JOJUADE's Posts
Nairaland Forum › JOJUADE's Profile › JOJUADE's Posts
1 (of 1 pages)
Àláàmù ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ mi lo jí mi ni dédé aago mẹ́fa aárọ̀ yìí. Mo sáré dìde, mo wólẹ̀ láti gbàdúrà, kíá, mo ti bọ́ sínú balùwẹ̀, gẹ́gẹ́bí ọmọ Ọkùnrin tó dùn ń wò, mo ta mọ́ra, mo gbé fáìlì kiridésíàsì mi, mo tún yẹ ara mi wò lẹ́ẹ̀kan si kí n tó bọ́ s'ójú ọ̀nà. Mo dé ilé iṣẹ́ tí mo kọ ìwé ìwásẹ́ sí, mo kọ orúkọ mi si ibi tí àwọn tó wá se ìfọ̀rọ̀wánilẹ́niwò fún isẹ́ kọ orúkọ wọn sí. Àtẹ̀jísẹ́ ìyá mi ló kọ́kọ́ wọlé s'órí èrọ́ ìbánisọ̀rọ̀ mi bí mo se tan èrọ náà. Lẹ́yìn tí mo ka gbogbo ádùrá tí ìyá mi ṣe fún mi tan, ni mo tún rí ọ̀rọ̀ ìtùnú àti ádùrá tí olólùfẹ́ mi Àbẹ̀kẹ́ tẹ̀ ránṣẹ́ sí mi, mo rẹ́ẹ̀rin músẹ́, ọkàn mi tutù, ayọ̀ mí sì kún. "Arákùnrin Adébáyọ̀ Adégoríọlá !!!" Akọ̀wé ilé iṣẹ́ náà ló ń pe orúkọ mi láti orí ìjòkó rẹ̀ níwájú ilé ìgbàlèjò ilé iṣẹ́ náà, "èmi re", mo dáa lóhún, "ẹ̀yin lọkàn, ẹ wọlé sí ófìsì tí ó wà ní apá òtún yín". Ọmọ Obìnrin tí ọjọ́ orí i rẹ̀ kò ju ọdún mẹ́rìndínlógójì lọ ni mo rí tó jòkó sórí àga nínú ófìsì ọgá àgbà ilé iṣẹ́ náà, "ẹ jòkó", mo se bó ti wí. "Mo ti wo àwọn kiridésíàsì yín, mo rí pé o yege nínú èkọ́ rẹ, kódà, o pegedé, ṣùgbọ́n, iwe tí o kà ju isẹ́ tí a fẹ́ gbàyàn sí lọ", "Mo mọ̀ bẹ́ẹ̀ mà", mo dáa lóhún, "kílódé tí o wá kọ ìwé láti gba isẹ́ yìí" ?? "Kí n lè máa rí ọwọ́ mú lọ s'ẹ́nu ni Mà". "Ọ̀rọ̀ rẹ kúkú yé mi", ọ̀gá ilé iṣẹ́ náà fèsì. "Ó da náà, hun ó fùn ń ọ ní'sẹ́ yìí tí o bá ti lè dá májẹ̀mú pé wàá ṣe kini kan fún mi", mo dáa lóhùn, "kíni kíni ọ̀hún "© 'Kunle JONISE. |
another one... ile IFE.. |
To start with... this video is 3years and some months old... it was recorded on the day fayose was given the flag at OLUYEMI kayode stadiums in Ado-Ekiti to run against fayemi as the PDP gubernatorial candidate in the EKITI2014GUBERNATORIAL ELECTION. if you do your findings very well, you will discover this is not the agbada they wore yesterday. let us stop spreading false and fake news. |
Wetin dey raise head inside his trouser? |
Fidelismaria:.na u go die |
Fidelismaria:. HENHEN,wetin apen? |
FTC.....HUN,dis is absolute rubbish. |
FTC....Wow.bak to d topic,d driver should b punished. |
THIS 1 NO B BOOBS AGAIN,NA BALOON |
dis 1 na baba oooo, He don old. |
Thanks for d information. |
oookuabo |
I dedicate this FTC to MY LATE DAD,but wait oo,who she help? |
I dedicate this FTC to my GOD. |
See whr akala put his hand! on top d big twin |
Izygab:. NIGERIA FOOLISH QUESTION! |
SALON |
shiki:JESUS! WETIN B NAME OF UR SCHOOL? |
nice one...... Happy birthday "P'WS" |
herzern:I wonder ooo |
HAPPY NEW YEAR 2016 TO ALL NAIRALANDER |
IYA sex addict.i pity u.rubbish |
1 (of 1 pages)
"