Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,155 members, 7,835,848 topics. Date: Tuesday, 21 May 2024 at 04:12 PM

Oluokunoluwole's Posts

Nairaland Forum / Oluokunoluwole's Profile / Oluokunoluwole's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 11:15pm On Mar 10, 2016
Ifankaleluya:



ERO-ABILU PE ORISI-RISI.....ADURA MI NI WIPE KI OLORUN MA JE KI E BO SI OWO(HAND) BABALAWO TI O NI EKO(KNOWLEDGE) DAADA. TORI KIN-NI KAN WA TI A N PE NI AKOFA(NEUTRALISES OF CHARMS OR MEDICINE IN SOMEONE's BODY), KINNI YI NI BABALAWO TO BA LEKO DAADA MA N KOKO SE LATI FI BA OGUN TO WA LARA ENIYAN JE TO BA FE BA ENIYAN JA. AASAN(gbolohun) RE WA, WON SI MA N SA OMIRAN LORI ESU PELU AWON EWE-IFA KAN.


SUGBON JU GBOGBO E LO, TI E BA TI RI OMO-OWU KI E KAN SI MI.
Baba eku ise opolo ejowo efunmi ni oogun yi lori email/oluokunoluwole4@gmail.com.eseun

KIISE OGUN TI MO LE FI SILE LORI FANRAN YI.

1 Like

Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 4:50pm On Mar 10, 2016
Ifankaleluya:


IFA-ISOYE TI O MA N JE GBOGBO OHUN TA BA KA KO DURO SIKUN WA LOKOKAN.


E LO RE WA IGBA-AHUN, ATI IKARA-HUN IGBIN.

AO JO MEJEEJI PAPO, AO LO

KO NI ATAARE NINU OO

AO WA TE NI IFA OFUN-SE (OFUN LOWO-OTUN ATI OSE LOWO-OSI) NI A N PE BAYEN

AO WA PE IFA RE SI BAYI

MO DE IBI WON TI N MUMI OGBON(WISDOM) MO BA WON MU

MO DE IBI WON TI N GBAMON-RAN IMO MO BA WON GBA

ADIFA FUN ORUNMILA NIJO TI N LORE KO MO-IFA, TI N LORE KO OGUN MO-OGUN

WON NI BAWO NI O SE NI GBAGBE

IFA NI EEWO-ORISA IGBIN KII-FA KO GBAGBE IKARA-HUN

BEENI AHUN KIIFA KO GBAGBE IGBA-EYIN RE

WON NI TI O BA GBAGBE BAWO NI O SE NI WO'NU ARA WON

ORUNMILA NI EEWO ORISA IGBIN KII-FA KO WO'NU AHUN

BEENI AHUN KIIFA KO WO'NU IGBIN

OFUN-SE FUN MI NIYE TEMI KI N MU SAWO.

AO MA FI MU EKO-TUTU.

BI WON TI MA N SE NIYEN, E LE TUN BERE LOWO BABALAWO MIRAN TI O BA MO IFA YEN.
E seun gann ni eku agba,baba se die ninu igba eyin ijapa ni abi odidi re ati odidi ikarahun igbin ni.e se pupo
ELA-BORU, ELA-BOYE, ELA-BOSISE.
Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 4:46pm On Mar 10, 2016
Ifankaleluya:


IFA-ISOYE TI O MA N JE GBOGBO OHUN TA BA KA KO DURO SIKUN WA LOKOKAN.


E LO RE WA IGBA-AHUN, ATI IKARA-HUN IGBIN.

AO JO MEJEEJI PAPO, AO LO

KO NI ATAARE NINU OO

AO WA TE NI IFA OFUN-SE (OFUN LOWO-OTUN ATI OSE LOWO-OSI) NI A N PE BAYEN

AO WA PE IFA RE SI BAYI

MO DE IBI WON TI N MUMI OGBON(WISDOM) MO BA WON MU

MO DE IBI WON TI N GBAMON-RAN IMO MO BA WON GBA

ADIFA FUN ORUNMILA NIJO TI N LORE KO MO-IFA, TI N LORE KO OGUN MO-OGUN

WON NI BAWO NI O SE NI GBAGBE

IFA NI EEWO-ORISA IGBIN KII-FA KO GBAGBE IKARA-HUN

BEENI AHUN KIIFA KO GBAGBE IGBA-EYIN RE

WON NI TI O BA GBAGBE BAWO NI O SE NI WO'NU ARA WON

ORUNMILA NI EEWO ORISA IGBIN KII-FA KO WO'NU AHUN

BEENI AHUN KIIFA KO WO'NU IGBIN

OFUN-SE FUN MI NIYE TEMI KI N MU SAWO.

AO MA FI MU EKO-TUTU.

BI WON TI MA N SE NIYEN, E LE TUN BERE LOWO BABALAWO MIRAN TI O BA MO IFA YEN.

ELA-BORU, ELA-BOYE, ELA-BOSISE.
Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 3:16pm On Mar 10, 2016
Ifankaleluya:
[color=#990000][/color]


Ogun-aanu ni ogun yen, sugbon kope. Ewe-ominsinmisn gogoro ati ewe-aanu, pelu eran ike-maalu, ti e ba ti gun tan,oti-shnap ni a o fi po, ao ko sinu igba-funfun tabi ike-funfun, ao wa tu bintu si, ao wa fi eran ike-malu yen gun lori. Lo ba tan!baba se omisinmisin pe meji ni ewo ni gogoro ejowo e se alaye re fun mi atipe se ale lo oye lux lati fi po oogun yi ifa agbe wa oooo

Ela-boru, ela-boye, ela-bosise.

1 Like

Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 2:40pm On Mar 10, 2016
Ifankaleluya:



mo ti fi esi ranse si e-mail yin. Bi e ba ti se, be ni o ri tori tokan-tokan ni mo fi yonda ifa yen fun yin.
baba kilode ti mo email yin ti e o funmi lesi ohun ti mo bere fun,mobeyin e damilohun awon nkan ti mo bere fun ifa agbeyin oo
Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 9:14am On Mar 06, 2016
healthFirst:
141

IFA IWE ISE ATI OSI DANU
I I
II II
I. II
II. II OBARA DAGISE NU
Egbo akoko ewe re, epo re gbogbo re lara igi kan ao gun pelu ikode kan ao pomo ose dudu ti a ba fe lo ao te nifa OBARA DAGISE NU sori iwon ba ti a fe lo, ap wa pe ofore si.
OFO RE: Mo da sasa awo ile ogbo, mo wewe, mo we osi danu, awo eriki odan. O difa fun Orunmila ni ojo ti awon oso ati aje ngbero wipe awon yio di oran si orunmila lorun orunmila ni e kole di oran simi lorun Woni iwo orunmila jeka wo ohun ti awon kofi ni ledi oran si o lorun, orunmila ni ojo ti omode bati ja ewe pegunrun tosi wa egbo pegunrun ni gbogbo ohun ti o ba n se ni buburu yio pada leyin re emi__omo_moti jawe pegunrun mosi wa egbo re loni gbogbo ohun buruku ti o ba n se mi ko pa da leyin mi....ao wa fi we ao si sun kehikehin
re nina
eku ise opoplo,ejowo ema binu si ohun ti mofe so yi oo.se igi pegunre ni abi igi akoko toriwipe ofo ti e ko si isele yi pegunre ni eko sibe,koyemi ni oo loje ki nbere ifa agbewa ooo
Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 11:20am On Feb 29, 2016
Ifankaleluya:
IFA-ISOYE

ODIDI OROGBO KAN, ODIDI ATAARE KAN, OBI-ABATA OLOJU MERIN KAN, EJA-ABORI KAN, EWE-ONIYEMIYE,EWE-EERAN ATI EWE ATORI. AO GUN PAPO TI YIO KUN NA DADA BI AGUNMU,AO WA TE NI ODU-IFA OLOGBON-MEJI,AO WA PE IFA RE SI

IFA RE: sabe lawo sade, asa lawo asagede,arara abori patoki awo ile orunmila, lodifa fun orunmila nigba ti baba nsawo ti ko ni iye ninu, ifa ni to ba bi ise tohun(to ba se bi ise temi lagbaja omo lagbaja ba ni. Ni e ma lo larin yen) ba ni, ifa ni iye-orogbo kiiku mo orogbo ninu ka je ko ma le koro,iye obi kiiku mo obi ninu ka so ko ma le yan,iye ataare kiiku mo ataare ninu ka je ko mo le ta ni lenu, eyi ti mo jaja gbagbe eja loni ko ja simi ninu,eeran loni kin ma ranti, atori loni ko to nikun mi worowo,ipanan merindinlogun ni ewe-oniyemiye ma n ni,gbogbo ara ni fi so. Ologbon-meji fun mi ni iye temi kin gbon sara-sara. AO MA FI MU EKO-TUN DIE-DIE.
NOTE
mo fi ifa yi sile fun iwulo awon eniyan ni. Ti iwo ti o n ta iwe ba ko sori iwe-re,lagbara lowo eledumare wa ri ija awon eleye. Mo fi odu-mererindinlogun bura.

FUN IMONRAN TABI OHUNKOHUN, E KAN SI WA LARI ifankaleluya@gmail.com
Ela boru, Ela boye, Ela bo sise.
eku ise opolo eledua a ran yin lowo,ti eba ni orisi isoye miran ebawa fi sita
Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 11:39am On Jan 01, 2016
Shomar:
Inu mi dun bi mo se wo gbogbo ohun ti o wa lori ikani yi. O wu mi lati fi kun, sugbon mi o ri ohun ti ko si nibi. A mo enikeni le bere ohun ti o ba je tuntun to fe. Mo se ileri pe awon baba ma gbami laye lati fun yin. Iba eyin baba teni ile awo yi o o o. Eyin na ni mo ni ke gbami laye.
ekaro ejowo mo nilo bibo asiri alaseje to gbona gidi ti koni eran ajiyo sugbon ti o nje bi idan,ekeji oogun ti awon customer fi ma ngbe ise fun ni ti onje gidi sugbon ti koni eran ajiyo.eseun gan ni
Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 2:46pm On Dec 12, 2015
healthFirst:
113

ATUWÓ
Ewe Ódan,
Ewe Tude
Egbo Tude,
Ao gun Awon ewe yi papo mo osé dudu ao ma we pelu agbo ré ni agogo mewa ale 10pm.. ao té aso funfun silé; ori é ni a ma duro si ti aofi wé tan....
Agboré;
Ewe Iyalode pupa ati funfun, Ewe ajeobale, Ewe akoko ao se lagbo ao ma fi wé ose okeyi.. ni alalé nio
se aso eyokan naa lao ma te sile ni abi eyokan fun ojo kan atipe se ti abawe ose naa tan la o ma lo mu aso naa kuro ni,ojo melo ni a o fi we agbo naa,ejowo e se alaye re fun wa.agba yin adale

2 Likes

Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 10:54pm On Dec 11, 2015
healthFirst:


Beeni...won yio ma di oko re lowo, won le fa aisan si lara...o tun seese ki iru okunrin bee ma le se deede gege bi okunrin lodo iyawo re. wahala nla ni. ki iru eni be mura gidi ni o.
baba kini iru eni bee lese aburu o ni kan yin
Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 11:10pm On Dec 09, 2015
Baba healthfirst se eniti iyawo re ni oko orun emere,se oko orun le maa fa ifaseyin fun oko aye re ni,ti o bari bee,kini eeyan lese si.eran wa lowo oo
Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 10:51pm On Dec 05, 2015
Won ni ki nru ebo fun awon agba ati omo emere kan ti moferi erami lowo
Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 10:48pm On Dec 05, 2015
Baba moti se iwadi tele,ejowo eran mi lowo
Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 3:08pm On Dec 05, 2015
healthFirst:
beeni baba,won ni ki nru ebo fun awon aye ati fun omo emere kan ti mo feri

Se e ti se iwadi ti won ti so fun yin pe Etutu ni ke lo se? Ni opolopo igba, o ye ki a beere lowo Ifa lati mo iru Etutu pato ti won yio gba lowo yin...opolopo igba ni o je wipe bi ao ba se iwadi ti a kan lo se Etutu, won o ni gba. Ma gba yin niyanju lati lo se iwadi ki e to soro nipa Etutu.

1 Like

Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 11:06pm On Dec 04, 2015
Ejowo baba healthfirst kadunasouth mo nilo bi eeyan sele se ipese etutu ebe awon agba,e ran mi lowo ooooo
Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 2:22pm On Dec 04, 2015
Baba healthfirst ejowo mo nilo oogun isoye to daju,olorun a ranyin se
Culture / Re: .. by Oluokunoluwole: 2:20pm On Dec 04, 2015
lawani:
E ku ise opolo o. Olodumare a ma ran yin lowo o. Ase Edumare.
ejowo mo nilo oogun isoye to gbona

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 32
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.