₦airaland Forum

Welcome, Guest: Join Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 2,074,693 members, 4,479,103 topics. Date: Wednesday, 19 September 2018 at 11:27 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (48) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (139621 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (45) (46) (47) (48) (49) (50) (51) ... (100) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 8:29am On Jul 30, 2009
bluespice,

Wa sere omo daada se daada lo wa. Se awon boyfriends o ja si?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 9:13am On Jul 30, 2009
bluespice:

eyin eyan mi ekaale oh,
ori ikunle ni mo wa tongue
tubabie, dokita, dayo enitemi, gatoosi, argent, fayaah ati gbogbo yin ti mi daruko yin
mi gbagba oh oruko yin kan le lati so ni tongue

bawo le wa sha?

A wa pa. Se iwo naa wa dada?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 9:44am On Jul 30, 2009
topsy25:

E jowo eyin temi ninu tireedi yi, e gbami laye lati fi ede geesi tumo oro yi fun iyawo mi. Ese gan an ti e gba mi laye.

The Statement is ironic in nature and it literally means:

You can't eat anything that is harder (stronger) than plantain, but you can eat guguru undecided This simply translate to: You're an hypocrite grin

@FL Gators,

Idakeji, (opposite) won le so wipe "o fi oju jo ekun sugbon ko pa eran je" meaning he or she displays the traits of flirt but he is clean and not engage in infidelity.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:37pm On Jul 30, 2009
Si, ajeniiti,

Gbogbo obinrin ni o ni egbo ni abe, awa okunrin ni a si ma ntoju iru egbo bee. Se debo ntoju tie daadaa undecided
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 3:19am On Jul 31, 2009
Remii:

@FL Gators,

Idakeji, (opposite) won le so wipe "o fi oju jo ekun sugbon ko pa eran je" meaning he or she displays the traits of flirt but he is clean and not engage in infidelity.
So watchu trying to say? Dayokanu displays the traits of a flirt AND he's still. . . .ehrrrm. . . .you know what I mean wink grin grin

@topsy
Thanks for the trasnlation. How you dey? So am a hypocrite? oga o, Remii, how could you?! embarassed*waves* sup argenti,,how you dey? a kan ni ka kin yin ni o. O t'ojo meta ati abo.

@all. . . .in kun o.

@IFELEKE
ehrrrm oga tisha, mii ti gbo lati odo yin for a while now. Bawo ni? Eku ise o, ema rera (or is it rora. Something that means don't stress sha)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 10:42am On Jul 31, 2009
@FL Gators, who's I, how can I? lol.
The word hypocrate is too harsh for that meaning, It may be close, you know Yoruba is deep, like people saying "Ko gbo ede ogbo eke" if someone does not speak Yoruba language well but knows how to use slangs to communicate to some associate when others present would not understand.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 12:10pm On Jul 31, 2009
FL Gators:


@IFELEKE
ehrrrm oga tisha, mii ti gbo lati odo yin for a while now. Bawo ni? Eku ise o, ema rera (or is it rora. Something that means don't stress sha)

Adumaradan,ibadi aran,orekelewa temi nikan, aaayo ati iyaafin IFELEKE kiss
bawo ni? se alaafia lo wa? awon ibeji mi nkan,se won o fun e ni wahala pupo? mo de lero pe o n lo fun ayewo awon oloyun ni ile iwosan?
Ma binu simi wipe o'o gburo mi, ise lo gbomi mu. se o mo 'pe mo gbudo sise takun takun lati le toju iwo ati awon omo mi kiss
will be waiting to catch up with you on YIM.

@gbogbo ile(toyin,remii,tope,tubabie,dayo,ajenti,blu,wolewumi,segoye apa keji,chi arobo,pafati,dokita fali et al)
Se alaafia ni gbogbo yin wa? E de ku popo sinsin opin ose.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 7:35pm On Jul 31, 2009
Egunugun le wo ile alagbede, kii se eewo, afara ni ko gbodo ja, o le lo shaving powder ti ko ba ti fi sile pe ju bo se ye lo, ki o ri daju pe low tabi medium strength ni oun lo o, sugbon abe ifari tabi clippers dara julo, o o ni ri kose deede ooo,  grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 10:22pm On Jul 31, 2009
Bawo ni gbogbo nkan o, ara o le bi? Se esin Oba nje'ko? stay cool.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 10:33pm On Jul 31, 2009
It means "is everything alright?" If the horse is not well fed or sick and lost appetite, would;t if injure or kill the queen if used for outing unknowingly by the queen, what is queenly if she does not bother about thewell being of her subjects and possesions, again, SE ESIN OBA NJE OKO?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 10:47pm On Jul 31, 2009
Kini pipe oruko, ikamefa, se ikamefa - six fingers or six folds or counting six or six wickedness or wickeds, ewo lewo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 12:51pm On Aug 01, 2009
EKu De de iwo yi ooooo!!!!

Kini update ti o sele ni ibi bayi !! Eja misi bi o se nlo! Lo ri owo yen!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by igbalajobi: 1:14pm On Aug 01, 2009
E jowo a bami se eto bi a se le fi pervert ranse si apa osi lona Abeokuta. O dabi e ni wipe Aro loruko ibe fun ayewo to peye
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by igbalajobi: 3:10pm On Aug 01, 2009
O seun. Aye re a da. Bi a ti se nbi ni naa niyen. Yoruba bo won ni oro lo ba moko moro wa. Ijoba polowo re ninu redio ati telifisan wipe eniti a ba ri wipe isesi, iwuwasi and isorosi re ni bakan ninu, ki a rekomendi iru eniyan bee si ibi ti mo wi yen. Nigba ti mo de ri wipe, oro re ko ba tawon elegbe re ninu agbo mu, ni mo se ro wipe o ye ki o bewon wo. Sugbon to ba ri wipe ko ye fun iru e nibe, wu iwa, so oro bi omoluwabi yoruba ogidi ki o ye so isokiso
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 3:11pm On Aug 01, 2009
E ku deede iwoyi o Se daada ni e wa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by igbalajobi: 3:19pm On Aug 01, 2009
@Dayokanu,
O seun omoluwabi, Alafia ni gbogbo ile. Se Abule yin ni US dun. Se e ngbadun Ijoba Obama?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by igbalajobi: 4:02pm On Aug 01, 2009
[igbagbe lo se e,iwo tiwa gbagbe pe gbogbo wa o le sun ka kori sibi kan na,bi ko ba siru wa nilu ilu o le dun gbogbo wa o le di pastor,alfa,lawyer abi dokita,a gbudo ni awon criminals kankan larin wa lati le mu ile aye dun,quote]]

Hen hen O tan ni inu mi. O se se soro, emi naa sese understandi re dada ni. Iru e o gbodo maa si ni adugbo looto.

[ma so fun mi pe o fe ma se bi gentleman ki won ba le mu e gege bi moderator,quote][quote][/quote]
Iyen je gege bi post president abi CEO
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 8:57pm On Aug 01, 2009
e'nle gbogbo yin smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 11:39pm On Aug 03, 2009
[size=15pt]ORISHA AKEBOJE ILU NAIRALAND (SIGIDI NLA)[/size]

Akede ti de oooo!!!

Agogo: kere ooo!! Kere ooo!!


Eyin Irumole Nairaland oooo!! E bo de oooo

Awon Irumole Dahun: oooooooooooo!

Eeti yin melo?

Irumole NL: [/b]Eeti wa Meji!!

Kini efin gbo?

[b]Irumole NL: [/b]Oro!!!!!!!!!!!!!!!!!!!

EYin irumole Nairaland oo! Won ti gbe [b]Ebo Irumole nairaland ooooo


Irumole NL: haaaaaaaaaaaaaaaaaa!! aiye akamara ooooo!!

E wa gbo ooo! Oju oni ti yin o! Ofo Aramasha [/b]so wipe!
(Eni ti o ba mo ara, eni ki o lo fi owo ra ina wo!)  grin   cheesy

Woni ki so fun yin oo! pe eni keni, ti o ba gbe sigidi nairalandu! ki o lo da pada!
[b]
nitoripe emi ti mo je MALU tiwo! tiwo!!
Alake nla ti o gba eran ni owo kinihun!!
be na ni mawuru mawuru ni ekun bi mo! ti ija ti ija ni omo jade!


Ni oni tohun o ba se be! haaaaaaaaaaaaaa! ni owuro kutukutu ola bi osupa aiye se jade,  ile a gbe oni tohun mi ni oo!!

Mo wi  ire,  abi  mo wi ire? ? ? cheesy cheesy cheesy

IRE OOOOOOOOOOSIGIDI OLOMOYOYO OOOO WANTED!!!
grin  grin    grin     grin     grin     grin      grin        grin     grin              grin     grin     grin     grin  grin    grin     grin     grin     grin      grin        grin     grin              grin     grin     grin

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 7:05am On Aug 04, 2009
Igbalajobi,

America toro bi oi a fi owuro pon.

Faakaykori abi ki ni oruko tie. Se orisha abule yin ni o gbe de ibiyi. O je gbe kuro nitori awa pe fi ere yen ko ina Isu egbodo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 7:40am On Aug 04, 2009
Arofo Iyawo tunutn

A gun'yan lebe, Iyawo ko je,
Ar'oka lebe, Iyawo ko je
Awon onilu de, Iyawo dide
Ijo onijo ni'yawo le jo
Ayo alayo ni 'yawo yo
Bi ise ba de Iyawo le lo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 9:13am On Aug 04, 2009
@Gbogbo Ile
Se Alaafia le wa?
ogbeni faakay, ti oluwo abule yin ba gba e mu pelu Orisha t'o o ji gbe wa si bi yii!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:31am On Aug 04, 2009
E jowo e gbe orisa naa wa ki nfi da ina ti mo maa fi sun isu egbodo ti iyawo mi toyin sese ra grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 10:28am On Aug 04, 2009
Ekaaro gbogbo ile, se alaafia lawa?topsy25:

E jowo e gbe orisa naa wa ki nfi da ina ti mo maa fi sun isu egbodo ti iyawo mi toyin sese ra grin
Jowo kini itumo "egbodo"?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 11:48am On Aug 04, 2009
dayokanu:

Igbalajobi,

America toro bi oi a fi owuro pon.

Faakaykori abi ki ni oruko tie. Se orisha abule yin ni o gbe de ibiyi. O je gbe kuro nitori awa pe fi ere yen ko ina Isu egbodo
grin grin E gbo!! Orisha baba nla baba wa ni oooo cheesy O ti wa soonu bayi!! grin

Wo ni ilu america ni o wa bayi ooo! E ba wa gbe! nitoripe ilu nairaland ti daru bayi!! grinRemii:

Arofo Iyawo tunutn

A gun'yan lebe, Iyawo ko je,
Ar'oka lebe, Iyawo ko je
[size=14pt]Awon onilu de, Iyawo dide [/size] grin grin grin
Ijo onijo ni'yawo le jo
Ayo alayo ni 'yawo yo
Bi ise ba de Iyawo le lo.

topsy25:

E jowo e gbe orisa naa wa ki nfi da ina ti mo maa fi sun isu egbodo ti iyawo mi toyin sese ra grin
haaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaa!! haaaaaaaaaaaaaaaaaaaa!! E wo ORISHA grin grin grin


Kokoro tin je efo, idi efo lo waa
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 2:13pm On Aug 04, 2009
tubabie:

Ekaaro gbogbo ile, se alaafia lawa?


Jowo kini itumo "egbodo"?
Kaaro tubabie, alaafia la wa iwo nko?
Isu(Yam) lo n je egbodo won de ma n fi se elubo naa(yam flour)

topsy25:

E jowo e gbe orisa naa wa ki nfi da ina ti mo maa fi sun isu egbodo ti iyawo mi toyin sese ra grin
ogbeni, se loju ala? abi risika lo fe e pe ni?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 2:32pm On Aug 04, 2009
Faakaykori,

Igi lasan ni emi ri o Mo si fe fi ko ina. Ki a fi se isu je
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Oluschenco(m): 2:50pm On Aug 04, 2009
Eyin temi, bawo lo se nlo, boya lemo pe leyin Yoruba, eru ni awon ede to ku.
Yoruba leads, others dey follow.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 2:55pm On Aug 04, 2009
Oluschenco:

Eyin temi, bawo lo se nlo, boya lemo pe leyin Yoruba, eru ni awon ede to ku.
Yoruba leads, others dey follow.

Looto! lona wo? undecided
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 3:14pm On Aug 04, 2009
IFELEKE:

Kaaro tubabie, alaafia la wa iwo nko?
Isu(Yam) lo n je egbodo won de ma n fi se elubo naa(yam flour)
Ifeleke Ose gan wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 3:37pm On Aug 04, 2009
Ede Yoruba is the most spoken Naija language outside our shores. as far as in the caribean
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 3:48pm On Aug 04, 2009
Ooto lo so dayo,
koda, ede yoruba gbinle ni ori le ede bi brazil,cuba,benin ati be e be e lo.

(1) (2) (3) ... (45) (46) (47) (48) (49) (50) (51) ... (100)

Top 10 Most Spoken Languages In All Of Africa / Learn How To Speak Hausa Here / Black African Nobility Of Ancient Europe

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (0) (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2018 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 114
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.