Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,157,970 members, 7,835,241 topics. Date: Tuesday, 21 May 2024 at 07:30 AM

Ifá Prayer For Today. - Religion - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Ifá Prayer For Today. (176 Views)

My Prayer For Trinitarians / Geomancy, One Of The Bases For Ifá. / The Word For Today (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Ifá Prayer For Today. by Ifafunminire: 8:07am On Dec 13, 2023
Ọmọ iyá ẹ̀yẹlẹ̀ ni òun náà pẹ̀lú.
Gbogbo wọn ló bímọ.
Ẹyẹlé nìkan ni ò bi.
Ọ wáá tọ Ẹ̀ji Ogbè lọ.
Èji Ogbè ni ki ọ rẹ̀ rúbọ.
Ẹyẹlé sì ṣe bẹ́ẹ̀.
Nigba ti ẹyẹlé ò pamọ,
Méjì l'ó pa.

This Ifa verse tells us of the barren Ẹyẹlé that delivered twins after doing the right sacrifice.
Ifá promises to give every barren woman children. Lóni ọjọ Isẹgun, Ifá a gbe wa ọ.

#Ifa #Isese #prayer.
Re: Ifá Prayer For Today. by correctguy101(m): 8:16am On Dec 13, 2023
Ifafunminire:
Ọmọ iyá ẹ̀yẹlẹ̀ ni òun náà pẹ̀lú.
Gbogbo wọn ló bímọ.
Ẹyẹlé nìkan ni ò bi.
Ọ wáá tọ Ẹ̀ji Ogbè lọ.
Èji Ogbè ni ki ọ rẹ̀ rúbọ.
Ẹyẹlé sì ṣe bẹ́ẹ̀.
Nigba ti ẹyẹlé ò pamọ,
Méjì l'ó pa.

This Ifa verse tells us of the barren Ẹyẹlé that delivered twins after doing the right sacrifice.
Ifá promises to give every barren woman children. Lóni ọjọ Isẹgun, Ifá a gbe wa ọ.

#Ifa #Isese #prayer.

Let me guess..

It must be said in the Yoruba language lest it lose its effectiveness...

That it?
Re: Ifá Prayer For Today. by Ifafunminire: 6:45am On Dec 14, 2023
Wọ́n ní kí Àdàn ó má ṣe dé ibí ẹ̀wọ̀ ẹmi
Ní ọ̀sán gangan ọ;
Wọ́n ní ẹlẹ́mi ó fi kànnàkànnà pa à o
Àdàn ó gbọ́
L'ó bá gbéra ni ọ̀sán gangan,
Nigba ti ẹlémii ri i,
Ó si fi kànnàkànnà pa á.

This verse tells us about the danger in disobedience. It is in the person's interest to listen to instructions to avoid needless troubles. Ifá a gbé wà.

#Ifa #isese #spirituality

1 Like

Re: Ifá Prayer For Today. by nearline(m): 2:56pm On Dec 14, 2023
correctguy101:


Let me guess..

It must be said in the Yoruba language lest it lose its effectiveness...

That it?
No. Any language works.

(1) (Reply)

Ex Satanist & High Ranking African Warlock Encounters Jesus | The James Kawalya / God Has Favourites / .

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.