Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,286 members, 7,957,742 topics. Date: Tuesday, 24 September 2024 at 06:53 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (201630 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (48) (49) (50) (51) (52) (53) (54) ... (100) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 9:55am On Aug 11, 2009 |
lol okay e ma binu a ni se be mo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 12:30pm On Aug 11, 2009 |
topsy25:Ore mi tope-lobi,ooto lo so, ede abinibi wa se pataki o se koko o de ye kia mu lokunkundun. Bawo ni? se alaafia lo wa? ji a sita lori yim. FL Gators:adumaradan temi nikan, bawo ni? se o sun daada? @gbogbo ile E ku ojumo oo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 3:26pm On Aug 11, 2009 |
Topsy, Awon Yoruba bo, won ni oro lo mu moko moro wa. Won si ni aiso oro yan oro lo pa elenpe akoko; to ni igba wuwo ju awo lo. Won si ni ti a ba fe mu obo, a man se bi obo ni. Iwo na sa mo pe opolopo awon omoge Yoruba lo ti sonu ni ilu ajeji. Won o ti e mo itumo oruko won mo. Nitorina a ni lati fo ede na si wewe ki o ba le ye won daada, ki a si fa won mora ki won ma tele okunrin ajeji lo Ti a ba ti fe won wole ko si ede ajeji mo Yoruba ni a ma so kulaaa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 5:31pm On Aug 11, 2009 |
dayo o wi'ire! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 5:32pm On Aug 11, 2009 |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 5:51pm On Aug 11, 2009 |
ibkaye, ki lo fa oju yobo? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 6:00pm On Aug 11, 2009 |
Translation please, my yoruba's a bit rusty |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 7:45pm On Aug 11, 2009 |
ibk wat happened to not letting them know how rusty our yoruba is? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tpiah2: 9:55pm On Aug 11, 2009 |
awon ololufe na da? e bo si bi. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 9:55pm On Aug 11, 2009 |
bluespice:oops |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 10:43pm On Aug 11, 2009 |
@Ibkaye, idanrawo ni mimoo se, maa gbiyanju lati so iwonba too ba mo, (Practice leads to perfection) |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 11:19pm On Aug 11, 2009 |
Remii: |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Krayola2(m): 12:36am On Aug 12, 2009 |
dayokanu: bobo yi, expert ni e o. Yoruba e le baje. damn!! I dey jealous u |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 2:40am On Aug 12, 2009 |
kini gbogbo radarada rederede ti o n sele nibibayi na. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 5:32am On Aug 12, 2009 |
Ara me riri, Mo ri ori ologbo late. Ibkaye, bawo ni ati fe gbo si pe iwo ko gbo ede awon omo Kaaro oojire? Paga!!!! Sangba fo!!!!! O ba ni ko baje, oro yi si ni atunse. Nitorina Ki ede Yoruba fifo re le tubo munadoko, Mo fe gba niyanju pe ki o lo si ile Chamoteesi fun Ose meta ki o lo ko ede. Ki o si dara po mo awon ojulowo Omo Oduduwa. Si Chamoteesi, Mo fe ran Ibkaye si o ki o le wa ko ede Yoruba fun ose meta. Sugbon mo fe ki o mo pe mo ti fi maagun si ara re ti o ba yewo, Orun ni ala. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 6:02am On Aug 12, 2009 |
odo tani? o mo pe oko ati iyawo ni won tele ni? magun to fi si lara o le sise jare |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 6:23am On Aug 12, 2009 |
Kai Chamoteesi, Ngbo iwo ni o n lagi ibkaye Oo ti e beru Olorun Omo ti ko ti gbo? lo tin je isu e? O ga o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 7:47am On Aug 12, 2009 |
dayokanu: Ibkaye wa lara awon taa ro wipe ko le je ogede sugbon ton je guguru. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:27am On Aug 12, 2009 |
Ibikaye àti bluespice, e jé kí eléyì jé ìgbà ìkeyìn tí e máa so èdè gèésì ní inu tíréèdì yi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:46am On Aug 12, 2009 |
dayokanu: dayo, alagemo ibkaye ti paso esi da, o ti gbo kira kira Laise aini aini, kamoteesi lo maa re |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 10:21am On Aug 12, 2009 |
dayokanu:ogbeni dayo, ose meta ke? se o fe ma'a se gbonmi si omi o to'o fun omidan yen ni? abi o fe ma rojo ina si labe ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 10:28am On Aug 12, 2009 |
You guys are being unfair |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 10:31am On Aug 12, 2009 |
Gbogbo yin funny sha @all Eyin eeyan mi oto ojo meta , se alaafia lewa?(Ifeleke, Blu, Dayo,Topsy,Remi,Ibkaye,Chamotex ati Fl Gators) |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 1:57pm On Aug 12, 2009 |
ibkaye ki lo wi? tubabie bawo ni? o to jo meta, se alaafia lo wa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 5:46pm On Aug 12, 2009 |
dayokanu: Ibkaye ti wa ni abe abo ni'le mi lati bi ose mefa s'eyin. Mo n ko ina bo labe gidi gan ni. Emi Chamotex, ado obirin bi eni nlagi. Egbon ee se gbe iyawo yin wa ki o wa ko ede ni agbegbe mi? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 5:58pm On Aug 12, 2009 |
chamotex:iyen ni wipe o n wo lata gidi gidi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 6:03pm On Aug 12, 2009 |
IFELEKE: ata nikan ko, moti debe debe |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 6:22pm On Aug 12, 2009 |
chamotex: se 'pe o ti di ''alani debe debe'' |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 6:27pm On Aug 12, 2009 |
emi niyen o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by posakosa(m): 6:30pm On Aug 12, 2009 |
IFELEKE: Ife, ki lon happen ? O kan ja mi ni face. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 6:37pm On Aug 12, 2009 |
posakosa:B, ma binu jo, ise lo gbomimu bawo ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 6:46pm On Aug 12, 2009 |
You people are not serious |
(1) (2) (3) ... (48) (49) (50) (51) (52) (53) (54) ... (100)
Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations) / HAUSALAND: Teach Me Hausa
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 34 |