Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,158,862 members, 7,838,086 topics. Date: Thursday, 23 May 2024 at 03:19 PM |
Nairaland Forum / Kadunasouth's Profile / Kadunasouth's Posts
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 17 pages)
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:01pm On Apr 16, 2016 |
Agbo idoti Abe to nfa isunki nkan omo okunrin ati idakole Bara totobi dada kan, ope oyinbo(pineapple) kan epa ikun ati kanun gidi die Ao fo bara na yio ma dada ao ge kekeke ao ko sinu oru agbo tabi koko ao tun ge pineapple na kekeke ao kosi ao ko epa ikun lelori ao ge oun na kekeke ko po die ao ge kanun gidi ni wanba si ao wa bu omi toma dada si ao de ao wa se ti yio jina dada apere toba ti jina omi agboyi yio duduwa lekannan oti jina nu ni ao so kale toba tutu dada ao ma mun ni tonbila kokan lojojuma leyin ose meji tanti lo agboyi ao lore ra ogede agbagba dudu to gun dada ao bo epore ao so sinu koko tolegba akogbodo ge ao bu omisi pelu oyin gidi sibi mesan ao se to ba jina ao je gbogbore lekannan ise ya NB ti oko bati ni iyawo agboyen nikan ni kose mase ti ogede o! NB agboyi yio ma kowa ninu yio ma lowa ninu emase beru idoti yen lonko ni abewa ti eyin gan base igbanse eru yio bayin pelu nkan idoti tama ya jade, ao si riwipe nkan omo kunrin wa jipepe yiowa bi ose ye kowa yio si ma sise daradara ti yio si yojade pada fun eniti tie ti sunki Adua wa yio gba lase oba odumare Mojuba awon agbagba 4 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 6:45pm On Apr 14, 2016 |
jcklsweet:Copy it out into a piece of paper, give it to elewe omo tell them u are the one to take it they will prepare it 1000naira can buy all 1 Like |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 6:42pm On Apr 14, 2016 |
jcklsweet:Copy it out into a piece of paper, give it to elewe omo tell them u are the one to take it they will prepare it 1000naira can buy all 1 Like |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:22am On Apr 13, 2016 |
jcklsweet:Abere topo die ao gun die alubosa ayu, kanafuru , kankadoro(ata ile) kafura pelebe ao ki lagbo pelu omin ao ma yomu ti on ba ti kawa lowo ao bu omin to gbona die sibikan ao to agboyi die si ao wa ki owo na bo pelu ogo oloun yio bayin lara mun 3 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:14pm On Apr 12, 2016 |
AdiscoPele: Koburu rara 1 Like |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:26pm On Apr 12, 2016 |
AdiscoPele:Beeni oda pupo yio fi tete daun omi agbo yen efi we osena kiewa funmi ni iroyin re leyin ojo die tie tilo 4 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:49am On Apr 12, 2016 |
Tevez83839:Emi okin se whatsup group, ma post agbo lati fo idoti abe okunrin to ma nfa ki oko sunki ti awan idoti yi bati jade nkan omo okunrin yio wa bosiye kowa isere yio sipe dada 2 Likes |
Health / Re: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by kadunasouth(m): 12:08am On Apr 12, 2016 |
iamhistreasure: Don't be scared pregnancy dream denote success, diligence and assiduous in pursuing your goal It could also means receiving recognition and prosperity But being that u are a young single girl the meaning maybe different in above The dream means difficulties and adversity beside some troubling secrets you may be hiding Another meaning of this ur dream, that if you are virgin, that you will loose your virginity before marriage so whatever it is be prayerful, prayer be the strongest method to solve problem For more information Cal 09090305775 1 Like |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:26pm On Apr 11, 2016 |
Hybrid01:Mo ti post ise yen seyin emawo ni page by page eo ri (Ero teso, kia le ri iyawo wa basun) elo se kia ni ona yio si lati wole lati jade 1 Like |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:27pm On Apr 11, 2016 |
[quote author=AdiscoPele post=44617688]Ejo baba, se ti a ba lo iseyi, se ibi na ko ni re si ori awon omo tabi ebi wa. Ejo sir, alaye yi wa fun awa ti a ko mo itunmo AROBI ni sir. Eseun pupo[/quote Ori ota ni ibi ma pada si Arobi means back to sender 2 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:17pm On Apr 10, 2016 |
OSE AROBI/Awe ibi danu Ose dudu, ewe esiponla, oju oro, ewe alupaida, ao gun gbogbo re mo ose. Ao maa fiwe ori de orun. NB: ako gbudo fi ose yi we gbogbo arawa Ewo nio 5 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:35am On Apr 10, 2016 |
Ade231:Yes new layed egg for that day, d egg must be used on the same day 2 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:10am On Apr 07, 2016 |
zenith329:Osan wewe, tabi osan were , osan kekeke lonje oronbo(lime orange) Omin agban na ama fin san owowa mejeji ni wash hands 1 Like |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:42pm On Apr 05, 2016 |
Aseje Atude Ao ra eyin agiriki meta ao bo yio jina dada to batutu ao bo epo eyin yi ao wa koko isasaun kekere kan ao lo ewe tude die ati egbo tude die ati iyere 16 ao lo ao da sinu koko isasun ao to omi oronbo die si akonifi epo si ati iyo ao gbe kana ao wa da eyin yi si ao se to ba tutu ao ra agban kan ao lu agban yi lona meta ao fi omiyi sin owo wa katoje aseje yi taba jetan ao fi owowa mejeji nu ara agbanna alefise sara tabi kalore jusi ori atan ide arawa yio tu patapata sugbon aseje yi osoro latije ama odaju NB taba jetan gbogbo arawa ni yio weak sugban leyin wakati die tabi ojo alafia yio de ona yio si si funwa ibare olodumare ati awan agbagba 4 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:54am On Apr 04, 2016 |
zenith329:Elelo sugbon ise na koni daun dada, sugbon ti ibile yio tete daun 1 Like |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:29pm On Apr 03, 2016 |
Atude/Asina/Bibo Asiri Ori ako alangba tapa lojo epo obo die ao gun papo dada ao ra igba olomori kekere ao gun ma ose niwanba ao fi eyin ojo po ose yi ao ko sinu igba kekere yi idire kogbodo kanle month tobati denu igba toba we oseyi ibikibi tobadurosi ore owo yio wa owa sibe lojona odaju 2 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:07pm On Mar 31, 2016 |
Asina Fun eniti Ona dima ti korise se ti koni owo lowo Ao ra koko isasun tuntun opolopo omin agban ao da omi na sinu koko isasun ao gbe kana ao lo epo obo kuna ao dasi ao tunwa da ose dudu si ao wa ma ro bi igbati anro amala toba ti darapo dada ao so kale kotutu ao ma buwe ijo keji loti bere si ni gba ise ati owo odaju ti aba wa lo gbogbo oseyi tan ona yio ti si funo dada owa gbe koko na lo si egbe ori atan owa so wipe ota to ndina mami tio lepe mi laburu ona tiedi motisi o tebako ti ekoba jawo month foyin male lonio eo tun gberi ma ao wa fo koko na male ao ma losi ile tara lai boju weyin Iba fun awan agbagba moju ba omoyin ni mi efi oju ire womi o 3 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 6:47pm On Mar 31, 2016 |
ATUDE ASINA Opolo aye meji ao waki ata ijosi merindinlogun bo lenu ao so sinu odo ao gun epo obo ma ao da ose dudu si ao gun po ao fi opolo keji sinu igba ao ko ose yi lelori ao fisile fun ojo meje ao mawe odaju 2 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 6:26pm On Mar 31, 2016 |
Atude/Asina/Apa Asasi Iru pete ao gun po mon ose dudu tale we lekan soso to badi ni idaji kutu ao to sibikan ao fi ose sinu kehin kehin tun tun ao wa ma kibo inu ito yi ao fiwe gbogbo arawa ao wa fi opolopo omin sin arawa iseyi dara gbo gbo asasi aifojuri ni yio ba omilo ao ju kehi kehin yi sori atan nio 4 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:19am On Mar 29, 2016 |
zenith329:Lila ni o |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:15pm On Mar 28, 2016 |
KolaBELIEVE: Beeni |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:05am On Mar 27, 2016 |
Eyonu Ao gun epo obo kuna dada ao poma ose dudu omi agbon lao fi popo ao kosinu awo sobi (awo ipese) ao ma buwe 3 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:40pm On Mar 24, 2016 |
AdiscoPele:Ao ma bu sinu ina ao mafi ni turare ao ma busi ogunna ao ma fi aragba turare ni iseyio akogbodo je o! 2 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:20am On Mar 24, 2016 |
Ebe/imule awon Agba todaju Alubosa elewe tutu kopo die ao gun dada ao popo ma ose dudu ao wa eyin adie Oojo ao do gbon fo lori die ti korofo eyin yi konibaje ao jo omin eyin yi sinu ose yi ao tun gun dada ao wa igba olomori ao ko ose yi si ninu ao wa fi korofo eyin yi gun ose yi lori logan gan ibi ti ati fo eyin na ni yio koju sinu ose, ao ti koko dogban fowo jin ibibe kato fi eyin na gun ki korofo eyin na maba fo. Ao ma buwe nigba toba wuwa. Iseyi daju ijo taba bere wiwe re ojona ni yio bere ise 5 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:46am On Mar 24, 2016 |
zenith329:Ti eba dana igi(firewood) edu igiyen toni ina lara oun ni ogunna 3 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:30pm On Mar 23, 2016 |
Isu gbegbe owa lodo awan elewe omo 1 Like |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:05am On Mar 23, 2016 |
Olulana Arisiki Todaju Koro isin egusi inure, koro palabe(Agbaluma) egusi inure ao lo papo ao gun ma ose dudu ao ma fiwe Gbolohunre Olulana lana ire ko emi Lagbaja omo Lagbaja tori bi isin baso omo araye alana debe, bi osan baso omo araye alana debe ki gbogbo omo araye lana ore nla nla kanmi kiwan fi ire owo wan wami ri NB tan bati bu ose yiwe lao ma pe gboloun ayajo yisi odaju 4 Likes 1 Share |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:11pm On Mar 22, 2016 |
Ogun Asiri bibo Fun Gbogbo onise owo/Jalabi odaju Odidi eye kowe ati opolopo ewe isaju odidi atare kan ao jo papo ao mudie nibe ao fi sin gbere 21 sori ao po iyoku ma ose dudu leyin ojo meje ao bere si fi ose yiwe odaju dada NB inu igba olomori lama ko ose yi si Mojuba awan Agbagba efi oju ireyin womi 3 Likes |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 4:14pm On Mar 19, 2016 |
Zenlife: Kokinse gbo gbo ise lose fi sori afefe tori awan elomiran lati malo si ona ti kodara Tebabere ise miran yato si iruse bayen mafunyin |
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:17pm On Mar 19, 2016 |
akani22:Era vitamin C ko mala yio lo Teba gbe igbesyi tikolo elore wa ewe abamoda tutu eyokan ki efi ra ina(fire) ferefe ni wanba ki ewa fun omire sinu sibi kie kan si ibibe eyi tobaku efi omin sibi kan means re papo kie wa fun ni idaji sibi mun igba ti ebamase lemeji yio folo yio si gbadun 4 Likes |
Health / Re: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by kadunasouth(m): 10:36am On Mar 19, 2016 |
Moppsys: The first dream was a good one refers to the reconciliation to occur but the second dream u had said no to that reconciliation that will never happened, that means ur differences was not ordinarily, was cause by evil or envied pple. Because dream of getting marry to a particular person means u can't get marry to that person in real life but nothing impossible before God if u pray and believe God may do it for u in miraculous way. The third dream reveal your effort and struggle to make thing work for better, that wil work as u wish if effot goes on Forth Dream reveal that a sign that u will over come the problem that settlement will take place, the dream however gave a warning sign that word secret that u most not popularise the wedding try n do it in small way The fifth deram was also a good one the only to be noted when u marry something upset or annoyance will happen but if u endure with situation u will enjoy at last 2 Likes 1 Share |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 17 pages)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 52 |