Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,485 members, 7,836,895 topics. Date: Wednesday, 22 May 2024 at 02:12 PM

Bosrote's Posts

Nairaland Forum / Bosrote's Profile / Bosrote's Posts

(1) (of 1 pages)

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by bosrote: 8:26pm On May 20, 2016
bosrote:


Eseun baba, e pe fun was sir. Ejo sir kATO se TUDE kila ma siwaju se sir e laye wa sir
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by bosrote: 12:23am On May 11, 2016
08101646045atwp:
Fun anfani eni to bere itumo Atude, yioda fun'o, ntani emosenun, opolopo nkan lama ngbo, sugbon Ti aomo itumo re, tabi Ti amo itumo re tojepe ao kakun. Edakun gbogbo omo Awo, emaje kojepe gbogbo ibere Ti awon eniyan ba nbere emojeka nilero pe Awo toni block nikan logbodo danu, tori Awo ni gbawo ni gbuo, aoni te lawujo Awo. (IDE) ipinle ideni wipe nigba ti eniyan ba nfi oju ko owu alantakun (Elena) tabi ti oba njeun loju oorun, tabi nla ala biba ara eni sun ni gbogbo saa, tabi otito akoko toye ki obi omo inu re, ti okobii, tabi okori owo deedee bi oti senri tele mo tabi onjawe koje funo biti telemo, itumo IDE ni yen, bia bawa fe se atude, nkankan nio koko siwaju. Aoni sasise'o.

Eseun baba, e pe fun was sir. Ejo sir kATO se TUDE kilo ma koko sir e laye wa sir

2 Likes

Culture / Re: .. by bosrote: 8:01am On Aug 26, 2015
Emi bere ogun somuroro mi o ri eni damilohun ejo baba e fun mi
Culture / Re: .. by bosrote: 11:02pm On Aug 11, 2015
Eseun Baba ejo baba month need ogun tin eyan fi month aeiri nkan loju ala tabi oomo to daju
Culture / Re: .. by bosrote: 10:10pm On Aug 01, 2015
Aboru aboye month ke awo ati ogberi o. Ewe ama je fun wa o ejo. Eni to ba month ogun pile idi yiyo ati ogun somororo bi eyan obirin ban se omi lai ni oyun ta bi omo lowo ko fi ta mi lere, ewe ama je fun wa o
Culture / Re: .. by bosrote: 9:46am On Jul 31, 2015
kadunasouth:
IMULẸ AWON AGBA
ẹiyẹ kowe kan ẹiyẹ ega tonifun3, ẹiyẹ obe3, ati odidi atare kan aojopọ, ao ma fi fọẹkọ mu ni ago kan oru pelu adua.


Eseun sir. Ejo sir ki ni ogun imule agba wa fun tanks

2 Likes

Culture / Re: .. by bosrote: 1:51pm On Jul 23, 2015
healthFirst:
28 OGUN KI ARUN ROPAROSE MA MU NI:
Opolopo ayan, odidi atare1. ao jopo, ao fi sin gbere si apa otun yika larin, ati si itan ese osi. Odara gan, ajesara ni Oogun yi je.

Eseun sir. Ejo AYAN as in cockroch ni sir ko ti ye mi ejo sir

2 Likes

Culture / Re: .. by bosrote: 8:37am On Jul 23, 2015
kadunasouth:


Ogun arisiki
Eye ega odidi atare kan ao fi ikode ha eye yi lenu ao fi atare si legbe ao jo ao fi foko mu lekan nan
Eseun sir. Ejo sir ki ni itumo ARISIKE? e la ye wa sir
Culture / Re: .. by bosrote: 12:52pm On Jul 22, 2015
bosrote:


Eseun ejo efun wa email yen

mi re email yen sir ekun si mi rotimimoses2009@gmail.com
Culture / Re: .. by bosrote: 10:51am On Jul 20, 2015
healthFirst:


Iru inkan bayi kiise oro ori ategun...ko ye ke so iru oro bayi nibi...eyin o mon wipe awon agba lo ba aburo yin wijo ni? e kan si mi lori e-mail.

Eseun ejo efun wa email yen
Culture / Re: .. by bosrote: 11:34am On Jul 16, 2015
IRANLOWO YEN NI MO TORO O
Ekaro Baba ati gbogbo agbagba inu page yi ejo eran aburo mi lowo o. Oron ojo kan ni wan omo obirin kan lojo ala to fi sward gin own ni nu. Lati ojo yen ni won gbadun ara won month. Won ni inkan marin kakakiri ni inu won ati pe to bati nse won nise ara won ma mi bi pe ikan ti ategun fe. Ejo eran mi lowo ki la le se si baba ati gbogbo ile ti aburmi lifi gbadun pada
Culture / Re: .. by bosrote: 4:32pm On Jul 10, 2015
Aboru aboye ejo ki ale lo fun HOMONAL INBALANCE BI OMU OBIRIN BA NSE OMI LAI LOYUN TABI OMO LOWO? TE BA NO EJO EFUN WA . EWE AMA JE
Culture / Re: .. by bosrote: 10:48pm On Jun 18, 2015
EJO SIR, MO NEED OGUN TI ALE FI WO AISON ROPAROSE SAN TO DAJU THANKS
Culture / Re: .. by bosrote: 10:41pm On Jun 18, 2015
kadunasouth:




ASEJE OWO KIAKIA
Ata ijosi isu dandan ao lo po ao fi se odidi igbin kan je ao pe ohun yi si lodin din nio

Olu igbo fi igbin toro fun ero ona, gbogbo nkan ti dandan ba tenu mo, dandan ni kose, eyin to laye moni bukata iye owo bayi ki oto to ojo bayi . Ao je igbin na ni odindin, opari

EJO SIR, IGBIN YEN SE AMA SE PELU IKARAHUN NI ABI BA WO ATI PE SE ISE YI NI IMULE? TO BA NI E LA HAN WA SIR THANKS

2 Likes 2 Shares

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 15
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.