₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,330,090 members, 8,443,822 topics. Date: Sunday, 12 July 2026 at 02:38 PM

Toggle theme

Ayokomi1010's Posts

Nairaland ForumAyokomi1010's ProfileAyokomi1010's Posts

1 2 3 4 (of 4 pages)

CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 6:44pm On May 15, 2020
Eniti o bere pe kinije ase oka,or ase okete,iru ejo oka ni je ase oka,iru okete nije ase okete.
By baba Ayokomi
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 6:33pm On May 15, 2020
E Ku irole o gbogbo ile eku ojo meta o,asiku ongbe emiwa a laja o,a de Ku ti cofidi 19,ao ni ba ajakale arun lo o,emi baba ayokomi1010 na ni mopada de o,gbogbo eyin ololufe Ogun awon baba wa,eku amojubami lehin number yi,bi enikeni ba gba Owo lowo re kise emi o,bamisoro labe aso Ki o to da enikeni loun,08075198871/08135072961,alafia arawa konidi fiafia o,gbogbo eyinti etije afani mi ninu ileyi ti e ma pemi ti e ma bere fun oun ti ko yeyin,tabi ti e ma dupe pe oun ti mo fisile sise fun yin,ati eyinti ema send card simi,eyinti e ma bere fun account number mi,timi Ki daun kise ti afojudi o,mo ko iwosi ni,oruko rere o sanju wura oun fadaka lo ni,kosi omo egbeyi ti o lewipe mo gba oun tabi lu oun ni jibiti,tabi mo bere Owo kan lowo oun,koda bi oro ayere ba need kojepe emi ni ma ba e se igbese,aniboseje kito sope ko send Owo o,ti o bade send Owo wa ri isere gba dandan botiwu Ki ilure jinna to,torina ema je Ki enikeni gba yin o,pe number mi kajo soro ni o,alafia fun yin[color=#990000][/color].
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 8:04am On Nov 19, 2018
E karo e ku ojumo o,mofe ta awon ti o ni ohun kan gba lowo olowo,alagbara,oyinbo,ati bebe lo lore ise kan pemi labe aso,tabi eniti o ni lo lati gba iwe igbelu ni orilede alawo funfun,tabi eniti o koni ibujoko.mo de pada,gbogbo eyin ti e ti dan awon ise mi wo,Emi baba Ayokomi,e ma fun ile lesi,eo ripe kise gbogbo igba le ma ri emi lori ikanni yi,tori kisi aye fun emi rara.pe mi si 08135072961/08075198871. lati ojo ti moti da ikanni yi sile,enikeni kole pe mo lu owun ni jibiti ni ori ikanni yi rara.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 1:40am On Dec 05, 2017
E karo Gbogbo omo odua,ao jire bi
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 6:13pm On Dec 04, 2017
Ogun Didu IPO oba oye tabi oselu,ati isegun nipa ipo
***************************************************
Ododo ewe iroko kan,moriwo ope kan eyiti yo soke Dada,eyo atare kan,ao lopo gbere kan ni Ori,
Gbolohun re*" Igbo Ki di Ki iroko mayo,larin igbago ni mariwo ti yo soso,emi lagbaja omo lagbaja Niki de Ori ipo Yi.

Asina
Omo adie ti o sonu lehin iyare,ao jo pelu odidi atare kan,ao wa toju oga gbigbe kan,ao wa lo oga gbigbe na Dada,ao da pomo ebu ti ajo yan,ao ro sinu igo kan,ao mafi sinap lo larolaro,lehin ti abati lo tan,ao fi omo odo lu iya odo ni emeta,iyan odo ti afi gun iyan je ni o.

Ohunmo Iwo ise
Ori igun,Ori akala,Ori eiye karo,etu ti won wo ninu ibon,iyo isebe die,ao gun papo, ao wafi te ifa irete meji,
| |
| |
|| ||
| |
ao wa pe oun re si,ao mafi fo eko mu die die,
Ohunre" kedere ni oju igun tole aye,kedere ni oju akala tode odun,kedere ni oju karo tole odo,kedere ni oju etu tole ibon,kedere ni oju iyo role obe,kedere niki ojumi maa to Gbogbo oun ti won ba nbawa Si odo mi.

Ise ti omo Yahoo fi gba obitibiti owo.ti a pe oruko ogun na ni oju AJA Ki gbo,
Omo AJA ti koti laju,atare nla kan,ata ijosi,ati igi aika lafijo,ojo ti o balo ojo keta ni onbara re a San owo nla fun ti kode ni le ba enikeni so,pe oun San owo nla bayi fun enikeni.

Mo bows,Pemi tabi bami soro ni WhatsApp 08135072961
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 5:23pm On Dec 04, 2017
Ikanni yi pe 3years ni oni,openi fun Olorun, torina opo enia loti se orire latara ikanni mi yi,kosi Si Eniti oleni mo gba owo kan ni owo oun tabi pe mo lu owun ni jibiti,koda awon ti o wami wa yin Olorun logo,ikanni yi ti di Egbe nla ni Ori WhatsApp, leyiti ati se ipade ojukoju re kakiri state, sugbon woli,alfa,babalawo,nikan ni a gba wole sibe kiwon le je olododo Ki won si ni imo Lori oun ti won gbe dani,Ki won ba matun ma dakun isoro awon ti o wa Sa bawon ,sugbon toripe ikanni yi pe 3years loni,ma sin whatsapp ti o je ti Gbogbo enia lati ma wa ojutu Si isoro enikeni,bakan ma fi awon ise kan Mark ayeye ojo oni,mosi fejeki awon omo wa olopolo pipe ri owo nla gba lowo awon agent won Ki won le fi ayo se odun,but mini fi ise omo Yahoo na sile ni Ori ikan ni yi o,Pemi tabi bami soro ni WhatsApp pelu ede yoruba,ati ise ti afi je tete tita.by ayokomi1010.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 12:00pm On Jun 09, 2017
alafia Olorun ko ma bayin,moti de pada,Gbogbo Iwo ti o bani Iwo se ogun koje,papa ninu oun ti mo ba kosi ikanni yi,lo ye ara re wo,se ogun ti je fun e ri bi beko lo se igbinyanju ti mu Ki ogun ma je fun ni,saju Ki o to ma se ogun Miran Ki o mo ba ma fi owo re sofo oo,fun Gbogbo woli alfa babaonisegun,babaalawo,sora fun gbaju e,jibiti,ogun ti o ba mo jewo pe o mo,idiyele ti eroja ogun ti ofe se fun Eniti o wa sodo re je ni Dede owo ti o gbodo gba ti o ba fe Ki ogun re je,Ki o si duro de idupe lati odo alejo re,bi okanjua aisododo bati wa lowo re ogun re koni je mo o fun awon ti wa se ajo lodo re,boti wu Ki o rewonje to wa pada pon laso kehin ni,tori na ododo di Iwo wa,Iwo ti won si so ododo fun na ti ajo re je,ma puro fun olore re,San esan toda fun Ki ayo na le ba o di ale,die lara eko ti a ko lara awon baba wa niyin,e se a ma juwa se o
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 11:33am On Jun 09, 2017
alafia fun Gbogbo omo odudua,e Ku a mojubami,a de Ku orugbe emi a laja o,eledunmare OBA abanise abawa se tiwa o Ase
Christianity EtcRe: Asiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re by ayokomi1010(op): 8:10pm On Dec 27, 2016
alafia Olorun ko ma ba Gbogbo enia,mo fe fun wa ni awon adua ti a le gba Ki Odun titun le di irorun fun ni mo bo
Christianity EtcRe: Asiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re by ayokomi1010(op): 8:52am On Dec 19, 2016
Alafia ni fun Gbogbo eyin ayanfe JEHOVAH
Adura ojo oni niyi,oni ni 19/12/2016,adura yi ni awon eniyan Olorun malo nigbati osun badi mokandilogun
ao ka psalm 61,ni iye igbati a ba lagbara atika,ti ao si gbadura na bayi
YAVAH-JIRE" Oluwa olupese,Alagbara julo iwo ni eniti ohun Gbogbo ko soro fun,loni tise ojo kokandinlogun osun yi,jowo mase jeki oro mi di isoro fun mi,ranmilowo lona mi Gbogbo loni Ki o si bukun mi,Ki o sifi ere sori ise mi,gbemiga ki o sifi oju rere re yimi ka,nitori Jesu Kristi Oluwa wa.Amin.adura yi ni fun ojokokandilogun ninu Gbogbo osun iyowu koje,jesu ni OLUWA,

fun Iwo Woli prophet and prophetess ti o fe dara po mo eto yi Lori whatsapp Ki o add number mi yi,08135072961/08075198871. tabi Iwo ti o fe iranlowo woli.
Christianity EtcRe: Asiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re by ayokomi1010(op): 11:23pm On Dec 18, 2016
ETO ADUA SOLOMON
ENI keni ti o bafe ojurere ati anu lati odo Olorun ,Ki o te aso funfun sile Ki o,duro Lori re,o dara ju Ki o wani ihoho,Ki o wa pe oruko yi, ELI YA AGLA,ADONAI JOD HE FO HE.21×,KI o wa ka 1Awon Oba 8:1-30. ti a base adura na ao di eni nla.
Christianity EtcAsiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re by ayokomi1010(op): 10:55pm On Dec 18, 2016
moki Gbogbo ojise Olorun ,emi awon woli a tiwa lehin o,Olorun orimolade,captain Abiodun,bilewu oshofa,ayobabalola,agbojesu,adeola,ati Olorun fakeye,Olorun jolugba,a bawa se o,oun ti o mumi da ikanni yi le,moje eniti o ti idile alawo jade wa,baba mi si lo kewu loju ona Islamic, sugbon sibe Olorun ni koti de ibiti oun fe lo fun iranse oun,loba lo ninu igoke emi 90 days,ti koni ariyan jiyan ninu,osidi Woli Olorun alaye loju ona ijo mimo Cherubim & Seraphim, Olorun silo gidi gan ti mofi mo nigbati moba ara mi,ninu okan Pataki ninu omo ti baba yi bi,ti won sifi asiri adua,Ati iru awon asiri nla to wa larin Olorun ati awon woli re, abajo ti Bibeli wipe (ASIRI OLUWA WA PELU AWON TI O BERU RE, YIO SI FI WON MO MAJEMU RE. ORIN DAFIDI 25:14.) ti enikeni bawa ni Olorun o fi asiri nla re han awon woli ododo re,ajepe iru enibe koni imo ijile ninu oro Olorun, Pataki nipe mowari bi aye se lo loni,lojeki da ikanni yi sile,opo enia loti rope kosi agbara adua mo,pe kosi oruko Olorun ti je mo,koderibe,koda oti jeki opo ojise Olorun gan ti darapomo aye,woti wo pe ewe ati egbo nikan ni ona abayo,pe adura ko gba mo koderi be o,toripe opo o mo base be Olorun ni,atipe opo o ni ASIRI ijinle awon woli lailai,lowo,kepemi Iwo da o loun ni Olorun wi,eyi lo mu mi Da group yi sile,Ki Gbogbo woli ojise Olorun ododo,tikise ti esun,dara po mo ikanni yi ti wasi salabapade ASIRI adua ati eto adua lokan o jokan,to yato si ogun,tori opo ojise Olorun tidi alawo kode Wumi be,Bibeli wipe awon enia mi segbe tori won koni IMO,o le darapo mo ikanni yi fun iranlowo adua ati iranwo awon woli Olorun,Iwo woli o le darapo mo ikanni yi lori wathsapp mi 08135072961/08075198871.JESU ni Oluwa Hallelujah. 4rm SNR AP PRT S.A. AGBOOLA. (Akiyesi mife ija esin,eleyameya,tabi lati fi enu abuku kan ijo tabi eka kan,tabi ojise Olorun kan,misi fe Ki enikeni fi number si Ori ikanni yi,sugbon o le fi eto adura sile,tikibati se ewe ati egbo.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 8:50pm On Dec 18, 2016
Ogun Awon Babawa pe Odun kan ti Olorun eledunmare Osa oke,ti owo emi omo yin,aburo yin,egbon yin,ore yin,baba yin,Ololufe yin,da ikanni yi sile, ni 04/12/2015,ni ojo ti o pe Odun kan gere,nibati soro yi,sugbon misini Nigeria ni date yi lofa,mofe Ki Gbogbo ololufe ikanni yi join mi lati se ajoyo yi,mosifeki a ri testimony awon ti o tiri afanije lati Ori ikanni yi Ogun awon babawa ti emi ayokomi1010,dasile,tori kuse nimu Ori onise wu o,kosi enikeni ti o le so pe mo pe oun ni idakoko ri ,tabi pe mo bere tabi toro owo lowo oun ri,emi fe Ki awon enia di olorire ni,Ki a de tu awon enia kuro ninu igbekun,tibari ijeri si wa Dada,mofe ta Gbogbo omo odudua lore oun nla,Mofe Ki fi ona ola ti Olorun fi ran awon babala wa,han awon enia,ni 2017 o tun gbodo se alaini owo mo.pemi ti o bafe Ki fi owo arami tojure sise fun e 08135072961/08075198871.oludasile ikanni Ogun Awon Babawa. ti e bari oruko mi,number mi Lori ikanni yi e sora o,bi won ba gba yin mini daun si o,Odun ayo lase o,moni idaniloju fun 2017 pe awon olugbinyanju a di olowo tori ati se iwadi odun yan a je ogun gan,sugbon mo bawon lo ninu ogun tabi ajo ti won bafi fi ijimere se ,ninu odun 2017, tori o lewu gan o, Ra ogede Ominni Ki o pemi oni oun ti wa se si Ki odun 2017,le de o,Ki o mani e Lara ni,08135072961/08075198871.4rm ayokomi1010 oludasile Ogun Awon Babawa
CultureRe: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by ayokomi1010(op): 2:22pm On Dec 03, 2016
eniti o bere pe ASIRI wo lobe ninu ise iranse ti o si ninu bibeli ,idahun mi re o ,ASIRI imo ijinle Olorun po lowo awon woli isaju ti won si pawon mo ti won o kowon sinu bibeli,tori komadi oun imulo fun taja teran ni,bibeli gan wipe ASIRI OLUWA wa pelu awon to beru re yio si fiwon mo majemure,Orin Dafidi 25:14, nibo ni JEHOVAH EL ADONAI, wa ninu Bibeli kideni won fi se bawo lawon woli se lo ti Olorun fi yara gbo tiwon,juti awon ti o Ku lo,Iwo na bere akara biti Elijah Ki eye Iwo gbe wa fun Iwo na,besini ASIRI yi siwa lowo awon woli mimo ti won fi irele sun mo Olorun biti Elijah, sugbon ejoreto sebi opo babalawo ti pe ara re ni woli loni ni o je kamo awon woli ododo mo,se o gbagbe pe bibeli wipe bi ogbon ba Ku fun enikeni Ki o bere lowo Olorun ni,ASIRI Olorun po,ti enikeni o mo o,sugbon ti Olorun si fi han awon woli re,tori agbara igbohun Irina imoaya,ala,ati bebelo siwa sibe ti Olorun fi fi asiri ohun ijinle han awon woli re o.Jesus is Lord. Hallelujah
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 1:14pm On Dec 03, 2016
E kasan o Gbogbo eyin Ojogbon, mati ikanni yi pa o,tori mifi aye sile fun enikeni lati ma polowo nkan,tabi mafi number sori abalayi,emi Ayokomi 1010,ti o da ogun awon baba wa ati ASIRI awon woli lailai sile,si Ori Nairalad, number mi ni 08075198871/08135072961,fun lati bami soro tabi darapomo wathsapp mi,ikanni ti e bari ti o tunje Ogun Awon Babawa, ti Ki batise ayokomi 1010,tikisi se number yi lefi pe enina,kise emi o,fake ni o,Eniti o bawu Ki oun naje adari kolo Hope ikanni ti e,ko wa oruko fun .ayo ni o,ajo nikan nimo fun enia lati fisi Ori ikanni yi,ati ibere oun teba fe
CultureRe: Asiri Ijinle Awon Woli Lailai by ayokomi1010(op): 12:56pm On Dec 03, 2016
ETO ADURA LASIKO-INIRA TABI IDANWO AYE
JEHOVAH-SHARAKAH: Fi oruko mimo Olorun yi gbadura bi idanwo tabi inira aye bawa fun enia,pe oruko ni pelu idojubole ni igba meje,Ki o si se adura na fun ojo 7 tabi ojo 3,Akoko adura na ni agogo mejila oru,ati agogo marun aro saju kato ba enia soro,kia ni Iwo yio si bori idanwo ati isoro na logan.+++
smileyETO ADURA LASIKO-INIRA TABI IDANWO AYE
JEHOVAH-SHARAKAH: Fi oruko mimo Olorun yi gbadura bi idanwo tabi inira aye bawa fun enia,pe oruko ni pelu idojubole ni igba meje,Ki o si se adura na fun ojo 7 tabi ojo 3,Akoko adura na ni agogo mejila oru,ati agogo marun aro saju kato ba enia soro,kia ni Iwo yio si bori idanwo ati isoro na logan.+++
CultureAsiri Ijinle Awon Woli Lailai by ayokomi1010(op): 12:07pm On Dec 03, 2016
Hallelujah +Hallelujah ++Hallelujah +++
Alafia fun yin ooo,oruko emi omo yin aburo yin ni SNR AP PROPHET S.A.NASE. Pataki oun ti o mu mi da ikanni yisile nipe,opo WOLI ode oni ti so agbara Olorun nu,ati papa julo,ASIRI awon woli igba lailai ti parun lo die die,ewe ati egbo nikan loku ti opo woli gbekanle loni,Emi Olorun wa mi simi lati gbe abala yi kale,kale ma fun arawa ni ASIRI imo ijinle nipa agbara mimo ati ASIRI ijinle awon woli igba lailai,enikeni ti o batije woli ododo lokunrin lobinrin,ni oledarapo mo ikanni yi,iwonba asiri la o ma fisibi,lori wathsapp ni ekunrere ASIRI wa number wathsapp na re,08075198871/08135072961. Awon woli nikan ni ikanni yi wulo fun o.Iwo ti o ba se ojise Olorun ti o si wa iranlowo woli okan le bami soro ni privet. Ao fe asa kasa ebu,tabi ija,tabi Fifi enu abuku kan eka ijo kankan tabi ojise Olorun kankan,Lori ikanni yi,beru Olorun Emi Awon woli ooo.Hallelujah
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 11:24am On Nov 26, 2016
ASEJE TI AFIRI OWO
Awo ilu toya loju agbo,ao ha Gbogbo aje ara tangiri kan,egungun eran ainiwo,ewe sawerepepe,ata ijosin 16,ao loop,ao fise Edo malu ti a ge si 16,je ao se ni epo iyo,ao fi aso kan su osuka kale ,lori re la o so obe yan ka,ao wo aso ti o dara si orun,ao daniyan owo nla ,ao je obe na.

ALEKO
irun oya,ao lo kunna,ao po mo ose ao mafi wo oko wa.

2.ao fi abere oporo kan tele igo,ao ju eso 4inches kan si,ao ko ewe ehinelebe si,ao ro oti si ,lehin ojo keta odi mimu.

(E jo mo lofun awon Eto kan lefirimi bi ojo meta sehin, Gbogbo Iwo ti o mope woli alfa baba alawo,onisegun,to pe oju owo ni e,add watsapp number yi Ki o le jafani ogun nla ati asiri ti o wuwo,08135072961/08075198871
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 8:38am On Aug 30, 2016
ekaro gbogbo ile ojumo ayo ni oni fun wa loni mofe fi awon ise nla si ori ikanni yi loni mafi se ibi
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 4:40am On Aug 08, 2016
e karo ninu ile yi e ku ojo meta o,ojumo aje loni je aje a yale wa wa o
CultureRe: .. by ayokomi1010(m): 2:34am On Jun 07, 2016
baba ifakaleluyah,Mo fe ka soro labe aso e Jo Mo fi ifa beyi ,08135072961
CultureRe: .. by ayokomi1010(m): 1:48am On Jun 07, 2016
a Ku ojumo o
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 1:31am On Jun 07, 2016
Ogun ti Obinrin fi ma gba owo lowo OKUNRIN, owo eyo kudi kan,OBINRIN na yi o fi si oju ara re mojumo,yi o yo laro ojo keji yio lo pelu ikode kan, 08135072961,fun bose pari Ise yi tori o lagbara mi le ko tan si ibi,tori arudale ni ti oko tipa,ni Awon OKUNRIN a ma ru owo nla owo won dale fun OBINRIN na,odaju saka.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 1:25am On Jun 07, 2016
Osole:olongbo dudu,eyele dudu, eye kowe kan,obi abata oloju merin,ao ge obi na si 200,ewe igi ose 200,kaka iru 200,igba ademo nla kan,ao ko Gbogbo nkan yi sinu igba na,ao gbe sinu agbada ,ao jo ao ro sinu sere,ao mafi oti lo,tabi ka ma fi fo eko mu,odaju wa mari owo nla gba Lori isere.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 4:57pm On May 22, 2016
Osole Imule Awon Agba:Odidi eye Owiwi kan,awo lili ti won bo toritori,ewe abamoda oojo,ewe owu akese,esuru pupa,odidi atare kan,ao ro sinu ado sere,ao pa akuko adie funfun kan,ao fi ejere ra ado na,ao le ihuhu adie na mo ado na lara,ojumeji kogbodo ri ado na mo o,ao ma loni 12am,aso funfun la o wo sorun o,ao wa fi ise yan fo eko tutu mu,aso funfun la o si ma wo ni ojo keji o.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 4:22pm On May 22, 2016
e Ku ile o Gbogbo ile,e Ku atijo la ki ara eni,motide bayi
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 3:54pm On Mar 31, 2016
ogun Awon baba wa on wathsapp group, 08135072961
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 10:55pm On Feb 26, 2016
OSOLE
eye igun toni ifun ninu eyokan,okete oojo tutu kan,odidi atare kan,ata ijosin Kongo kan,ewe lapalapa funfun to resile 101,ao jo po ao fi ori po,ao mabu diedie laro laro ao mafi eko gbigbona lo
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 10:40pm On Feb 26, 2016
e kule o gbogbo omo odudua mo se ise awo losi orilede BENIN, ni koje ki e ri mi lori ikanni yi lati bi ojo meta,sugbon ope fun olorun molo layo mobo layo motun ba eyin na layo eledumare Seun
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 6:43pm On Jan 27, 2016
OSOLE OWO
Okan maalu ti ko wo omi,omudun ewe akoko 101,pati omonigedegede,epo jebo,ao lo awon ewe yi,ao ge okan maalu yan si 16,ao se pelu epo iyo,ati ata ijosi,ti o ba tutu,ao da sinu Awo funfun,ao wo aso to dara,ao joko si aye to dara,ao pe Ohun re si,ao wa je obe na,
Ohunre:- igbe nla ni eran nla ke,e ma GBE owo nla wa fun mi,enikan kiridi omonigedegede o,ki e wa Fi owo nla bemi nise loni. ao ma je obe na diedie fun ojo merin tabi marun,osise gan ni o
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(op): 4:04pm On Jan 18, 2016
IYONU ASINA EBE AWON AGBA ATUDE
Ao toju abo adiie olopipi,totobi ,ao wa wa opolopo imi gbigbe,ao gun ninu ile ni ihoho,lai ni si ohunkankan Lara wa,ao ta epo pupa yipo Odo ti a fi gun,ao si ma ta epo pupa diedie si inu re bi ase gun,titi ao fi gun kunna dada,ao wa po mo opolopo ose,ako sinu ikoko tuntun,ao mawe ni ago mejila si ago kan oru,kankan titun kokan ni ojo kokan,o daju.

1 2 3 4 (of 4 pages)