₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,326,255 members, 8,425,712 topics. Date: Friday, 12 June 2026 at 11:28 PM

Toggle theme

.. - Culture (12) - Nairaland

Nairaland ForumNairaland GeneralCulture.. (1882978 Views)

1 2 3 ... 9 10 11 12 13 14 15 ... 99 Reply (Go Down)

Re: .. by kadunasouth(m): 4:56pm On Jun 26, 2015
OGUN OWO ARA MOTOR ILE OKO
Ao pa omole kan ti konige ni ibikankan ao wa atare to gbo ao kibo inu omin ao wa fi blade la ao yo atare inure kuro ao wa fi omole yi ropo sibe ao we lowu dudu ati funfun ao mafi sara to bawa larawa aburukan koni koluo owo gidini toba wa lara ile ole koniwo ile na tobawa lara motor ole konigbe besini koni ni accident pelu ase oloun togaju oloun lalagbara
Iba eyin agba gbao!
Re: .. by gawab: 6:33pm On Jun 26, 2015
healthFirst:
52 IKO FE
Ao je koro ibepe a o gbemi, kia ma je ayu ati orisirisi eso bi osan, ibepe ati beebe lo.
E jowo ogun wo ni enia le lo ti gege ofun yio fi lo patapata.
Yio ma ju yin se o.
Re: .. by pappykay0428(m): 12:52am On Jun 27, 2015
healthFirst:
Awa o ki se Awo Ika... ki lo de to fi je wipe awon oogun ija le n wa? Kini e fe fi won se?
Ko e kin se awo ila sugbon nkan ti won pe ni Yoruba,ti a ko de ba se a to do oun I gbagbe.
Re: .. by pappykay0428(m): 12:57am On Jun 27, 2015
healthFirst:
52 OOGUN KI OLE TABI AYE MA FOJU SI MOTOR WA LARA

E wa suku agbado ori akitan, ki e wa ewe eko ori akitan, ki ewa fi ewe eko yen we suku agbado ki eto di ni ikobere... ki ewa fi sinu moto abi nkan ti e fe kan ji... Iba agba ni mo se.

E kan si mi fun Ogidi Oogun Owo ti kii le je ki ole ji motor wa.
E jowo ise wo ni eyan lese ti yin o fi pade alanu tiree ,Eni ti yin o se lore...Aboru boye oo
Re: .. by kadunasouth(m): 4:09pm On Jun 27, 2015
OGUN IKORIRA ati ITUSILE
Ao wa eyin ororo adie wa bora si ihoho omo luabi wa ma fi nu gbogbo arare pelu adua sise gbogbo isoro igbese ayere wase fun bi iseju marun wawa wo ewure pada walojusi ori akitan tabi orita meta tobati ju okogbodo soro siyan tabi koboju weyin toma fi wole re pada danwo okere sugbon olagbara pupo
Adurawa yio gba o!
Re: .. by gawab: 5:01pm On Jun 27, 2015
kadunasouth:
OGUN IKORIRA ati ITUSILE
Ao wa eyin ororo adie wa bora si ihoho omo luabi wa ma fi nu gbogbo arare pelu adua sise gbogbo isoro igbese ayere wase fun bi iseju marun wawa wo ewure pada walojusi ori akitan tabi orita meta tobati ju okogbodo soro siyan tabi koboju weyin toma fi wole re pada danwo okere sugbon olagbara pupo
Adurawa yio gba o!
Kini ale lo si gege ofun?
Re: .. by avsnet: 9:20pm On Jun 28, 2015
healthFirst:
7. ITAJA \AFERO
ODI-IKA
! !
!! !!
! !!
! !
Oni dandan l'aa difa Ile Ado, Oganjo ola laa gbabo lale Ife.
Ojo meje oni gbungbun laa gbohun Alajogun.
Oun ni Orunmila da nigbati o daja, tiko ri eni baa naa.
Ti nwon ni awon ko ni ba'fa se l'Otu-Ife.
Orunmila ni iro ni nwon npa, eke niwon nse!.
"Nse ni aa da gijan jingbo, nse ni aa da tete jin aatan.
Nse ni aa da gbodogi jin eleko.
Oni ero igbara, ero igboro tiwon l'awon o ba'fa se,
"Gbooro, ewon maa wo won bo, gbooro".
O ni Ina loni kiwon wa bami na.
Ira l'oni kiwon wa ba mi ra.
Iru l'oni ki won o maa ru wa.
Ogiri l'oni kiwon o maa dawa girigiri.
Obalufon Ife l'oni kiwon o maa ya wa sodo mi.
Nje gbogbo eni ti nwon l'awon o ba ifa se,
Gbooro, ewon maa wo won bo.
Gbooro!.

Ao fi Iyerosun te'fa odi-Ika, ao pe ayajo yi sii, ao fe danu siwaju ninu Ile Itaja wa.
E jowo e se atunyewo odu ifa ODI IKA to wa pelu gbolohun yi. Ifa ODI se regi, sugbon ti odu IKA yato is ohun ti e te jade sibi. Se ohun odu ti e te jade yi ni ki a tele abi odu IKA eyi tii se ojulowo gangan? E seun o, isese a gbe wa o. Ase.
Re: .. by nathpope(m): 5:39am On Jun 29, 2015
following.
Re: .. by Nobody: 7:17pm On Jun 29, 2015
avsnet:
E jowo e se atunyewo odu ifa ODI IKA to wa pelu gbolohun yi. Ifa ODI se regi, sugbon ti odu IKA yato is ohun ti e te jade sibi. Se ohun odu ti e te jade yi ni ki a tele abi odu IKA eyi tii se ojulowo gangan? E seun o, isese a gbe wa o. Ase.
Hmmm...Rara o...Odi-Ika la pee kii se adape Odi tabi Ika nikan...e lo wo Odu mejeei yi...apapo won la lo fun gbolohun yen.
Re: .. by Nobody: 7:19pm On Jun 29, 2015
pappykay0428:
E jowo ise wo ni eyan lese ti yin o fi pade alanu tiree ,Eni ti yin o se lore...Aboru boye oo
Eyonu ti wa lorisirisi lori abala yi, e gbiyanju ki e pada sehin die, e o ri awon ojulowo Eyonu ta ti fi sita.
Re: .. by Nobody: 7:21pm On Jun 29, 2015
pappykay0428:
Ko e kin se awo ila sugbon nkan ti won pe ni Yoruba,ti a ko de ba se a to do oun I gbagbe.
Beeni sugbon kii se lori afefe...orisirisi eeyan lo wa ti a ko mo iwa won...bi ao ba sora ao gbe agbara fun eni ti ko ye.

Awon Oogun wonyi po to si daju daada sugbon bee na lawon janduku eeyan wa lori afefe.
Re: .. by Nobody: 7:22pm On Jun 29, 2015
gawab:
E jowo ogun wo ni enia le lo ti gege ofun yio fi lo patapata.
Yio ma ju yin se o.
E koko lo se iwadi re na.
Re: .. by 2rez: 8:47pm On Jun 29, 2015
Ekun ise takun takun o... Oluwa yio ma so agbara dotun, amin. Ejowo mo fe bere fun ogun IDAKOLE. Ese sir.
Re: .. by idrisalomagold(m): 10:54pm On Jun 29, 2015
healthFirst:
Mo n bo.
Ejowo e o mai ti dahun ibeere temi. Oogun tabi egboogi tabi ohunkohun ti o le mu nnkan omokunrin tobi daadaa.
Re: .. by Nobody:
x
Re: .. by Nobody:
x
Re: .. by Nobody: 6:45pm On Jun 30, 2015
BELEJE

E teti beleje o,
ke gbohun tawo o gbodo se,
Awo kiiparo o.
Awo kiidale awo.
Awo kiisan bante awo egbe re o.
Egbe re laake o.
Eegbe re looko o.
Egbe re lola.
Tofi dele owa orangun olomo.
Oogboye o!.
Re: .. by idrisalomagold(m): 6:48pm On Jun 30, 2015
healthFirst:
OOGUN ALEKO
ori eJo sebe kan, ori alabahun kan. odidi Atare kan, ao Jo papo, ao wa lo ebu ogun po mo etu ibon gidi, ao ma fi fo eko tutu mun.

Sugbon eto itoju to muna doko wa fun ohun te beere sugbon kii se inkan ta le fi sori afefe. Orisi eto meta wa ti a ma n se ni sise n tele fun inkan omokunrin to ba kere tabi ko sise daada. E kan si mi lori e-mail...sugbon kii se ofe o.
Ese gan ni. Sugbon mi o mo ejo sebe rara. Ati wipe, emi lero wipe e maa bami wa eyi ti mo maa re si inu omi tutu tabi 7up ti mo ma yo mu. Ti mo ba n wa ori ejo kiri timo tun jo oogun po. Ara ile mi a so mi di Aroni tabi Egbeji. Sugbon fun ikeji ti e so yen, mo maa kan si yin laipe yi.
Re: .. by idrisalomagold(m): 7:32pm On Jun 30, 2015
healthFirst:
OOGUN ALEKO
ori eJo sebe kan, ori alabahun kan. odidi Atare kan, ao Jo papo, ao wa lo ebu ogun po mo etu ibon gidi, ao ma fi fo eko tutu mun.

Sugbon eto itoju to muna doko wa fun ohun te beere sugbon kii se inkan ta le fi sori afefe. Orisi eto meta wa ti a ma n se ni sise n tele fun inkan omokunrin to ba kere tabi ko sise daada. E kan si mi lori e-mail...sugbon kii se ofe o.
Arakunrin mi 'Healthfirst' ejowo kinni email yin? Mo gbiyanju lati wo 'profile' yin sugbon mi o ri email yin. Atiwipe mo nilo lati kan si yin tori awon ohun ti mo ni lati salaye fun yin lori iranlowo ti mo n fe. E seun gan.
Re: .. by Nobody: 10:44pm On Jun 30, 2015
idrisalomagold:
Ese gan ni. Sugbon mi o mo ejo sebe rara. Ati wipe, emi lero wipe e maa bami wa eyi ti mo maa re si inu omi tutu tabi 7up ti mo ma yo mu. Ti mo ba n wa ori ejo kiri timo tun jo oogun po. Ara ile mi a so mi di Aroni tabi Egbeji. Sugbon fun ikeji ti e so yen, mo maa kan si yin laipe yi.
Erin n pa mi o! kekekekkee!...Egbeji...o da bee.
Re: .. by scholes0(m): 10:47pm On Jun 30, 2015
O ti pe to mo ti dahun lori owu yii....
Sugbon E ku ise takuntakun, Ogbeni Onisegun.
Re: .. by idrisalomagold(m): 11:03am On Jul 01, 2015
healthFirst:
Erin n pa mi o! kekekekkee!...Egbeji...o da bee.
Erin n pa emi na. Mo ri leta ti e ko sori 'email' mi, mo si ti da esi re pada. Ejowo e wo email yin. Ma maa reti esi. A dupe gan o.
Re: .. by avsnet: 2:28pm On Jul 01, 2015
healthFirst:
Hmmm...Rara o...Odi-Ika la pee kii se adape Odi tabi Ika nikan...e lo wo Odu mejeei yi...apapo won la lo fun gbolohun yen.
E seun e ku ifesi si oro mi. Sugbon o dabi wipe ohun ti mo nso ko ye yin to, e je ki ntun alaye mi se.

ODI
!
!!
!!
!

IKA
!!
!
!!
!!

OTURA
!
!!
!
!

ohun ti e te jade gegebi ODI-IKA kii se ODI IKA bikose wipe ODI-OTURA ni, e bawa se atunyewo nipa wipe;

1. Se Odu ODI IKA ni ka ma te gegebi o se to ati botiye fun ohun yi, abi;

2. Se Odu ODI OTURA ti e te si oju ewe yi (eyi ti e pe ni ODI IKA) ni ka ma te fi pe gbolohun yi.

Odara ki a tete se atunse arin yin, ni mo se ntenumon.

E seun, mo dupe lekan si. Ogbon ati Imon yin ko ni dobu. Ase!
Re: .. by 2rez: 4:41pm On Jul 01, 2015
healthFirst:
OOGUN ALEKO
ori eJo sebe kan, ori alabahun kan. odidi Atare kan, ao Jo papo, ao wa lo ebu ogun po mo etu ibon gidi, ao ma fi fo eko tutu mun.
Ese fun esi yin. E derin pami lori oye ti eko si email ti e fi ran se si mi. Owo yen gara gan ni o,lol. Ewo ni ejo sebe ati pe se oni iran lowo te le se fun mi lori wi wa awon ohun elo yon yi? Lai foro gun, mo ma da esi pada si email yin. Eku ise takun takun
Re: .. by sammyjay76(m): 10:03pm On Jul 01, 2015
healthFirst:
OOGUN ALEKO
ori eJo sebe kan, ori alabahun kan. odidi Atare kan, ao Jo papo, ao wa lo ebu ogun po mo etu ibon gidi, ao ma fi fo eko tutu mun.

Sugbon eto itoju to muna doko wa fun ohun te beere sugbon kii se inkan ta le fi sori afefe. Orisi eto meta wa ti a ma n se ni sise n tele fun inkan omokunrin to ba kere tabi ko sise daada. E kan si mi lori e-mail...sugbon kii se ofe o.
EJOWO FUN WA NI OGUN ARA DIDA SHAKA NINU EGUNGUN TABI KI O TETE MA RE ENIYAN NINU EGUNGUN KO MA LE DURO PE PATAKI FUN EGUNGUN.
ESE
Re: .. by TrueProfits:
hmmm
Re: .. by TrueProfits: 6:55pm On Jul 02, 2015
hmmm
Re: .. by Nobody: 11:01am On Jul 03, 2015
avsnet:
E seun e ku ifesi si oro mi. Sugbon o dabi wipe ohun ti mo nso ko ye yin to, e je ki ntun alaye mi se.

ODI
!
!!
!!
!

IKA
!!
!
!!
!!

OTURA
!
!!
!
!

ohun ti e te jade gegebi ODI-IKA kii se ODI IKA bikose wipe ODI-OTURA ni, e bawa se atunyewo nipa wipe;

1. Se Odu ODI IKA ni ka ma te gegebi o se to ati botiye fun ohun yi, abi;

2. Se Odu ODI OTURA ti e te si oju ewe yi (eyi ti e pe ni ODI IKA) ni ka ma te fi pe gbolohun yi.

Odara ki a tete se atunse arin yin, ni mo se ntenumon.

E seun, mo dupe lekan si. Ogbon ati Imon yin ko ni dobu. Ase!
E seun fun afiyesi, Odi-Ika ni ifa yen sise pelu.
IKA
!!
!
!!
!!
Re: .. by KEHINDE633(m): 10:09pm On Jul 03, 2015
[color=#000099][/color] Iba akoda, iba aseda, iba omode ile, iba agba ile, iba oja to kun tio lero, iba
Re: .. by KEHINDE633(m): 10:14pm On Jul 03, 2015
[color=#000099][/color]

Re: .. by KEHINDE633(m): 10:17pm On Jul 03, 2015
OGUN IKORIRA ati ITUSILE Ao wa eyin ororo adie wa bora si ihoho omo luabi wa ma fi nu gbogbo arare pelu adua sise gbogbo isoro igbese ayere wase fun bi iseju marun wawa wo ewure pada walojusi ori akitan tabi orita meta tobati ju okogbodo soro siyan tabi koboju weyin toma fi wole re pada danwo okere sugbon olagbara pupo Adurawa yio gba o!
1 2 3 ... 9 10 11 12 13 14 15 ... 99 Reply

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From GhanaHow Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo?Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re234

Viewing this topic: 1 guest(s)