Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,152,457 members, 7,816,074 topics. Date: Friday, 03 May 2024 at 02:31 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! (171598 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (58) (59) (60) (61) (62) (63) (64) ... (73) (Reply) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Idowuogbo(f): 4:01pm On Jan 10, 2011 |
dadi ni mo ji , omo ajiri kilon shele ni lu obama yin , shey won tin fi visa wo bus ni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tanimz(f): 4:03pm On Jan 10, 2011 |
^^ Mi o mo ni pa iyen o. Shugbon, mo gbo pe wo fe change citizenship process. Se e fe wa ki wa ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tunnytox(m): 8:21pm On Jan 10, 2011 |
@Dayokanu Abi e o ri n kan a se omo ilu kan na ni emi at Dayokanu! Ilu nla ni ilu Ogbomoso awon oloriire eeyan lo n gbe Ogbomoso Ogbomoso je ka jo debe o 2ce Eeyan nla lo l'Ogbomoso ilu Ogbomoso ko ni baje Eeyan nla lo l'ogbomoso o Ilu Ogbomoso ko ni baje. Ogbomoso O o ya ka lo ka lo f'ewure ji'yan ni'le Lawyer Moni Ni'le ala'yinde o oko Muji that's one of the evergreen songs of Chief commander Ebenezer Obey. Obey's music is philosophical, entertaining and evergreen I hope to start a thread for Obey's music later on the music section. Mo ni awon orin Obey fun awon omo ilu wonyi: Abeokuta, Ilesa, Ondo, Ibadan at Ogbomoso awon awe orin yi ko soro lati fi sowo lo ri email nitori ko wuwo pupo ( some of the tracks are less than 3mb, i can forward this to anyone who is interested. I'm not sure if its illegal though ) @ Ileke idi mi o mo oriki ile Ekiti bayi sugbon ti mo ba ri ma fi si orii tireedi yi lai pe ojo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by IYANGBALI: 8:32pm On Jan 10, 2011 |
Idowuogbo:@Idowuogbo pls help me out with the meaning and correct pronounciation of your name,is it 1,IDOWUOGBO-OLD LADY 2,IDOWUOKO-VILLAGE GIRL OR IDOWUOKO-SOMETHN BELOW i was arguing this with Dayo Kanu and bebe idi bebe idi said no 1 is the true meaning of your name,while uncle dayo said it was the second one,but i told them that it should be the 3rd one,so pls set the record straight madam |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tunnytox(m): 8:34pm On Jan 10, 2011 |
oludashmi: O gbiyan ju die awe emi na mo die ninu oriki Ijesa Osomaalo Ijesa osere oni ile obi omo eleeni ateeka omo eleni ewele omo olobi wo wo ti ri wo omo olobi wo wo ti ri wo (odun mi pe mi o mo ami fi si awon oriki yi ) Eyi to'ba feni a wo sapo eni Eyi ti o fe ni a wo si inu igbo Eranko buburu a m a ron muje @idowuogbo Idowu Ogbo abi kere leti, idowu esu le'yin Ibeji (BTW Alaba ni emi na!) se omo Eko aromi sa legbe legbe ni idowu abi omo Ijesa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Idowuogbo(f): 11:01pm On Jan 10, 2011 |
awwh alaba ni e , awe iwa gan la abigbeyin, awon yeye mi oshe de idogbe ni omo eko le mi o, eko akete. sugbon mi o gbe eyo ri @iyato-nid-olugbala wa mo ti so fun re tele pe , idowuogbo loruko mi kilo fe fa gbogbo paparrazzi sho ra re o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by lincDzinc(m): 12:14am On Jan 11, 2011 |
ADURA: Odun yi atu ra ko ni le koko mo mi *2 Oun ti mo dawo le, ayo ni, Oun ti mo bere yi o se fun mi Odun yi atura ko ni le koko mo mi. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tunnytox(m): 8:12pm On Jan 11, 2011 |
@Idowuogbo O ga se a ni so fun awon mummy ati daddy ki won fun e ni Alaba at Idogbe bayi? ki o ma ba lo ma jowu nitori emi ni Idogbe leyin mi. Anyway mo ki Idowu omo Eko akete Ilu ogbon, Eko a romi sa legbe legbe mi o mo oriki Eko ju be yen lo Nje ari eniti o ranti iroyin agabaye ti alaago meji osan ni ori redio asoro ma gbesi ti ipinle oyo? Iroyin na ma n saa ba lo bayi: E kaa san o Iroyin agabaye lati enu , Egbo koko inu iroyin naa: 1. ado Oloro kan ti bu gbamu ni ori leede Iraq 2. Ile saaro (Siera Leone) etc Pls add more if you can remember |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by dayokanu(m): 7:11am On Jan 12, 2011 |
tunnytox: Mo ni CD yen ninu moto mi, Ojojumo ni mo man gbo orin yen |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by ifyalways(f): 9:38am On Jan 12, 2011 |
^^^ashawo. Is this an open invitation,so she wud come ride with u? Eka-aro,awon Iyawo ati omo nko? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by oludashmi(f): 9:50am On Jan 12, 2011 |
tunnytox:Ose gan ni Omo 'bo ni 'wo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by dayokanu(m): 5:48pm On Jan 12, 2011 |
ifyalways: O dabi wipe iwo gan fe je nibe. Or do you want to ride me also? I would have to report you to wifey(Your aburo) where has she been self? Iyawo mi emi ko ri mo o, Ifyalways ti fi iyawo mi pamo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 10:08am On Jan 15, 2011 |
inhin omo-ujesa, oju rin daa? Omo Egboro lomi ki-in o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by lovejo(m): 3:56pm On Jan 16, 2011 |
E ka le ni ile , se ara le, mo ni ki emi na da si eto yi ni o gege bi omo yoruba. Ajo se wa ko ni baje oo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Idowuogbo(f): 3:59pm On Jan 16, 2011 |
tunnytox:ha momi ofe fun mi ni alaba , she ire ah je alaba pay as u go wa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by dayokanu(m): 8:29am On Jan 17, 2011 |
Abeg who can help me upload one King sunny Ade song titled Ile labo simi oko. Or where can I play it online? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by ifyalways(f): 6:42pm On Jan 17, 2011 |
dayokanu:We want amala,Omo Ogbomosho. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by dayokanu(m): 8:08pm On Jan 17, 2011 |
You want Amala? Oya come and meet me at home and bring my wife along, Over a year now |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by sulad82i(m): 4:48pm On Jan 18, 2011 |
dayokanu: I have some Sunny Ade's cd but dont know d one u r asking |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by dayokanu(m): 5:41pm On Jan 18, 2011 |
It starts like this: Asiko laiye eda kan ko mo ola, Aimasiko lon damu eda, Lori apata ti Jesu ni mo wa, Ogun aiye kan ko le bami leru mo. Tori, Emi ti mo wipe toluwa lase, Koroko ki hu lori apata, Lola Oluwa ko so wa dele o, Ka ri ere oja je, Ka ko ere oko dele. I think its in the Ogun Album |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by IYANGBALI: 1:23am On Jan 20, 2011 |
dayokanu:no it is in orisa album{lol} |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by sulad82i(m): 5:30pm On Jan 20, 2011 |
dayokanu: Alright. Let me check my collections and I'll let u know if i have it. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Remii(m): 4:48pm On Apr 27, 2011 |
Eyi s'oju wa na Eyi s'oju wa na Oun to s'oju eni kii s'eyin eni Eyi s'oju wa naaa Igba otun ti tun de si ile Yoruba. Ki Olorun fun awon Gomina tuntun ti asese yan ni ogbon ati agbagra ti won fi se bi a sen fe Amin |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Seunshikem(f): 4:59pm On Apr 27, 2011 |
Amen o Olorun a kuku gbadura wa dele. Awa omo yoruba ko ni kabamo IJN |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 5:14pm On Apr 27, 2011 |
Eyin omo oduduwa, eku ise ti e se lana at'oni. Successful election. Odua a gbe a o! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by dayokanu(m): 5:26pm On Apr 27, 2011 |
Aji sebi oyo laari, oyo ki ise bi baba eni kan kan |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tubabie(f): 11:55pm On Apr 27, 2011 |
Adupe ti awon ara Oyo se daada, ti won gba osi ati iranu ti on je Akala yen jade! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by dayokanu(m): 12:07am On Apr 28, 2011 |
Ki lon shele si awon Yoruba Okun ati Kwara? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by sulad82i(m): 6:03pm On Apr 28, 2011 |
Owee (Proverb) Ojo pa alapa o di amugun fun ewure Eniti to tu ito si le ton paa re, o mo nkan ti won nfi ito se ni af'Apoti rori kii gbadun oorun. Olobe lo loko Ai gbo'fa la n wo'ke, ifa kan ko si ni para Ileke ma ja sile ma ja soko ibikan sa lo ma ja si This and many more on facebook group http://www.facebook.com/group.php?gid=130674528822 |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by sulad82i(m): 6:05pm On Apr 28, 2011 |
Owee (Proverb) Ojo pa alapa o di amugun fun ewure Eniti to tu ito si le ton paa re, o mo nkan ti won nfi ito se ni af'Apoti rori kii gbadun oorun. Olobe lo loko Ai gbo'fa la n wo'ke, ifa kan ko si ni para Ileke ma ja sile ma ja soko ibikan sa lo ma ja si This and many more on facebook group Facebook Group http://www.facebook.com/group.php?gid=130674528822 |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tubabie(f): 9:44pm On Apr 28, 2011 |
dayokanu: Awon Yoruba Okun ko si ni Kwara, Kogi ni won wa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Oluschenco(m): 9:47pm On Apr 28, 2011 |
Aku orire kuro lowo ijoba ipa ni ile oodua |
(1) (2) (3) ... (58) (59) (60) (61) (62) (63) (64) ... (73) (Reply)
Most Frequently Used Insult In Nigeria / Funny But Wise African Proverbs. / Efik/ibibio Names And Their Meaning
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 60 |