Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,230 members, 7,836,109 topics. Date: Tuesday, 21 May 2024 at 08:52 PM

OlayemiOniroyin's Posts

Nairaland Forum / OlayemiOniroyin's Profile / OlayemiOniroyin's Posts

(1) (2) (3) (4) (5) (of 5 pages)

Politics / Re: Buruji Kasahmu's Security Guards At An Event (Photos) by OlayemiOniroyin(m): 2:49pm On May 11, 2016
According to Yorubas, tiro ba lologun odun, ojo kan lotito ma ba. Asepamo lo wa, asegbe kan ko si. Beside, iwa omo ni mu omo sokigbe.

18 Likes 1 Share

Culture / Re: Ooni Ogunwusi Transforms His Ife Palace (photos) by OlayemiOniroyin(m): 6:08pm On Apr 29, 2016
I think the next thing for Oba is to have football club. The idea would boost the image of IFE and create economy opportunity for the town
Celebrities / Re: Tiwa Savage And Tee-billz Separate. See What He Posted On Instagram by OlayemiOniroyin(m): 11:10am On Apr 28, 2016
See what Buhari is causing now
Politics / Intrigues As Osoba Returns To APC - PUNCH by OlayemiOniroyin(m): 7:22am On Apr 09, 2016
A former Governor of Ogun State, Chief Olusegun Osoba, left the All
Progressives Congress after falling out with the state Governor, Ibikunle
Amosun. GBENRO ADEOYE looks at the return of Osoba to the party and
the intrigues that are likely to follow
The return of former Governor of Ogun State, Chief Olusegun Osoba, to
the All Progressives Congress did not come as a surprise to many people
as defection has become the hallmark of Nigerian politics. But many
people were amused by it.
Osoba, a foundation member of the APC, had left the party for the Social
Democratic Party after falling out with the Ogun State Governor, Ibikunle
Amosun, before the 2015 general elections.
And his exit was not a quiet one, by any means. The former deputy
governor of Ogun State, Segun Adesegun; three senators and six members
of the House of Representatives, including Osoba’s son, Olumide, also
dumped the APC for the SDP.
Osoba’s statements were also loud enough as he spewed fire and
brimstone over his exit from the party and vowed not to forgive Amosun.
Osoba and Amosun’s quarrel was largely about the soul of the APC in the
state. There were many sides to Osoba’s defection from the APC. One
version was that Osoba wanted a more inclusive executive to
accommodate the people who worked for the party to ensure Amosun’s
victory at the 2011 governorship election.
Although there were entreaties by some APC leaders and traditional rulers
to unite the opposing parties, all amounted to naught as Osoba vowed not
to forgive the governor.
For instance, while addressing some APC members from the 236 wards in
Ogun State at a consultative forum in May 2014, before his defection to
the SDP, Osoba had said,
“Your executive members came to me, they said they don’t trust me
again, they said they don’t believe in me again, that I will soon forgive
and say everything has been settled. They said I will tell them that some
Obas (traditional rulers) have appealed to me….
“When they said that, I asked them again, if they have fully concluded and
we went into an inner meeting and inside there, I vowed to them that I will
not forgive or reconcile with anybody. As I stand before you today, I
swear before God and Jesus Christ, my Lord, I promise you all that the
issue of forgiveness is no more. If you stand firmly as a warrior, that is
enough for me.
“If you are ready, there is no more room for reconciliation. If thousands of
people prostrate, it is what you want that I will do, it is what you say that I
will say; I will stand where you stand. I want to appeal to you, don’t be
distracted. They said they have given them the party structure, leave them.
Are you dragging the party with them? It is those that have people that
have the party.”
But in the end, after all said and done, Osoba and his camp lost out as SDP
candidates for the 2015 general elections failed in their various bids,
including Akin Odunsi, who Osoba had hoped would defeat Amosun.
So, with Osoba’s return to the APC, analysts say Ogun State politics is set
to light up with interesting twists ahead of the 2019.
Osoba had attributed his return to the Alake of Egbaland, Dr. Adedotun
Gbadebo, and the Awujale of Ijebuland, Dr. Sikiru Adetona, both of
whom he said facilitated the move.
However, some analysts have said that there must be more to the story,
particularly as Osoba had rebuffed such peace moves initiated by the
traditional rulers in the past.
One school of thought has attributed the Osoba’s return to the APC to a
peace move that started at a meeting called by Prof. Segun Gbadegesin, a
renowned scholar and former Head of Department of Philosophy and
Dean, College of Arts and Sciences, Howard University, Washington DC,
the United States, in December 2015, following the launch of his book,
“All The Way: Serving With Conscience” in Lagos.
There, Gbadegesin was said to have appealed to Tinubu and other South-
West APC leaders to close ranks.
Governor Abiola Ajimobi of Oyo State, who was reportedly the only
governor at the meeting, was said to have been directed to open
negotiations with rival groups in the party.
But according to another school of thought, the return of Osoba to the
party signifies a gang-up against Amosun ahead of 2019 governorship
election in Ogun State.
When Osoba was recently welcomed back to the party with open arms
amid applause by some APC chieftains, including its National Leader,
Ashiwaju Bola Tinubu, at a meeting at the former’s residence in Lagos,
Amosun was missing.
Also absent at the meeting were the Minister for Power, Works and
Housing, Babatunde Fashola, and his colleague in the Ministry of Solid
Minerals, Dr. Kayode Fayemi, both strong APC members in the South-
West.
Some analysts have described the absence of Amosun at the meeting as a
sign that he was probably not happy with Osoba’s return; a situation they
opined might divide the Ogun State chapter of the APC in future.
A political analyst, who is close to happenings in the APC, Mr. Olugbenga
Okunola, described the choice of Osoba’s residence as the meeting point
where his return to the party was announced “as instructive and
significant.”
“Everything is not well in the Ogun State chapter of the party yet,” he
said.
“Many people may not understand it or think it is significant, but the fact
that the meeting was held at Osoba’s residence and not at the Ogun State
Government House or Amosun’s house as the leader of the party in the
state, was instructive in itself. It is giving Osoba credence as the leader of
the APC in the state.”
Meanwhile, it is rumoured that Amosun, Fashola and Fayemi have all left
Tinubu’s good books and therefore have something in common. The three
of them have found a strong ally in President Muhammadu Buhari.
Amosun is also said to be one of the President’s closest politicians in the
South-West.
According to analysts, for some time, Tinubu and Amosun have not been
on good terms, starting from the latter’s nomination of his candidate, the
Minister of Finance, Kemi Adeosun, for the state.
It was said that Tinubu had preferred another candidate.
However, Okunola said Amosun had later conceded the nomination to
Tinubu, but that Buhari insisted on working with Adeosun.
“At the time, the Tinubu camp argued that it had given Ogun State the
position of the Vice-President, which was taken by Prof. Yemi Osinbajo,
but Amosun felt that he had no input in it,” Okunola said.
“So, Amosun felt that if he had no input in the choice of the state’s
ministerial nominee, how then could he table the affairs of his state before
whoever emerged for the position? It is believed that he later conceded the
slot to Tinubu but the President wanted Adeosun.
“But then, Amosun is known to be close to the President, so it was
difficult to prove that he had not pushed the President into accepting his
own candidate.”
Now as politicians set for the 2019 general elections, the opinion of some
pundits is that Osoba’s return to the APC is all part of a scheme between
the Tinubu and the Osoba camps against Amosun ahead of the polls.
Okunola, who referred to it as a ‘gang up’, said, “Politics, particularly in
Ogun State, is all about alliances. The Tinubu camp has formed an
alliance with the Osoba group to support Senator Olamilekan Adeola,
popularly known as Yayi, for Ogun State governorship of the APC in
2019.
“So, if Amosun wants a candidate of his choice to succeed him, he will
have to convince his alliances to back such a candidate or else he will
lose. Another way is for Amosun to arrive at the choice of a candidate
with his alliances, so that he can have their full support.”
However, according to Dr. Idowu Johnson of the Department of Political
Science, University of Ibadan, it is too early to interpret Amosun’s
absence at the meeting where Osoba announced his return to the APC as a
sign that he still has friction with the returnee politician.
He said, “We cannot say because Amosun was absent at the gathering, he
was not on good terms with Osoba.
“One thing we should realise is that everybody is fighting for their space,
including Osoba. Before Osoba could return to the APC, some of the
bigwigs in the state must have convinced him to take the decision.
“The other thing is that the PDP cannot make any headway in Ogun State
now because most of its stalwarts who benefitted from the past
administration would not come out to finance the party. They would want
to lie low for now, so for the next four years, the APC would dominate in
the state.
“For now, Osoba has no option but to go back to the APC to remain
relevant in the state. “Beyond politics, the reality is that everyone is
fighting for where they would get their livelihood and remain relevant in
the coming years. Osoba is coming to become relevant and he has to
reconcile to get that relevance, get some contracts and so on.
“Amosun is one of the most respected governors in the South-West and he
is in the good books of the President. Maybe by 2019, they can start
playing games but for now, they will not do that.”
In his view, a Professor of Political Science at the University of Ibadan,
Prof. Adigun Agbaje, said Osoba’s return to the APC would not have any
positive impact on the lives of residents of Ogun State.
Agbaje, who described Nigerian politics as lacking in ideologies, noted
the possibility of a gang-up against Amosun.
He, however, added that there is always room for negotiations in politics.
He said, “The events surrounding Osoba’s return underscore the
formlessness of Nigerian party politics and the lack of an effective role of
principles, which some people call ideology. It underscores the fact that
these are not parties; they are just amoebic amalgamations of short term
interests and personal goals.
“Osoba has said that his return was facilitated by leading Yoruba
traditional rulers, but I would say they fast tracked it because there was an
assumption that he was bound to return to the APC.
“His return has implications for APC politics in Ogun State. If the nature
of politics that has played out in the past continues, then it is a zero sum
game. But Osoba’s gain returning to the APC may be the governor’s loss.
“Whichever way it is, the governor will find a niche for himself and he is
already serving his final term as governor. Complex negotiations and
maneuvers and so on will be going on, but at the end of the day, it is the
people that lose. The politicians never really lose. The equality of
Nigerian politics will also lose.
“Politicians will always make some alliances, some temporary money and
gains in terms of power play, but the people always lose. It is a situation
where the politicians do not offer the people meaningful choices and the
parties are more or less the same.
“You can talk about one man in the APC today, few days later, he is in
PPF, another time, he will be in CTC and so on. At the end of the day,
Osoba’s return will not have serious significant positive impact on the
quality of lives of the Ogun State people, whichever way we look at it.
“This has to be tied to the national level of the APC. The feeling is that
Amosun is closer to the President than to Tinubu. This has implications.
All may be well tomorrow, who knows but at the moment, all is not well
because it took the governor a dogged fight against the Osoba group to get
a ticket for the second term. But we cannot dismiss the possibility of
negotiations in the future even though realistically, it will be difficult to
believe that the two of them can mend fences to the extent that all will be
well. But in politics, anything is possible.” www.punchng.com/intrigues-as-osoba-returns-to-apc/
Webmasters / I Need Expert That I Can Help Me Work On My Blog by OlayemiOniroyin(m): 4:59pm On Mar 28, 2016
I want to bring my blog up in term of standard view for a blog and other things that it requires. Please, anyone that can do this should contact me through whatsapp :08032394964
Webmasters / Re: Submit Your Website Url For Review, And Get Good Backlinks And Traffic by OlayemiOniroyin(m): 4:28pm On Mar 28, 2016
olayemioniroyin.com
Culture / “asiri Iwa Ọwọ Femi Solar Ti Tu Si Mi Lọwọ” - Oniroyin by OlayemiOniroyin(m): 10:43pm On Mar 21, 2016
Ohun ti mo fẹ salaye nibi, mi o ko ohun to le ti ẹyin rẹ yọ. Asiri nla kan nipa iwa ọwọ Femi Solar ti ẹnikẹni seese ki wọn ma mọ ni mo fẹ tu jade. Yato si wi pe mo mọ ọ gẹgẹ bi gbajumọ olorin, ile emi ati ẹ ko jina sira wọn. To ba si jẹ eleyii ni yoo mu ajosepọ wa bajẹ, i don kia fiditi.

Sugbọn ki ni kan lo damiloju, eniyan ko ni gbin ẹpa, ko wa fi ka agbado. Ohun ti ẹda ba gbin ni yoo ka.

Femi Solar ọmọ Oladele maa gbọ, oni yii ni maa tu asiri iwa ọwọ re fun gbogbo araye pata.


Ti mo ba pari alaye mi tan, e le pe mi ni onilara, to ba wu yin, e le ni mo kan fẹ ba a loruko jẹ lasan ni. Iwọfa lẹnu, ohun to ba wu ẹlẹnu ni ko fẹnu sọ.

Lakọkọ na, mi o mọ ohun to ma n se bọbọ naa to fẹran lati maa tẹriba to ba n ki awon eniyan, atọmọde atagba lo ma n bọwọ fun nigba gbogbo. Tẹrintẹyẹ lo fi n ki gbogbo ẹni to ba pade lọna. Ẹmi irẹlẹ rẹ dabi ẹni ti n sise Oluwa, bẹẹ ise orin nise rẹ.

Bawo ni olorin yoo se wa ti oju rẹ yoo ma tutu nigbogbo igba? Awon olorin temi gbadun swagger wọn, tajutaju ni won fi n gbera. Oju won a ranko bi oju amọtẹkun, oju won a pọn bi ẹrẹyin, a wa maa sana sarasara bi tina ilagbẹdẹ.

Sugbon ti Femi Solar ko ri bẹẹ, ki i binu ki i ja, ki i kapa soke gangan bi bọọda mi oke ohun oniṣeeni janganna lọrun. Awọn asiri iwa ọwọ Femi Solar ni yii.

Ti oun ati awon ọmọ rẹ ba ti ode ere de tabi ti won ba n mura lati lo kọrin, o fẹran lati ma ba awon ọmọṣẹ rẹ sere pupọ. To ba n sere pelu wọn, agidi ni eniyan yoo fi mọ ọga yato si ọmọsẹ. Won jọ maa n lọ pọfupọfu gba mọ ara won lọwọ ni. What a palapala ilu apala! (ẹ ma binu pe mo so oyinbo jare, bọbọ yẹn lo kọs ẹ).


Ẹniwee, Jasa orin Solar ti doorun ti ko se fọwọbo mọle laelae. Oore ọfe atokewa Oluwa lo ye ki gbogbo wa o beere fun. Aanu Oluwa rekọja ohun gbogbo, ohun nikan lo si le mu ni di alaseyori. Lọjọ kẹwaa osu kerin odun yii, lala o lu!
10-04-2016


Femi Solar yoo ma se ifilọlẹ fidio orin GRACE ati awo orin tuntun rẹ to pe ni MERCY BEYOND ninu gbongan nla ti Genesis to wa nibadan nile Oluyọle. Aimoye awọn olorin ni wọn yoo pejupese sibẹ lati ko awon orin tuntun naa jade bi ọmọ tuntun jojolo. Funfun lẹyẹ n su, ẹ wọ asọ funfun wa pade Solar, o da mi loju wi pe, ọjọ naa yoo larinrin yoo si miringindin. #GbaBẹẹ

http://www.olayemioniroyin.com/2016/03/asiri-iwa-owo-femi-solar-ti-tu-si-mi.html

Politics / Re: Fayose Browsing At College Of Education E-library, Ekiti (Photo) by OlayemiOniroyin(m): 12:42pm On Dec 29, 2015
His name is Peter- The Rock. You guys better leave him alone. No amount of criticism will let him turn back from his own way of living. Beside, if his people love him that way, what is our stress? I used to hate him, but not any more.

1 Like 1 Share

Travel / Re: General U.s.a (student) Visa Enquiries-part 8 by OlayemiOniroyin(m): 6:19pm On Dec 13, 2015
Please, can someone go to the embassy for interview with the scanned copy of the I-20 form?
Travel / Re: General U.s.a (student) Visa Enquiries-part 8 by OlayemiOniroyin(m): 6:12pm On Dec 13, 2015
Walspring:


If you haven't submit then you have 30 days grace to check I.e if you fill the form and you havent submit then you can retrieve it back if it's not above 30 days

But if you have submitted, am sorry you can't view the whole form but only your confirmation page


Please, can someone go for visa interview with Scanned copy of I-20 form?
Politics / Words On Marble..ayodele Fayose by OlayemiOniroyin(m): 8:36am On Oct 31, 2015
" In Bauchi state were you had the PDP chairman and the
FCT Minister they couldn't get 5% of the votes, I won the
presidential elections for PDP (In Ekiti State), won all senate
and House of Reps seast and all 26 state House of Assembly
seats. I am like Israel surrounded by his enemies but always
come out strong. My name is Peter , the rock, if you fall on
the rock you break, if the rock falls on you you break, so
leave the rock alone".- Foyose
Fashion / Ebony Finex Stitches: The Secret Of African Fashion by OlayemiOniroyin(m): 6:05am On Sep 15, 2015
Please, kindly check the link bellow for detail about Ebony Finex Stitches' creation



www.olayemioniroyin.com/2015/09/ebony-finex-stitches-ni-awon-omoge.html?m=1
Culture / Omo Naijeria Setan Lati Dije Fun Ipo Aare Orileede Spain - Olayemioniroyin.com by OlayemiOniroyin(m): 8:04am On Sep 13, 2015
Omo Naijeria Setan Lati Dije Fun Ipo Aare Orileede Spain - www.olayemioniroyin.com


Ko to di wi pe ma kan lu agbami oselu ti n gbona felifeli bayii ni ilu Spain, nibi ti Arabirin Helen Mukoro to je omo ipinle Delta lati orileede Naijeria ti setan lati dije fun ipo aare orileede Spain, mo royin ki e gba mi laaye ki n ti owo bo itan awon isele to sele bi
nnkan bi ogota si aadorin odun seyin ni ilu Amerika.

Sebi won ni bi omode o batan, yoo ba aroba. Awon agbalagba ile Yoruba ni won ni aroba ni baba itan.

Kini je itan? Kini je aroba?

Ti e ba fun mi laaye die si, mo fi dayin loju wi pe mejeeji ni maa salaye lai senuku sibi kankan.

Odun 1929 ni won bi gege bi alawo dudu omo ile Amerika ni Atlanta, Georgia to wa ni orileede
Amerika.

Jije alawo dudu omo ile Amerika tunmo si wi pe orirun re tabi iran re se wa lati ile Afirika to je ile adulawo.

Nnkan bi ago mefa koja iseju kan, lojo kerin osu kerin, odun 1968 ni awon agbanipa yin-in ni bajinatu lojiji ni ile itura Lorraine to wa Memohis, Tennessee latari wi pe enu re ti mu ju nipa jija fun eto omoniyan, paapa julo, eto awon omo adulawo ile Amerika ati iponlogo re eleyii to lodi si eleyameya ni ilu Amerika.

Bi won tile seku pa a ninu agbara eje to n san bi omi odo Ogunpa, sugbon ero re ati igbagbo re ko ba a
wonu ese mefa lo.

Ni awon akoko yii, ilu Amerika je ilu ti won ri awon alawo dudu omo ile Amerika gege bi awon eniyan ti ko dogba pelu awon alawo funfun omo ile Amerika.

Won on te eto awon alawo dudu mole, won si n re won je nigbogbo ona.
Itan tile so fun wa wi pe won ko ka awon alawo dudu si eniyan eleran-ara, oju eranko inu igbo ni won fi n wo awon eniyan ti awo won ba dudu.

Bi alawo funfun ba wo inu oko nla akero, to ba ri alawo dudu lori ijokoo, ofin ilu Amerika nigba naa so wi pe ki eniyan dudu dide naro fun alawo funfun lati joko.

Iru igbe aye yii je ohun ti akoni yii lodi si nigbogbo ojo aye re gege bi alawo dudu omo ile Amerika.

Ni odun 1965, o salaye fun awon oniroyin wi pe ile Amerika je awon eniyan dudu ni gbese pupo gan-an
latari imunisin tabi imunileru awon eniyan dudu to ti waye ni awon igba kan seyin ninu itan ile Amerika.

O ni nipa sise eleyii, ile Amerika ti jebi tite eto omoniyan loju mole. Lara awon esun mi-in to menu ba ni ifiyajeni lona aito.

Lori awon esun mejeeji yii, o beere fun aadota bilionu owo ile Amerika ($50B) gege bi owo itanran lati san fun awon eniyan alawo dudu omo ile Amerika
ati awon alaise ti won ti te eto won loju mole.

Martin Luther King Jr ko si mo lonii, won seku pa baba Yolanda Denise King leni odun mokandinlogoji (39).

Won pa oninuure nibi o ti gbe n sise Oluwa oba, awon ika eniyan pa oko Coretta Scott King nibi o ti
gbe n kilo iwa ibaje.

Sugbon oro akoni to so kale lodun 1963 ni awon onkotan agbaye so wi pe yoo maa wa titi lae bi Opa Oranmiyan ti n be lode Oyo Oba Lamidi Adeyemi III.

"Mo so fun yin, eyin ore mi. Bi o tile je wi pe a n dojuko isoro toni ati tola, mo si lala. O je ala eleyii to ridi mule ninu ala ile Amerika.

Mo lala wi pe ojo kan orileede yii yoo dide lati gbe igbe aye to ni itunmo otito gege bi igbagbo re: ' A di otito yii mu gege bi eri ti wa, wi pe aparo kan ko ga jukan lo; ibi o si ju ibi lo.'

Mo ni ala wi pe lojo kan, ni ori awon oke pupa to wa ni Georgia, awon omo eru igba kan ati awon omo olowo eru igba kan won yoo le joko papo lori tabili kan naa gege bi tegbon taburo."

Die lara oro Martin Luther King niyii eleyii to se niwaju opo eniyan ni ojo kejidinlogbon osu kejo odun 1963 ni Lincoln Memorial, Washington D.C.

Ni akoko ti Martin Luther King n ro ala re fun awon eniyan nipa ojo iwaju awon eniyan dudu ile Amerika
lodun 1963 ni ilu Washington, Barack Obama, omo ile Amerika alawo dudu, eni ti iran re se wa lati orileede
Kenya, wa ni Honolulu leni odun meji nibi to ti n yi taya kiri adugbo ni orileede Amerika kan naa.

Leyin odun merindinlaadota (46) ti Martin Luther King ti ro ala re fun gbogbo aye, Barack Obama wo inu ile
nla funfun lo ni Washington D.C. gege bi aare ile Amerika akoko ti o je alawo dudu.

Ala Martin Luther King wa si imuse nigba ti ilu Amerika gbe Barack Obama soke lodun 2009.

Nje a tun le fi okan si i wi pe ala yii kan naa maa wa si imuse ni ilu Spain?
Arabirin Helen Mukoro to je omo ipinle Delta lati orieede Naijeria wo ilu Spain ni odun 1992 nibi ti omobirn naa ti rese wale to si ti ridi joko remuremu.

Onkowe ni, amofin ati agbaoje nipa ise otelemuye to dangajia tun ni pelu. Ninu osu karun-un odun yii, omobirin naa gbe apati lati du ipo alase ilu Denia to wa ni orileede Spain sugbon to fidiremi.

Isubu yii ko da omi tutu si lokan rara pelu bo tun se dide lati gbe apoti ibo fun ipo aare orileede naa.

Helen Mukoro ti da egbe oselu sile eleyii to pe ni Union De Todos, labe egbe oselu yii naa ni yoo si ti maa dije fun ipo aare eleyii ti yoo waye ninu osu kejila odun taa wayii.

Gege bi alaye Helen Mukoro, itunmo Union De Todos to je oruko egbe re ni "wiwa ni isokan."

Ibeere ti n fi maa kadi alaye mi naa ni wi pe: n je awon eniyan ilu Spain le fi owo sowopo pelu isokan lati gbe alawo dudu akoko wole gege bi aare orileede
naa?

Olayemi Oniroyin ni oruko mi, ala mi ati igbagbo mi ni wi pe ni ojo kan, eni ti n je eran ogunfe , uyan Ekiti
ati obe egusi ko ni loun jaye mo, nitori teru-tomo ile yii ni o maa fi ayokele se faaji lo je eja tutu nirole.

Orisun iroyin: www.olayemioniroyin.com
@OlayemiOniroyin
Celebrities / When Men Were Still Boys: Oga Nla And Obesere by OlayemiOniroyin(m): 8:54pm On Aug 31, 2015
When men were still boys: Oga Nla and Obesere

Culture / Aso Oge Funke Akindele Ta Lenu Yeriyeri by OlayemiOniroyin(m): 8:15pm On Aug 31, 2015
Aworan Funke Akindele niyii niluu Oba nibi to ti n yo ayo ojo ibi re to ko laipe yii (August 24). Ka ma paro, Funke Akindele ta lenu! Lati irun ori re de bata to wo sese ni i sana bi ti ina elentiriki.

Aso kaba to wo tun leku! Aso naa kii se tile yii, toke okun ni. Aso ti won fi goolu ati owu dudu ran pelu bata onile gogoro lese.

Aso naa o de orunkun re; ilaji itan lode. Eleyii to fi anfaani sile lati ri ilaji itan ese re nita. Itan omoge naa tutu loju bi edo eran ti won ko jade lati inu omi bee lo mo lolo lailabawon bi ara omo tuntun jojolo.

Yato si eyi, aso oge re tun rora si igbaaya re sile ferefe, eleyii to je wi pe ko si okunrin ti o gboju sona ibe ti ko tun ni fe tun wo leekan si.

Atike oju re ko poju, iwonba naa si tun ni itote pupa enu re.

Eniyan dudu ni Funke sugbon o dabi eni wi pe oju re ti n funfun.

Odun 1977 ni won bi Olufunke Ayotunde Akindele si agbegbe Ikorodu to wa niluu Eko.

Ojo aje to koja yii lo si pe omo odun mejidinlogoji (38).

A ki Jenifa wi pe oku ori ire. Igba odun, odun kan ni

http://www.facebook.com/photo.php?fbid=882443721841512&set=gm.1038794672838508&type=1

Celebrities / OMG! Funke Akindele, Iyabo Ojo And Doris Simeon Were Childhood Friends. by OlayemiOniroyin(m): 8:12am On Aug 30, 2015

Politics / Re: Amaechi Fires Back: Wike Also Corrupt; I Won’t Appear Before His Commission by OlayemiOniroyin(m): 6:25am On Aug 30, 2015
Amaechi and Wike again?
Culture / Ibadan Omo Ajorosun: Ohun To Ye Ke E Mo Nipa Ilu Ibadan by OlayemiOniroyin(m): 6:58pm On Aug 28, 2015
Leyin awuyewuye to ro mo ipapoda Oba Sijuwade
Olubuse II, Ooni ti Ile-Ife ati bi awon oloye se tako
iroyin to jade nipa bi baba se goke aja, won ti pada
so wi pe lotito ni Oba to wa ni ipo keta ninu awon oba to lowo ati ola ju ni ile Afirika ti lo ba awon babanla re.

Ni odun 2014 ni magasiini agbaye Forbes se atejade
awon Oba ile adulawo marun-un ti won lowo ju lo.

Bi won se to lori ila ni yii:
1. King Mohammed VI, Morocco
2. Oba Obateru Akinrutan, UgboLand, Nigeria
3. Oba Okunade Sijuwade, Ile-Ife, Nigeria
4. King Mswati III, Swaziland
5. Otumfuo Osei Tutu II, Ashanti, Ghana

Lonii, Oba Okunade Sijuwade o si mo, ki lo fe sele si
awon ola ati dukia oba ti a bi ni ojo kinni osu kinni,
odun 1930?

Iroyin to koko jade fi ye wa wi pe ojo kejidinlogbon
osu keje odun 2015 ni Alayeluwa Oba Okunade
Sijuwade gbese ni ile iwosan to wa ni ilu London leyin aisan ranpe.

Bi o ba je wi pe ilu Nigeria ni baba dake si, o seese ki iroyin yii ma lu sita saaju igba ti awon oloye kede
ipapoda oba naa.

Ayafi ti a ba n tan ara wa je, iroyin to jade saaju ikede yii mu edun okan deba awon asaaju isese Ile-Ife ati ile Yoruba lapapo. Eyi lo fa bi awon oloye se n binu ti won si n kanra mo awon oniroyin.

Gege bi Oba to wa ni ipo keta ninu awon oba to lowo ju lo ni ile Afirika, kini Oba Okunade Sijuwade ti se lati mu eto ilera gberu ni Ile-Ife tabi Naijeria lapapo?

Pupo ninu awon olori/oloselu wa naa lo feran lati lo
maa gba itoju ni oke-okun laibikita fun awon ile
iwosan wa gbogbo.


Ti a ba yo Ile iwe Ifafiti ti Obafemi Awolowo to je ti
ijoba apapo to wa ni Ile-Ife kuro, kini ohun
idagbasoke ti a tun le naka si to wa ni Ile-Ife? Iru igbe aye wo ni awon odo n gbe? Iru ipo wo ni awon
wa? Eto wo lo wa fun awon omo wewe? Se
igbelaruge asa ati isese nikan lo se pataki julo ninu
igbesi aye eda laibikita fun igbe aye awon mekunnu?


Ti a ba n so nipa owo, ola, iyi, agbara, okiki ati ipo, eyi to poju ni Edua fi fun omo Adelekan. Sugbon ibeere mi ni wi pe, nje awon nnkan yii fara han ni Ile-Ife to je orirun Yoruba? Sebi awon Yoruba nibi ta ba pe lori, enikan ki fi ibe tele.

Kini ni awon oyinbo ni ni awon ile iwosan oke okun ti awa naa ko le ni? Iwadii tile fi ye wa wi pe pupo ninu awon dokita alawo dudu ti won sise ni ilu Amerika ni opolopo won je awon omo Nigeria. Ani awon olopolo pipe sugbon ko si ohun elo to munadoko.


Oba Okunade Sijuwade ko si mo lonii, Alayeluwa ti
gbe aafin re lo salakeji, oba to je leyin Adesoji

Aderemi ti deni idaro, omobibi inu Yeyelori Emilia
Ifasesin Sijuwade si ti deni agbe gege, ko si ni wu mi
ki n si awon iwe iranti eleyii to se afihan awon asise
tabi tabuku Oba gidi.

Boya tori wi pe Ooni ti sise ri gege bi Oniroyin
akoroyin fun ile ise iroyin The Nigerian Tribune lo je
ki n fe daso ro lara. Sebi won ni awo kii se ibaje awo. Eewo orisa!


Mi o ni so ipa ti Baba Tokunbo ko nipa June 12 ati bi
iya ojosi se je Mosuudi 'Emuke' Abiola lajegbe? Mi o
ni menu ba asise oko Olori Monisola. Mi o ni menu
ba bi Asoju Oodua se koyin si omo Yoruba nitori
owo. Awon alaye yii wa lodo ikun mi sugbon mi o ni
dale awo ise iroyin laelae.

Mi o ni salaye bi Ibrahim Babangida se ri ona wo
ojubo Oduduwa Atewonro. Mi o ni so nipa eni to gbe Oye Adimu, okan ninu awon oye pataki ni ile Yoruba fun Atiku Abubakar nitori owo.

Mo ti pinnu wi pe mi o ni so iye owo dollar ti Oga Jonathan gbe lo saafin baba Adedotun lati ra awon oba ile Yoruba pa raurau. Awon asiri wonyii ni mo ti pinnu wi pe mi o ni tu; mo si se ileri wi pe mi o ni se bee.

Se ija to wa laaarin Ooni ati Alaafin tile pari patapata abi ife oju lasan ni won ba ara won se?

Kini awon agba mejeeji jo n du mo ara won lowo? Akoba wo leyii se fun awon omo Yoruba?

Olayemi Oniroyin, bi eniyan lami lofun mi o ni soro.
Mo ti tilekun enu mi bi enu bode ewon. Mo si ti ko
gege-ikowe mi logbon ohun ti mi o fe ko ko faraye ri.

Mi o ni so gbogbo ohun ti mo mo nipa oko Olori
Ladun Sijuwade; eyi ti mo mo nipa olowo ori Dalapo
ni mo si ti faso bo mole patapata.

Bi eniyan ba fe mo bi baba Gbade Sijuwade se pataki to, ilu London ni ke e ti lo beere wo lowo oba
Elisabeeti, oba alaso funfun.

Sugbon lonii, Oba Okunade Sijuwade o si mo. Bi won fi egberun odun kun ojo ori baba, ojo kan o jokan ti
oba o pada waja naa ni.

Iku o pa eni a n pe, iku o pa eni ti n peni. Eni o waye ti o ni ku kan ko si, sebi gbogbo wa la o fi ile aye yii sile lojo kan.

Iku ti pa darodaro aso aro ko si lode mo.
Iku ti pa akosun, aye o rosun para.
Iku pa lekeleke, efun o si mo laye.
Oba Sijuwade ti se bee gborun lo, sangbafo!
Mo ki gbogbo ara Ife ooye lagbo, wi pe won ku
aseyinde oba Sijuwade.

Sebi eyin lomo olodo kan
oteere. Eyi lomo olodo kan otaara.
Odo to san wereke, to san wereke
To dehinkunle oshinle to dabata
To dehinkunle adelawe to dokun
Onikee ko gbodo bu mu
Ababaja won ko gbodo buwe

Ogedegede onisoboro ni yio mu omi do naa gbe
Soboro mi wumi, eje ki ibi dandan maa ba alabe
Won kii duro ki wa nIfe ooni,won kii bere ki wa nIfe
ooye

Ko ga, ko bere laa ki wa nIfe oodaye
Bi won ko si ki wa nIfe, won kii to abere
Oju bintin la fi n wo ni
Emi wa ki oba nIfe,mo lo akun
Oba nii lo sese efun
Adimula,won a ni apalado
Bante gbooro, ni mufe wumi
Segi owo ati tese,
Kafari apakan ka dapakan si
Yeepa orisa, aso funfun
Oun nii mu Ile olufe wumi
Apadari eni,apalado eniyan
Ebo ojoojumo,nii mu ile won su nii lo
Awa lomo oni fitila rebete
Ina ko nii ku nibe tosan toru
Ibe ni baba wa gbe n ka owo eyo
Awa lomo onilu kan, ilu kan
Ti won n fawo ekun se
Aketepe eti erin ni won fi nse osan re
Onikeke ko gbodo jo
Ababaja ko gbodo yese
Kikida onisoboro ni yio jo ilu naa ya
Ogun ko see da gbe
Baba taani ko mo wipe irin ti po lagbede
Oun ti o ba mu alagbede, ko ni mu eni to n fin ina.

www.olayemioniroyin.com/2015/08/ibadan-omo-ajorosun-ohun-to-ye-ke-e-mo.html?utm_source=twitterfeed&utm_medium=twitter&m=1
Culture / Ibadan Omo Ajorosun: Ohun To Ye Ke E Mo Nipa Ilu Ibadan by OlayemiOniroyin(m): 6:38pm On Aug 28, 2015
: ... /1TLgbQ6

Awon Yoruba bo, won ni okun ko le gun gun gun ko
ma nibi to ti wa. Gege bi iwe Oba Isaac Akinyele se so fun wa, nnkan bi senturi kerindinlogun (16 century) ni won da Ìlú Ẹ̀bá-Ọ̀dàn eleyii to pada di Ibadan sile.

A mo nnkan bi odun 1829 ni a le so wi pe iran

Yoruba bere si ni se alakoso ilu naa.
Baale ni oye ti won ti n je ni ilu Ibadan, bi won si se n je niyii titi di odun 1936 ti won yi pada si Olubadan
nigba ti won bere si ni joba.

Oba Isaac Akinyele tun so ninu iwe re, 'Itan Ibadan'
eleyii ti won gbe jade lodun 1911 wi pe apapo awon
jagunjagun lati awon ile Yoruba ti won bori Fulani ni
won koko te ilu Ibadan do leyin ti won le awon Fulani danu sigbo.

Eleyii si wa lara ohun to mu ilu Ibadan je ilu to lagbara ju lo ni akoko naa.
E Je Ka Wo Oriki Ilu Ibadan
Ibadan mesi Ogo, nile Oluyole.
Ilu Ogunmola, olodogbo keri loju ogun.
Ilu Ibikunle alagbala jaya-jaya.
Ilu Ajayi, o gbori Efon se filafila.
Ilu Latosa, Aare-ona kakanfo.
Ibadan Omo ajoro sun.

Omo a je Igbin yoo, fi ikarahun fo ri mu. Ibadan
maja-maja bii tojo kin-in-ni,
eyi too ja aladuugbo gbogbo logun,
Ibadan ki ba ni s'ore ai mu ni lo s'ogun.
Ibadan Kure!

Ibadan beere ki o too wo o, Ni bi Olè gbe n jare
Olohun.


B'Ibadan ti n gbonile bee lo n gba Ajoji.
Eleyele lomi ti teru-tomo 'Layipo n mu. Asejire lomi
abumu-buwe nile Ibadan.


A ki waye ka maa larun kan lara, Ija igboro larun
Ibadan.



E Je Ka Wo Awon Oba To Ti Je Ni Ilu Ibadan
Ba'ale Maye Okunade (1820-1830)
Ba'ale Oluyedun
Ba'ale Lakanle
Bashorun Oluyole 1850
Ba'ale Oderinlo 1850
Ba'ale Oyeshile Olugbode 1851-1864
Ba'ale Ibikunle 1864
Bashorun Ogunmola 1865-1867
Ba'ale Akere I 1867-1870
Ba'ale Orowusi 1870-1871

Are Ona Kakanfo Obadoke Latosa 1871-1885
Ba'ale Ajayi Osungbekun 1885-1893
Ba'ale Fijabi I 1893-1895
Ba'ale Oshuntoki 1895-1897
Ba'ale Fajinmi 1897-1902
Ba'ale Mosaderin 1902-1904
Ba'ale Dada Opadare 1904-1907
Ba'ale Sunmonu Apampa 1907-1910
Ba'ale Akintayo Awanibaku Elenpe 1910-1912
Ba'ale Irefin 1912-1914
Ba'ale Shittu Latosa (son of Are Latosa) 1914-1925
Ba'ale Oyewole Foko 1925-1929

Olubadan Okunola Abass 1930-1946
Olubadan Akere I 1946
Olubadan Oyetunde I 1946
Olubadan Akintunde Bioku 1947-1948
Olubadan Fijabi II 1948-1952
Olubadan Alli Iwo 1952
Olubadan Apete 1952-1955
Oba Isaac Babalola Akinyele 1955-1964
Oba Yesufu Kobiowu July 1964 -
December 1964

Oba Salawu Akanni Aminu 1965-1971
Oba Shittu Akintola Oyetunde II 1971-1976
Oba Gbadamosi Akanbi Adebimpe 1976-1977
Oba Daniel 'Tayo Akinbiyi 1977-1982
Oba Yesufu Oloyede Asanike I 1982-1994
Oba Emmanuel Adegboyega Operinde I (1994-1999)
Oba Yunusa Ogundipe Arapasowu I (1999-2007)
Oba Samuel Odulana Odugade I (2007- titi di akoko
yii)

E ma gbagbe wi pe Ifafiti akoko ni ile Nigeria lale wu
jade ni ilu Ibadan lodun 1948. Ibadan naa si ni ilu to
tobi ju lo ni iwo-oorun ile Afirika. Bakan naa, ko si ba se fe menu ba itan Ibadan ti a ni menu ba "Alaafin Molete", Lamidi Ariyibi Akanji Adedibu, oloselu nla to file boora lodun 2008.

www.olayemioniroyin.com/2015/08/ibadan-omo-ajorosun-ohun-to-ye-ke-e-mo.html?utm_source=twitterfeed&utm_medium=twitter&m=1

www.olayemioniroyin.com
Culture / Igbeyawo Toyin Aimakhu Ti Bere Si Ni Yoro Bi Oori Ti Won Gbe Sinu Oorun Bayii by OlayemiOniroyin(m): 6:22pm On Aug 28, 2015
... /1KdnpYB

Laipe yii ni omobirin naa yo oruko oko re kuro ninu oruko re. Bakan naa ni awon eniyan tun kiyesi wi pe awon foto oko re to wa lori ikanni instagram re lo ti fe e gbonyo tan.


Adeniyi Johnson ti n be iyawo re bayii, o ni oun loun jebi ohun to n fa wahala laaarin awon mejeeji. E le ka alaye re nibi: http://www.facebook.com/photo.php?fbid=881199908632560&set=gm.1037407549643887&type=1


Awon kan ni oko re se asemase kan ni, isele naa si bi Alakada ninu pupo ju.

Awon eniyan kan ti n be Toyin wi pe ko maa binu, nigba ti awon kan n naka abuko si oko re ati gbogbo okunrin gege bi olojukokoro, to je wi pe gbogbo ejo ni jije lodo won.

E tun le ka ohun ti awon ololufe Toyin n so nibi: http://www.facebook.com/photo.php?fbid=881200005299217&set=gm.1037407549643887&type=1

www.olayemioniroyin.com

Culture / Re: Iroyin Lede Yoruba: Tani Okunrin Ti Bimbo Thomas Feran Lati Kiisi? by OlayemiOniroyin(m): 10:54pm On Aug 27, 2015
Babe2sure:
John Dumelo ni o.

Lol
Culture / Iroyin Lede Yoruba: Tani Okunrin Ti Bimbo Thomas Feran Lati Kiisi? by OlayemiOniroyin(m): 10:40pm On Aug 27, 2015
"Oserekurin Ti Mo Fe Lati Je Ete Re Ni...": Tani Okunrin Ti Bimbo Thomas Feran Lati Kiisi? http:///CvZEee4IS3

(1) (2) (3) (4) (5) (of 5 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 111
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.