₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,330,084 members, 8,443,790 topics. Date: Sunday, 12 July 2026 at 01:15 PM

Toggle theme

Ayokomi1010's Posts

Nairaland ForumAyokomi1010's ProfileAyokomi1010's Posts

1 2 3 4 (of 4 pages)

CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 7:34am On Jan 08, 2016
OGUN FUN OBINRIN TI OKO RE KORIRA
ao toju eyele kan ao pa eje re sinu Oyin ao ropo ki Obinrin mafi pa oju ara re ti won bafe Joni ajoseopo pelu oko re
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 7:00am On Jan 06, 2016
OGUN EYONU FUN KI WON MA FERAN WA
ao toju ori ti afise obe,ao wa pa eje ako alangba kan le lori,ao po papo,ao ma fira ori idodo wa,o daju
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 6:56am On Jan 06, 2016
OGUN EYONU TI A MALO LO SI ODE TAFI GBA IYIN NI BE
ao fi epo pupa te ejiogbe si atelewo alafia,ao tun fi omi na te pelu iyo isebe,ao wa pe ohun yi si ao wa la,ao fi owo iyoku sa ori,kama lo sode na ao gba iyin nibe, ohun re:amo roro loruko ti won pe iwo epo,amayegun loruko ti won pe iwo omi,amuludun loruko ti won pe iwo iyo,omi kiti laye o,ejiogbe kiti lawujo ifa,ki emi lagbaja omo lagbaja gba iyin nibi gbogbo loni o.
ejiogbe
! !
! !
! !
! !
ogun yi dara gan ni o asegbayin la o ma se o ni ojojumo aye wa ao ni te lase edunmare
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 6:36am On Jan 06, 2016
E karo gbogbo ile, A de ku aseku odun,odun a yabo fun wa o,Amin ase edumare, E jo ohun ti o je keri owo mi lori ikanni lati bi ojo meta nipe moni adua kan ti mo mase ni ipari odun si odun titun ohun lo fa,sugbon moti de pada bayi,ati pe se ogberi lo po lori ikanni yi ni tori enikan pere ni mori ti o sese fi Ogun ti e si ori ikanni yi lehin mi,se bi ani kajo yara wa logbon ni,enikeni lo le fi ogun si ori ikanni yi,sati je olododo,olodunmare abawa se o
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 4:59am On Dec 31, 2015
beni ajegun Miran wa
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 4:58am On Dec 31, 2015
ori eye Awo ni ti a tun peni etu
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 7:42am On Dec 26, 2015
OGUN OSOLE OWO TO MA SISE KIAKIA
odidi ejo kan,kibase gbigbe tabi tutu,Awo lili tolori,ipe ore 21,odidi atare kan, ao jo po,ao mafi fo eko tutu Mu,ninu omori Igba ti koridi joko.odaju saka lase olodunmare
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 7:31am On Dec 26, 2015
e karo o asi ku odun,iwon ojo ti o ku ki odun yi pari ao ni sagbako ninu aiye o,ayo la o fi wo odun titun amin.E karo o gbogbo ile o
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 4:29pm On Dec 22, 2015
OGUN OSOLE TO DARA
Ori ejo oka kan,ori ere kan,epo jebo,owo inaki kan,ewe inabo,afara Oyin,ao gun won papo,ao po mo ose,ao ma we,dandan ni Igba adara de fun wa
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 2:43pm On Dec 22, 2015
mofun enikeni ti o je oni mi mo,ni afani lati ma Mu ogbon tiwon Na wa sori ikanni yi,ki o sati maje oun tolese jamba fun Awon eniyan,ki o si maje oun to ni eroja eniyan ninu o,ki o si ma je ogun iro o ki a ma tan awon eniyan je,ki won mo ba ma se owo ati akoko won lofo,ki ari dajupe ogun toto toje o,ni a fisi ita,kani iberu olorun lokan ese gan,iba olorun iba eyin agba o
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 2:25pm On Dec 22, 2015
oje oro adete,ale ri bi inu Igbo,awon oni side si ma gbin si ile,efilo Awon onisise won a jure ibi ti o bawa ni ilu te ngbe
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 7:28am On Dec 21, 2015
E karo Gbogbo eyin omo odudua,ojumo oni asanwa sola ati aiku bale oro oni ojo aje yi,ari ti aje se,adeda aseda adaniwaye koni je Kaye fiwa sinu ide o,alo abo wa loni ire ni o,lase eledumare,aku ojumo o
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 3:04am On Dec 21, 2015
igi sao,oun loma so eso tiwon fi ta ayo olopon yan
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 3:03am On Dec 21, 2015
igi Ajara Na ni won tun peni ogbolo,bi aba re sinu OMI omire ama yo gbolo
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 3:00am On Dec 21, 2015
ao yo igbin Na ni tutu ni o
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 5:22am On Dec 20, 2015
OGUN FUN ENITI WON JEKI OGUN JE FUN MO
Igbin kan,ao bu iyo sile ti o ba ti yori ti o fi enu kan iyo yan to bati ku,ao wa yo kuro ninu ikalahun re,ao wa gun igbin yan po pelu epo obo,ati erupe orita meta,ao wa gun mo ose,inu odo la o ti gun o,ao ma we ose na,won a yoda wa kia,Ogun asibere si sise Lara eni,won ni ba ise tabase je mo,odara gan ni o
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 5:14am On Dec 20, 2015
OGUN AWORO ATI ASINA OWO
odidi Awo igala kan,opolo 16,obi abata oloju merin 16,odidi atare 16,ao ko si arin ifa Awo gala na pelu owo nla kan,500 or 1000,ti aba ti kosi oju ifa Awo gala na tan,ao gbe sinu agbada ao jo papo,ao mafi foko tutu Mu,tabi ki a ma fi hot lo die die,odaju
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 4:53am On Dec 20, 2015
OGUN IWOSAN STROKE
AO toju igi osunsun,ao lo tiyo kunna dada,ao wa Sa enina ni gbere ni apa ati ese,ao fi ra.
ao wa wa oge oro adete sinu igbakan,ao ju odidi eko tutu kan si,ao fo papo dada,ao mafi wo owo ati ese eni na,pelu ogo olorun alafia de niyan.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 4:43am On Dec 20, 2015
OGUN AROBOKU OKUNRIN TI KOLE BA OBINRIN SUN
AO toju egbo Ajara,ao ge wewe sinu igo kan,ao jo eyin adie ibile 7 si,ao da opolopo omi agbon si,lehin OJO keta ao ma Mu.
Egbo sao,iyere,sugar onikoro die,ao gun papo ao mafi Mu eko gbigbona.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 4:37am On Dec 20, 2015
OGUN ONMO NLA
odidi eye karo kan,ori olongbo kan,egungun eye akala die,eja ojiji kan,odidi imo ope kan,odidi atare kan,ikode meta,ao jopo gbere kan si igbayawa,iyoku Ogede omini pupa la o mafi koje,kosi oun kan ti o sokunkun siwa koda won a tunma kowa ni OGUN loju orun pelu.odaju iba eledumare o
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 4:15am On Dec 20, 2015
OGUN IWOSAN LAGUNLAGUN
AO toju epo-igi pandoro,odidi atare mejo,orogbo mejo,ako kanhun,ata ijosi,iyere,iyo isebe,ao gun ni agunmu,eko gbigbona niyo ma fi lo diedie,pelu ase olorun Koni gburo aisan na mo
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 6:14am On Dec 19, 2015
OGUN IWOSAN LAGUNLAGUN
ao toju epo igi padoro,odidi atare mejo,orogbo mejo,ako kanhun,ata ijosin,iyere,iyo isebe,ao gun ni agunmu,eko gbigbona niki eniti lagunlagun tabi kokoro inu eje baja,mafi lo kotun gbodo se mo,pelu ase olorun,iba eyin agba o
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 7:33pm On Dec 18, 2015
OGUN ATUDE AYE isawuru kan,epo obo ao gun mo ose ao ma fi we
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 7:25pm On Dec 18, 2015
OGUN OSOLE YAN
ao ma bu diedie la o mawa se eyin adie ibile kan lojumo,ti a ba tise eyin tojina tan ao bo epo re,ao mawa Fi eyin yan ba etu-ogun tajo yan je,be lase malo o
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 1:49pm On Dec 17, 2015
OSOLE OWO NLA
ao toju odidi okete kan ,opolopo ewe ewuro,tagiri odidi kan,Gbogbo owo tane,odidi atare kan,ao jo po ,ao mafi eyin adie ibile je lekan lojumo
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 1:14pm On Dec 17, 2015
OGUN Ti AFI MADE ONI JALABI MOLE
ao wa ewe omisimisi,ao gun mo ose ao fi ito ti aba ko to laro po,ati ito enuwa toje ti owuro kutu,lehin ti a po tan ,ao ma bu fun Awon to wa sodowa ki o mafiwe,Gbogbo Igba tiwa nikan ni won mari ro.
2)eiyele kan ao la ni aya,ao ko ewe abo 9 si,ati ewe amunimuye die,okun sokoto wa,odidi atare kan,ao jopo,kama funwon lo die die.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 8:38am On Dec 07, 2015
Ebe Awon agba yan,ohun toje odu ori ewe ahunekun ni ESO tobawa Lori ewe egele,ti a tunpeni mafiowokan Omo mi.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 8:34am On Dec 07, 2015
Ajegun yan,Omo atare Meje ni fun obinrin,mesan ni fun okunrin
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 8:27am On Dec 07, 2015
e karo,aku ojumo rere o, Awon baba wa Ni iwure yi dara pupo Lati ma lo ni owuro kutu papa julo OJO aje, Ao bu OMI tutu sinu igba kan tabi Awo,ao te ejiogbe si ori omi na,ao wa wure yisi,lehin na la o mu die nibe ao da iyoku sile ni enu ona ile wa ao fi ese alafia te mole bo sita,Iwure:-) OMI sepesepe nise OMI alaketu,agbara gbururu nise OMI ete ife,o dara fun eyin aja eyin aja funfun nini,o dara fun OMI iyirisi OMI iyirisi ntan yiriyiri,nje o ori wa di ori Ade loni o,orun wa di orun ileke ola,ESE wa di ESE bata ola loni,nitoripe ojukan ti oka Ba joko si lohunje oka lo Ba oka,ojukan ti ere jokosi ni ohunje ere ba ere,ojumo Ki Mo Ki adariwurun ma bere OMI,ejiogbe o sebi odu mererindilogun ni se erusin fun ejiogbe,Ki won wa fi oun rere sin mi loni o,kiri aje se ohun rere.Ase ase ase . ! kabiyesi eledumare oba ajiki o,aiye toto akamora iba o,ire ni mase nitemi Omo obasayero,mi o Ni se ika,sugbon bi aye bawa so ire di ibi ipade di ohun o.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 8:08pm On Dec 05, 2015
OGUN EBE AWON AGBA
obi pupa kan,funfun kan,ewe ata ijosi,ao gun Mo ose ao mawe.
(²) igbin kan,odu ori ewe ahunekun,epo obo,ao gun dada ao fi ose po ao ko sinu aso funfun,wiwe ni odaju

1 2 3 4 (of 4 pages)