Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,157,903 members, 7,835,017 topics. Date: Tuesday, 21 May 2024 at 12:57 AM

.. - Culture (56) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1831202 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (53) (54) (55) (56) (57) (58) (59) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by cancioamor: 11:27am On Feb 17, 2016
number mi re ooo. 008079869007 .. mo juba agba
Re: .. by elegushichilling: 12:52pm On Feb 17, 2016
healthFirst:
.
ejowo baba healthfirst, ejowo efesi si ibere mi nitori olorun.
Re: .. by elegushichilling: 1:01pm On Feb 17, 2016
healthFirst:

E beere lowo awon elewe omo. Inu Okiti Ogan ni won ti man ri Olu Ogan...Ikan ni sugbon isale patapata lo ma n wa, o soro lati ri die.

won niwipe won tun ma'un pe ni itun.
Re: .. by Nobody: 4:21pm On Feb 17, 2016
elegushichilling:

won niwipe won tun ma'un pe ni itun.

Itun ko o...Itun yato si Olu Ogan...Inu Igi Ope Oguro to ti ke ni won ti ma n ri itun...inu Okiti Ogan ni Olu Ogan wa.

1 Like

Re: .. by Nobody: 4:31pm On Feb 17, 2016
Iwo to pe ara re ni Alfa, to wa nilu Badagry, ti a fi iwe ranse si o lehin to fi Olun se leri wipe iwo yio fi iyoku owo ranse sugbon lehin igba ti iwe te e lowo tan, ao gburo re mon, benikan o ri o, ranti wipe Oba Orun n wo o. Iwe to wa lowo re ko le se e ni anfani kankan...emi lo wi bee. Ko si Ogun kankan to ma jise fun e ninu iwe yen ayafi to ba fi iyoku owo mi ranse. Ase gun.
Re: .. by belatoxx: 4:34pm On Feb 17, 2016
Babahealthfirst ejowo e fun wa ni ogun ero agbana ....Ti agbana ban da eyan lamu ki ni o le lo... Ese pupo
Re: .. by Naturewonders: 5:28pm On Feb 17, 2016
healthFirst:
Iwo to pe ara re ni Alfa, to wa nilu Badagry, ti a fi iwe ranse si o lehin to fi Olun se leri wipe iwo yio fi iyoku owo ranse sugbon lehin igba ti iwe te e lowo tan, ao gburo re mon, benikan o ri o, ranti wipe Oba Orun n wo o. Iwe to wa lowo re ko le se e ni anfani kankan...emi lo wi bee. Ko si Ogun kankan to ma jise fun e ninu iwe yen ayafi to ba fi iyoku owo mi ranse. Ase gun.
hahaa.....Atoni ni suuru ma ni awon eyan o.etun ti gbe ogbon jibiti ati yahuyahu de ori eto omoluabi wa.iru yin ma fi iwa yin dena elomiran ni.abi se ese ni lati gba omolakeji re gbo ni.fun idi iyi mo ro onitoun lati se apology ati atuns.Eni kankan wa oni si see o.
Re: .. by Naturewonders: 5:42pm On Feb 17, 2016
Eyin ti en post ogun ayederu te jiko ninu iwe oniwe.Ejowo ewo ipa ti o lonka ti blog yi ko ninu aye awon eyan ki e dawo re duro.Puro niyi abuku lon mu wa
Re: .. by simpleworld: 9:41am On Feb 18, 2016
baba healthfirst this book is how much? Omo Yoruba ni mi
Re: .. by Nobody: 8:45am On Feb 19, 2016
simpleworld:
baba healthfirst this book is how much? Omo Yoruba ni mi

E kan si mi lori whatsapp
Re: .. by Nobody: 8:51am On Feb 19, 2016
OJU ODU

2 Likes

Re: .. by Naturewonders: 12:32pm On Feb 19, 2016
healthFirst:
OJU ODU
Ejo baba odu wo ni won pe ni ese kan ola.
Re: .. by Nobody: 9:41pm On Feb 19, 2016
x

2 Likes

Re: .. by Nobody: 9:52pm On Feb 19, 2016
healthFirst:
Iwo to pe ara re ni Alfa, to wa nilu Badagry, ti a fi iwe ranse si o lehin to fi Olun se leri wipe iwo yio fi iyoku owo ranse sugbon lehin igba ti iwe te e lowo tan, ao gburo re mon, benikan o ri o, ranti wipe Oba Orun n wo o. Iwe to wa lowo re ko le se e ni anfani kankan...emi lo wi bee. Ko si Ogun kankan to ma jise fun e ninu iwe yen ayafi to ba fi iyoku owo mi ranse. Ase gun.
.
Re: .. by auggswell: 11:04pm On Feb 19, 2016
healthFirst:
135
OGUN OYUN IJU
Isu alubosa were
Kanhun bilala
Odindi atare 3
Iru
Aidan
Ewe omisinmisin
Bakaa
Aogun papo yiokunna, aodasi inu omi orombo were, yomaamu Ni GAASI kookan Ni aaro ki otojeun, leyin21days ki o lo ya scan, pelu ogo oloun yio ti poora.

e SEUN gidigan baba health first fun ise takuntakun yin , please sir, se aidan toro ni tabi Aidan onigun
Re: .. by dmjznth: 6:07am On Feb 20, 2016
Igba!!! Aku Owuro Ni Thread Yio,ejo Ki Eniyan Ba La Ala Wipe Oun Nje Nkan Lati Inu Igbonse Tio Jade Lati Oju Ara Oun.Kilo Nfa Ati Kini Kio Ose?Eyi Agba.
Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:19am On Feb 20, 2016
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ajuwase'o
Re: .. by marv006: 12:55pm On Feb 20, 2016
healthFirst:
116

BI AYE BA DE EEYAN MOLE
Odindi Aaye Okete kan, ao gun ninu Odo pelu Ata Ijosi die ati Eepo Obo die pelu Ose dudu. Ao maa we ninu Apere ajadi fun ojo meje pelu omi to lo wooro.

Baba mo ki yin fun ise nla te nse fun wa o, ewe a maje o. Nje ta ba ti se bi eti so, tasi lo bi etiso, se ao ri ayi pada rere. Baba ejowo,e yo nda ise yi fun mi.

1 Like 1 Share

Re: .. by Nobody: 5:54pm On Feb 20, 2016
auggswell:

e SEUN gidigan baba health first fun ise takuntakun yin , please sir, se aidan toro ni tabi Aidan onigun

Aidan Onigun

1 Like

Re: .. by Nobody: 5:56pm On Feb 20, 2016
marv006:
Baba mo ki yin fun ise nla te nse fun wa o, ewe a maje o. Nje ta ba ti se bi eti so, tasi lo bi etiso, se ao ri ayi pada rere. Baba ejowo,e yo nda ise yi fun mi.

Yio je fun yin lase awon to nile. Iba Agba.
Re: .. by Nobody: 6:00pm On Feb 20, 2016
x

1 Like 1 Share

Re: .. by Nobody: 6:06pm On Feb 20, 2016
IWE LILO EWE , EGBO ATI ERANKO TI WA FUN TITA, E GBIYANJU LATI NI IPIN NINU IWE AGBARA YI. E LE RI IWE NA RA NI ILU IJU-ISHAGA NILU EKO TABI KI E SAN OWO SINU ACCOUNT WA, KA SI FI RANSE SI IBIKIBI TE BA WA.

2 Likes

Re: .. by Nudewhenu31(m): 8:20am On Feb 21, 2016
Baba health first, e ku agba, e pe, e gbo, odododun laa r'orogbo, odododun laa ma ri yin ba. Ejoo, oruko mi ni Joel, mo n gbe ni Fadeyi, Lagos, bawo ni mo se le ri iwe iwulo ewe ati egbo ra, ati pe elo ni iwe owun? Number mi ree 07030420960
Re: .. by damilola3264: 1:53pm On Feb 21, 2016
Baba healthfirst ewe a ma je funyin o! ejowo kini obirin ati okunrin tio ba ri oyun(pregnancy) ni le lo. eshe agbayin o dale o!
Re: .. by damilola3264: 2:09pm On Feb 21, 2016
baba healthfirst elo ni iwe yi ati wipe account number wo ni ama send re si
Re: .. by Nobody: 4:53pm On Feb 21, 2016
damilola3264:
Baba healthfirst ewe a ma je funyin o! ejowo kini obirin ati okunrin tio ba ri oyun(pregnancy) ni le lo. eshe agbayin o dale o!

Ao kan le dede fun yin loogun kan lai se iwadi to jinle nipa ki lo fa airoyun ni si eni na lara. E kan si mi lori whatsapp...ao le fun yin logun yen lori ibi.

1 Like

Re: .. by Nobody: 4:54pm On Feb 21, 2016
damilola3264:
baba healthfirst elo ni iwe yi ati wipe account number wo ni ama send re si

E kan si mi lori whatsapp tabi ke pe number mi, ao so iye owo fun yin ati account number
Re: .. by Nobody: 5:23pm On Feb 21, 2016
x

3 Likes

Re: .. by damilola3264: 11:51pm On Feb 21, 2016
healthFirst:

Ao kan le dede fun yin loogun kan lai se iwadi to jinle nipa ki lo fa airoyun ni si eni na lara. E kan si mi lori whatsapp...ao le fun yin logun yen lori ibi.
esheun sir bawo ni asele se nitori emi o si ni whats app agbayin a di ale. ewe a tun ma fun yin lashe Eledumare wa
Re: .. by Nudewhenu31(m): 2:58pm On Feb 22, 2016
Ejo sir, ki la n pe ni dingi?

(1) (2) (3) ... (53) (54) (55) (56) (57) (58) (59) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 26
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.