Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,594 members, 7,958,828 topics. Date: Thursday, 26 September 2024 at 04:13 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (381192 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 9:32pm On May 24, 2007 |
haywhy: ROFLMAO! " " very funny! o le se nattin! ologun eke! agadagodo nikan ni? you for find safety pin! efizii ti poju! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by haywhy(m): 9:35pm On May 24, 2007 |
omode re ko mo oogun o n pe ni efo! Sugbon sha, ma se suuru titi ti ma a fi ri owo e, Ni igba naa wa mo pe sanma meje lowa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 9:38pm On May 24, 2007 |
" " |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 9:39pm On May 24, 2007 |
Oga Ikomi, Se e ti lo san ohun ti awon omo iya yin ni ki e san? We will fine him the following: 7 tubers of yam 7 kolanut, don't forget ose oji too 7 bottles of shnapp 4 yards of akwa ocha 3 white oke okuko i know he can't afford atulu, so we'll take a white goat. all in favor say aye Oro Ounje sa ni ti awon omo nna. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by haywhy(m): 9:39pm On May 24, 2007 |
Egba mi ooooooooo! Mi o she nkan kan fun ikamefa ooo! Abi kiwa lode ti kole soro? Owo temi ree loke fun fun nene oo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 9:39pm On May 24, 2007 |
Babalawo, Gbagbe bobo yi jare, ko da yin mooo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ikomi(m): 9:47pm On May 24, 2007 |
@Segoye2, lo shora e ooohh. Iwo paddy egbe, ma se paddy le seoo. lol |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 9:51pm On May 24, 2007 |
haywhy: babalawo eke you go soon wound! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by haywhy(m): 9:55pm On May 24, 2007 |
Ikamefa wooo, efrebo oo! Eeti ri naa! A a ma ti itori pe afe je maalu ki a ma pe maalu ni buroda ni! Iro oo! Bobo segoye, dakun mo ni lati ba e chaati ni ori ero yawu mesenja! Kini ero re. Oro naa se pataki pupo ooo! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 9:55pm On May 24, 2007 |
Ogbeni Ikamefa, se ire ni babalawo daadaa, oda na, ole ran mi lowo ni yen kee |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ThiefOfHearts(f): 9:56pm On May 24, 2007 |
Ikomi, o shi wa nibi? Mo ri pe awon ara ilu re tin sekun pe o ti parapo pelu awa yoruba "buruku". O tete kuro nibi before a koba re |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 9:58pm On May 24, 2007 |
babalawo mu owun, ki ni e fe ba mi sooo, omo iya ni gbogbo wa ni bi yi, nitori na, e je ka ma so lo ni bi yi abi e le te mi ni ago lori segoye2@itsabove.com emi o ni messenja yahoo ra ra ra msn ni mo ni, |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by haywhy(m): 9:59pm On May 24, 2007 |
Oseun ore mi tooto, Odua yoo gbe o! em es en yen naa daara too! Ose un! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 10:10pm On May 24, 2007 |
Oda,, Babalawo, Kini oruko ti anpe Mouse ni ede Yoruba? ati wipe kini pasti tensi Mango ati table, ti e ko ba gbaa ajepe, babalawo ironi ti yin! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by haywhy(m): 10:12pm On May 24, 2007 |
Fun mi ni msn e bobo yi! Em es en! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 10:19pm On May 24, 2007 |
oruko mi @ hotmail dot com |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 10:20pm On May 24, 2007 |
Tiyin da? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by niceuzor: 10:20pm On May 24, 2007 |
Oluwa jesu What kind of a thread is this? ****Seun this is tribalism**** |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by haywhy(m): 10:28pm On May 24, 2007 |
segoye ur not online ooooo? I don add u now! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 10:40pm On May 24, 2007 |
Ma binu jare, mo se woo ni, ati wipe, mo ti acepti re, sugbo mi ko ri oo mooo ooo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 10:41pm On May 24, 2007 |
Eyin omo iya mi, ema binu si mi rara, babalawo mi fe bami soro kekere kan. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 10:50pm On May 24, 2007 |
segoye2: ha ha! maka ogbeni? ngbo haywhy won ba e wi! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 10:53pm On May 24, 2007 |
Babalawo Iro gba emaalii mi, ko de ba mi soro, okan addii mi ni,, I ro ni bobo yen so jare, tire ni mo gbagbo, so ro fun mi, bawo ni ase ma se ise na? Abi kin lo si soo si ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by amor4ce(m): 10:55pm On May 24, 2007 |
Hey y'all, i'm new here. i don't know how to speak yoruba even though i am proud of our heritage. even the encyclopaedia britannica described us as the most urbanised in sub-saharan africa. I will be very grateful if this forum could be used to teach the nigerian tongues. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mukina2: 10:56pm On May 24, 2007 |
ikamefa: ikame bawoni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 11:05pm On May 24, 2007 |
mukina2: omo i dey jare mo wa! iwo n ko? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 11:07pm On May 24, 2007 |
I nu mi dun pe o pari ile eko jiga ti a mosi Encyclopedia ti Ilu Britannica, sugbon bawo ni asele ko e ni yoruba lai si ami? ani ami oke, isale and Arin? pa pa julo ami isale isale? so fun wa jooo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ijogbon(m): 11:08pm On May 24, 2007 |
een lee ni oko'o! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mukina2: 11:21pm On May 24, 2007 |
ika ki lo sen le |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by NiteAngel(m): 11:24pm On May 24, 2007 |
Mo ti rin arin ta'kiti, eyi le ju comedy lo. Awon to de ti so'nu abi ti won ti s'omo nu bi oko, eleda a je ke wa ri o. Ede wa, asa wa, ti a ni; e je ka gbe l'aruge. Mo kira, mo tun gbe di fa'won to moye okun yi o. Ise'dale a gbe wa o. Ase. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by WesleyanA(f): 11:51pm On May 24, 2007 |
ma fi thread yi practice yoruba mi. mo o mo pe yoruba le la ti ka to yi. lmao @ mobolowowon |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 11:57pm On May 24, 2007 |
segoye o ,segoye o,segoye o, e melo ni mo pe o. Asin de Arin de opa jini jini loruko ti a n pe eti agbon titi lo,ruko ti an pe iwo ese baa mu afi laka sonu juajua loruko ta n pe emi olokan ewe alesonso joba loko tan won gbagbe ati ro Segoye se oro wipe mo ti lo ni, mo ni mo n wole agbara lo, o si ti gbagbe mi ki n to de . O ti fe ma kanju la obe gbigbona. Se o ti gbagbe ni, wipe oniwara ni i fun wara kiniun, A ki i kan ju tu olu oran nitori igba re ko to ni se lobe.Awon eke babalawo po lode o. So ara re gidigidi. Ipin loju ikun nimu ara ile eni ni ba ni mu were sansan lara ta pee. To o , mo ti de pada o. Mo ri wipe ki n to de , awon olugbodi (ikamefa) ati arabinrin Mukinatu ti ro le, won si tun sa pa lati fi gboro jeka, okun o! Olufidu, emi ko ni ba o jiyan ede, ti o ba lee ri eni ti o ba tun mo ijinle ede yi beere lowo re wipe nje a a le pe oga ni alagemo. Mo mo dakodako daradara sugbon oga gangan ni eranko ti a n pe ni alagemo.Ninu oruko eranko yi ni a si ti mu owe ti arabinrin olulayo pa jade |
(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 35 |