Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,159,788 members, 7,841,057 topics. Date: Sunday, 26 May 2024 at 08:03 PM

Kadunasouth's Posts

Nairaland Forum / Kadunasouth's Profile / Kadunasouth's Posts

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 17 pages)

Religion / Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 10:09pm On Mar 18, 2016
talktofemi:


se eniti kiise musulumi le se ise ati bawo ni yio se se.
Rara o!
Abala yi wa fun elesin Islam, (musulumi) ti eni ti kokin se musulumi bani ifesi iru enibe ni latiwe si islam, igbayi loto le ni anfani ati se
Ese pupo fun ibere yin
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:32pm On Mar 16, 2016
Atude asina kia kia
Akara ori atan(imi gbigbe ) die, egbo tude epo obo odidi atare ao kosinu koko isasun tuntun ao wa ko ori bo mole ao jo papo dada ao ma fi epo pupa la die die lalale ona yio si funwa ni kia kia iseyi daju

4 Likes 1 Share

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:52pm On Mar 15, 2016
zenith329:

Ejowo baba kadunasouth, mo ti bere akopa lowo awon elewe omo sugbon woni awon ko mo ohun ti o jebe, ejowo sir, kini oruko miran ti akopa je?
Eye gunugun(eye igun) iye apare to gun dada ni wan peni akopa
Eyokan ni wan ma bayin tu, wan sile ti tu kale fun tita

3 Likes 2 Shares

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:33pm On Mar 15, 2016
wale259:
E jo sir,se opolopo eyan lelo.
Beeni

1 Like

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:50pm On Mar 15, 2016
zenith329:

Ejo sir, ki lo je igo ngori, e salaye?
Ododo ori re, flour to wa lori agogo igun, eo ri oun ma te condoro yio gun yio wa kako oun lema ja 99

3 Likes

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:33am On Mar 15, 2016
wale259:
Baba kaduna,e jo e fesi si ibeere mi yi...se inu fitila na lati ma lo kuna abi ale lo lori olo...
Ale lo lori olo

3 Likes 1 Share

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:38am On Mar 14, 2016
Seylad2009:

E jo wo mo ni lati bayi soro lori ago. E Jo wo e fi numba iba araeni soro yin rese si mi lori seylad2009@gmail.com tabi 08066717262.
Ese pupo
09090305775

2 Likes

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:07am On Mar 14, 2016
Zenlife:


eiyele ti aye tabi to ti ku?
Ao le mole ti yio ku le kanna tabi kadu sinu koko ijo nkan ao sese wa fi ori pa lara

2 Likes

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:23pm On Mar 13, 2016
Ousmaf:


Ejo baba Agba yin a dale e o sini ri ogun akoba, oruko miran wo latule pe 'ewe ola', ese Olohun Oba to ga julo aman ran yin se, ameen.
Ewe oja tabi ewe igbo tiwan nmu

5 Likes

Health / Re: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by kadunasouth(m): 11:04pm On Mar 12, 2016
Dammed93:
I was asked to help grate okra by my to be mother in law, while grating it, I tasted the raw okra. What does it mean

Your dream has two meaning good and bad depend on haw u felt during the dreaming, hawever to see okra in a dream refers to the problems, happiness and changes about work, school or relative and family as well
But in your own case if u felt being embarrassed While grating it and tasting it means brief illness and difficulty to make money
But if u were happy by grating it and taste signifes money progress and hapiness and also if u r a graduate d woman wil make connection to get u job and vice versa
To collect okra in your dream indicates that as long as you prove yourself in business life, you will be respected in each environment and you will be at the top of the agenda. Besides, you shouldn’t be unnatural with your friends in your school life and you should behave as yourself.

2 Likes 1 Share

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:40pm On Mar 12, 2016
Ogun iferan ki gbogbo aye le nife wa
odidi eyele funfun,ao fi ori ra gbogbo arare, ewe alupayida ewe egele, ewe ewuro oojo, Odidi atare meta, a Jo gbogbo re po, a po mose ao tun fi ori die si, a maa fi we lararo.

5 Likes 3 Shares

Culture / Re: .. by kadunasouth(m): 6:49pm On Mar 03, 2016
akingbemi:

ejo baba se gbogbo iye abiya akuku ni tabi melo ni? ati pe bawo ni eniyan tin fi apa lu apa re sir?

Iye die die lema tu, gege bi adie mase fi apalu apare to bafeko tabi tobafe fo gege be leyin na mase niwaba, eo ka apa abiya yin soke eo tun da pada lemeta eo ranti nkanna lese kese

3 Likes 1 Share

Religion / Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 6:35pm On Mar 02, 2016
aktab:
Salam alaekun Uztadz e ku igbiyanju,e jowo se pelu aluwala la o se adua yi tabi ko need aluwala ki a to se,elekeji ibeere mi ni wipe se mo le din akara elepo fun rara mi ni ile tabi ki n ra lo dara ju.
Ma salam
Ko pan dan dan kase aluwala, alese aluwala, asi lese lai se aluwala obinrin ti konirun kole se iseyi tabi okunrin ti jenaba wa larare konilese tabasi ti soro siyan ao le sema otun di ojomiran
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:29am On Mar 01, 2016
Aseje Owo (money)
Abo adie alawo meta(3 color) ao pa ao ge kekeke si ona to ba wuwa, iru iyere ata ijosi ewe ologosese ao gun gbogbo re ao fi se adie yi lepo niyo
To ba tutu ao fi iyere osun te ifa eji ogbe ao pe ofore si ao dasi ao koje
Arin igi oko lo longosese nti de ade tie gbogbo ibi ti month badurosi ni kiwan ti ma de mi ni ade owo nla nla, eji ogbe baba ifa wa gbe alanu temi komi nibi ti mobaduro si Ase

7 Likes 2 Shares

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:16am On Mar 01, 2016
geejayjax:

Pls, if u don't mind translate it. Thanks
Translation of ogun is not allow on this thread

3 Likes

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:58pm On Feb 28, 2016
possible26:


BABA ejowo e fun mi ogun premature ejaculation


Ewe lapalapa funfun ati pupa ewe egele funfun ao gbo dada ao se ao ma mun laro ati ale
NB ewe egele yi kiki egun ni gbogbo arare ale ko gbogbore sinu odo kagun kia bu omi si dada ki awa se pelu ase tabi ki aki ora toba lagbara bowo kafi gbo odara

5 Likes 1 Share

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:54pm On Feb 28, 2016
geejayjax:


Pls can you post what u wrote in English... Pls, I didn't understand it... My ulcer has reduce but the back pain it caused is still slightly there
.. Thank you
Copy it out and take it to elewe omo u can't spend more than 300 give then five hundred to bust their moral they will prepare it for u and take it morning and night very effective

4 Likes 1 Share

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:18pm On Feb 28, 2016
belatoxx:
Babakadunasouth ejowo ki ni a le lo si atosi ojo pipe mo ti lo orisirisi ogun e jowo e sa nu fun mi.


Ewe erunyantefe pelu odidi atare kan ao jo emafi omi bore hole lo tabi omin ojo eko gbodo lo omi tap o!
Eo ma lo die die leyin tati lo to kuna dada

2
Kanafuru pelu obi gidi kan ati kafura die elo kuna eo ma kanda si enu teba fesun ati kie to jeun lararo die die

3
Egbo sapo epa ikun ati eso bara eo fi omin didun se eo ma mun lojojumo

4 Likes 1 Share

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:03pm On Feb 28, 2016
Ogun Promotion
(Agbega lenu ise)
Ori Asa awodi, Awo ekun odidi atare ao jo ao fi sin gbere 61 si ori iyoku ao fi oyin la tan patapata odaju osi dara pupo


Iba fun alaye lorun (s.a.w)ti gbogbo aye wari fun iba fun umul li abati(aramu alai naru kolibu habahu) iba awan agbagba ti wan ti ile ife oye wasaye, iba fun gbogbo emi toma kanga kanga, iba emi keji moju bao ema pada leyin mi eje ki ojumi se. Amin

4 Likes

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:37pm On Feb 28, 2016
Agbo Gbogbonise
Epo aganho, epo Afara, Epo igi pandoro ao wa ki gbogbore lagbo ao ma yomu diedie ao ma bu omin si ao ma gbe kana titi di bi osu kan tabi jubelo kotosa

3 Likes

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 3:59pm On Feb 27, 2016
Ose Awure
Ewe rere tako tabo ao gun yio kuna ito idi eni lao fi pomo ose dudu ao ma fiwe. Ofore
Ojo ni oro ito mule ki oromi komu okunrin ati obinrin kiwan kowo wa funmi kiwon wa bunmi lowo .






Ike ati ola olorun kolore ba eni ti oloun torire da ewe ati egbo

5 Likes 1 Share

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:02pm On Feb 27, 2016
Turare Aworo
Epa to ni epo lara tanti yan ewe omisimisi gogoro ao gun papo ao ma fi ni turare pelu ogunna

4 Likes 1 Share

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:31am On Feb 25, 2016
ALIUDAVID:
Ekale o, ejo oruko wo ni won tun pe
ewe 'rekunrekun' iba eyin ti olorun
gbe ase ile aye fun.
Ewe na oloruko meji rekureku kifa kokoja ona
Ewe na common lodo awan elewe omo eko sinu pepa ewe rekureku ki efun wan, wan ofun yin

2 Likes

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:52pm On Feb 24, 2016
Ogun ito sugar
Iru woro ao ko tele koko ao wa ko ewe ewuro bo mole ao bu omi si ao se dada ao ma mun

Ogun ito sugar odaju
Ewe efirinla ewe gova ewe ejirin ao ko gbogbo re sinu koko ao bu omisi ao se dada leyin ose meji ta nba lo ogun yi dada laro ati ale ki alo se ayewo wanko ni ri sugar lara wa mo

5 Likes

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:38pm On Feb 23, 2016
systembayo:
baba ejo ki ni Ogun ti Omo university le se tio fi ma ri owo school san.monise lowo sugbon ko si ise ejo aranmi lowo emaje ki won le ni school.ejo ooooo.
Ewe ata epo obo ao lo kuna dada ao gun po month ose dudu ao ma fi epo pupa para kato lore we oseyi asiri obo latima san owo yi pelu ase oloun

5 Likes 2 Shares

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:51am On Feb 23, 2016
Ogun Atude Ituwo tiwan bade owo eniyan mejeji
Odidi bara kan ao gesi 16 ao ko tele ape ao wa gbe ori musu tonirun le lori ao fi odidi atare kan si legbe ao jo ao popo ma ose ao mafi we owowa mejeji
Iba akoda iba aseda iba eyin aye ewa tumi nide edi kidi bara ki gbogbo ide owomi kotu danu ki owo mi bere si ya fun owo nlala ki magba
Ogorun eyan lelo oseyi



Moju ba re olodumare

4 Likes 2 Shares

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:52pm On Feb 21, 2016
Kollyk11:
ajinde ara yio maa je ooo.aye oni pa yin ti bi aso to ti gbo ooo.ejo baba kadunasouth.mo ti ni aru ulcer ati iba lati nkan bi last may.ko si nkan ti mi o ti lo amo pabo loun jasi.bi ki ori ma fomi legbe kan ati eyin ju .ara atun ma gbona laro kutu.o ma n re mi ni gbogbo igba.ejo kini ero pe oun se mi ati kini mo le lo.e seun oooo

Ogun ulcer todaju
Aidan bi meta eo wafi obe ge isu arare eo so iyoku nu eo ko si inu roba kan totobi niwan ba eo wa ko ose bi oni 50 naira eo da meji idakan oseyi eo kosi eo wa bu omisi eo gbe kale di ojo keji eo wa mafi tele inu lararo keto jehun eo tun ma mun die die teba felosun yio lo patapata tie ko ni gburo remo lase eledumare tolaye ati orun
Iba eyin agbagba o!

5 Likes 1 Share

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:44am On Feb 19, 2016
Ogun kokoro omun
Etu ibon gid,i iyere ao lopo ao pomo ori ao mafi wo (ao ma fi pa omun na ao ma fiwo, yio pa kokoro na)

4 Likes 1 Share

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:37am On Feb 19, 2016
Ogun isori
Egun esusu ori oka odidi atare kan ao jo papo ao mala pelu epo pupa lalale . Apa ota koni kawa o lase odumare

4 Likes

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:59pm On Feb 18, 2016
Turare itaja
Ewe tagiri ati iru woro niwanba die ewe tagiri yio poju iru lo ni ilopo meta ao ma businu ogu ina ao mafi ninu shop wa tabi ile
Odara pupo

3 Likes 3 Shares

Health / Re: Dream Says Lot About Your Life Knows Yours Interpretation by kadunasouth(m): 3:56pm On Feb 16, 2016
Complement of season to all the fans on NL
There were series of calls day to day asking question about seeing vagina or male organ in a dream, for the benefit of questioners, I decided to put together dream related to vagina or penis
1.
Vagina in a dream means relief for person who is facing challenge, sorrow,pressure, difficulty,or hardship,
2
It could also signify satisfaction and fulfilment of one's desire marriage or relationship or exposing of a secrete.
3
If a man look at woman vagina in a dream it represented the high standard woman has achieved in his eyes, it hawever atime could mean his wicked state of mind.
4
If a woman look at a man's sexual organ in a dream it represent her strength and manlike drive.
5
If a prisoner or a man in bondage find himself having a vagina in a dream it means his release from prison or loose from bondage or someone Who is depressed it means relif from his depression.
If one has to appear in court of law, means he will win his case, or is facing an opponent it means that he will conquer him.
6
But seeing the vagina of an elderly woman in a dream means loss of business.
7
If one re enters the womb of a woman through her vagina in a dream it means his death.
8
A man with a vagina in a dream: He is not faring well and is being humiliated orthe reverse. But if he has worries or in jail he will be freed
9
Sucking or licking the wife vagina:
Is a minor relief
10
Biting the vagina of an unknow woman in a dream it mean relief and joy
11
If a woman dream that fire is coming out of her vagina, means she will give birth to a king
For enquiry call 09090305775

3 Likes

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:24pm On Feb 16, 2016
belatoxx:
Babakadunasouth@ Ki ni won pe ni Akara ori atan e jo e la ye mi adura wa yio gba
Imi gbigbe(igbe ti wan ya sori atan toti gbe dada)

3 Likes 1 Share

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (of 17 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 46
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.