Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,195,585 members, 7,958,813 topics. Date: Thursday, 26 September 2024 at 02:33 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (49) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (201671 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (46) (47) (48) (49) (50) (51) (52) ... (100) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 6:26pm On Aug 04, 2009
Eekasan, eyin omo yoruba.

topsy25:

E jowo e gbe orisa naa wa ki nfi da ina ti mo maa fi sun isu egbodo ti iyawo mi toyin sese ra grin
wetin? ahhhhhhhhhhh shocked shocked shocked
Maa gbe orisa wa le mi o angry tongue

dayokanu:

Ede Yoruba is the most spoken Naija language outside our shores. as far as in the caribean
really, bawo lo se moh?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 6:31pm On Aug 04, 2009
Kaasan omo odua daada! bawoni aiye e?

eyin omo yoruba, kini ki a se fun awon omo niger delta ti won da ilu ru kiri yi? se ki a ko ogun lo ja won ni? baba mi ni ogun gan o! grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 6:32pm On Aug 04, 2009
@Jassie

Se ogun fun wan na.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 6:40pm On Aug 04, 2009
ha iya agba! nigbati iwo olori aje ti wa ni ibi yi, ki o kan se epe fun wan ni. . . aiye won ti baje ni iyen! tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 6:48pm On Aug 04, 2009
tubabie:

Ekaaro gbogbo ile, se alaafia lawa?


Jowo kini itumo "egbodo"?

Isu tuntun, nigbati isu ba sese njade,  ni won maa npe ni EGBODO (do re do), o le je eyi keyi bii ewuru, ar'eyin gba kunmo, nangan nangan, ewura ati beebeee lo, kii se iru kan pato nigbati IGBODO (do re re) je isu gbigbe ti won oi tii lo si elubo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 8:51pm On Aug 04, 2009
:d ;d ;d ;d
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 9:17am On Aug 05, 2009
YORUBA KALENDA

Sere - January,
Erele - February,
Erena - March,
Igbe - April,
Ebibi - May,
Okudu - June,
Agemo - July,
Ogun - August,
Owere - September,
Owaro - October,
Belu - November,
Ope - December.

Aiku - Sunday
Aje - Monday
Isegun - Tuesday
Ojo 'ru - Wednesday
Ojo'bo - Thursday
Eti - Friday
Abameta - Saturday
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 1:34pm On Aug 05, 2009
Okare remii!
mo ranti atijo ti a ma n fi awon oruko ose ati osu ko orin. . .

@gbogbo ile
E n le oo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 3:47pm On Aug 05, 2009
jassie:

ha iya agba! nigbati iwo olori aje ti wa ni ibi yi, ki o kan se epe fun wan ni. . . aiye won ti baje ni iyen! tongue

Se iyawo mi ni o npe ni aje shocked sad Iwo gan an oso cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 12:00am On Aug 06, 2009
Oba o le pe meji lafin! Eyin imu ju abe lo! kinihun ni oba eran grin

Iba idi omo ki oma gbon be sekere!! ye!! Ere kini aja ba ekun se! ani ka lo sokisonbolo! grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by deyg(m): 12:06am On Aug 06, 2009
se o le fi opo ina se tooth-pick.tabi o le so yoruba fun interview.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 12:22am On Aug 06, 2009
faakay:

Oba o le pe meji lafin! Eyin imu ju abe lo! kinihun ni oba eran grin

Iba idi omo ki oma gbon be sekere!! ye!! Ere kini aja ba ekun se! ani ka lo sokisonbolo! grin

Se alafia ni?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by deyg(m): 12:27am On Aug 06, 2009
alafia la wa ooooooooo.e se gun ni oooooooooo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 12:43am On Aug 06, 2009
Remii:

Se alafia ni?

E ma binu oo! oko lo yun mi ni grin grin grin grin grin grin grin

Oda bi npe tanbolo abi kokoro nlo je kini nah grin grin grin grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 8:09am On Aug 06, 2009
@faakay, Jowo, mabinu o sugbon a dabi eni wipe waa losi trend yi https://www.nairaland.com/nigeria/topic-181300.2080.html lati lo maa so oro alufansa re ni be, awon omode wa ni trendi eyi jeki o wa pelu ede to b'eti mu, lol
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:17am On Aug 06, 2009
faakay:

E ma binu oo! oko lo yun mi ni grin grin grin grin grin grin grin

Oda bi npe tanbolo abi kokoro nlo je kini nah grin grin grin grin grin grin


Lo fi oko e ho ogiri nau grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 3:14pm On Aug 06, 2009
Ibo ni ìyàwó mi tóyìn àti òtá mi ìfélékè wà
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 4:11pm On Aug 06, 2009
topsy25:

Ibo ni ìyàwó mi tóyìn àti òtá mi ìfélékè wà
Ogbeni tope-lobi
se risika lo fe e bere ni? risika wa labule to o fi si iyawo mi toyin temi nikan de wa ninu aafin mi to n gbadun pelu oyun awon ibeji lanti lanti to n sokutu kutu ninu e.
mo se gbe won de lati ile iwosan awon oloyun ni. tongue
btw, ji a sita lori yim

@gbogbo ile
bawo ni oo se alaafia le wa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 4:59pm On Aug 06, 2009
In karo o, topsy and Ife.
How you dey?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 6:20pm On Aug 06, 2009
FL Gators:

In karo o, topsy and Ife.
How you dey?
Adumaradan,orekelewa,eleyinju ege,aaayo ati iya'afin IFELEKE kiss bawo ni? se alaafia lo wa? mo n reti e ni corner wa, je ka soro. wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 8:45pm On Aug 06, 2009
e kaale ni be oh
mo ki gbo gbo yin
talo wan'le?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 9:16pm On Aug 06, 2009
@bluspice, o ma to jo meta a, se ara nle o,
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 11:41pm On Aug 06, 2009
ojo meta at'abo gan ni
mo wa jare
o kan se mi die ni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by oyinda3(f): 5:35am On Aug 07, 2009
Remii:


Sere - January,
Erele - February,
Erena - March,
Igbe - April,
Ebibi - May,
Okudu - June,
Agemo - July,
Ogun - August,
Owere - September,
Owaro - October,
Belu - November,
Ope - December.


ehh what language is this?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 5:48am On Aug 07, 2009
I think its yoruba, look at the names of the weekdays

@Ife
I dey o jere. e se n. kiss
If the gmg am taking has wifi, i'll hit you up on the way home tomor.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 2:02pm On Aug 07, 2009
oyinda.:


ehh what language is this?
It's our language. . .Yoruba language for months and days.

FL Gators:

@Ife
I dey o jere. e se n. kiss
If the gmg am taking has wifi, i'll hit you up on the way home tomor.
aiight. . .se alaafia lo wa? kiss

@gbogbo ile
e n le o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 6:36pm On Aug 07, 2009
Ojo Aiku - Sunday
Ojo Aje - Monday
Ojo Isegun - Tuesday
Ojo ru - Wednesday
Ojo bo - Thursday
Ojo Eti - Friday
Abameta - Saturday
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 9:12pm On Aug 07, 2009
we rarely use these words nymore
i know friday as jimoh
yeah cos of the islamic influence i know. . .
but seriously, how many people still use these words?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 9:15pm On Aug 07, 2009
I do. I usz dem wordz errday! Oni lo'jo jimoh! tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 9:20pm On Aug 07, 2009
lol o serious wink
see what i mean tho?
u said ojo jimoh not eti. . . .
bawo ni ore cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 9:22pm On Aug 07, 2009
Only just realised there are numbers in yoruba a few weeks ago grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 9:24pm On Aug 07, 2009
bluespice:

lol o serious wink
see what i mean tho?
u said ojo jimoh not eti. . . .
bawo ni ore cheesy

Oopz! Eti ni mo fe soh! cheesy
Dada ni o! iwo nko? se kosi la'buru? wink

ibkaye:

Only just realised there are numbers in yoruba a few weeks ago grin grin grin

Yu hvin a laff arntchu?! lipsrsealed grin

(1) (2) (3) ... (46) (47) (48) (49) (50) (51) (52) ... (100)

Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations) / HAUSALAND: Teach Me Hausa

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 38
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.