dey. iwo nko?
I didn't miss the baby shower, did I? embarassed
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 7:05pm On Jul 06, 2009
topsy25:

Pafaati, mo fe ki o mo pe bi a se nbara wa ro ejo ni a nse nkan miran leyin ti oju ba ti pa firin grin cheesy

Ti o ba fe wada ooto ti o wa ninu oro mi, beere lowo Ifeleke a si so fun o pe mo tu fun toyin loyun. Nitooto, oyun naa ti nlo si bi osu meta nisinsinyi wink

E seun o, ki e si ma jolifikeeti
ooto ni sugbon ogeni tope, o ti ma n paro ju! se loju ala lo ti fun toyin temi loyun ni abi lori beedi ti emi ati iyawo ti ma n sere ori papa alafaragba?
awe, we e puro ju!

FL Gators:

IFE,
Mo wa pa. thanks for asking.
You nko? smiley
I hope those robbers did not come to disturb you again eh? angry
shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked But. . . . but. . . . .I. . . .ehrrrrm. . . shocked shocked shocked shocked

IFELEKE shocked
adumaradan temi nikan, aayo ifeleke se alaafia lo wa? mo ti miss e gan ni oo infact, kiss kiss kiss
awon ole yen(armed robbers) o to be lati wa disturb mi mo, mo ti gbaradi de won, trust me.

ma da ogbeni tope yen lohun joo, o ti ma n paro ju.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 2:38pm On Jul 07, 2009
argent:

Toyin ba wo ni?
Mo gbo pe o ti l'oyun tongue
Se baby n kick?

Omo yen n kick jare. emi o mo pe omo osu meta ma nju apa ju ese bi omo yen o shocked Nitooto, omo naa ma ni agbara bi ti baba e shocked

Ajeniti, ijo wo ni iwo maa loyun fun ore mi debo Jowo kia o ti npe ju o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 2:39pm On Jul 07, 2009
FL Gators:

shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked But. . . . but. . . . .I. . . .ehrrrrm. . . shocked shocked shocked shocked

IFELEKE shocked

Se o n ti ojo omo ti mo fun e loyun e ni wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 2:42pm On Jul 07, 2009
IFELEKE:

ooto ni sugbon ogeni tope, o ti ma n paro ju! se loju ala lo ti fun toyin temi loyun ni abi lori beedi ti emi ati iyawo ti ma n sere ori papa alafaragba?
awe, we e puro ju!

Awe o, o dabi fo we mon kue wi undecided O so wipe ooto ni oro mi, o tun nso wipe iro ni. Se oyun ibeji ti mo fun iyawo mi ni o n da e ni opolo run

Jowo emi o fe ki ori e daru o nitoripe ore ni si ni o je
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 5:10pm On Jul 07, 2009
FL Gators:

((((((((((((hugssss)))))))))))))) Long time oh.
sorry, I just bumped you with my big belly, ifeleke has already done his job tongue
Didnt you notice have been missing here, the doc says am going to have twins

Anywaz, I dey. iwo nko?
Please dont miss the baby shower
Wont miss it for anything in the world tongue

kiss kiss kiss kiss mo ti miss e gan ni. Ki lo nshele?
Se o ti ya s'are bimo niyen?
Ranti lati invite mi fun naming oh, mo fe je jollof rice ati chicken.
Btw, tani baba omo larin ifeleke ati farotika  grin

topsy25:

Omo yen n kick jare. emi o mo pe omo osu meta ma nju apa ju ese bi omo yen o shocked Nitooto, omo naa ma ni agbara bi ti baba e shocked

Ajeniti, ijo wo ni iwo maa loyun fun ore mi debo Jowo kia o ti npe ju o

oyun ke  shocked ni'gba ti debo o ti ra rolls royce fun mi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 5:35pm On Jul 07, 2009
topsy25:

Omo yen n kick jare. emi o mo pe omo osu meta ma nju apa ju ese bi omo yen o shocked Nitooto, omo naa ma ni agbara bi ti baba e shocked
awe, se omo ti o fun loyun ni ijare lo ro wipe a n soro e ni?
topsy25:

Awe o, o dabi fo we mon kue wi undecided O so wipe ooto ni oro mi, o tun nso wipe iro ni. Se oyun ibeji ti mo fun iyawo mi ni o n da e ni opolo run

Jowo emi o fe ki ori e daru o nitoripe ore ni si ni o je
tope ore mii, o se o ku akitiyan ati atotonu, oyun ibeta(olosu meji abo) lo wa ninu iyawo mi,lo mu risika omo iya olobi to o fun loyun nijare was sile e. . .

argent:

Ranti lati invite mi fun naming oh, mo fe je jollof rice ati chicken.
Btw, tani baba omo larin ifeleke ati farotika grin
ajenti, emi na a lo to be lati fun iyawo mi loyun leyin opolopo ere ashekara kara.
ma worry, mo ma invite e specially ti awon babies mi ba ti de sugbon ranti lati mu ololufe e debo dani oo. . .

@toyin temi nikan
bawo ni? se awon babies mi n kick? kiss
@gbogbo ile
e n le oo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 5:55pm On Jul 07, 2009
IFELEKE:

awe, se omo ti o fun loyun ni ijare lo ro wipe a n soro e ni?tope ore mii, o se o ku akitiyan ati atotonu, oyun ibeta(olosu meji abo) lo wa ninu iyawo mi,[b]lo mu risika omo iya olobi to o fun loyun nijare was sile e. . .[/b]e n le oo

Iyen ni pe omo iya olobi ni farotika fun l'oyun, oga oh shocked shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 6:27pm On Jul 07, 2009
argent:

Iyen ni pe omo iya olobi ni farotika fun l'oyun, oga oh shocked shocked
ma da ogbeni tope yen lohun joo, nitori mi o tu asiri e lati ojo yi lo je ko ma so isokuso si emi at iyawo mi.
O lo si ijare ni osu di e seyin lati lo sinmi,leyin ojo bi melo kan ni iya olobi mu omo e risika wa wipe ki tope ma a ko ni ishiro ati ede geesi(english and maths)nitori idanwo ti iyen fe se.
se ni oju tope wo omo naa to si bere si ni ko ina bo. laifa orogun, omo naa loyun tope de sa kuro nijare.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 7:17pm On Jul 07, 2009
argent:

Wont miss it for anything in the world tongue

kiss kiss kiss kiss mo ti miss e gan ni. Ki lo nshele?
Se o ti ya s'are bimo niyen?
Ranti lati invite mi fun naming oh, mo fe je jollof rice ati chicken.
Btw, tani baba omo larin ifeleke ati farotika  grin

Ibeji ni gatoosi ma bi - taiye ma jo farotika, kehinde si ma jo ifeleke. grin grin grin

oyun ke  shocked ni'gba ti debo o ti ra rolls royce fun mi
Aya mi iwo lo nsoro bayi? Mo ti ra rolls royce fun e lati osu to koja. Abi oti gbagbe ni? Se kin tu ra iketa fun e ki o to le loyun fun mi ni?

Ma se beyen o, emi o ti setan fun e lati yokun nisiyin. Mosi fe ma gbadun e bio se da bii sisi nisiyin. kiss

Farotika? Ngbo?? So pe ko je bee - ase iwo ni o fun omo iya olobi loyun? Oma se o. sad

Mo ki yin Dokita Tomobirin ati ronkeotobee si ori oro pataki yii o. . .ayo ni e ma ba ni bi yii o! Olorun a pese aya rere ati oko rere fun yi o. Ekaabo sori eto.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:52am On Jul 08, 2009
IFELEKE:

ma da ogbeni tope yen lohun joo, nitori mi o tu asiri e lati ojo yi lo je ko ma so isokuso si emi at iyawo mi.
O lo si ijare ni osu di e seyin lati lo sinmi,leyin ojo bi melo kan ni iya olobi mu omo e risika wa wipe ki tope ma a ko ni ishiro ati ede geesi(english and maths)nitori idanwo ti iyen fe se.
se ni oju tope wo omo naa to si bere si ni ko ina bo. laifa orogun, omo naa loyun tope de sa kuro nijare.

Se e rii eyin eeyan mi (debo ati ajeniti), emi gege bi eni kan o le maa ifeleke omo kekere yen maa fi oro jomitoro oro rara nitoripe o kere si nomba mi cool Emi o tie mo nkan ti toyin ri ni ara omo yen ti o fi le je ki o ba ohun soro rara debi ti yio wa maa pee ni iyawo ohun embarassed

Yooba bo won ni ki a ti ibi eefin kiye si'na; se ifeleke o mo pe ohun fun toyin ni oyun tele ni, ti o wa je pe igba ti mo se polongo pe o ti ni oyun osu meta ni ohun se nso oro kunba kungbe si emi ati iyawo mi angry Mo palu fun e naa

Se e rii, yooba ni onikun lo mo'ka, obinrin ni o mo eni ti o l'oyun; e so fun toyin ki o jewo eni ti o ba ohun sun ki o to d'oyun wink cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:56am On Jul 08, 2009
argent:

Iyen ni pe omo iya olobi ni farotika fun l'oyun, oga oh shocked shocked

E woo, e ma da ifeleke lohun. Eni ti o mo nkan ti o nso. Ti a ba tie ni ooto ni pe mo fun omo kan l'oyun ni IJ London, iyen fi han gedegbe pe mo pe l'okunrin. Emi o dabi ore wa oke ohun ti o fun obinrin l'oyun ri. A tie mo boya o ni koboko l'abe gan tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 3:43pm On Jul 08, 2009
IFELEKE:

awe, se omo ti o fun loyun ni ijare lo ro wipe a n soro e ni?tope ore mii, o se o ku akitiyan ati atotonu, oyun ibeta(olosu meji abo) lo wa ninu iyawo mi,lo mu risika omo iya olobi to o fun loyun nijare was sile e. . .
ajenti, emi na a lo to be lati fun iyawo mi loyun leyin opolopo ere ashekara kara.
ma worry, mo ma invite e specially ti awon babies mi ba ti de sugbon ranti lati mu ololufe e debo dani oo. . .

@toyin temi nikan
bawo ni? se awon babies mi n kick? kiss
@gbogbo ile
e n le oo
LOL, IFE and topsy, both of you are so not serious grin
I'm too young to be pregnant o shocked shocked
And I no wan play housewife. So How about 3 more years, then you can ask me how my baby is kicking tongue tongue

argent:

Wont miss it for anything in the world tongue

kiss kiss kiss kiss mo ti miss e gan ni. Ki lo nshele?
Se o ti ya s'are bimo niyen?
Ranti lati invite mi fun naming oh, mo fe je jollof rice ati chicken.
Btw, tani baba omo larin ifeleke ati farotika grin

oyun ke shocked ni'gba ti debo o ti ra rolls royce fun mi
ko kuku si nkan to n sele. Awan okunrin mejeji ye kan fe ko mi si wahala tongue

Invite you ke? How we go forget you if you be the main main of the parrry? So should the color be, blue or pink or both? grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 4:04pm On Jul 08, 2009
E n le ni tiredii yi o. Kilonsele eyin eyan mi?

Oda wipe asiko ka maa loyun kaasi ma bimo niyiii grin

Gbogbo eyin omoge tie ti loyun bi Flgator ati Argent ti o n mura naa eku ise o, ema gbe omo olomo fun elomiran o.
Olorun aa maa fun yii se.

Eyin okunrin kilosele naa, se e wa pa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 4:14pm On Jul 08, 2009
topsy25:

Se e rii eyin eeyan mi (debo ati ajeniti), emi gege bi eni kan o le maa ifeleke omo kekere yen maa fi oro jomitoro oro rara nitoripe o kere si nomba mi cool Emi o tie mo nkan ti toyin ri ni ara omo yen ti o fi le je ki o ba ohun soro rara debi ti yio wa maa pee ni iyawo ohun embarassed

Yooba bo won ni ki a ti ibi eefin kiye si'na; se ifeleke o mo pe ohun fun toyin ni oyun tele ni, ti o wa je pe igba ti mo se polongo pe o ti ni oyun osu meta ni ohun se nso oro kunba kungbe si emi ati iyawo mi angry Mo palu fun e naa

Se e rii, yooba ni onikun lo mo'ka, obinrin ni o mo eni ti o l'oyun; e so fun toyin ki o jewo eni ti o ba ohun sun ki o to d'oyun wink cool
ogbeni, agba ofifo to  n dun yonmu yonmu ni e. . .
emi o le ma a ba e taaka bi omode atiwipe, okunrin ti o ba to okunrin lo ma n paruwo oyun kiri.
okunrin meta ati abo ni mi, mi o le ma a se awuyewuye bi awon kan ti won o tookurin se.
Iwo le ma paruwo lo,emi a si ma a toju iyawo ati oyun mi lo tongue

topsy25:

E woo, e ma da ifeleke lohun. Eni ti o mo nkan ti o nso. Ti a ba tie ni ooto ni pe mo fun omo kan l'oyun ni IJ London, iyen fi han gedegbe pe mo pe l'okunrin. Emi o dabi ore wa oke ohun ti o fun obinrin l'oyun ri. A tie mo boya o ni koboko l'abe gan tongue
awe, iwo lo mo n kan ti o n so, lo gba oyun risika,ye sakakiri mo!
koboko mi n gbona feli feli mi o ni soro ju,bere lowo iyawo mi toyin grin
@gbogbo ile(toyin,debo,tope,ajenti,pafati,dokita tomide obinrin,ronke otito,fiki fiko. . .et al)
e n le o, se alaafia le wa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 4:40pm On Jul 08, 2009
FL Gators:

LOL, IFE and topsy, both of you are so not serious grin
I'm too young to be pregnant o shocked shocked
And I no wan play housewife. So How about 3 more years, then you can ask me how my baby is kicking tongue tongue
ko kuku si nkan to n sele. Awan okunrin mejeji ye kan fe ko mi si wahala tongue
ma da ogbeni yen lohun joo, mo understand pe o fe aruwo nipa oyun yen. wink kiss

@tubabie
bawo ni? otojo meta
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 6:16pm On Jul 08, 2009
tubabie:

E n le ni tiredii yi o. Kilonsele eyin eyan mi?

Oda wipe asiko ka maa loyun kaasi ma bimo niyiii grin

Gbogbo eyin omoge tie ti loyun bi Flgator ati Argent ti o n mura naa eku ise o, ema gbe omo olomo fun elomiran o.
Olorun aa maa fun yii se.

Eyin okunrin kilosele naa, se e wa pa?

Tubbabieeee kiss kiss
mo ti miss e gan. Ibo la wa la ti ijo yi?
Se iwo naa lo fun 9 month course ni? tongue

FL Gators:

LOL, IFE and topsy, both of you are so not serious grin
I'm too young to be pregnant o shocked shocked
And I no wan play housewife. So How about 3 more years, then you can ask me how my baby is kicking tongue tongue
ko kuku si nkan to n sele. Awan okunrin mejeji ye kan fe ko mi si wahala tongue

Invite you ke? How we go forget you if you be the main main of the parrry? So should the color be, blue or pink or both? grin

too young to be kini? when you were doing it with ifeleke, o mo pe o ti kere ju abi? tongue
babe yi o ti loyun jo, stop hiding it
Ifeleke, toyin ma deny oyun e?

debosky:

Ibeji ni gatoosi ma bi - taiye ma jo farotika, kehinde si ma jo ifeleke. grin grin grin
Aya mi iwo lo nsoro bayi? Mo ti ra rolls royce fun e lati osu to koja. Abi oti gbagbe ni? Se kin tu ra iketa fun e ki o to le loyun fun mi ni?

Ma se beyen o, emi o ti setan fun e lati yokun nisiyin. Mosi fe ma gbadun e bio se da bii sisi nisiyin. kiss

Farotika? Ngbo?? So pe ko je bee - ase iwo ni o fun omo iya olobi loyun? Oma se o. sad

Mo ki yin Dokita Tomobirin ati ronkeotobee si ori oro pataki yii o. . .ayo ni e ma ba ni bi yii o! Olorun a pese aya rere ati oko rere fun yi o. Ekaabo sori eto.
kilode to se ma n fi mi sile anyhow? mi o like e oh. mo miss e gan ni kiss
O mo pe rolls royce mewa lo promise mi, abi bawo lo se fe ki won mo pe olowo l'oko mi?
E mi gan o ti redi lati bi omo kankan, mo si n enjoy something e lo naa grin grin
topsy25:

E woo, e ma da ifeleke lohun. Eni ti o mo nkan ti o nso. Ti a ba tie ni ooto ni pe mo fun omo kan l'oyun ni IJ London, iyen fi han gedegbe pe mo pe l'okunrin. Emi o dabi ore wa oke ohun ti o fun obinrin l'oyun ri. A tie mo boya o ni koboko l'abe gan tongue

oko omo iya olobi, iyawo e n ko?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 6:19pm On Jul 08, 2009
Eyin omo kaaro ojire, se dada lew? tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 6:28pm On Jul 08, 2009
Moyola:

Eyin omo kaaro ojire, se dada lew? tongue

Dada ni awa, iwo na ko, se o wapa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 7:23pm On Jul 08, 2009
IFELEKE:

@tubabie
bawo ni? otojo meta

Ifeleke mo wa alright. Ojo kan pelu o. se alaafia lo wa? saa ma gbadun, kosi nkan kan to se e!! cheesy

argent:

Tubbabieeee  kiss kiss
mo ti miss e gan. Ibo la wa la ti ijo yi?
Se iwo naa lo fun 9 month course ni?  tongue
Argentttt ba wo ni omo oniwa tutu?
Emi naa miss e sugbon mi o gburo e rara,kilode
Oya gba eleyi lati okan mi kiss kiss wink

Asiko ko ti to fun 9months course fun mi o shocked
Sugbon laipe lai jina a maa debe grin

Ma so fun mi nipe Debosky ko se okunrin to lati fun e loyun lati igba ti e tin baboo? O ma se o undecided
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 8:29pm On Jul 08, 2009
tubabie:

E n le ni tiredii yi o. Kilonsele eyin eyan mi?

Oda wipe asiko ka maa loyun kaasi ma bimo niyiii grin

Gbogbo eyin omoge tie ti loyun bi Flgator ati Argent ti o n mura naa eku ise o, ema gbe omo olomo fun elomiran o.
Olorun aa maa fun yii se.

Eyin okunrin kilosele naa, se e wa pa?

LOL. egba mi o. emi ko lo yun o. Na Argent I dey help plan her baby shower grin grin
Abeg, eba mi bere lo wo e color gift to fe kin ra. Se bulu ni o, t'abi pinki, abi ki n ra mejeji? cheesy cheesy

nba bere lowo e alafia e, sugbon o d bi pe gbogbo wan ti bere. inu mu dun si alafia e (that yoruba was kinda rusty. But I tried grin grin )

IFELEKE:

ma da ogbeni yen lohun joo, mo understand pe o fe aruwo nipa oyun yen. wink kiss
Mo moh pe waa uderstand me.
Thanks baby kiss grin

argent:

too young to be kini? when you were doing it with ifeleke, o mo pe o ti kere ju abi? tongue
babe yi o ti loyun jo, stop hiding it
Ifeleke, toyin ma deny oyun e?
Doing kini? shocked shocked
TO baje wipe o feran IFELEKE, oje ma je ki egbon mi dayokanu gbo.
Aafe lupa cheesy cheesy
Sebi IFELEKE nanti sope ere lo n se, wipe o n a duro di 3years wink tongue

Where's Topsy sef? I dey worry o embarassed se ko si, talo gbe e lo?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 10:09am On Jul 09, 2009
FL Gators:

LOL, IFE and topsy, both of you are so not serious grin
I'm too young to be pregnant o shocked shocked
And I no wan play housewife. So How about 3 more years, then you can ask me how my baby is kicking tongue tongue
ko kuku si nkan to n sele. Awan okunrin mejeji ye kan fe ko mi si wahala tongue

Toyin temi nikan kiss ma binu pe mo lo nsoro nipa oyun wa ninu tireedi yi, ifeleke omo buruku yen lo ti mi si; siwaju sii, mo tun nfe ki awon ore wa ba wa yo fun ore nla nla ti Olorun se fun wa cool Ma je ki awon eeyan gbo pe o kere ju lati loyun o ki won ma lo maa ro pe o fe wa resiponsibu wink

(1) (2) (3) ... (34) (35) (36) (37) (38) (39) (40) ... (100)

Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá / Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 103
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.