Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,158,876 members, 7,838,128 topics. Date: Thursday, 23 May 2024 at 03:55 PM |
Nairaland Forum / Kadunasouth's Profile / Kadunasouth's Posts
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 17 pages)
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 4:14am On Dec 17, 2016 |
possible26:Ogede omini to ti de to ti seje |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 4:11am On Dec 17, 2016 |
OGUN BASIRI TO BIA BUKATA KIA KIA ewe tude, egbo tude,eru alamo, gbogbo meteta yi die die ki e wa gun papo mo ose dudu iwe ekan soso, leyin naa ni e o wa lowa ewe lah funfun iyalode funfun pelu ewe oparun eo wa se papo lagbo ao wa fi ose yii we lale ni ita gbangba lekan soso Ari Owo dada Odaju Taara. 2 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:40am On Dec 15, 2016 |
IMULE AWON AGBA ASINA. Eye obe merin, ao lo pelu ata ijosi merindinlogun ati ewe ola die ao walo ra eja abori tutu.ao gesi ona merin.4.ao wase pelu epo ati iyo toba tutu ao se adura si ao wako je. Odaju 3 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:57am On Dec 15, 2016 |
Aseta odaju Ogede omini to pon 16 adan kan alakan kan ewe rafo rafo odidi atare ao jo po ao teni ifa irete meji ao mafi fo eko mu ao pe ohun yi si Oba oniware wasewaa, tin ba ifa sota oju opon lokusi, Oba oniworiwosewo to nba ifa sota oju opon lokusi, orunmila ni ota ti tan, ifa moni otaku, orumila ni taloku, moni oku babalawo to gbo ifa yanran yanran ti fi ifa pa babalawo egbere je, orumila ni kole pami, oni to bani oun yio pami, arare ni yio pa, nitori ti rafo rafo ba pon omi sinu tan, inu arare ni pansi, orumila ni ota tan, moni otaku, ifa ni taloku, moni oku onisegun tomo ewe month egbo yanran yanran, orunmila ni kole pami, oni tobani oun yio pami, omo arare ni yio pa, ti alakan ba da ewu tiko suwan tan orun arare ni gbewo, orunmila ni ota tan moni otaku, oni talo tun ku, moni oku alufa tomo tira yanran yanran ti fi tira pa alufa egbere je, orunmila ni kole pami, to bani oun yio pami arare ni yio pa, ni tori ti ogede ba pan tan ti inure adi omin, omin to ba pan sikun na ni mu ogede ra, omi inure na ni yio pa, orunmila ni ota tan, ifa moni ota ku, oni tani otunku moni oku oso ile aje ile, oso ode aje ode, emere woli, alaroka etc, orunmila ni wankole pami koda bi gbo gbo wan ba darijo, ni tori ti adan ba pete pero tan, oro idorikodo niba, ori idori kodo nisi kusi, oro idorikodo ni yio ba gbogbo awan otami, ori idorikodo yi ni wan yio si kusi, irete meji te ori awon ota mi mole kiwan oku, ki nraye setemi 4 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 3:38pm On Dec 07, 2016 |
Aseje Awure Ewe ogo elewuji ao lopo ma ata ijosi merin ao fi se saki malu ta gesi merin je lepo niyo ao je lori aga to fine ao si fan sori ta nba jelowo fila si gbudo wa lori wa taba jade ao fi 10 naira merin se sara fun obinrin yio je fun wa o Amin 3 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:20pm On Nov 30, 2016 |
EYONU ASETA TABI ENITI KO RORUN SUN ewe kinlefimise topo dada ati odidi opolo kan ggigbe or tutu ao Jo pelu atare odidi kan. Ao mafi foko tutu mu lale abi kama la pelu epo ninu awo sobi 2 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:50am On Nov 25, 2016 |
Aseje ilosiwaju fun eniti ifaseyin ndalamu(solution to setback) Ewe isaju ao lo loto ewe aje aolo loto, ewe orijin loto iyere ao ra eja aro wan obawa ko ifunre jade akoni ge ao so sinu koko tuntun ao bu omin die si ao bu epo die si ao fi ewe isaju si atun fi ewe aje si ao fi ewe orijin si ao fi iyere die si ao fi iyo niwan ba si ao de ao se jinna ao so si ori osuka ao ao se opolopo adua si adua ilo siwaju ninu ayewa ewa sowipe ewe isaju loni kinma je asaju ni gbogbo ibi ti mobade ao tun sadua ao koje 4 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:19pm On Nov 18, 2016 |
ASINA EYONU.aoju epo obo.sinu.Ina tiyio pon bi eyena.aowafi nkan yokuro nibe ao wafi sori olo aofi osun kan lelori ao lo papo ao da sibikan tabati lotan aobu die tabafe lo nibe aoda sinu abokan ao da epo pupa si ao tunjo eyin ororo kan si alelo eyin agric aoro papo ao gbemu lekan na.odaju |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:34pm On Nov 08, 2016 |
possible26:Iyekiye toba wuwa oleje meta tabi 16 o depend bi ose base poto meta fun ose die merindinlogun fun ose pupo |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:49pm On Oct 24, 2016 |
OSE ERO ATI ITURA ogede omini tio pon meta aogun tepotepo ati ewe bomubomu ao po mo ose dudu ao ko sinu ike green ao ma fi we ao ra aso green opa meta ao mafi nura NB ose yiwa fun eni tara ni ti ota koje kori alanu, ero loje fun asasi ati ifokanbale ati asina 7 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 6:30am On Oct 13, 2016 |
superbouck:Aidan nla kan eo ge egbegbere nibi isure keke eo ko sinu roba ti owo lewo ose dudu gbigbe bi elubo sibi meji sinu re omin swan abi omi ojo leo dasi eko gbodo de eo fi le be toba di ojo keji eo ma yomu die die kie to jeun larara koto to ose meji ulcer na yio lo pata pata 2 Likes |
Health / Re: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by kadunasouth(m): 6:48pm On Oct 04, 2016 |
Pls Bear with us I will answer all the question b4 end of week though some of questions ve been answer in previous pages but I will take my time to re answer them in full details thanks |
Health / Re: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by kadunasouth(m): 6:41pm On Oct 04, 2016 |
bashiruhammed97:Dream of previous school previous house, sex in dream while find ur self being wet already in ur waking life is bad omen and set back but sex in dream or romance in a dream without being discharge(without being wet) in ur waking life is temporal success means a success at that time but wil not last while sucking breast of young girl without wet symbolise profit and satisfaction. In a nutshell any association or affair with women in dream and got wet is a bad omen Hawever sucking a breast milk of a women which often occured in a dream may be warning to you as it signify imprisoment be prayful while seeing varginal or kissing varginal in a dream is a freedom loose from bondage profit in one business, success and progress |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:01pm On Sep 23, 2016 |
Sego4:Odidi atare kan 1 Like |
Health / Re: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by kadunasouth(m): 12:20pm On Sep 04, 2016 |
bodnel: Be prayerful pple in groupe wil assist u may be in ur family or place of work 2 or more pple unite and contribute to bring up but another meaning of it not good as some of ur belonging or luck not cast away by another person whatever is it brayerful God be with u |
Health / Re: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by kadunasouth(m): 12:13pm On Sep 04, 2016 |
digitalcare: The dream are not bad as rabit signifies success, energy, luck, prosperity so on but condition u wew while seeing it matter, were u try helping d rabit or try to chase it, or be friendly we help to deep explanation but mere seeing if is white is totally good signifies success and profit but black may also mean thesame but addition to black u ve something bothering u to figure it out but mean time u were able to do so or about to do So, giving money be expecting to receive more money in a real life and be prayerful and help pple I mean begar normatal haw smal give then ur life wil prosper |
Health / Re: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by kadunasouth(m): 11:45am On Sep 04, 2016 |
ANOONWA: Be prayer ful it wasn't a good dream because in a real life pple suppose appreciating u will not get closser to u or result to hatred Pray for him to rest in peace and not to disturb u then do sacrifice buy anything eatable of ur choice most be 3 different thing keep it in black nylon (poly bag) with 90 naira give it to beGar most be a man standing alone, as u do this u wil not see him again then thing will go well with u 2 Likes |
Health / Re: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by kadunasouth(m): 11:44am On Sep 04, 2016 |
Be prayer ful it wasn't a good dream because in a real life pple suppose appreciating u will not get closser to u or result to hatred Pray for him to rest in peace and not to disturb u then do sacrifice buy anything eatable of ur choice most be 3 different thing keep it in black nylon (poly bag) with 90 naira give it to beGar most be a man standing alone, as u do this u wil not see him again then thing will go well with u |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:20am On Sep 04, 2016 |
EYONU AWORO TODAJU ORI OLOGBO, EWE REKUREKU, EWE SAWEREPEPE, ODIDI ATARE KAN AO JO PAPO,AOLO SUGAR ONIKORO EYO MARUN MO,AOMA LA NI ARARO 3 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:22pm On Sep 01, 2016 |
AWIJARE EJO Ori owiwi, oronro eran, odindi atare kan, ao jo po ao fi ebu na te ifa Ogbe alara OFO RE: Owiwi loni ki e gba temi wi, Oronro loni ki e gba temi ro, ao ma to je, ao tun fi die sari, nire nire la nsoro atare epanupo kie dami lare 3 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:15pm On Sep 01, 2016 |
Eyonu to nmu owo wa ati iferan Ewe akoko oojo eyokan eso werenjeje 16 ao gun ma ose dudu tawe lekan soso ese kese taba ti gun ose yi lalore we pelu gboloun yi Aki fewe kewe joye leyin akoko teyi wumi toun wumi lanfi nwo werenjeje gbogbo ibi timo bade kanma nifemi pelu owo owo wan odaju 5 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:36am On Aug 30, 2016 |
ASIRI BIBO TODAJU Ori Olongbo dudu kan,Ewe wawa topo, ewe aje sefun sefun topo odidi atare meta ao jo papo ao ma fi miliki olope lo ni idaji kutu die die odaju 3 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:27pm On Aug 24, 2016 |
emtar: Beeni IGORI AGOGO-IGUN 99 |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:04am On Aug 21, 2016 |
1234567890A: E send sms pe lati ukadmission si 09090305775 ma get bak siyin ema binu opolopo ama pe lai ni idikan pataki lofa |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:21pm On Aug 18, 2016 |
09090305775 1 Like |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:08pm On Aug 17, 2016 |
DonTheodol: Owa sugban osoro lati se fun eni ti koba ma nipa ewe ati egbo dara dara tori egbo igi te malo funwan oni osunwan so ele kan simi lori ero ibani soro towa ni first page Adua wa yio gba 1 Like |
Sports / Re: Rio2016 Olympics: Nigeria Vs Denmark 2 - 0 (Full Time) by kadunasouth(m): 8:17pm On Aug 13, 2016 |
Up Nigeria 1. 00000 |
Sports / Re: Rio2016 Olympics: Nigeria Vs Denmark 2 - 0 (Full Time) by kadunasouth(m): 8:09pm On Aug 13, 2016 |
We gonna make it by d grace of GOD |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:28pm On Aug 05, 2016 |
cashkid:Any one sugban to basepe aye leri ema koko pa kie to jo 1 Like |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 4:53pm On Aug 05, 2016 |
Ogun arisiki todaju Odidi eye lekeleke ati odidi atare kan ao jo ao lokuna ao mafi anything to ba dudu lo iseyi bi coke, pepsi, maltina, tabi kada tada sinu omin ko dudu etc ao ma fi lo iseyi die die odaju 3 Likes |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 17 pages)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 46 |