Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,890 members, 7,838,199 topics. Date: Thursday, 23 May 2024 at 05:07 PM

Kadunasouth's Posts

Nairaland Forum / Kadunasouth's Profile / Kadunasouth's Posts

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) (12) (13) (14) (of 17 pages)

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 6:03am On Nov 10, 2015
Eyonu
Eru oju aro epo obo ao lopo ma ose lux ao ma fiwe lalale odaju

1 Like

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 6:00am On Nov 10, 2015
Ose Awure
Ewe tagiri ewe sawerepepe ewe imi esu ao gun ao fi ori popo man ose dudu ao ma fi we

2
Omunu ewuro ewe orijin tutu epo obo ori ose dudu ao gun papo ao ma fiwe

3 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 5:55am On Nov 10, 2015
Fun gbogbo omo ilewe lati pass Exam (secondary/university)
Eso werenjeje eyo meta eyo atare Meta ewe alupaida meta ewe atare die ao lo papo ao fi sin gbere meta si orun owo wa mejeji odaju
NB ti exam bati ku ose kan lati sin, lasiko tasin owo yio ma hunwa sugban mumara oti bere ise niye

6 Likes 2 Shares

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 1:14pm On Nov 01, 2015
Ifa re ni lokeyi

Bostilo:
Modupe lopolopo sir. E jowo baba ogberi ni mi mio mo biwon se te ifa. Ejowo esanu mi sir. Kini mole se bayi toriwipe ogun promise and fail yi bami ja gidigan ni o

1 Like

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 1:11pm On Nov 01, 2015
Ogbe-fun

2 Likes

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 10:39am On Nov 01, 2015
Ogun iferan gbogbo aye
Ao fo eyin agiriki meji sinu igba ao se adua si ao gbe agbada kana ao da omi agban si to bati ho ao da eyin yi si ao fidin lai si iyo nibe ao koje opari

5 Likes 3 Shares

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 10:34am On Nov 01, 2015
Ogun Aleko
Ori Apanri oko atare kan ao jo papo month ose ao ko sinu ikarahun igbin ao ma fi fo oko wa
NB ogun yi tun sise fun eni tiwan ba mu okore

3 Likes 3 Shares

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 10:17am On Nov 01, 2015
Ogun Asma
Ikarahun igbin ao lo dada yio kuna ao walo sugar oni koro eyo meta mon ti yio kuna dada ao mala yio gbadun pelu ogo oloun

3 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 10:13am On Nov 01, 2015
EBE AWON AGBA
Eyin Adie ororo Eyele funfun kan ao jo papo ao lo kuna ao ma fi ro ekuru je opari

4 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 10:09am On Nov 01, 2015
AWURE
Epo obo ao lo kuna ao fi omi agbon pomo ose dudu ao ko sinu awo dudu ibile (awo ipese) ao ma fiwe

3 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 9:58am On Nov 01, 2015
Ogun promise and fail
Ogah gbigbe 1 efun ado, osun buke,imi ojo, ikumu ojia, ewe areyin kosun, odidi atare ao jo papo ao fi omi agbon pomo ose dudu ao kosinu fitila oloju kan ao wa te ifa ogbe fun (ogbe ofun) si ori ose na lori
NB inu fitila oloju kan lama ko ose yi si lao sese Wa te ifa yi si lori ao mafi we odaju
Promise and fail yio da gbere

5 Likes 2 Shares

Celebrities / Re: Fans Fault Lilian Esoro's Makeup For Her Traditional Marriage by kadunasouth(m): 2:33am On Oct 31, 2015
Aba! People can see beta thing ne? She look good jare keep it up but reduce dat make...............................


Up
Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 12:58am On Oct 29, 2015
Ogun ti akofini je nkan loju orun
Ao wa ajesi adie ao jo pelu odidi atare kan ao lo ti yio kuna dada ao fi foko mun lekanna opari

5 Likes 2 Shares

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 12:46am On Oct 29, 2015
Aseje Isan Gbese
Ewe atewobga, igbin nla to bono 1 ao hge igbin yi si ona 9 ao se pelu iyere epo iyo isasun tuntun to ba titutu ao fi iyere osun te ifa eji ogbe oa pe gbolohun re si ao koje

Agbada nla bale ogun gege, Oka nla bale orosin, Apo egusi bale oko jebejebe, Lodi fa fun ABDULLAHI omo oba lalade oyo abdullahi ni eee!, woni kilo subu te , oni osunmila je gbese egberun oke, orunmila sebi oni ohun tofi san gbese nile, woni orunmila sebi owo mejeji ni yaga fi ngbare tie lodo eledumare, owo emi L omo L ni kin nfi gbare mi lowo, nitoripe ojukanna ti igbin baduro si ni ire tire nfawa ba, oju kan nan ti emi L omo L ba duro si ni ki ire tmi koma fawabami, kinrowo san gbogbo gbese timoje ni kia kia ki asiri mi kobo, nitoripe ifa kifa kan kibori EJIOGBE eji ogbe baba ifa, eji ogbe baba ifa

5 Likes 2 Shares

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 2:18pm On Oct 26, 2015
Apagun Apa asasi APa Egun idile
Eran Malu Ekiri kan, Odidi Agban kan koko isasun ibile tuntun kekere kan ao so eran sinu isasun na ao wa lu agban yi nibi iho re ao jo omire le eran yi lori ninu koko isasun ao gbe kana to bajina ao se adua si ao so senu lekan na ao wa so agban yi sinu koko yi odi ori apata ao wa sope egun kegun ide kide airije airimu airina airilo kotu danu lara mi lati onilo ao lemole lori apata na ao malo ile ma wo eyin o!

5 Likes 1 Share

Culture / Re: Eye Odidere by kadunasouth(m): 11:16pm On Oct 25, 2015
ÒKÉTÉ
Okete je ọkan ninu eranko abami to lagbara pupọ.
Amọn gbe ninu iho.
ELEDUMARE fun ni asẹ pupọ.
Okete kii fi ọwọ tabi ẹsẹ gbẹ iho,
iru ni okete ma'nfi gbẹ iho,idi eyi ẹo le ri erupẹ lẹnu isa okete,
bi eniyan ba gbẹ iho okete igbamiran ama se isa mon e'yan lọwọ.
Ti aba gbẹ isa kan okete ti o ba fi ahọn Kan ilẹ gende kan ko faa jade,
okete ni asẹ kan ni ipari Iru rẹ, bi eniyan ba'nle okete lọ toba fi asẹ Iru rẹ nan ilẹ,kosi bi eni nan tile lagbara to yo subu lulẹ,awọn idi eyi lobi owe ''ORO TOKETE BA BALẸ SỌ NI ILẸ GBỌ'' ti eniyan ba pa okete ti eni na ba ge asẹ iru rẹ sinu isa rẹ okete na yo tun da pada wo inu isa na lẹyin ọdun kan eyi lobi owe ''MIO LE FI ILE BABA MI SILẸ LOUN SEKU POKETE LỌDỌỌDUN'' ti okete baa ti bimọ yo yọ yara fun awọn ọmọ rẹ ninu Isa kanan wọn yo yọ palọ sibẹ eyi ni anpe ni agburu okete ibẹ ni gbogbo wọn tiun jẹun, ti okete bati darugbo daadaa ti ẹnu rẹ ko ran onjẹ mọ awọn ọmọ rẹ abo ni wọn o ma fun lọyan mu, eyi lobi owe ''BI OKETE BA DAGBA ỌMUN ỌMỌ RẸ NI MUN'' okete fẹran ekurọ pupọ ẹkurọ ti a ba ri ninu isa okete a kii pe ni ekurọ eese lama npe eyi lobi owe ''KAKA KI OKETE MAJE EESE A FI SAWADANU NI''
okete a ma dide rin bi eniyan lọganjọ oru yo si ko ounjẹ lọwọ tabi ko gberu,ọdẹ tabi ẹnikẹni ko gbọdọ pa okete toba wa ni ipo na.
Orukọ miran fun okete ni ewú,okete Kii jade ni ọsan eyi lobi owe''AKI RI EWU LỌSAN'' ti eniyan ba gbẹ Isa kan okete toba gbe awọn lelẹ ao gbọdọ faa Ju ki iru rẹ ma ba bo,ti okete ba boru mo eniyan lọwọ amunbọ loun fa.
ti eniyan ba pa okete toun sun lọwọ to bu eeru si oju ọnan yo ri oju ẹsẹ okete toti jade pada eyi lomu awọn agba ma pe ni AKUDAAYA' ti aba tu ifun okete ama ri mọlẹ nitori aja,bi aja ba jẹ ifun okete aja na yo ya digbolugi/were.
bi eniyan ba fẹran lati ma jẹ okete ju,o rọrun fun awọn agba lati ma wo ifun ẹni nan.
Eemọ ati iyanu pọ lori ọrọ okete sugbọn kosi aaye. Ao ma tẹ siwaju laipe..

4 Likes 2 Shares

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 5:43pm On Oct 25, 2015
[quote author=KolaBELIEVE post=39350290] amin ase! Moti lo ise yi, ejowo se koleewo tabi ewu kankan. Iba ooo[/quote
Kolewu rara
Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 12:20am On Oct 25, 2015
OSO... also called money rituals or blood money. Some people don't know the differences between oshole and awure.. oso is what they use human being for the preparation of the wealth... and some of the results of oso it's. . E.g.. to see money inside big pot by chanting the name of the person you used. The money will dissappear inside the pot within some hours. And also can be used by sending ghost or spirit of such person to goto the bank or anywhere to bring u huge money.. or carried calabash on top of such person head and be picking money And it has big repercussions like. E.g.. not live long. Suddenly death. .earing ghost voices anywhere you go. And some people's got mad immediately they did it. Because it's not compatible with his star......
 beware of wicked people they will told you that it's basiri ( good fortune ) or oshole ( wealth booster ) what u have to notice from their talk. It's to know how it will work for you. Once u detect how it will works. So try and run for your life....

 OSHOLE or AWURE NLA or  AKO AWURE or OSHOLE TUTU ( wealth booster) this is the best thing to do it has no repercussions and powerful than AWURE.. any OSHOLE it's require ANIMALS AND SOME LEAFS OR BARKS no human blood shed.. it's good for those who is looking for progress especially the person that has the particular job that his doing. Oshole can not drop money in front of you oo.. it's not a magic or miracle it will just boost you work and your progress.

 AWURE ALSO CALLED APEDE. ... Awure it's good it's also work for progress of anything human being his doing.. it's has no blood shed of HUMAN BEING or ANIMALS. It's only has some leafs , barks .. and anything that has no blood.. though some required Ants.insect..e.t.c no repercussions


 N:B... my advice for people's that is reading this blog. Is to be careful of all those uselss people that need you to run business. Everybody need money. Why can't he did it for himself.. so be careful thanks.....

7 Likes 2 Shares

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 12:12am On Oct 25, 2015
Lionhearted:


Igbagbo mi nipe ko si Osole ti ko ni ewu tabi ewo. Nidi eyi, maa ro yin ki ema fi ru oogun bayi sita.

Opolopo eniyan lo n ka abala yi.

Iyato walarin oso (ki eniyan seso) eleyi lo ma nmu ewu dani tori awan oun elo tan malo fun bi eka lara eniyan tabi oku oun loma lewu to sima ma nfa emi kukuru, ti eyan ba peyin kewa seso esa fun iru enibe, oda bi wipe eko gbo agboye iyoba
Osole na lonje awure kokin lewu rara koda eyi tiwan bafi ewo si te ba lu ewore ise ye aya ma baje ni ko ni payin lara
Sugbon ki eniyan seso(oso) oun ni wan peni money retual oun ni koda rara so ti yeyin

2 Likes

Religion / Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 3:40pm On Oct 24, 2015
Adua Isegun Ota (Asete)
Tabaji nidaji kutu kato lo kirun Asuba lai ti soro si eni kan kan
Ika arin owo alafia wa ao beto die si ao wa fi kan amuje wa pelu kika lakadi jakun 66
Tobadi aro kutu hai wawa lore fi akara elepo se sara ti otare koba jawo lati man sa sio yio kudanu gba gbo agbara towu koleni
Eleyi daju
Olohun nikan lala gbara julo to se farati

1 Like

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 1:16pm On Oct 23, 2015
Oshole Oni okan Malu(cow)
Odidi Okan Malu Oju iho meta lowa lara okan
Malu, Ao fi atare sikan,owo towu
wa sikan, Igbo mumu sikan, aowa jo gbogbo re
papo, ao lo ti yio kuna dada ao wa mafi miliki olope lo ebuna die die odaju

2 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 5:18am On Oct 23, 2015
KolaBELIEVE:
ejowo se gbere kan ni?
Ao sin gbere yipo owo wa mejeji kolonka

2 Likes

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 10:41pm On Oct 21, 2015
KolaBELIEVE:
ewe a ma je oo! E jowo se tutu awon ewe yi abi gbigbe? Ati pe gbolohun yi: se tete loni ki owo matemi( not caught) ni abi tete loni ki owo matemilowo? Se koni repercussion? E seun. Iba oooo
Tete loni ki owo matemi(owo = money, man temi =not disgrace me) no repercursion)
Gbo gbo nkan ti month ba post kosewu nibe to balewu ama fi ami ewore si, idi eleyi kolewu rara

3 Likes

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 9:00pm On Oct 20, 2015
KolaBELIEVE:
ejowo, se imi ojo na ni rerinkomi?
Ewe imi esu lo nje rerinkomi otoni imi ojo

2 Likes

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 9:28am On Oct 20, 2015
omoalade144:
Eku ojumo baba ajinde ara yio ma jeo amin.Ejowo baba kadunasouth edaun awon ibere me mofi iyonu OLORUN beyin ni o.Isesere ki sogun tie komaje,ewe ama je fun yin o ASE.
Elora Bara kie pani panssa kie bu epo pupa si ki e wa mu ororo eyin adie kan kie fisi kie tun wa bu eposi lori kie juba awan agba kie tun wa so nkan tefe lofun kie wa fi ideri re de kie wa we lowu dudu ati funfun kie dogban gbesi igun kan ninu shop abi kie fiko
Toba ti feme jera ero ati omose yio de pelu ase edumare

2
Elore wa tagiri kie pani pansa kie wa lo epo obo kopo dada kie tun wa eyin ororo kan ao fi epo obo tele inu tagiri yi eo fi eyin ororo si eo tunwa da epo obo lelori ti akoni ri eyin yimo ao dogban mase ni ti ara eyin yi kofi ni kan tagiri na ao wa we lowu dudu ati funfun ao soko
Apere toba ti fe bere ise ao ma gbo igbe omo adie ninu shop lekokan oti daun niye

3
Eye kowe ewe isaju odidi atare ao jo ao budie ninu ebuyi ao fi sin gbere 21 sori ao po iyoku ma ose ao ma fiwe odaju

3 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 9:26am On Oct 20, 2015
Elora Bara kie pani panssa kie bu epo pupa si ki e wa mu ororo eyin adie kan kie fisi kie tun wa bu eposi lori kie juba awan agba kie tun wa so nkan tefe lofun kie wa fi ideri re de kie wa we lowu dudu ati funfun kie dogban gbesi igun kan ninu shop abi kie fiko
Toba ti feme jera ero ati omose yio de pelu ase edumare

2
Elore wa tagiri kie pani pansa kie wa lo epo obo kopo dada kie tun wa eyin ororo kan ao fi epo obo tele inu tagiri yi eo fi eyin ororo si eo tunwa da epo obo lelori ti akoni ri eyin yimo ao dogban mase ni ti ara eyin yi kofi ni kan tagiri na ao wa we lowu dudu ati funfun ao soko
Apere toba ti fe bere ise ao ma gbo igbe omo adie ninu shop lekokan oti daun niye

3
Eye kowe ewe isaju odidi atare ao jo ao budie ninu ebuyi ao fi sin gbere 21 sori ao po iyoku ma ose ao ma fiwe odaju

2 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 2:35pm On Oct 18, 2015
Elosi odo awan elewe omo ki ebere eso afola wan afunyin eso ni keke gege bi wan se pa ere ni wan se pa oun na kekeke ni bi oka baba



jades5050:
e jo kin lo nje AFOLA se ewe ni abi eso

1 Like

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 2:30pm On Oct 18, 2015
omoalade144:
Ewe ama je sir o.Ejowo sir se ama ge die lara ewe ogede yen ni abi gbogboe lama gun mo awon eroja toku,kepe sir o.
Ema ge die niwan ba nio

2 Likes

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 2:28pm On Oct 18, 2015
jades5050:
e jo sir ki ni oruko i mi ti Won tun pe ewe ola tabi ti o tun nje
Ewe oja niwan tun pe(igbo)

2 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 12:45pm On Oct 18, 2015
Eyonu Atude Asina owo ojo
Ao wa ogorun naira tuntun eyokan itana rerinkomi topo ewe ola die atare kan ao jopo ao lo ao da sinu oyin ao ma la ni aro

4 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 9:51am On Oct 18, 2015
Owo (respect)
OROGBO KAN EYO ATARE META AFOLA META
OJU OLOGBO META
Ao jo gbogbo re, ao maa la die die
Otun sise fun irin ajo

3 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 9:46pm On Oct 16, 2015
Ao te ifa ogbe legbe otun irete legbe osi (ogbe-ate)

2 Likes

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) (12) (13) (14) (of 17 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 50
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.