Ayokomi1010's Posts
Nairaland Forum › Ayokomi1010's Profile › Ayokomi1010's Posts
OGun AJEGUN. ao toju oga aye kan,ao fi ako Okuta ge iru oga na ni aye,ao lo pelu omo atare mesan,ao fi si gbere yipo owo mejeji. o daju. |
e karo gbogbo Omo odudua,ojumo ayo loni ma je fun wa o |
oruka bi meta tabi Meje lama lo fun Ogun na |
kilode ti eyin eniyan ma tan Awon eniyan je ri,won kipe ajata ajiyo ni eran NLA ni odo Awon agba ife e ma serantipe odua o fe iro, eje Ki a se Awon eniyan lore tori ola, elowo gbogbo oun ti Mo post lori ikanni yi baba eleba ise buburu nibe,Awo ire lawa,boya keso pato pe bi won se pe ajata lodo tiyin nu,mise ota yi rara o,emi asi mako ogbon Mo ogbon ni, oruko meta ni afi pe Erin lodo tiwa ajinaku Eran NLA, oun ti Awon baba tiwa fipe ni eran NLA nipe ti eba pa Erin lodo tiwa won a ni Ki logun pa won a ni eran NLA,tori kosi iru eran Igbo teni ba lara re,emaje kama kabuku arawa kama fi ona ogbon han arawa loto ,ese ifa kan wipe okan nikun awodi okan nikun Omo ASA,kaluku lajo ni OKokan Ni kun, kabiye si o |
Gbogbo eniyan ti eledumare fun ni imo nipa tewetegbo to je,lo lefi Ogun ajo toni afani fun ilo gbogbo Omo odua si ori ikanni yi o,kasi Jo yara ni ogbon Awon baba wa,ewe ama je o |
OGUN TAFI WE ISE OSI DANU Ao toju odidi ori etu kan,iye agbe meta,iye aluko meta,ikode meta,iye lekeleke meta,iye akala meta,iye igun meta,iye awodi meta,ao Jo po pelu atare odidi kan,ao po Mo ose,ao kosinu igba olomori,ao te ifa osa meji si lori,ao ma fi we,ao bere si ri se,iba eyin agba o. |
enikeni ti o ba ni oro ida konko lati bami so Ki o kan simi lori (prophet.nase.Solomon10@gmail.com) tabi whatsapp 08135072961 tabi 07087811181,abanise a ba wa se tiwa o amin |
eku dede asikoyi o Mo wipe eleda wa koni gba abodi o |
ajo osole,oni ijapa ti Mo ju sita yan,oun tole yo Awon eniyan kuro ninu ipoju ni,asimo iru ajo toye ko mawa Lori itakun aiye lujara mise omode Awo,ohun ti o baye eniyan a bere ni o Awon baba wa ni itose lo ni oyo oni ibere Ki si ona,se efe lewa tele ni,emi Mo oun telero pelu eran NLA,emi kise Awo sese de o,ti won tun gbogbo elo ajo pe ni oruko ti awon baba NLA wa o pe ri, gbogbo eni tobafese ajo yi eran Erin Igbo,lawon baba NLA wa pe be to ripe oun na leran to tobiju,emina ni ikanni temi (Ogun Awon baba wa to sonu)Ayokomi1010@gmail,elowo ikilo to wa be,emi kifi ise to bani eran ajiyo or ajata sori ikanni tori ko mu ogbon dani fun Awo ododo yato si Awon Awo soka o,ese pupo ewe a ma je o baba health |
OGUN IWOSAN AYE ewe ela,ewe alupayida odidi atare kan, ao jo po ao da sinu omori isaasun ao wa ko oruka irin si,ao wa da epo pupa si ao ro po, ao wa fa Ogun yan si enu akuko adie,ni emeta,ao ma fi oruka ni si lenu ni okokan yio ma gbemi,ti o bawa di OJO keje ao pa adie na,ao lainure ao Ba awon oruka na,ao ko ao ma fun eniti Asian ba nse yio fi bowo re,aisan re yio San ni OJO na ase eledunmare ni,iba eyin agba o aiye mojuba o,mowole mo pa igbunmo o,mofori bale fun gbogbo ajunilo. |
OGUN APAGUN Ori ako pepeye itana igi ose toresile,odidi atare kan aojopo ao ma fi fo eko tutu Mu,o ma pa Ogun buburu ninu ara ni o da ju |
moki gbogbo omo Yoruba pe aku dede asikoyi o a si ku ojonla Jimo toni koni je ase mo wa o,esin kan o sope kama se ajo o,oun ta lo gba wa lati ile ajeji ema je kopa ti awon baba wa Lara o,mi sope ki a ma sin olorun Oba okan soso o,eledunmare o,sugbon karanti pe larubawa ni asa Ati itoju ara nipa ilane tiwon won o parun o,Israeli na be,oyibo alawo funfun na,ki omo Yoruba madi atemere lagbaye Ati ki iya maje wa mo ni mose sin ikanni yi o,Ohun gbogbo ti o Ba je ododo le ma ri lati Odo mi,tikosini ni ipalara,be ni mosi fe ki gbogbo away taba darapo mo ikanni yi Na ma se,karanti pe eni riwatan to mo korowa iwo wa o,so ododo fun enikejire oje Idunnu eledunmare ESE ewe amaje Ogun ama je o odua agbe wa o Ase. |
moki gbogbo omo Yoruba mosi ikanni yi fun afani opolopo omo odudua fun Ogun nla Awon baba wa ni ile karo ojire ti o ti sonu ti Ati sodi ohun igbagbe ti awon alawo funfun si fi etan ati owo gba kuro lowo wa,esin o sope ka ma se ASA ibile wa o,omo Yoruba eje karonu o,Ikilo mi o fi aiye gba enikeni lori ikanni yi fun oro ti koye omo Yoruba tabi ebu iwa ibaje fifi ago ibanisoro sori afefe,atipe oun gbogbo tabafe ko si ori afefe komu ogbon dani kosi wulo fun Awon eniyan ki o si ma pawonlara odua agbe wa o |
OGUN EYONU TI A FI RI AYE LO oju malu mejeji,ao fi tele koko atare odidi meji,itanna reerinkomi,aojopo ao mafi Oyin la ninu Awo funfun fun OJO Meje,AO ri iyanu olorun. |
OGUN OSOLE IJAPA KEKERE KAN,IGBIN KEKERE KAN,ODIDI ATARE KAN,ERAN NLA DIE,AO JOPO,AO LO DADA AO DA SI MEJE,AO FI OTI OYINBO LO FUN OJOMEJE AO RI OWO NLA,PELU OGO OLORUN OBA ALAH |
OGUN APORO GBOGBO LESE. EWE TABA TUTU,IFUN AKUKO ADIE,AO KO WON SINU IGO KAN,AO GBA ITO IDAJIN AWON OMO TI KOTI BALAGA AO RO SI TI YIO KUN,LEHIN OJO KETA ODI LILO,SIBI MEJI FUN AGBA,OMODE SIBI KAN.OUN GBOGBO LO SISE FUN.ODAJU |
e kale babakaduna ati gbogbo Omo Awo,ejo e Funmi ni Ogun tole pa arun Lara OKUNRIN ti oyun jade loju nkan omokunrin re ti o basito oju nkan Omo OKUNRIN amata gidigidi,ejowo efunmi ni Ogun iwosan re nisi edakun |
e Ku ojoro,ejo ajowo ni Almelo fun ikan Omo kunrin,to tu oyun jade ti o Ba tun to oju nkan Omo kunrin a ma ta gidi gan,e dakun kini a le lo si |
Aye mojuba o,moki gbogbo ojogbon ti olorun ni Ki won mafi tewetegbo se Omo araye lore,e Jo mobere Ogun kan tosi dunmi lokan,e si Dami loun ejowo mofi olodumare be gbogbo ile,Ogun na nipe ti nkan Omo kunrin ba kere ju OJO ori re lo,atipe oyun funfun Jade ni nu nkan omokunrin re,Ki le Ba obinrin lajosepo ju ekanlo ti a fi sunlo,kini mole lofun ejowo,baba ati gbogbo ojogbon e sanumi |
ejo ajowo lalelo bi oko ba kere,ati ti enia o le ba obinrin sun ju ekan pere lo,edakun gbogbo Omo awo |
E karo gbogbo Omo Awo,ejo ti nkan omokunrin enia ba kereju ti enia kosi le ba obinrin sun ju ekan lo,ejo Ogun wo lale lo fun to ma sise kiakia,ese ewe amajeo |
[quote author=Ifadamilola30 ,ti aba fe lo Ogun adodun na,ale lo ni ori simenti tabi Ki a gbe olo lo enu ona |
OGUN OSOLE AWORO WO OWO Ao toju alangba tako tabo,owo eyo kudi 16,ao wa ya enu ako alangba na ao ko owo kudi 9 si ninu,ao ko meje sinu abo alangba na,ao wa fi ako tele inu ikoko ao gbe abo le,bi igbati won Jo se asepo ao wa fi igi nla die si egbe osi,odidi atare ni egbe otun,ao Jo papo,ao ni ro po rara ti a fi jo tan o,ao lo kunna Dada ao ma fi oti lo laro laro,opo ero ama wa si odo eni pelu owo nla. pelu ogo Olorun yio ri be odaju Dada,iba eyin agbalagba o |
Ogun Adodun Nla.ao toju aiyan kan ao lo ni enu ona wa ao wa fi ori po,ao ma fi wo nkan omokunrin wa ti a ba ti fe ba Obinrin ni ajosepo,be na ni Obinrin na le lo fun OKUNRIN ki o Sa ti fi pa oju ara re saju ki OKUNRIN to ba ni ajosepo,Adodun yi ni agbara pupo,Iba eyin agba oooooo,ewe ama je o. |
E karo oooo,baba,ati Gbogbo omo odua,Igba akoko mi re Lori ikanni yi o,ama ju wa se o |