Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,120 members, 7,814,932 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 12:00 AM

MJAhmed's Posts

Nairaland Forum / MJAhmed's Profile / MJAhmed's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by MJAhmed(m): 4:39pm On Mar 13, 2016
skypeme:
Mo fe gba gbo gbo wa ni moran lori afefe yi, Gbo gbo awa ta ba ni asiri ogun to le, ogun bi AYETA, AMUDO, ati be be lo, mo gba wa ni moran pe ki a ma fi si ori afefe yi mo, to ri pe awon eni e ke ati eni bi won le ma lo fun ise ibi ta bi lati se jamba fun eniyan

I would like to advice everyone of us with very powerful charm, charms like BULLET PROOF, TOUCH AND FOLLOW ETC not to leave such on this trend again, it should be kept secret and save against the people who would like to abuse the charm, i saw some group of young boys age 16, 18 & 20 buying rings to be used for AMUDO / TOUCH & FOLLOW, They were even saying in yoruba that: ma doo omo birin yen laye, iya re a ba bebe

Meaning, I will Bleep that young girl and her mum will come begging. please kindly yield to my advice let us protect our loving yoruba charm not to fall into the wroung hands
I like this guy really made point thank you for this God bless you
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 10:20am On Mar 12, 2016
wale259:
Baba,e jo kini itumo ki ma gba ogorun eyan lelo oseyi.
baba Kaduna south means that ogorun eyan lelo(hundred people can use it) that many people can use the soap

2 Likes

Culture / Re: .. by MJAhmed(m): 3:00pm On Mar 06, 2016
Ifankaleluya:
Boya ki e tun lo bere lowo awon agbalagba, OMI-AGBON NI WON N PE NI OMI - APEGUNRUN. EWE-PEREGUN SI DA WA LOTO.

Bayi ni won se ma n lo omi agbon lati fi pa egun, epe, ati ise run.

A o lo wa omi-agbon to po daadaa, ao wa mu oguna to ti pon daadaa ninu ina,ao sare ju si inu omi(owo(hand) ni ao fi mu ogunna yen ninu aro),ao ju si ori-olo,ao lo,ao po mo ose dudu,omi-agbon yen ni ao fi po ose yen. Kanrinkan titun ni ao fi we ose yen ni odo to n san.

Gbolohun yi ni ao ma pe ti a ba ti n we ose yen:

ojo ti ina ba wo inu omi ni egun aye re tan, ki egun aye mi ko tan loni.

Owo(hand) mi ti ba omi-apegunrun lo ni, ki gbogbo egun aye mi ko tan loni,
ati egun, ati epe, ati ise(poverty) aye mi ko ma ba omi lo loni, ko je ki n gbaye se rere.

Ao ju kanrinkan yen si odo,yio ma ba omi lo.
am really convinced but I want u to shed more light, I may agreed that no ese IFA call like that, but there is an IFA called owanrin adasenu(owanrin wese) or no such as an ese ifa thanx.
l like ur last post, about omin pegunrun will be very effective
Culture / Re: .. by MJAhmed(m): 1:25pm On Mar 06, 2016
healthFirst:


Igi Akoko ni an pe ni Pegunrun. Oruko Ifa re ni Pegunrun.
this is nothing but true is also call ewe ogunbo to elomiran oba due oko baba elomiran ani oko baba oun lotobi julo ibi ima awan nkan parisi ibeniti elomiran ti bere, eje kama nisuru funrawa, oduwa ateworo ni ife yio gbe gbogbo wa obami oke olodumare koni jeki asise o! amin

2 Likes

Culture / Re: .. by MJAhmed(m): 11:04pm On Feb 26, 2016
Zalam5:

Hmmm ,e se gan ,Iya lenun nla lo je funmi bi etisesowipe ko wopo ni Africa ,katomawaso nigeria,iyen tunmo siwipe mio le ri eegbo igi yen ra niyen baun
O de dun min sha undecided undecided
[color=#000099][/color] shocked
rarao talosope kowopo elosi odo awon elewo omo , owa kakiri kosiwan, opo Loja owode awan elewe omo ni offa ati ekogan pelu koda Mora oni hundred naira laipe epefunwan ni igi nla tabi asorin

1 Like 1 Share

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 5:51pm On Feb 17, 2016
08101646045atwp:
Eni ti kokini kule, onlopadanu ekaabo, lafi nki ojogbon wa, baba nkaduna ati gbogbo Omo awo pe: Ago'onile'o!. Olorun ama fun yin se, lase edumare. Fun eniti obere idi Ti ofi jepe owo Ki duro si lowo, oroyi pinsi ona topo, pataki ibe nipe onilati se akiyesi arare, Ki ole mo iru ogun Ti walo,
. AKIYESI PATAKI
. 1) Iru ise ti onse
. 2)bi isere se nmun owo wole si
. 3)awon bukata to nfi owo re gb
Toba sepe bukata to nfi owore gbo koba poju ere isere lo, Ti owo koba tun wa duro lowore, ajepe kotun ye ojo ibi re wo, Toba bosi June, oni lati otun Ni lati mo awon asiri kokan nipa arare lati ma kiye si, Ki ona re leba rorun laye.
Ti koba wa ba awon ibeyen lo, oni lati se atude daada, bi awon ide onje oju oorun, ibalopo oju oorun, jankariwo oju oorun tabi oju aye, ijakadi oju oorun, ati ise agbana ti ma nmun Ni na ikan tan keyan otorikan, tabi Ki eyan sise odindi kan wa so owo di owo guguru ati epa moni lowo, ati opolopo ebe awon agba.

Gbogbo ise Ti mo ndaru koyi loti wa Nita, kefara bale ka oju iwe lati here pepe, ohun Ti koba ye wa ka tun beeree. AJUWASE'O!
alaye ye koyewa dada esoro lori osu June ebawa yonana re koyewa Dada tori egban mi kanwa June ni Toni Iru isoro be mama reti esi

..
Culture / Re: .. by MJAhmed(m): 1:31am On Feb 09, 2016
Abimde:
zaudi mr copy &paste ise onmo yen oye ki o le refrence ayokomi 1010 toti copy e wa.
.

awan copy and paste ti yapa ninu thread yi o, ojulowo Ogun nbe low baba kadunasouth ati baba healthfirst,
ibere ?Eni tose copy and paste bawo lose fese ekun rere alaye Lori Ogun to lore copy,

se dandan ni ka post Ogun ni?
eje ka sora

2 Likes 1 Share

Religion / Asiri Nla Loju Ona Sufi by MJAhmed(m): 7:09pm On Feb 05, 2016
fun alalufa ati omokewu asiri NLA bi atise le gbe ile aye ati aluyo lnbo lona
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 12:13pm On Jan 29, 2016
08101646045atwp:
Eni ti kokini kule, onlopadanu ekaabo, lafi nki ojogbon wa, baba nkaduna ati gbogbo Omo awo pe: Ago'onile'o!. Olorun ama fun yin se, lase edumare, awon enion nri akitiyan yin ati opolopo igbi yanju yin ninu block, ninu block yi nimotiri awon Awo ti nwa nje fawo egbe'e, ati ninu awon opolopo block toje ti omo awo!, ati Alfa ati Woli ati onisegun omo awo lomo awo amaje lailai. Mowa nfi asikyi be gbogbo omo awo patapata Lori oogun tabama fisi block kama se aye wore daada, komaje eyi toma mu okan kuro tomafi mewa paro, fun apere, eni tonwuko tani kolo ewe minsinminsin pelu esore ati opolopo atare sinu oti, apa ikolotito sugbon esominsin misin tamo si oju olongbo kogbudo poju Lara, seloma tun wu nkan miran sile, fun idieyi gbogbo omo awo eje kakiye Sarao, bakan na fun iwo ogberi ti okomo ojutu ogun, tio bari nkan ti koyeo ninu block ti koyeo beere, won kimuyan sibere, odara Ki won bue juki ofi owo arare serare lo, bakana gbogbo oloro alufansa Lori awon ikan Ni, eje ka kiye Sara. Ajuwase'o. Letter timo koyi kiise fun blocks nikan kiisise fun eebu tabi oro iwosi rara, bikose fun Akiyesi, ogbon ologbo Ni kiije kapagba Ni were, fun awon opolopo blocks toje ti omo awo ni. Akoni se asise lola Eledumaawon.by P.Arojah
ki epe baba amaju yin se good observation leleyi Joe o! adura yio gba awo nki awo

1 Like

Culture / Re: .. by MJAhmed(m): 3:57pm On Jan 28, 2016
Eedrice1:
Baba Ki E Pe Bi Mope Se 'pe O, Mo Ti Gbiyanju Aajo Awure Owo Olosekan Ti A Fi Oga Ti Iru Ka Daada Yen Ati Aajo Oni Isu Dandan Ati Ata Ijosi Ti E Fi Si Ita Yen Sugbon Ti Mio Ri Ise Re, Ejowo, E Fi Imiran To Je Bi Idan Si Ita Fun Wa Ki A Le Je Anfani Yin Ni Ayeraye. Ewe A Maa Je O. Ase
etera ma ajegun Dada otobi ise orisi marun ti mo danwo lori ikanni yi ti osi jefunmi ju bi moti lero lo, bi meta lati odo baba healthfirst ati meji lodo baba kadunasouth ,awan baba mejeji yi ise wan daju
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 8:33am On Jan 26, 2016
kadunasouth:

ẸYỌNU AWỌN AGBA
Ifunni ekete kan, egbo akerejupon , ati ewe ajẹọbale, ao jo papọ̀, ao po ma ọṣẹ dudu oni apo nkan, ao ma fiwẹ leralera.

akoko wo lodaraju ti ale malo ise yi? or igba kugba ni?
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 8:22am On Jan 25, 2016
Ifadamilola30:


Baba mi, e dakun se a ma fi ikode kookan to ku ha apa eye yi kookan ni?? Abi bawo ni sir??
molero wipe ama fi ha lapa ni tori emigan fe bere, sugbon motise mokibo apare no,mofi ha lapa ni
Culture / Re: .. by MJAhmed(m): 5:33am On Jan 19, 2016
[quote author=gbengaeba007 post=42112500][/quote].

nje osese kia ko owo eyo senu alangba gbigbe bi? ko sese otumosi alangba tutu tiwon sese pa lemalo
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 8:11pm On Jan 18, 2016
baby124:
grin grin grin
Wow... All the incantations for every kind of jazz. Where lalasticlala. Some heavy babalawo de NL o.
becareful with this people no be play play o!
is an advise

3 Likes

Business / Re: Checking Your GTBANK Account Balance Via SMS by MJAhmed(m): 6:10am On Jan 18, 2016
it doesn't work on my phone why pls, I did but no reply
Culture / Re: .. by MJAhmed(m): 8:56am On Jan 13, 2016
kadunasouth:

Aseta todaju

Igbin to pinu 3 ewe kasan eru alamo odidi atare kan ao jo papo ao rosibi kan tiaba felo ao bu die nibe ao te ifa obara eka si ao wa pe ofore si ao fi omi gbigbona lo tabi eko gbigbona

Kowe leye aye agbigbo leye ode orun ton bari hihihi amako awon agbagba sanko sanko losode orun, ese oba taye lape obara eka, obara eka bamika Awon otami lese losi ode orun, owo mowo ibiwon lewon lori eru maru ibiwon da siwon lara , ti igbin ba fa ikarahun re atele, gbogbo aburu ti awon ota baro simi komon tele won leyin



baba o! ese pupo igbawo lodaraju lo ti alema lo ise yi, ogbo atoe, yio da fun yin o, aseye lalakan nsepo, aseye leo mase o, Amin


.

2 Likes

Culture / Re: .. by MJAhmed(m): 8:42am On Jan 13, 2016
kadunasouth:
Iyonu
baba o! ese pupo igbawo lodaraju lo ti alema lo ise yi, ogbo atoe, yio da fun yin o, aseye lalakan nsepo, aseye leo mase o, Amin
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 3:24pm On Jan 10, 2016
Arisiki
opolo malu ,oga gbigbe ewe ola ao fi omin agban se opolo malu ao to oyin sibi kan si ao koje opari

3 Likes

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 3:23pm On Jan 10, 2016
Arisiki
opolo malu ,oga gbigbe ewe ola ao fi omin agban se opolo malu ao to oyin sibi kan si ao koje opar

3 Likes

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 3:14pm On Jan 10, 2016
osole nla to nsoni di Olowo
okan malu ao ki ori igun si iho kan, aotun fi egberun kan naira we Igbo ao kisi iho elekeji , ao wa ki atare si iho eleketa ao jo ninu ikoko tuntun ao mafi foko mu lararo,
lowo bade
iba Baba Kadunasouth

3 Likes

Culture / Re: .. by MJAhmed(m): 10:43am On Jan 07, 2016
[quote author=healthFirst post=33338613]18 AGBERO ONI FUNPA: Egbo akarejupon ati owo osi ikun,ao fibo inu oruka Ogun, Ao we ni owu dudu ati funfun, ao wa pa akuko adie fun, yio sun ninu eje yen titi di ojo keji, ao wa ko ni ojo keji yen ao fi awo dudu rann ni ifunpa. Odaju.
Erore:Apa eni tio ro soke yio wale bi a ba ti kuro ni sakani eni na o. ewe a make o baba ese pupo fun ise yio yio ma juyin se amin

3 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by MJAhmed(m): 10:34am On Jan 07, 2016
kadunasouth:


bi igbawo lale lo ise yi, se aroni abi asale edakun ebawa yonono re dara dara
ATUDE TODAJU
Ewe tude egbo tude iyere ao lo ti yio kuna dada ao ra isasun tuntun ao fi se odidi igbin kan je lepo niyo lodidi ni ao se igbin yi o akoni ge ti obajina ao so kale ao je ko tutu ao wa bo gbogbo aso orun wa ati oruka ao wa ni ihoho omoluabi ao wa da aseje na si ilele ao kunle ti ao wa ka owo wa mejeji seyin wa ao wa se adua itusile ao wa fi enu gbeje lodindi iseyi daju danwo kori botiri
Ike oloun ola oloun komaba alayelorun
NB ori ilele cement or tiles lamada aseje yi si leyin ti ati nunu dada ao dasi ao waje

Iba akoda iba aseda iba agba merindinlogun lotu ife iba baba iba mama iba omode iba agbalagba iba okunrin iba obinrin efi oju rere womin o! Ase edumare
Contact me 08028358926a@gmail.com

3 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by MJAhmed(m): 10:10am On Jan 07, 2016
kadunasouth:



se Alelo ise alakala yi fun omo bi odun mejo? ewe ama jeo!






OGUN ALAKALA
Aoje atare 7/9 pelu gbolohun yi ao tusi igberi wa ao wa sun
Arapasa loruko ta npe ile aye 3, olokanran gunkan lanpe esu odar
a 3,Mariwo ye ye ye lanpe ogun 3, efun kimu igun 3, edi kidi ile 3, Akiki odidi made ku iroju ana 3, Odumare jowo bamisegun alakala kiosi gbemileke otami Odumare Ase

3 Likes 1 Share

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 44
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.