Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,397 members, 7,815,867 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 07:47 PM

Ayokomi1010's Posts

Nairaland Forum / Ayokomi1010's Profile / Ayokomi1010's Posts

(1) (2) (3) (4) (of 4 pages)

Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 7:44am On Apr 12, 2023
Naturewonders:
Ejo baba se etu elese merin ni abi eye awo ti won pe ni eye etu.eseun pupo
eiye etu ti ape ni awo

1 Like

Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 7:22am On Apr 01, 2023
E karo aku ojumo o, aku osun titun loni atuwalara o
Culture / Re: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by ayokomi1010(m): 10:21am On Mar 24, 2023
EMI prophet Ayokomi, ti moje oludasile ikanni Yi ti de pada bayi, oluwa yio ranwa lowo, fun awa ti a Fe eto adura, tabi awon asoyepi kan Lori aiyere, boya o si Fe se eto adura kan loni imonipa boselese, ao ba e se Koda ao tun Fi ranse yala boya Nigeria tabi oke okun, number mi niyin oun na ni Whatsapp, 08135072961
Culture / Re: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by ayokomi1010(m): 10:18am On Mar 24, 2023
E karo gbogbo Ile, alafia oluwa olorun awon Omo Ogun yio wa pelu wa
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:13am On Mar 24, 2023
E karo gbogbo Ile, aku ojumo ire loni, oni ni ojo eti, olodunmare amu ajogun buburu eti kuro loju ona aiye gbogbo wa ati eyin ololufemi ni Ori ikanni Yi, moki eyin elesin Islam pe eku ongbe emi yo rehin osun o, bakan na moki eyin Omo lehin Jesu na pe eku irin Ajo Lent ogoji ojo, e pari re layo, e se odun ajinde pelu ayo, moki elesin adayeba, awon alaseku a bawa se o, emi baba ayokomi na ni mokiyin alase ati oludasile Yara Yi :- Ogun Awon baba wa, 08135072961/08075198871.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:36am On Mar 23, 2023
Ogun atosi
Odidi bara egunsi, ao be epo arare danu, ao get si merin, kanun Ako die, isuepaikun, ao se Lori Ina pelu omi didun, ao ma mu gasi kan ni osan, osan, odaju
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:24am On Mar 23, 2023
Ogun ajegun fun eniti o lo Ogun ti o ki sise.
Atelewo inaki, ewe ela, oga kan, ase oka, oko atare, ao jopo gbere yipo orun owo mejeji
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:20am On Mar 23, 2023
Ogun oko ti o tiku tiko sise mo, tabi ko le mo.
Egbo igi osunsun, egbo idi apata, egbo igi aika, odindi aipon eso eyin, eja ojiji, ijapa, atare odidi kan, eri agbado, ata jije, iyere, ao gun won Po , ao sagbe mimu Eko lalelale.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:14am On Mar 23, 2023
Ogun iferan Gbogbo enia ati ibiti ati sise.
Ori ologbo tobani irin kan, eweji, ewe ajeobale, atare odidi kan, ao jopo ao ma Fi epo la, tabi kama Fi fo Eko tutu mu, a sile Pomo ose kamawe.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:07am On Mar 23, 2023
Ogun iwosan Ile gbigbona.
Stare odidi kan, otanu iroko, orogbo gbigbe, ewe ahara gbigbe, ao lowo Po, ale dasi oyin kama la, tabi kama Fi omi tutu lo
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:05am On Mar 23, 2023
Afanni wa fun Iwo tobafe pemi salaye aiyere, tabi arun tabi amodi kan se o, tabi Iwo ti onleri awon ise ti a Fi sile se funrare tofe Kaba e se, Ka Fi ranse si e, kibaje ni Nigeria tabi ni okeokun, number baba Ayokomi niyi timoje Alase ati oludasile Ogun Awon baba wa,
08135072961,oun na ni Whatsapp mi, ti o bati setan fun oun ti o Fe kamojuto ma pemi o, Kisi aiye lati Mafi akoko sofo funmi o
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:05am On Mar 23, 2023
Ogun ituwo Awebidanu
Ao toju Ori alangba tutu, oun na la Leni adaripon tabi orikoko, ao toju egbo tude, ati ata ijosi 7 fun obinrin, 9 fun okunrin, egbo ibepe Ako, epo obo die, ao gun mo ose ti ale we ni ekan, ao Fi epo pupa para, ao we ose na pelu kankan titun, si Odo tosan, tabi si Inu baluwe wa, ha ara Ade enia by baba ayokomi gangan, oludasile ikanni Yi:-ogun awon baba wa 08135072961
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 9:57am On Mar 23, 2023
[color=#000099][/color]OGUN AWURE TI AMA FI RI OWO NA LOJOJUMO LABE BOTIWU KORI.
Ao toju, ewe ila iroko, ewe igi iPin, erupe akitan nla to gba eru dada, ao bu erupe akitan na, ao gun nkan meteta Yi Po mo ose, Ao Fi onronro malu Po, ao kosinu asunwo aso funfun, ao ma bu we ni aro , Oro Yi la o maso ti aba Po ose na lowo, Ohunre:-ipin loni ki e pin ore nla kanmi loni, ilairoko loni ki e ro ore nla ti o lami kanmi loni, pinran pinran ki pin eran ko ma pin ti oronro fun, ti aba gba Ile ti a gba itan, Odo akintan lama ko lo, eko ore nla wa funmi lati oni lo.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:27am On Feb 22, 2023
Lati December 4 2015,ti Moti da Yara asiri Ogun Awon baba wa, sile mi bere owo lowo Omo egbe Yi kankan ri o, mo Pataki oruko pupo, afi eniti o ba salaye Oro aiyere funmi ni Iwon igbati o pemi ni ma so igbese toye ko gbe fun, toripe otito Inu ni awon baba mi Fi sise lose yewon, emi o wa Fe sawo odale alaso pipon, torina ekiyesi ara o, kiwon ma lo afani oruko ati ife ti awon enia ni si Yara Yi luyin ni jibiti o, number mi niyi 08135072961.By Baba ayokomi1010,oludasile Inu Yara Yi, Ogun Awon baba wa, Koni baje o, Ile ati ona eni kokan Koni baje o, enikeni tobawa Fi oruko tabi afani Inu yarami Yi lu jibiti gbogbo ise Toba se laye, elomi ni o je, kise oun Tori oka ki jere Omo re, eiye kijere Omo re, ase wa. Sugbon gbogbo eniti o ba wa si Inu Yara Yi tofi Ogun otito sile tose awon enia ni afani, ti ko ba Yara Yi he, ti ko lu jibiti, adara lati owuro aiye enibe titi di ojo ale re ni, Koda onitoun ajere ara re atun jere Omo, Tori ogo Omo elewuji enikan soso ni iru enibe pe, igbaa enia ni o ma je ipe re fun owo ola aiku bale Oro asewa .

1 Like

Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:17am On Feb 22, 2023
Akiyesi gbogbo eyiti e wa si Ori ikanni mi mawa polowo Yara yin, e dawo be duro lati akoko Yi lo, eyin enia mi baba ayokomi kobere owo lowo enikeni o, ema jeki won gba yin o, eniti o ba Fe ni Oro adaso pelumi number mi na niyi ko yipada 08135072961,lehin re e ma ni Oro pelu enikeni nibi o mi ni idaun si eniti won ba lu ni jibiti o, mose ikilo oemi ni tiyin Baba Ayokomi1010,oludasile Ogun Awon baba wa.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 10:12am On Feb 22, 2023
E karo o gbogbo Omo Yoruba atata, gbogbo Awa ti awa ni Yara ikanni Ogun awon baba wa, ojumo ayo ni oni fun wa, eto idibo to bowa Yi emi enikeni wa o ni losi o, emi baba ayokomi Yi moda nkanni Yi sile tide pada bayi, lati ma ta yin lore okan o jokan asiri tewetegbo Yoruba. Number Whatsapp mi niyi, 08135072961.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 4:38pm On Jul 06, 2020
E ku ojo meji meta o gbogbo omo egbe Ogunawonbabawa
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 9:33am On Jun 21, 2020
OGUN IWOSAN AYE
ewe ela,ewe alupayida odidi atare kan, ao jo po ao da sinu omori isaasun ao wa ko oruka irin si,ao wa da epo pupa si ao ro po, ao wa fa Ogun yan si enu akuko adie,ni emeta,ao ma fi oruka ni si lenu ni okokan yio ma gbemi,ti o bawa di OJO keje ao pa adie na,ao lainure ao Ba awon oruka na,ao ko ao ma fun eniti Asian ba nse yio fi bowo re,aisan re yio San ni OJO na ase eledunmare ni,iba eyin agba o aiye mojuba o,mowole mo pa igbunmo o,mofori bale fun gbogbo ajunilo.


Moti fi ise yi sile ninu ile,lojoti o tipe oun ti o tun mumi mu padawa ni pe iseyi ni babawa Alh ti mosope olorun gbe dide Lori aisan ti oti to odun meji,ti won de bunmi ni 20000,toripe eniti a se lore ti kodupe o dabi ki olosa ko eru eni loni,mowa tun da ise yipada wa fun gbogbo omo egbe Ogunawonbabawa pe komaje afani e mafi ojudi ise yio.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 9:15am On Jun 21, 2020
Ogun asiri bibo.
Ewe omodun tagiri,ewe ati ododo tannaposo,epo jebo,ewe iyalode,ejeki a lopomo ata ijosin,ejeki a bo igbin kan kayo idoti re danu ka son komo dada kaju sinu isasun lodidi,ejeki ase leponiyo pelu awon eroja yan,ejeki aje,lase edunmare ao ri bibo asiri.

Ogun Awure owo
Ewe iyalode funfun ati pupa,erun Alamo,imi ojo,owo eyo kudi 10,ejeki a gun mo ose ka ju sibikan ninu yarawa laiko sinu ora tabi igba tabi ike,kama we larokutu oda owo koni da oluware.


Ogun nla tiobinrin fi ti ara okunrin la ati eyiti okunrin fi ti ara obinrin la,ati ise igbelu oyinbo fun fayegbami ati asikire wa ni ile fun eniti o bafe,
Kosi ilu ti o lewa ni Nigeria yi ti emi kifi ise ranse si,tiabati jo soro ti o funwa ni address re,ati phone number re,ti o siti sanwo wa,e bere mi tabi ko oro sile ninu gbogbo enia ti o je afani mi ninu ile yi emi oludasile Ogun awon babawa,enikeni o le pemi ni scam,Tori mi lu enikeni ni jibiti,Ade dupe iwon ba ore ti adaniwaye se fun wa,Ade dupe lowo awon tilo isewa boya yala eyiti afi owo arawa se fun won,tabi eyiti a fisile Lori ikanni yi,tio je fun won,ti won de send owo siwa ni idupe ati awon ti o send card simi,koda ni ijeta enikan tun jomi loju ti o fi 20000 si account mi,pe aisan ojo pipe ti awon ti nawo damu si,pe oun ri iwosan latari inu ileyi,Alh na ki olorun bami Lora emi yin ki ola yin ma wa le o,majeki won fi oruko mi lu o ni jibiti o,pemi si 08075198871 08135072961
Baba Ayokomi lomada e loun,kise pa mi tabi awon omose mi,ire o.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 8:21am On Jun 02, 2020
Orin igi ata ni ema run si akokoro yan o,e rira lowo awon elewe omo.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 8:20am On Jun 02, 2020
Ogun akokoro eyin
Ao bu petrol sinu cup kan,ao bu iyo sinure,kafi owu tutu kan si.

Oran ataa e ma run nigba gbogbo yio lo
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:41am On May 29, 2020
E karo gbogbo ile o.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 12:13pm On May 27, 2020
Number group na nisyi,ti o bari number Miran yatosi eyi kise baba Ayokomi o,majeki won gba e o
08135072961/08075198871
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 12:11pm On May 27, 2020
E Ku ojumo o,aku iyaleta ao ri batise ao ri ona gbegba o,gbogbo omo egbe Ogun awon baba wa.emi Aree na ni mo kiwa o,gbogbo enia ti o je ojogbon ati omo Yoruba ibile ti o fe iranlowo mi si awon ti eledumare ranmisi Ki e bamipade lati wa sinu yara kan ti ma dasile loni fun afani yin Ogun awon baba wa,ni ori whatsapp,eyiti akoko dasile ni odun 2016 Lori whatsapp otikun fun opo enia,awon woli Alfa onisegun enia Dudu ati ti oyinbo nikan lada sile fun ositi kun ao gba enikeni wole sibe yan mo,toripe ati se ipade ojukoju nibe,atigbe kakiri ipinle ni orilede yi,
Sugbon eleyi ti ama dasile Lori whatsapp loni tise 27/05/2020.o mawa fun gbogbo enia ti o fe Ogun ibile awon baba wa, tabi o fe bami soro labe aso lati sise fun o lati Owo mi,
Lati ojoti moti da ikan niyi sile ni Nairaland kosi enikeni toleni mo lu oun ni jibiti,tabi ise ti a fisile ko sise fun oun,mode dupe fun eyin ti e ma send card simi fun data,ati eyin ti e ma bunmi lowo pe Baba ayokomi e gba, ina o ni tan lowo yin o,oju Owo koni pon yin.
Eleyi ni number Group na ti ama dasile loni ni whatsapp wa,Iwo ti o bati fe darapo wa kansimi pe omo egbemi ni e ni Nairaland Lori Ogun awon baba wa, made add whatsapp re sori group na
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 9:25am On May 21, 2020
E karo o,mope gbogbo eyin omo egbe Ogun awon baba wa, ati eyinti e tele wa ninu ikanni yi ,ejeki ari enia meji meta soro ti o ti Dan ise inu ileyi wo ti o si ba be,abi inu ileyi koni ihulo kankan fun wa,ejeki a so,mofemo awon ti o duro Dede fun inu ile yi,atipe e je afani mi,kini afani tiyin na ti e fe fise kuse koriya fun wa,e se pupo amo riri yio,aisan o ni da enikokan wa gunle o,Ogun aye o ni bori wa,ao lu aluyo o.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 9:19am On May 21, 2020
OSE TUDE ODO TI ONA ENIA BA DOJURU.
Ori aparo 1,odidi atare 1,aoyo gbogbo omoinure,ota inu iroko,egbo tude die,aogun gbogbo repo
mose iwe meje.....lilore
Ori ikunle laotiwe oseyii ,kankan meje laofiwe ose meje na....(Lilo fun eniyan kan)
....tested OK ...
4RM PRESIDENT OGUN AWON BABA WA.BABA AYOKOMI NA NI O.
AKU IMURA ODUN ODUN AYO LA O SE.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 6:07pm On May 20, 2020
Alafia fun yin o gbogbo omo egbe Ogun awon baba wa,ayo nitiyin o[sub][/sub]
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 2:12am On May 17, 2020
OGUN AGADAGODO ELE
Iye igun,ihe aparo,ori atioro,ao jowon po pelu atare odidi kan,ao di ni owu Dudu ati funfun mo agadagodo,ao loran ni awo obo, omo atare 7,lama fipe,
Ohunre:-ise ni pa igun,osi nipa aparo,ile akogbe nipa atioro,aye obo kidara titi koma so ewon mo idi,jki aburu ati ajalu bayi majalu lagbaja.

OGUN ASEGBE
Ori asa,ori olongbo,awo ekun,odidi atare ao jopo,ao di lowu Dudu ati funfun ao ran ni awo ekun,
OHUN RE:-Imotu imojo imo enini Ki dale,toripe ti gbogbo eye ba ngbimo asa ti won ba foju kan asa imo won atuka,imotu imojo imo enini Ki dale,bi gbogbo eranko ba gbimo eku ti won bafi oju kan ekunn ekun imo won atuka,imotu imojo,imo enini Ki dale, bi gbogbo eku ba gbimo ologbo bi won bafi oju kan olongbo imo won atuka, Ki gbogbo aburu ati ibi ti won di ni tori mi tuka, gbogbo aburu ti nbe lona ko tuka.

ISORI NLA.AIPERI.
ao toju aso funfun opa kan,ao kun egbe kan ni osun,ao kun egbe kan ni aro,ao bu iyo si Lori ao fi igbin le,ti igbin ni bati je iyo yan ti o Ku,ao jopo ao ro sinu sere kan,ao mafi omo atare meje pe,ao gbe sinu ile wa,tabi kaso mo ile,
Ohunre:-ojo ti aso funfun ba foju kan aro ni ise re tan,ojo ti aso funfun ba foju kan osun ni isere baje, ojo ti igbin ba fenu kan iyo,ni yio gbona orun aiperi,gbogbo eniti o ba porimi nibi koma so lorun aiperi,ti a ba ti pe la o ma fi sere yan koja oriwa.

ETO BI ABAFE FE IYAWO LE IYAWO WA TI O TUKA.
Ao toju abela pupa kan,ao ko oruko iyawo ti o wa nile si,ao tan ina si,ao ma sa oruko yi,JAHURAHTAJAH-TUBIH 21× ELI LAH HAOLAH-SEMIRAH3×
ao gbadura Olorun orimolade gbogbo oun ti lagbaja omo lagbaja lo ti o fi tu oro iyawo ti mofe fe ka,Ki o baje lati oni lo.

OSOLE ASINA TIPATIPA.
Ori oka NLA,ao fi tele inu isasun,odidi atare,ata ijosi,ao fi eso werepe bo mole,ao Jo kama fi oti lo,botiwu Ki ona di to yio la.mo
4r[/color][color=#990000]m President
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 6:44pm On May 15, 2020
Eniti o bere pe kinije ase oka,or ase okete,iru ejo oka ni je ase oka,iru okete nije ase okete.
By baba Ayokomi

(1) (2) (3) (4) (of 4 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 45
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.