₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,330,450 members, 8,445,511 topics. Date: Wednesday, 15 July 2026 at 08:04 AM

Toggle theme

Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán - Culture (5) - Nairaland

Nairaland ForumNairaland GeneralCultureÀwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán (9453 Views)

1 2 3 4 5 6 7 8 Reply (Go Down)

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 9:57pm On Nov 09, 2023
Adìyẹ Odò — Kiwi

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 10:04pm On Nov 09, 2023
Agánrán — Senegal parrot, Green parrot

Popular Proverb :
1. Agánrán tó bímọ sílẹ̀ tí kò ní ìkà, ọmọ tirẹ̀ kọ́, ọmọ ẹlòmíràn ni.

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 10:18pm On Nov 09, 2023
Ìkóódẹ — African Grey parrot

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op):
Ọ̀pẹ́ẹ̀rẹ̀ — Bulbul

Popular saying:
1. O ùn sọ òyìnbó bi Ti Ọ̀pẹ́ẹ̀rẹ̀

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op):
Ẹiyẹ Omi — Flamingo

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 8:25am On Nov 10, 2023
Reserved
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 8:29am On Nov 10, 2023
Still reserved
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 8:30am On Nov 10, 2023
Reserved for birds
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 8:37am On Nov 10, 2023
Reserved-
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 8:42am On Nov 10, 2023
Reserved
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 4:06pm On Nov 10, 2023
Ìrẹ̀ — Cricket

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 4:23pm On Nov 10, 2023
Ẹ̀fọn/Yànmù-yánmú — Mosquito

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 4:24pm On Nov 10, 2023
Ẹ̀ka/Àkányín — Black Ant

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op):
Ìjàlọ/Èèrùn — Soldier Ant

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 4:37pm On Nov 10, 2023
Èèrà

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 4:44pm On Nov 10, 2023
Kòkòrò Sugar

Well I don't know the precise name for this in Yoruba, I'm trying to make some research if it has a name in Yoruba, and If it doesn't, I'll give it a name!

But for now, Let's call it "Kòkòrò Sugar"

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 5:03pm On Nov 10, 2023
Ìdun — Bedbugs

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 5:05pm On Nov 10, 2023
Èkùọ́ — Beans weavil

Popular Saying:
1. Èkùọ́ L'alábàkú Ẹ̀wà

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 11:48am On Nov 13, 2023
Ikán — Termite.
Òkìtì Ọ̀gán — Termite Mound


I don't know why my post keep getting removed by the Bots, I haven't done anything wrong, Lalasticlala, Myndd44 Seun pleas do something!

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by caye(m): 9:05am On Nov 14, 2023
Raydos:
Ikún — Ground squirrel
Ikun n j'ọgẹdẹ, / ikun is eating a banana
Ikun n re'di, / Ikun shakes her behind joyfully
Ikun o mọ wípé / ikun doesn't know that
oun to dun/ what sweetens one
nii n pa ni
/ could end up killing oneself
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by dominique(mod): 11:25am On Nov 14, 2023
Your hidden posts are now visible, stop spamming front-page topics please
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:32pm On Nov 14, 2023
Iná-Orí — Lice

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op):
Esunsun/Ilé Esun/Ibà — Flying termite

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:49pm On Nov 14, 2023
Eṣinṣin — Housefly

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Zimri(m): 1:06pm On Nov 14, 2023
Raydos:
Iná-Orí — Lice
WTF grin
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:09pm On Nov 14, 2023
Agbọ́n — Wasp

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:10pm On Nov 14, 2023
Oyin — Bee

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:12pm On Nov 14, 2023
Alábọ̀nbọ̀n/Lábọ̀nbọ̀n — Bumblebee

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:21pm On Nov 14, 2023
Aáyán — Cockroach

Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:22pm On Nov 14, 2023
Labalábá — Butterfly

1 2 3 4 5 6 7 8 Reply

Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní YorùbáÌsàmì (labelling) Ní Èdè YorùbáÀwọn Èso Ati Irúgbìn Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Awòrán234

Why Is Bleaching Considered Especially Bad?8. Odu Okanran Meji- Be Ready To Take Up Challenges.Enu Ani (ndokwa ,ukwani Or Aniocha) Sons And Daugthers